text
stringlengths 9
354
| label
int64 0
1
|
---|---|
Kíni pàtàkì ẹ̀mí ọmọ ènìà ní Naija? Pàápàá àwọn ọmọdé? #SaveBagega | 0 |
Tàkan sí i ní pa olókìtí. #Owe #Ikilo #Yoruba | 0 |
Ìṣọ́ òru lójoojúmọ́. Ariwo àdúrà ń gbogbo ìgbà, síbẹ̀ nǹkan kò ṣẹnu 're. A kò rí ipa dáadáa lára àwọn tí ó ń kóra jọ ṣe ìṣọ́ òru (Nàìjíríà). Ó mọ̀ wá ga o! | 0 |
@user @user @user @user ohun to seni laanu ni wipe awa funra wa ko mo nipa ohun to je tiwa gaan | 0 |
Àfọ̀njá ti kó ẹyẹlé pọ̀ mọ́ adìẹ, Fúlàní ti di ọmọ-ogun Ìlọrin, ó ń gbèrò láti jagun kúrò lábẹ́ Aláàfin Awólẹ̀. #ItanFulani #Darandaran #Yoruba | 0 |
Kò rọrùn fún ọmọ aráyé láti fẹ́ràn ẹni. Ọ̀rẹ́ ó dé inú, ẹni a fẹ́ la mọ̀; a ò mọ ẹni t'ó fẹ́ 'ni. #Ife #Owe #Yoruba | 0 |
RT @user: @user Ha, rara o. Aya fi awon asu ma tanba. | 0 |
Ọmọge Ṣàṣá kan fẹ́ ṣá mi. Ó lóun fẹ́ẹ́ gb'owóo irun #India, òun fẹ́ ra aṣo #Egypt fún ọdún. Mo wáá ní, kí ló ṣe irun àti aṣo #Yoruba? | 0 |
Ẹni tí kò bá si ńlé ni ewúrẹ́ rẹ̀ ńbí kan. / It is the goat of an absentee owner that gives birth to only one offspring. #yoruba #proverb | 0 |
@user @user ẹ ti bẹ̀rẹ̀ lálẹ́ yìí, does everything have to do with village people? Well, àwọn ẹlòmíì ni wọ́n ń ṣe ara wọn lóòótọ́. BTW, data is unavoidable for people like me | 0 |
Ṣé ìjọba #nigeria ò tí ìtó wá wọ̀rọ̀kọ̀ fi ṣe àdá lórí ìdaṣẹ́sílẹ̀ #ASUU? Ọdún mà ńtán lọ. #FEC | 0 |
Ààlò ò rànkà🤔 Bóo bá gúnyán fúnwon, won á lóní Kókó 🤔 Bóo bá sebè fúnwon, won asì ló té lénu Àfi kólúwa gbéwa lékè @user @user @user @user @user @user @user @user @user #yoruba #owe #ASA2020 | 0 |
Ẹ̀wẹ̀wẹ̀, ègún ìdílé sì lè jẹ́ àfiṣe. L'àwọn àgbá ní, èpè ò jà b'ẹ́nìkan ò rọ̀ ọ́, ara iṣẹ́ burúkú ọwọ́ ọmọ-ènìyàn ni àfiṣe lọ́pọ̀ ìgbà, àmọ́ kì í ṣe pé kò sí àfiṣe aláfọwọ́fà o. #OgunIleAye #EgunIdile #Yoruba | 0 |
Ó ṣòro fún Ọmọ-adúláwọ̀ láti ṣe ìrìnàjò jáde kúrò ní Ilẹ̀-Adúláwọ̀ — ṣùgbọ́n bẹ́ẹ̀ náà ni ó nira láti rìnrìnàjò láàárín ilẹ̀ náà. #OhunAgbaye #Yoruba #IweIrinna #IweIwolu #Visa @user https://t.co/jRpzd4YMgj | 0 |
@user Hmmm... Ọ̀rẹ́ á ma tan ni pa nítorí ọrọ̀ 😪 | 0 |
RT @user: Obirin so iwa nu, oni owun ooori ile oko gbe! """"""""@user: Ìwà lẹwà ọmọ ènìyàn. #yoruba"""""""" | 0 |
Ọ̀ràn ẹgbẹ́ òṣèlú APC ti di ẹni tí a ní pé kó ṣe tó; tó wá ṣe tó-tò-tó, àwọn ọmọ Nigeria lọmọdé làgbà ń jìyà mọ́yà. #IjoOle | 0 |
Ẹni tó jọba tán tó tún ńwo òkè fẹ̀ fẹ̀ fẹ̀, ṣé ó fẹ́ di Olódùmarè ni? A person, already crowned a king, still kept looking upward in dire expectation; does he want to become God? [Contentment is it; lack of contentment can be stressful.] #Yoruba #proverb | 0 |
RT @user: @user O da ti ofin ijoba Nigeria ba gba yin laye lati se. Itiju nla lo je fun wa lehin adota odun ominira pe ... | 0 |
RT @user: @user Gbogbo won loma fii koo ina loru apadi,,awon eni ibi tin pon omo ree baluwe,,pasito indeed! | 0 |
Wọmbiliki-Wọmbia is the word for unredeemable glutton in Yorùbá Language. . Yorùbá is fún to learn. . #babayooba #yorubalanguage #learnyoruba #learnyorubawords #yoruba #yooba https://t.co/cSJns6Y2Je | 0 |
Ará Èkó ò mọyì ará oko """" - the Lagos folks; urban no not the value of the farm dwellers; rural ► http://t.co/JzIV9Obs5L #Blogs | 0 |
Èyí ni àwọn èèyàn wa rí wípé owó gegere wà níbẹ̀ ni àwọn ìlú fi gbà á bíi iṣẹ́, ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí gbógun ti ìlú òdì kejì. #OgunIleYoruba | 0 |
Bẹ́ẹ̀ ẹ̀dá ọmọ ènìà náà ló fi ilẹ̀ yìí ṣe ibùgbé. Òtútù tí ń yani ní wèrè. Ẹlòmíràn a sì gbé odidi ìgò sẹrí. Kiní ọ̀hún fẹ jọ ògógóró. | 0 |
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé Wèréwèré ni ó máa ṣé òbúkọ tó fi máà ń gun ìyá ẹ kìí se werewere #NjeOMo ? 🤔 #NjeOMo #EdeYoruba #Yoruba #Lagelufm967 https://t.co/QgUpjmvvGb | 0 |
@user @user Egbe Agba boolu ManU ti le akoni mogba; David Moyes,won fi Ryan Giggs ropo e gege bi fidihe....#MoyesGone #Idanoripapa | 0 |
@user: #Owe: Ẹni tó gbin òkúta sínú ebè tó pèé ni èbù iṣu, ìgbà tóníyán bá ńjẹ iyán òun náà yóò máa jẹ ìka. @user"""" #Yoruba | 0 |
#Layajoaoni lodun 1987 Donald Trump gba odidi oju ewe New York times kan lati bu orileede Japan | 0 |
Yoòbá ni bí a bá rán 'ni níṣẹ́ ẹrú, à á fi ọmọ jẹ́ ẹ, Ọ̀gbẹ́ni Philips ò fi t'ọmọ jẹ́ ti rẹ̀ rárá, ó ṣetíkunkun sí àṣẹ ọba. #OleBini | 0 |
RT @user: Ẹni tí ò fẹ́ wọ àkísà, kì í bá ajá ṣe eré e géle. / Don't play rough with a dog, if you don't want to end up in tatter… | 0 |
Bí àwọn ẹ̀gbin ẹranko tí a ti gbé èròjà àtọwọ́dá sí lára bá balẹ̀, tàbí kí ìfẹ̀ ẹranko tí ó ti jẹ àpòpọ̀ oúnjẹ àtọwọ́dá bá fọ́n sínú àyíká yóò lapa búburú lórí ilé ayé, tàbí kí a jẹ irú ẹran bẹ́ẹ̀ lóúnjẹ, ara ló ń bọ̀ wá f'àbọ̀ sí láì pẹ́. | 0 |
RT @user: @user Eyi to je ti ilu o r'oju, oruko re na o ni pare o! | 0 |
Eemo l'Agege! Aafaa fi eyin adie ati iyo we fun Aanu, won lo fee fi soogun owo ni - Alaroye | 0 |
Ogbólògbó ajà fún ẹ̀tọ́ @user ṣe àtakò ìjọba #Nigeria ní ìlú #Berlin #WhereIsOurMoney #OwooWaDa http://t.co/Mq4RH0pfVn | 0 |
Mo fẹ́ di ejò 🐍, mo fẹ́ máa gbé owó mì. Àbí kí n di ọ̀bọ làgídò. 🐒 Oríṣiríṣi là ń gbọ́ ní Nàìjá 🇳🇬 Mo gbédìí o! | 0 |
RT @user: Tí omi bá pọ̀ ju okà lọ, ọkà a máa dí kókó. / Excessive water makes the yam flour meal lumpy. [Moderation is crucial;… | 0 |
Ìjọba wa ò ṣe iṣẹ́ ẹ wọn bí iṣẹ́, ó kù díẹ̀ k'á à tó. Ìjọba mẹ́tẹ̀ẹ̀ta làbùkú kàn. @user #IjobaWaKala #Nigeria #Yoruba | 0 |
Ole to ji kakaaki Oba o ku ibi ti yoo ti fun #YorubaProverb | 0 |
@user ló ń bọ́ lọ́wọ́, ọ̀rọ̀ nípa bí a ṣe ń ta ara ẹni láyé ayélujára ló ń sọ #SMWCONTENT @user http://t.co/bIwgfdd9nI | 0 |
🎶 Ta lẹ̀ ń kó wá bá! Àdìgún ọmọ́jọmọ lọ tírin bá kan irin ìkan a tẹ̀ fún-ùn kàn | 0 |
Fún ẹ̀yin tẹ́ ẹ ní #Benin ò bá #Yoruba tan, ẹ fi ara burúkú balẹ̀ kí ẹ gbọ́ làbárì. #YoobaEdo | 0 |
RT @user: """"""""@user: Ìsẹ̀yín ni adájọ́ ń gba owó-ẹ̀yìn, a sì gbéjọ́'Sanjọ́ aláre fún 'Túnjí ẹlẹ́bi."""""""",Eni a gboju okun le o jen… | 0 |
#iroyin, #yoruba, L'Osun, onorebu wo gau ; won lo gbe ise akanse ilu Ila lo sile e l'Osogbo… https://t.co/ovvRrHGsQW | 0 |
RT @user: Ọmọ àlè ní í fi ọwọ́ òsì júwe ilé bàbá ẹ̀. #SpeakYoruba #learnyoruba #language #InYoruba #Yoruba https://t.co/f93MGlMLdE | 0 |
Àwọn ọ̀rẹ́ mẹta ni ìyà ń jẹ, kódà ó ti sọ wọ́n di pákò. Wọ́n pa ìmò pọ̀ láti wá ọ̀nà àtilà. Wọ́n ń wá Àṣírí Ajé. Ǹjẹ́ àbùjá wà lọ́rùn ọ̀pẹ? Ǹjẹ́ àṣírí ajé wà? Kíni ìgbẹ̀yìn àwọn tí ń kánjú wá owó? #AsiriAje #Atelewo #YorubaBooks #Yoruba https://t.co/hE72UVFxsp | 0 |
Imado iba se bi elede aba'lu je, eru iba je oba eeyan o ni ku kan. #yorubaProverb #TweetinYoruba | 0 |
Òtútù yìí pọ̀ :( http://t.co/I3S5Gdzn | 0 |
8. #Parioweyii Ẹyẹ ò lẹ́san tí yóò san ìyáa rẹ̀... #Ibeere #Yoruba #Owe | 0 |
@user @user @user @user @user @user Se chenji no re? Awa oni ki ema ja o amo efun wa lepo iya nje eyan | 0 |
@user ọmọ ọ̀tin, oní yẹ̀yẹ́! | 0 |
RT @user: @user abi oooo awon ooluko wa o ran asa wa lowo ohun to buru ni | 0 |
Ijoba Jonatanu! Ekan un kigbe megawatu! megawatu! Beni Nijeria wa di ile okunkun. Ko sino, ko si epo, ijoba masanfani ni ijoba Ebele o! | 0 |
ÒWE ÌKÌLỌ̀ / A PROVERB OF WARNING: Ejò tó múra ìjà, ẹ sọ fún wípé kò gbọdọ̀ gba àárín ìjàlọ́ kọjá. Tell a snake that is prepared for battle, not to pass through the lane of soldier ants. | 0 |
ALÁÀFIN KÁRÀÁN: ÒUN ÌṢỌ̀TẸ̀ Ọ̀YỌ́ Ọba aninilára tó burú jáì ni Aláàfin Káràán jẹ́. Ó ma ń pàṣẹ nínà gidi ní iwájú àti ẹ̀yìn fún àwọn ọmọ ìlú, bí ó bá ṣe wù ún, títí wọ́n ma fi gbé ẹ̀mí mì. Aláàfin Káràán ṣígun lọ sí Àga Oíbó. Ogun tó ṣí lọ yìí, mú rìkíṣí | 0 |
Bí ọmọdé bá ṣu imí burúkú; eṣin burúkú ní í gbo ó nídìí. #EsinOro🐎 #Yoruba | 0 |
Ikilo Pataki! Eye pe wa ni Yonmirin abi Aje Okuta ma mu omi - Mazi Ndimele Asoju apapo IBO Ohaneze Ndi Igbo lo se ikilo no fun awon Yoruba | 0 |
RT @user: """"""""@user @user @user Abdul Rahman Sudais (Imam ni ilu Makkah) da gbere fun aiye loni... http://t.co… | 0 |
@user @user àwọn Àjàyí àti CMS náà ló kọ̀yìn sí àwọn àṣà tòun ìṣe yìí, wọ́n ní kò dáa, irinṣẹ́ Èṣú ni wọ́n pè é fún wa. | 0 |
Ẹ kó owó wa padà. Hán! hán! kílódé, ẹ fẹ́ jẹ wá run ni. #OwooWaDa #WhereIsOurMoney | 0 |
#iroyin, #yoruba, Iranse okunkun ni Makarfi ati Fayose je ninu egbe PDP - Kashamu: Seneto… https://t.co/yxUH88d1kO | 0 |
To bá jẹ pe tèmi nìkan ni, kini wọn fẹ fún mi, ikuna ni kí ènìyàn máa bá ijoba jà To bá jẹ pe tèmi nìkan ni, kini wọn fẹ fún mi, ewu ni kí ènìyàn máa bá ijoba jà. | 0 |
Gbogbo igi kòkó rẹ̀ ló jóná mọ́lẹ̀ pátápátá, ọ̀yà àti òkété sì ya bo oko gbàgúdá rẹẹ̀ pẹ̀lú wọ́n sì fi jẹ tán #Itanilumasee | 0 |
Àmó wà rògò bàyí ó, bwódà Tàjú tí kà àntí Múlìkà pélú bwódà Súràjú lórí bédí nínú ìlé ìtúrà tí'nbé lókè lòún 🙆🏽 tà làwà késí bàyí 😥 #yoruba | 0 |
Eemo Wolu @user ko Soja ati awon janduku Niger Delta ti won boju ya wo ipinle Osun lori oro idibo gomina! #OsunDecides | 0 |
@user @user is this it? Ordering soldiers to kill your own citizens? Unarmed protesters? We will not forget History will never forget! A ò ní ṣépè, àmọ́ ẹnu wa ò ní gbófo. Ẹ̀yin náà kúkú bímọ #EndSARS https://t.co/GfvLtsTT0n | 0 |
Ká bá 'ni l'óde ò tó ká bá 'ni délé. Ilé ẹ̀lòmíì ò ṣe é rí, kò ṣe é wóò. Gbogbo agbègbèe rẹ ló ń ṣàáyán, tí ń bu tìì. #Lagos #Sanitation | 0 |
@user @user Baba yìí fẹ́ dá nkan lẹ̀ :) | 0 |
Iron un pa iro fun iro.............. Enu e le wa yen..................... | 0 |
RT @user: Àtùpà kì í ní'yì lọ́ọ̀sán, ṣùgbọ́n a máa gba'yì lọ́jọ́ alẹ́. / A lamp is not valued in the afternoons, but does get ap… | 0 |
RT @user: @user Ole ti won ja kuro ni wasa. Ajanaku koja mo ri nkan firi; ti a ba r'erin, ka so pe a r'erin. Ewon de fun ada… | 0 |
RT @user: Ọ̀pọ̀ ló fẹ́ láàpa láì lápá, bí èèyàn ò sì lápá, kò leè láàpa. / Many want to make a mark without effort, yet without… | 0 |
Ọkọ̀ tí ó kó ọtíi #Guiness wó lulẹ̀ ní #3RDMB, ó sì fa súnkẹrẹ fàkẹrẹ láti #Adeniji. @user http://t.co/Hg9Wxz3lHU | 0 |
Leyin aponle ... Abukun lokan.. #Yoruba https://t.co/qEvhA9HzLM | 0 |
10. #Parioweyii Ẹni tí a bẹ̀ tí ò dárí ji 'ni... #Ibeere #Yoruba #learnyoruba | 0 |
RT @user: @user Ijoba mon ibi ti won wa,won si mon awon ti o ko won lo,sugbon oun ibanuje ni pe Ijoba ti fe fi awon omo na … | 0 |
RT @user: @user Ogbon won fe jora won na. Fashola npa mekunu lekun. On da won sinu ibanuje laibikita.Opo ko ni ilemo. ... | 0 |
#Yoruba Ohun obinrin yii sọ pe ki i ṣe arun Korona, #Covid19 lo paayan rẹpẹtẹ ni Kano, bikoṣe ẹrọ #5G. """"""""Ẹrọ yii ni wọn tan ina si ni Kano to bẹrẹ si i pa gbogbo wọn."""""""" Ohun ti obinrin naa sọ ree Irọ funfun balau Ẹ ka a lori: https://t.co/6VjAElikID | 0 |
ọjọ ija kọ la n wa òogun aluwo #TweetYoruba #TweetYorubaDay | 0 |
Adìyẹ ń jẹ ìfun ara wọn -- https://t.co/MdRwlD0h90 | 0 |
Ìjàngbọ̀n/wàhálà = trouble (ọmọ oníjàngbọ̀n - troublesome child;boy/girl) #InYoruba #Atunko | 0 |
#iroyin, #yoruba, Kayeefi! Pasito ku sori obinrin ninu oteeli: Yoruba ti won so pe iku akin… https://t.co/mwycUHf5n6 | 0 |
Ẹ̀rù bà á, kò le è gbé ọmọ titun padà síletò ni ó bá gbé e jù sílẹ̀ nínú igbó. #ItanObaIgala #Yoruba #Kogi #Igala | 0 |
RT @user: @user ogbeni GEJ ni wipe oun o ti raye tiwon,pe oro iyawo oun se koko ju rakatia yen lo | 0 |
Ògóró ẹ̀yin mi ń ro mí, awẹ́ ìdí ń fà mí ro. Ọjọ́ wo la máa dé ìlú Oṣòdì Tápà báyìí! | 0 |
Yorùbá people will still put pepper inside puff puff and chin chin, wait, se wọn ṣé epe ata fún yín ní? #yoruba https://t.co/kxuPFooU0p | 0 |
RT @user: Ẹni tí bíńtín ò tó, púpọ̀ yóò jìnnà sí i. / Abundance will be far from whoever is not contented with a little. [Conten… | 0 |
RT @user: Shangba fo! #TweetinYoruba Ogbeni @user ja no, Amofin @user ba ko lu pelu oko bolekaja. https://t.co… | 0 |
Ní idán kejì, ìran kẹ́ta, Àrẹ̀mú sọ nípa ikú, ó ní : Kí la ò rí rí? Ẹṣín ta, ta, ta, ẹṣín kú; Ènìà rìn, ó rìn sọnù; Wọ́n bímọ--ọmọ́ kú! | 0 |
Ìtànjẹ ni, fáwọn òyìnbó láti sọ fún wa pé òtúbàntẹ́ láwọn nǹkan wọ̀nyí #Asa #Yoruba #Superstition | 0 |
@user .@user nikon lo gba tear gas sara ni. Abi oponu le pe awon ara Ekiti ni? Ema fi pele pele paro. https://t.co/WbP5oERwf2 | 0 |
Iwo ti an wo aparo bi ki a fi da ila, ori eiye ni o pa eiye. I am going golfing no time to translate 🏌️♂️#Yoruba #Wisdom https://t.co/RuzthSVruF | 0 |
#iroyin, #yoruba, Awon meta ti won fiya je Isiaka n'Ileefe ti foju bale ejo: Tolulope… https://t.co/3rwhWZITfu | 0 |
Eni a fe la mo, a ko meni feni denu. Inu jin! Eniyan won, eniyan soro. #Yoruba #IronuAkewi #OlayemiOlatilewa | 0 |
Lánàá ní orí @user, ààrẹ Ẹgbẹ́ Ọmọ Yorùbá New York, Alàgbà Démọ́lá Oyéfẹ̀sọ̀ ní kò bójú mu kí àwọn èwe má gbọ́ èdè. #IMTD2016 | 0 |
RT @user: @user @user @user @user ti a ba ni ka wo daada, opolopo amulumala ni àwon ti fi yí às… | 0 |
Mo kí olóṣèlú gbogbo. Àwọn ọlọ́wọ̀'gbálẹ̀, àwọn ẹlẹ́ṣin. Ẹ rọra kó owó wa jẹ o. """"""""Ó kù lódò"""""""" ni omi aṣiwèrè! | 0 |
Ìjọ ọba #SaudiArabia fi ọ̀gbẹ́ni #RaifBadawi si àtìmọ́lé nítorí ó lóun ò ṣ'ẹ̀sìn #Islam mọ́. Mo wá ní, ṣe dandan ni? #FreeRaif | 0 |
RT @user: @user Eje ki abere lowo awon jegudu jera adari wa oooo | 0 |
Èle ►► by force (kò gbà, mo bá fi ọwọ́ èle mú u - s/he didn't accept, so I handled her/him with force) #Learn #Write #Read #Speak #InYoruba | 0 |
Ìsẹ̀yín ni adájọ́ ń gba owó-ẹ̀yìn, a sì gbéjọ́ 'Sanjọ́ aláre fún 'Túnjí ẹlẹ́bi. | 0 |