text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
Jẹ́jẹ́ ni ìjọ̀gbọ́n ń jókòó, èèyàn a sì máa lọ fà á lẹsẹ̀.
0
#al-qaeda tí fẹ́ẹ̀ẹ́ pa #Africa run. Ó yẹ ká fura o.
0
RT @user: Àwọn ẹ̀dá ẹranko àti ewéko ń dínkù lórí ilẹ̀ ayé, bẹ́ẹ̀ náà ni ti ẹyẹ yìí tí kò sí ní ibòmíràn lórí ilẹ̀ ayé àyàfi ní Nepal..…
0
To difa fun eni ti ko toonii Ω̴ą to n dena de eni""""""""@user: Ajunilo o' le juni paa.""""""""
0
Àṣà àwọn àtọ̀húnrìnwá nígbà yẹn lọ́ọ̀hún bí wọ́n bá fẹ́ jí wa ní nǹkan ni láti lé wa lọ sinmi ní òkè òkun. #Slavemasters #Amunisin
0
Ẹ rántí o pé ogun ní í ṣini mú, èpè ní í ṣini jà. Èpè òbí àwọn ọmọ yìí á jà bópẹ́ bóyá. #BokoHaram #OurMissingGirls @user
0
... àfi pọ̀ọ̀ alákorí tún bì lẹ́ẹ̀kejì. Ṣé ti pá ni kí a m'otí yó kẹ́ri ni? #OmutiGbagbeIse #yobamoodua
0
@user Iku ojiji lo ma de ba e o.ewo ni iwa palapala ti o fi owo @user te si iwe @user ? http://t.co/FqgLgg31cE
0
Ẹní gbé kèrègbè ògógóró mu, tó wa fi ewé akòko kọ́'lẹ̀kùn. Olúwarẹ̀ fi ẹ̀tẹ̀ sílẹ̀, ó ń wo làpálàpá nìyẹn o ẹ̀yin ará mi. :)
0
#iroyin, #yoruba, Awon akekojade Ilesa Grammar School wo Gomina Aregbesola lo sile ejo… https://t.co/3PGXjuO5MY
0
Tani àwọn Yorùbá máa n pe ni ọmọ papanlangi? |#EdeYorubaDunLeti #yoruba #MondayMotivaton #kahush #COVID19 #ChicagoRiots #sackdawnbutler #방탄소년단 #ImTiredOfThisLockdown #창빈이의_빈나는_생일을_축하해 #ธรรมศาสตร์จะไม่ทน #qanda #Monday
0
RT @user: Ọmọdé ò mọ tẹ̀tẹ̀, ó ń pè é l'ẹ́fọ̀ọ́. #writeyoruba #Yoruba #proper https://t.co/N4vwGGP47B
0
Bákan náà, tí alábaraméjì tí ó diwọ́ disẹ̀ sínú bá re ọ̀run, dandan gbọ̀n ni, a ó ṣe orò fún un. #AsaOro #Yoruba
0
Wọ̀bìà yọ́ tán, ó pe ẹlẹgbẹ́ẹ rẹ̀ wá jẹ. #Owe #Yoruba
0
Ó yá 'ni lẹ́nu, nígbàtí a gbẹ́ ẹ yín léyín tán, ẹ wá ń fi eyín ọ̀hún gé wa jẹ, ṣó dáa bẹ́ẹ̀! @user @user @user
0
RT @user: Èèmọ̀ wọ̀lú o! Èèyàn mẹ́rìnlá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tún ni àjọ @user sọ pé wọ́n ti kó ààrùn kòrónà. Èèyàn méjì ní ìlú Àbùjá.Èèyàn…
0
RT @user: """"""""Owo ti mo fẹẹ gba lọwọ salawa Abẹni lo koba mi"""""""" @user https://t.co/Umcjcfgd1Q https://t.co/gZikyea1Mw
0
Àtipé ẹpo tó ṣọ̀wọ́n ló tún fàá kí àwọn èèyàn máa gbé epo sínú ọkọ̀ rìn. Tó fi wá di pé àwọn ọkọ̀ ngbiná lójú títì káàkiri! #Nigeria
0
RT @user: @user @user Ogbufo yi ku die ka'ato
0
Wọ́n fún ọ ní ọbẹ̀, ò ń ta omi sí i, o gbọ́n t'ẹ́ni t'ó sè é? #Owe #Yoruba
0
D) Àrọ̀nì Olóògùn ìkà ni Àrọ̀nì lójú ayée rẹ̀. #idahun #Ibeere #Yoruba https://t.co/qjfpE93Wpm
0
2 nigba ti ara ilu ba ko lati fun won lowo riba ti won beere fun. @user @user @user #TweetinYoruba
0
📸 Aiye ti di aiye olaju. Olaju oje ki ori Awa omo Nigeria o pe mo. https://t.co/odQ2zyFd7d
0
RT @user: """"""""Àìlè m'ójú kúrò ní ń jẹ́ k'ẹ́rù wèrè pọ̀"""""""". Translation: """"""""Inability to take the eyes off things causes a lunatic to have…
0
Àwọn kan wà ní kọ̀rọ̀, tí kò jẹ kí òṣìṣẹ́ àti òṣìṣẹ́ fẹ̀hinti rí ẹ̀tò wọn gbá lásikò. #MayDay #ippis #nigeria
0
Wọn ò l'ẹ́kọ̀ọ́, wọn ò níbẹ̀rù àgbà, wọ́n ń lẹ́nu sí ẹni t'ó jù wọ́n lọ. #Jegudujera #OminiraNigeria #NigeriaAt56
0
@user @user @user @user Bẹ́ẹ̀ni o. Ọwọ́ epo l'ayé ń báni lá. Kò ṣ'ẹ́ni tó fẹ́ báni lá'wọ́ ẹ̀jẹ̀ o. Ayé lẹ rí yẹn
0
Ìlú 🇳🇬 ò fiṣẹ́ yinni. Ń'nú òjò nínú ẹ̀ẹ̀rùn, òṣìṣẹ́ ìjọba ń fóòró ẹ̀mí kiri nítorí ìlú, bó dìparí oṣù, owó àmúrelé ò ká nǹkan. #Kilawanwork
0
EPE! """"""""Iku ojiji ni yio deba enikeni to a ba fe fi on eburu gba ijoba lowo @user"""""""" Gomina Godswill Akpabio ti ipinle Akwa Ibom lo so be
0
O ya aláìgbọràn bíi ewurẹ́"""" #Yoruba #Animal #Metaphor
0
RT @user: Oyin ń sé, Agbó̩n ń sé Béè Ojú olóko rèé kùndùkundu #EndPoliceBrutalityinNigeraNOW #EndSARS
0
.@user @user @user Ahhhhhhh! Se lotito ni @user pa Egbon re Atkins?... ewo oju apayan! http://t.co/BvpgRmJXo5
0
♫ Ẹnu wọn l'ẹ̀fà, ẹnu wọn l'èje, àwa ò b'ẹ́lẹ́nu méjì ṣ'eré mọ́"""""""" - #Orin #MusiliuIsola #Yoruba #Enulebo
0
Won ni ni baba iro, Tabi sugbon ni aremo e !!! #BBNAIJA #ARSENEWENGER #Nigeria #DSTV #AppleIphone #MTVBASE #BET9JA #FACEBOOK #ENGLISH #SYRIA #YORUBA #MOUSE
0
'Fàkìà' lẹwà, ẹ ò rántí wa. Ẹsan á ké o! Bámúbámú ni mo yó, ẹ ò mọ̀ pé ebí ńpa ọmọ ẹnìkankan #Nigeria
0
RT @user: @user @user @user @user @user @user Ole gbe ole gba, jaguda paali ni OGD ati Sa…
0
Falana gbo ti e...... Oto leni ti a fi egba no.........
0
RT @user: Àìnísùúrù ìnàkí, ló sọọ́ di ará inú igbó. / Gorilla's impatience is what made it an inhabitant of the forest. [Be pat…
0
Ejo se oro rirun yi ni won hun ba Gomino @user so ni, ani ki e son owo awon osise, ewo ni ere ori itage? https://t.co/lItD0vJ2gN
0
#Oshodi ti dàrú o! Wọ́n sọ tajútajú sílẹ̀, ọlọ́pàá ń yìnbọ sókè, ọmọ-ìta ti ń ṣiṣẹ́ ibi. @user
0
O fẹ́ẹ́ j'ẹja àrọ̀ sísìn (nawọ́ sí i kóo kú) tí a fún lóògùn àtètè-múni-tóbi tí ń kó àrùn bá ará ìlú Èkó. Owó ni. #owoekoekolongbe
0
Ète àti pa ògógóró run kí tòkè-òkun ba gbapò rẹ̀ ni mo kà á sí bí a bá fi òfin de ọtí ògógóró. #Ogogoro #Yoruba
0
A ò jẹ́ orúkọ #Yoruba mọ́, bíkòṣe orúkọ Larubawa àti orúkọ èèbó, elòmìíràn kì í ṣe ẹrú àmọ́ ó fún ọmọ rẹ̀ lórukọ ẹrú. #Nigbatiwonlo #BHM
0
Ah! ṣẹ́ẹ tiẹ̀ rí àwọn onípolówó ọjà tí wọ́n máa npèmí lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ yìí ṣaa!!! #muslimrage #ìbínúmùsùlùmí
0
Ibo odun 2015: Awon oloselu koju ija buruku sira won http://t.co/8L9fs0rfuc
0
@user @user gẹ́lẹ́ ni, jẹgúdújẹrá alájẹìwẹ̀hìn. Bámúbámú ni mo yó n ò mọ̀ pé ebi ń pa ọmọ ẹnìkánànkan #StellaOduahGate
0
RT @user: Ọgbọ́n àgbọ́njù ní ńsọ ẹni diwin; bí oògún bá pọ̀ lápọ̀jù a sọni di wèrè; bóbìnrín bá gbọ́n àgbọ́njù, péńpé laṣọ ọkọ-ọ ẹ̀ ń…
0
RT @user: Alatako, agbe dina eniyan """"""""@user: Irú ènìyàn wo ni à ń pè ní elénìní? #Ibeere #Yoruba""""""""
0
Ọ̀rọ̀ #BokoHaram yìí mà wá dójú ẹ̀ o.
0
Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ ré bọ́, Ṣọ̀ún sáré dé bẹ̀, ó fa idà yọ, ó bẹ́ Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ lórí, ó gbé oríi Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ dé aàfin. #Gbomoso
0
RT @user: """"""""Eni ri nkan he. To fe ku pelu e ooo. Owo eni to ti sonu nko? Aye l'aba, aye l'ao fi si le lo.""""""""
0
RT @user: 5. #PariOweYii Ìkòkò dúdú kò yẹ á bù ṣán... #ibeere #Yoruba #Owe
0
Àgùtàn tó bá bá ajá rìn á jẹ ìgbẹ́, ajá tó bá bá ewúrẹ́ rìn á jẹ èpo iṣu. /#Yoruba A sheep that moves with dogs... https://t.co/QW1bPcblmy
0
AmohunMaworan: Iyawo Aare Nijeria Patience Jonathanu Bu Igbe Ta! http://t.co/2oXtWCvwon via @user
0
Ẹ dáná sun géndé mọ́kàndínlọ́gbọ̀n, àwọn ọba lọ́la. Ọmọ tí ò m'ọwọ́ m'ẹsẹ̀ lẹ rán lọ sí ọ̀run àrìnmabọ̀. #BokoHaram @user :(
0
RT @user: Bi iná ba ńjó lóko, màjàlá a ṣe òfófó. / When a farm goes aflame, the flakes (fly home to) bear the tale. [Nothing ca…
0
RT @user: @user @user nko ro wipe iyen see se ni ile Naijiri ija eleyameya ati elesinmesin koo ni je ki o ...
0
RT @user: NNPC don dry! Buhari is absent, Dino tí Sọ̀rọ̀ Sókè 🤷🤷🤷😂😂😂 Yoruba Nation Now! 📢📢📢📢📢📢📢📢 #StoneBadLeaders when you see t…
0
Àìsí nígbó tó bẹ́ẹ̀ náà ló fà á tí wọ́n fi gbé ọmọ Ọbà f'Ọ́ṣun, a kò leè sọ ìyàtọ̀ ẹranko ẹhànnà orí ilẹ̀ẹ wa mọ́. Kí ni ọ̀nà àbáyọ sí ti ìdìnkú ẹran ìgbẹ́? Bí a kò bá wá wọ̀rọ̀kọ̀ fi ṣe àdá, a ó pàdánù ẹranko, orúkọ wọn yóò sì bá wọn lọ. #EranIgbe
0
Omo to ni baba oun o mo obe se itan bi won se le iya e lo lo fee gbo. #funny #YorubaProverbs
0
RT @user: @user e ma so bee o, aa di alakoba gidi fun yin, bee na lemi se n kilo fun yin...waa ri to ba ya. Ejo lowo nin ...
0
@user @user @user @user Nígbà tí nǹkan ò ṣe wọ́n, they will refund this one
0
Ó mà ṣe o, ẹ ò ráyé àwọn aṣòfin wà lóde, a tí ń rí ẹlẹ́yàmẹ́llẹ́yá, èyí lékenkà ☆ http://t.co/PXMnbExO7h #RiversCrisis #Yorubaversion
0
RT @user: Kò sí òògùn aláròká #oroiyanju #yoruba #subtitles https://t.co/v71DmG6AVT
0
RT @user: 15) Èèwọ̀: Ṣàngó kì í jẹ ___ Èṣù kọ ___ Ìkòyí ò gbọdọ̀ jẹ ____ #ibeere #Yoruba
0
Rárá o, líle ti á jẹ́. Ọ̀làjú tó dé ti la ojúu wa nílàkukà, a ò mọ̀tún yàtọ̀ sósì. #SKKY #yoruba #yobamoodua
0
RT @user: Ẹni ebi ń pa ò gbọ́ wàásù. #EsinOro #Yoruba
0
K'á fi ẹnu á dákẹ́ l'ọ̀rọ̀ ìjọba wa. https://t.co/wZz8BwOPWU
0
Àwé a gọ̀ o, a tún fẹnu họ ra pàápàá. Torí a ti gbà láti máa tẹ́lẹ̀ wọn tàṣútàṣú @user
0
@user: Ota po gan o"""" #IdanOriPapa #BarcaFC #ManCity #UEFA
0
Radarada oun sepe fun awon osise ti won o sanwo fun lati ye joo... #TweetinYoruba
0
RT @user: Ta ló máa gbà wá lọ́wọ́ àwọn ìjọba òde òní? Àwọn oníṣẹ́ ọpọlọ ni wọ́n ń fi ìyà jẹ. Bí wọn kò t'akọ̀ròyìn mọ́lé, wọ́n á pa…
0
Ẹ̀bù ìkà Àkàrà @user :)
0
@user @user @user @user @user Wọ́n ní ènìyàn kò sunwọ̀n láàyè, bí a bá kú là ń di ère. B'ó bá ṣe pé mo ti 'yámútù' bíi èdè àwọn aráa wa lókè Ọya, ariwo á ti ta, nítorí gbogbo àwọn akẹgbẹ́ẹ̀ mi níbi iṣẹ́ jẹ́ ẹlẹ́rìí wípé mo ra bọ̀ti @user tí mo sì bá jẹ̀gbẹ̀ndẹ̀ ń'núu rẹ̀.
0
Biafura! Biafura! @user Nnamudii Kanuuu wo bi ose ko iya je awon omolomo. Eni Sango toju e wole koni bawon B'oba koso lae! https://t.co/nHHbfI6Ws5
0
@user lotito ni eni to gbin ebu Ika omo re a je nibe dandan
0
Dollar wan! Poun no wan! Awon alakowe fariga won paruwo kosowo kosowo, nigba ti e hun ji owo pamo, e o ronu igba ohungb! Idajo ti de bayi
0
FOLKTALES: The Story of the Sworn Enmity between the Hawk and the Chicken. ÌTÀN: Ìtàn Bí Àṣá àti Adìyẹ ṣe di Ọ̀tá Ọ̀run Ò Gbẹbọ https://t.co/TfpjqgVOYJ
0
Purọ́purọ́ wọn ní bí a ṣe dúdú lójú, la dú lọ́kàn, lọ́pọlọ, torí ìfẹ́ ara tirẹ̀, èké fi àgálámàṣà sọ wá lórúkọ tí a ò jẹ́. #YorubaMoOlorun
0
.@user Bí yànmùyánmú bá kẹnu rẹ̀ ṣoṣoro bọ ènìyàn lára láti mu ẹ̀jẹ̀ t'ó wáyée rẹ̀ wá mu, ó ṣeéṣe k'ó gbé àìsàn ibà wọ ara onítọ̀hún. #AyajoOjoIba
0
Obìnrin tó kúrò nílé ọkọ padà sílé baba, wọ́n a ló ṣe kíni? #ibeere
0
Bí ó bá lọ́gbọ́n láàárín ènìyàn dúdú, òní sápò ara rẹ ní. Wọn lé bínú pa ọ tọpọtọpọ. Agadagodo ọ̀tẹ̀ ọwọ ọmọ adúláwò ló wà."""" - Olanrewaju Adepoju (1972) #AfricanPoetry #Nigerianpoetry #Yoruba #Ewi #OlanrewajuAdepoju https://t.co/r9Q4tFbquR
0
Iru olopa wo leleyi o..... @user e ba wa da Saria fun olopa yi. Ewo atiniloju olopa. https://t.co/3ICuARPEQm
0
Any Yoruba persons speaking against Sunday Igboho is OMO ALE. #Biafra #BiafraExit #biafranfreedom #Yoruba #OduduwaNation #oduduwaExit #Oduduwa #EndSARS #EndBadGovernanceinNIGERIA https://t.co/S8crzwqaJl
0
@user Shey awon fulani adaran lo tun wa jo'le abi awon hoodlums. #SundayIgboho #Fulaniherdsmen #StaySafeNigeria #Yoruba
0
#Otoge ti le @user kuro ni ilu o Ki lo tun ku to yio se? Eni ti a belori ton senu wuye....🎼🎹🥁🥁🎷🎺🎸🎻 https://t.co/dEqPbLR6EB
0
Ẹ wá o. Gbogbo rògbòdìyàn tí ń lọ ní òke-Ọya yìí ti sú èmi o. Ọgbọ́n wo la fẹ́ dá sí i báyìí o? #BokoHaram
0
Àìṣòdodo. Ìmọtaraẹninìkan. Àìnífẹ̀ẹ́ ara ẹni t'ó ju ti tẹ́lẹ̀. Ọ̀gá ló kọ́ wa bẹ́ẹ̀
0
Iroyin tó te @user lọ́wọ́ sọ pé @user àti àwọn méjì miran ti @user mú tí wọn sì fojú bale ejo lọ́jọ́ru yóò tún sún oorun ọjọ́ kejì lọgba ẹ̀wọ̀n, https://t.co/Tjqv0Dy6WE
0
Kò yẹ kí irú ọkọ̀ #BRT yìí ó máa rìn nígboro Èkó, èéfín tí ó ń fín wa ju ti igi ìdáná lọ. #Obalende #BRT @user @user #Lamata https://t.co/Bq6UA2ahMx
0
Subhannallah Khadija ti sọ ara ẹ di Cardi B 😂 https://t.co/zdMLP578w9
0
Kótán-kótán lajá nlámi. A díá f'álájẹjù tó torí bọ ìsaasùn ọbẹ̀. A díá f'óṣèlú Naija tó tọwọ́ bọ̀wá lápò. #naija
0
Àjẹ́ ké lánàá, ọmọ kú lónìí.. #WhoKilledDeleGiwa
0
Àwọn ẹhànnà tan 'ná, wọ́n sì pa á padà. Òṣì ọrùn!
0
ÌJÀKÙMỌ̀ ni orúkọ tí wọ́n ń pe èèyàn tí ó ń hu ìwà ọ̀daràn nínú ìlú. Ẹni bẹ́ẹ̀, kìí ṣe iṣẹ́ ibi ní ọ̀sán, àfi ní òkùnkùn. Òhun ni wọ́n fi sọ wípé, ÌJÀKÙMỌ̀ KÌÍ RIN ÌRÌN Ọ̀SÁN, ẸNI A BÍI IRE KÌÍ RIN ÌRÌN ÒRU
0
#Oduduwa #yoruba #EndPoliceBrutalityinNigera #endsars @user Baba eje Ka fi ORO ale awon SARS tinwon oba fe lo Lero, Ao fe won Nile Kaaro ojire mon...@user RT NOW
0
Ikú ò pé méjì, ọ̀kan ṣoṣo àjànàkú tí í m'igbó kìjikìji. Ikú tí í pa ọlọ́lá, pa tálíkà, olóríibúu rẹ̀ kì í b'ẹ̀rùn ẹnìkan. #IkuOdaju
0
RT @user: Ó wu ẹrú kó ṣe bí ọmọ orúkọ rẹ ni kò jẹ́. / A slave would love to act like a free-born but his name would not let him.…
0
@user @user @user @user @user @user @user @user @user Kí nìyẹn fi kàn wá? Kò bá à ru igi, k'ó rù ju èyí tó ju igi lọ fi rán ara rẹ̀ ńlé ìwé, ṣebí alátiṣe ló máa ń mọ àtiṣe ara rẹ̀. Ojú àánú ni @user ń wá, ojú àánú sì ti fọ́, ti ìkà l'ó kù. Bàtà ni @user ò rí wọ̀ lọ sí ilé ìwé ni tìrẹ. Igi ṣíṣẹ́tà ni báyìí 😒
0
K'á máà bá òpó lọ ilé olórò, ọgbọ́n èrú èèbó l'ó bá ilẹ̀ adúláwọ̀ dé ibi a wà yìí, dáradára ni kí wọ́n tó wá ba ti wa jẹ́ poo. #Yoruba
0