text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
#PariOweYii » Èké ní í pa eléèké, #Ibeere #Yoruba
0
@user kí ló ṣe jẹ́ bẹ́ẹ̀? Bad agreement ti á jẹ́? Orúkọ ọjà àtijọ́ kan l'ó di """"""""Àgbádárìgì"""""""" kí a tó yíi sí Bàdágìrì. #Badagry
0
@user ó jẹun kò lápá... o ní yẹ̀yẹ́ :)
0
Inú àwọn èèyàn wa máa ń ro mí. Gbàgede yìí wá fún ìfọ̀rọ̀-jomi-toro ọ̀rọ̀, kí a bá ara wá sọ nípa èdè abínibí, àmọ́ bẹ́ẹ̀ kọ́ ni ti wọ́n rí.
0
A ti gba wèrè m'ẹ́sìn. Bí a ní """"""""ló ewé àt'egbò"""""""". Wọ́n á ní """"""""irọ́ o! Ìwé mímọ́ ní kí a má já'wé"""""""" :(
0
RT @user: Àyájọ́ òní ní ọdún 1930 ni bàbá baba Fẹlá, Josiah Jesse Ransome-Kútì yún'sẹ̀ òrìṣà, tí ó gba èkuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra. #Yorub…
0
.@user alai ni itiju, iwo ko lo fe lo gba owo James Ibori bi odun melo seyin? Ose je ija awon ole ponbele lo man gbe? Won sa si e ni? https://t.co/no0QVj9M0R
0
@user @user Àfi bí ẹni pé làákáyè wọn ti tẹ̀ síwájú.Tí wọ́n bá rí agolo #Raid lọ́wọ́ wa, ńṣe ni wọ́n ń fò lọ ba sí kọ̀ọ̀rọ̀ kan
0
RT @user: @user tani e n tan pelu esa yii laaro kutukutu. Enu yin dun
0
#iroyin, #yoruba, Owo ti te Rasaki to fi majele sinu amala to pa eeyan marun n'Ibokun… https://t.co/t5sD5bkG9I
0
RT @user: @user @user Àṣìwí ò tó àṣìsọ. Ìyá ọba kan wà láyé àtijọ́ tó pe'ra rẹ̀ ní Ìyá ọ̀bọ.
0
Lọ́dún bíi méjì sẹ́hìn, mo lá àlá burúkú t,ó fi ẹ̀rù s'ọ́kàn mi d'ònìí nípa 3RDMB, àfi k'ó máà ṣẹ ni, torí b'ó bá i le ṣẹ, rẹ́rẹ́ á run!
0
Ǹjẹ́ níbo l'á ti pàdé Ògún? A pàdé Ògún níbi ìjà, a pàdée rẹ̀ níbi àgbàrá ẹ̀jẹ̀ ti ń ṣàn. #OsuOgun #Yoruba #Asa #Isese
0
@user @user Ẹ̀gbọ́n, Ẹ lọ jókòó sibi kan, ìṣe tí àwọn ará Èkìtì rán yín ní kí ẹ kojumo. #TweetinYoruba
0
RT @user: Bí ọkọ̀ kan ó re Ejìnrìn, ẹgbẹgbẹ̀rún ẹ̀ á lọ. / If a bus won't go to Ejìnrìn town, thousands others will. [Alternativ…
0
Ó dìgbà tí a bá sọnù, kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí í wá ara wa rí - Henry David Thoreau #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/L9GfkQGhq6
0
RT @user: Ẹ̀yin Àràbà, ṣé ó dì'gbà tí wọ́n bá ní ilẹ̀ Áràbù ni ẹ ti wá, kí ẹ tó dá sí ọ̀rọ̀ yí.
0
Ọ̀gá kí ló dé? Kí ni k'á ti pe ti ìwà aburú? Aburú ibẹ̀ ní í ṣe ìwà ìbàjẹ́, èyí tí ò lóǹkà.
0
Ọ̀ràn à ń gbé 'ni lónìí, gbé 'ni lọ́la yìí ti wá ń kọjáa bẹ́ẹ̀ o. Ó ti sún kan ọba, ajínigbé ti di ajọ́bagbé. Ìwà ìbàjẹ́ àná ti gbilẹ̀.
0
Ọ̀ṣọ́ ọlọ́ṣọ̀ọ́ ò yẹni; ṣòkòtò àgbàbọ̀ ò yẹ́ ọmọ èèyàn. One never looks good in other people's finery; borrowed trousers do not fit the borrower. #Yoruba #Proverb #Owe #YorubaProverb
0
Wọ́n fi ère pe eré, wọ́n pajá lọ́bọ, wọ́n fi itọ́ funfun sínú, tu pupa síta, nítorí ìfẹ́ ara ti wọn nìkan. #OminiraNigeria #NigeriaAt56
0
A ti f'ojú sọ A ti f'ẹnu sọ A tún fi gbogbo ara sọ O kàn ń ṣe bọ̀dá bọ̀dá... 🎶 @user
0
Gbogbo wa la ní èèwọ̀, ó kàn dun ni ni, a ò kà á sí mọ́ torí ọ̀làjú, ó sì ń kó bá wa. #eewo
0
Ẹni kan ló mọ sunkere fakere ojú pópó Ìpínlẹ̀ Eko fà kìkì. Ìrìn-àjò tí kò ju ọgbọ́n ìṣẹ́jú lọ ṣe bẹ́ẹ̀ di wákàtí méjì mo ní lọ́wọ́. Kini a ó ti ṣe ọ̀rọ̀ àwọn Àjàgbé tó ojú pópó kan yìí. Ó tọju sú mi. #evacuatetrailersonLagosroads# @user https://t.co/5iy7CBu1Xg
0
Egúngún kò mọ iyì ara rẹ̀ ni ó ṣe kó àpò kọ́ ọrùn; bí kò kó àpò kọ́ ọrùn taní jẹ́ dúró de ará ọ̀run? #EsinOro🐎
0
Tí wọ́n bá ní """"""""Sùúrùlérè"""""""", bíi ti aya ààrẹ wa #Patience kọ́!
0
RT @user: Omi ló tán lẹ́hìn ẹja, tí ẹja fi di èrò ìṣasùn. The loss of water's backing is what made the fish an item in a cookin…
0
Ere kini aja nba ekun se? https://t.co/Msc5sMHcRB
0
RT @user: Won Ti Pa Oga Oniroyin Ni Ilu Eko: Ogbeni Dimgba Igwe to je igbakeji alase ati olootu agba fun ile ise iwe iro... http://t.co/L…
0
RT @user: Ọ̀ràn ilẹ̀ níní lóde òní kọjáa sísọ, nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti larí mọ́ ilẹ̀ tí ó jẹ́ wípé àwọn abulẹ̀ṣowó tà fún ẹni méjì t…
0
BBC News Yorùbá - ‘Tunde Kelani yan mi jẹ lori fiimu ‘Toluwanilẹ’ https://t.co/pM4Y9knnHY
0
RT @user: Eni ti ko ba ni'fe iya ti o bi i tokan-tokan, a padanu ibukun nla ni'le aye e @user does making my own Yoruba prov…
0
RT @user: """"""""Kosi lailai. Odo to ba gbagbe orisun re yoo gbe ni @user: Kíni ng bá jẹ gbàgbé ilẹ̀ Yoòbá?""""""""
0
@user Kí ló le tóyẹn🤷🏾‍♀️
0
Aya Chike Akunyili re'bi àgbà ńrè. #RIPProfDoraAkunyili
0
RT @user: """"""""@user Akunpa!!! Ikuro ninu egbe oloburela si egbe alatako ko tun iyenye kan lara egbe wa..... Shagari http://t.…
0
Me self I know nw Awon Alhaja yen Won le doyan pa #Yoruba https://t.co/C9plf9sL8q
0
.@user ijekuje o je ki e gbon. Se reluwe ti Hitler lo Ku ni enpon le ni 2015. Ni ilu Oyinbo ti Eti wa se oko fakafiki ni wan nlo?
0
Bíkòṣe ìyànjú òyìnbó láti pa iṣe wa run, pẹ̀lú ètò tí yóó mu wa gbàgbé àṣà baba ńlá wa. #kojoda #yorubacalendar
0
Èèyàn nìkan kọ́ ni kò gbọdọ̀ ta félefèle, ewúrẹ́, àgbò àti ẹran ọ̀sìn tó ba rín s'ọwọ́ olórò di sàárà. #AsaOro #Yoruba
0
Ibo oôdun 2015 ti n sun moôle,Haa, Atiku fee ba ti Jonathan je o http://t.co/EprZkrfNhk
0
Bí omí bá yalé, ikú ọ̀dọ́, àti lásìkò ìjàm̀bá ni a tún ń gbé Gẹ̀lẹ̀dẹ́. #Gelede #Yoruba #IWD #IseseLagba #obirin
0
Nínú Àkúrẹ́ ni wọ́n ti pa olóyè náà, tí ó tún mú kí ọ̀rọ̀ tó wà nílẹ̀, tún bọ̀ dàrú si. Fún ọdún mẹ́ta, rògbòdìyàn ń lọ, tí ó mú kí wọ́n pàdánù ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àti dúkìá, èyí tí ó mú kí Benin rán àwọn ọmọ ogun lọ sí Àkúrẹ́ ní 1818. Ogun 1818 jẹ́ ogun tí kò pẹ̀ẹ́
0
Òru là ń ṣ'èkà; ẹni tí ó bá ṣe é lọ́sàn-án ò ní fi ara ire lọ. #EsinOro🐎 #Yoruba
0
@user Awon amuni buni eran ibiye #Yoruba
0
Awon eni ana ni ijoba Nijeria. Eba wa fi towo towo se odigba o se fun @user @user @user @user Iwanba ti eji no ti to
0
8. #PariOweYii Ààtàn ní í jogún àkísà... #Ibeere #Yoruba #Owe
0
Sábàbí aáwọ̀ àárín-in Ifẹ̀ àti Modákẹ́kẹ́. Aago 1 #IjaIfeOyo
0
RT @user: O ma se o! Mi ò ri #tweetyoruba losé tó kója... E jé ka tun se #tweetyoruba lòjó mìí. Jooo
0
Lágbájá npe Jésù. Tẹ̀mẹ̀dù npe Allah. Làkúsègbè npe Ọrúnmìlà. Bẹ́ẹ̀ ni ìwà ìbàjẹ́ ló wà lọ́wọ́ gbogbo wọn.
0
Ta ló rántí Kókóró? Hahah. Gàrí ni wọ́n fi nṣe é. ah! A ti jẹ̀jẹkújẹ sẹ́yìn ṣá!
0
Oya eje ki ako ija igboro lo ba @user Oya eko ada, kunmo, ake ati ibon shakabula ki a lo tu @user sile. Oga @user eni ba je gbi, lo ma ku gbi, ele lo ba Fayose sewon, iyen o kan enikeni. https://t.co/aYr9T2luOM
0
@user @user @user @user Lọ́jọ́ kejì, NB ní àwọn ti darí ẹ̀sùn náà sí ẹ̀ka tó yẹ. Wọ́n fi mí lọ́kàn balẹ̀ sórí asán. @user #EtoOnibaara #consumerright #brandnegligence #LiveYourBestLife @user @user @user https://t.co/PXxaS93vbg
0
♪ Pátá ń jábọ́ ọmọge lọ wọ ṣòkòtò ♪ - #AsoKobaleNiSoosi :(
0
RT @user: @user Eko ko se oju munmun fun egbe agbabolu brazil lale yi o.#FansConnect
0
#iroyin, #yoruba, N'Ileefe, Dauda gba eru ole, lo ba foju bale ejo: Tolulope Emmanuel… https://t.co/lnTZatXEVj
0
@user Nǹkan tó ń dun àwọn nìyẹn àbí 🤣
0
Ikú àgbágbìí tún ti mú ọ̀kan lára àwọn àwòrò ṣàṣà eré ìtàgé ilẹ̀ Yorùbá lọ ọ̀run àrèmabọ̀. Bàbá Jímọ̀ Àlíù tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àwòrò ti sáájú wọlẹ̀. Ó di gbére, ó d'àrìnnàkò, ó tún d'ojú àlá. #Yoruba https://t.co/XOZnS4nhUK
0
Kí tún ní í pànìyàn láì ṣekú? Ọ̀jẹ̀ Onímọ̀ Yorùbá yún'sẹ̀ òrìṣà. Ọ̀jọ̀gbọ́n Abọ́sẹ̀dé Olúwọlé ti gbé kiní ọ̀hún rọ̀run. Oṣù kẹsàn-án ọdún yìí l'ó pé ọdún kan tí mo rí ìyá níbi ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa Èṣù tí a ṣe ní @user. Ikú dá Yorùbá lóró!
0
Ẹni táa fún ló'bì tí kò ṣ'ọpẹ́, báa fún un lọ́'mọ kò ní ṣà'na. / A person who gave no thanks when offered kolanut, wouldn't pay his dues if given a bride. [Whoever showed no appreciation for small favours is unlikely to reciprocate major acts of kindness.] #Yoruba #proverb
0
A ò fẹ́ ẹ́ l'óhunkóhun ṣe pẹ̀lú àṣà àbáláyé, a ti gbàgbé wípé, ìṣèṣe l'ó bí ọ̀làjú. @user @user #IseseHoliday #Yoruba
0
-Ojú ló ńkán àrẹ̀mọ tó ńdé fìlà, tó bá gorí ìtẹ́ bàbá rẹ̀, yóò dé ohun tó ju àrán lọ. ~~~~#Yorùbá The heir who's wearing a cap is merely in haste, he'll get to put on far more than a velvet headgear upon... https://t.co/UOUqniMRr0
0
Ni àwọn àgbà fi ní """"""""Ọwọ́ tí ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá gbé, ara rẹ̀ ní fi ń nà. #owe #yoruba #owoogede #yobamoodua
0
Ẹ̀yin àjínigbé! Ẹ ò ṣe lọ máa jí àwọn jẹgúdújẹra, àwòdì jẹun èpè sanra olóṣèlúu wa gbé, ẹ óò rí owó t'ó t'ówó gbà. Àmọ̀ràn ni. Ire o!
0
RT @user: Àyájọ́ òní, ọgbọ̀n ọjọ́ 1874 ni Ìyálóde Ìbàdàn, Ẹfúnṣetán Aníwúrà filẹ̀ ṣaṣọ̀ bí ẹbọra. #Yoruba #iseleana #history @user…
0
#AwonAdojutiYoruba 👇 Odaran, onijibiti Samson Olugbenga Oyekunle Owo ti te adojutini omo, wan si ti ran ni ewon ni ile America. Awon olopa otelemuye ilu Poland ni wan mu Oyekunle ni ilu Wroclaw. Oyekunle ti fi imu danrin ni America. Ewon osu metalelogota gbako ni won won fun. https://t.co/I4Hj391ikC
0
Jẹ́ kí ńfìdí hẹẹ́, ni àlejò fi ńti onílé sóde/Let me just hang in here, is how the guest takes over the house from the host #yoruba #proverb
0
Màjàlà = soot, burnt grass (iná jó koríko, màjàlà gba afẹ́fẹ́ kan - fire burns the grass, soot takes over the sky) #InYoruba #learnyoruba
0
RT @user: Ni ile aye ti ẹbí ẹni ò fẹ́ k’álà, bẹ́ẹ̀ sì ni wọn ò fẹ́ k’ákú. #Yoruba #YorubaPoem #OgunLaye
0
@user 1.OLE 2. JEGUDU JERA #Yoruba language
0
RT @user: @user Ko ni da fun won, awon asinwin asi'ere.
0
Kò sọ̀rọ̀ nípa ọmọ tí #bokoharam kó mọ́. A ò gbọ́ èsì ayọ̀ láti iye ijọ́ yìí.
0
RT @user: Ti eyan BA FI tipa BA omo, molebi, tabi ARA e lopo, ki lo ma se? #MarchAgainstRape #TweetYoruba
0
🎼 ohun ojú ti rí, ẹnu ò lè sọ, (ẹnu ò lè sọ) ọmọ t'ó bá l'ágídí, ẹ fi wèrè tọ (ẹ fi wèrè tọ)
0
@user Wọ́n kúkú fẹ́ kó gbogbo ẹ̀ jẹ tán ráúráú!
0
RT @user: Bí a bá ra aṣọ ẹgbẹ̀fà, tí a sì nà á han eèyàn ẹgbẹ̀fà, aṣọ ọ̀hún ò níyì mọ́. / If we buy an expensive item of clothin…
0
máa gbọ̀ndí kiri àdúgbò Áwù, aṣọ kù lọ́jà, èwo ni ti bóńfò, èwo n taṣọ pénpé kí ẹ dá, #Ewi #omoge #iwoyi
0
#FreeEvans? Ori yin kuku ti daru tele! Eyin omo iran kiran. Ani ki wan ti e je ki ewa ma lo, iwa yin o jo iwa eniyan ra ra Iwa eranko gba ni
0
Ehín erin = ivory (ọ̀gbẹ́ni Philips àti ikọ̀ rẹ̀ jí ehín erin Ìbíní ➡️ Mr Phillips and his team stole Benin's ivory) #InYoruba #learnyoruba
0
Ogun* Ati ri ina ni kanga o! Won ni oba alaye fun abirun loyun ni Ilisan. O·ba Michael Moôjeed Sôonuga fun Toôpe Oguntoye loyun osôu meta.
0
RT @user: Ni òwúrọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kan, ó tọ́ ìyá-a rẹ̀ lọ láti ṣ'àlàyé ọ̀ràn náà tí ojú-u rẹ̀ ń rí nílé ọkọ. Ó sọ fún ìyá-a rẹ̀, wípé…
0
Ọ̀rọ́ pọ̀ nínú ìwé Kọ́bọ̀, òlóòrayè ènìyàn nìkan ni ó lè kà á tán. Báwo ni a ṣe fẹ́ b'ẹ́gbẹ́ pé ní Nàìjíríà. Mánamàna ni iná mànàmáná ń ṣe, pi pi pi ni, kò dúró, àfi bí nǹkan àlejò tí ó ń ṣe ségesège. Epo rọ̀bì ni a fi ń taná lórí ẹ̀rọ-amúnáwá. #IbajeAyika
0
RT @user: @user E kuku wa di Sarumi di kaka, di kuku niyen o.
0
A gba ukuuku a gba kemberi Nje nibo lati gbe pade ogun? A pade ogun nibi ija A pade re nibi ita A pade re nibi agbara eje ti nsan Agbara eje ti ndeni lorun Bi omi ago Bomode ba ndale Ki o mase da Ogun Oro Ogun leewo Ara Ogun kan go go go!
0
#iroyin, #yoruba, Abenugan tele, Dimeji Bankole je loya lowo, lo ba foju bale ejo: Awon… https://t.co/Hf2pAnuss2
0
@user ? :( Èé ti rí? Ẹ ó sì máa ṣe bí ẹni tí ò gb'édè #OmoYoruba
0
Ìrèní = four days (ewúrẹ́ jín sí ọ̀fìn, ó gbé inú ọ̀fìn fún ìrèní ➡️ the goat fell into the ditch, it stayed there for four days) #InYoruba
0
Ìbọn t'ó wọ ìlú """"""""ẹ̀bá ọ̀dán"""""""" ò ṣẹ̀hìn obìnrin alágídí yìí. Ní 1872, #IyalodeIbadan yá ọmọ ogun Ìbàdàn ní ìhámọ́ra ogun.
0
Àfi bí àgùtàn, à ń tẹ̀lé wọn gọ̀ṣú-gọ̀ṣú, a ò já ara wa gbà lọ́wọ́ ète wọn. A ò tí ì já ara wa. @user @user #IseseHoliday
0
RT @user: """"""""Ó dára, Jọkẹ́. Kí a pa Yẹ́misi tì. Délé ńkọ́? Kí ni èrò rẹ nípa Délé? Ǹjẹ́ lè jí alùmọ́gàjí náà gbé? Yorùbá Detective Fi…
0
wọn ma kìí mọ́lẹ̀, tí wọ́n ma lọ pá dànù ní ojúbọ ni.
0
Ilú tí ọmọ ológì ò mọ ẹ̀kọ pọ́n #Nigeria
0
O ní “who Yorùbá epp!"""""""" Orí ẹ ò dáa pínìnpínìn fọ́rọ̀ akídanidání tí o fọ̀ jáde ní káà ẹnu. Iṣẹ́ ti dáhùn lára ẹ. Ó ṣe! #EdeAbinibi #IMLD17
0
Mo ti wo ipinle Osun lati gabruku ti Omisore ati lat le le @user kuro lori alefi - @user Fani Kayode Lo so be!
0
RT @user: @user nkan ti Fashola so ko mu Ogbon lori
0
Kàkà kó sán lára ìyá àjẹ́, ó ń fi gbogbo ọmọ bí obìnrin, ẹyẹ́ ń yí lu ẹyẹ. Ẹ ti fẹ́ẹ̀ kó owó wa mì tán. Ẹ̀ ń wùwà tani yóò mú mi. #IjoOle
0
RT @user: Erin ẹgàn-an Myanmar ń bẹ ń'nú ewu, àwọn adẹ́mìí légbodò kò jẹ́ kí wọn ó gbáyé, erin kan lọ́sẹ̀ kan ni wọ́n ń pa. https://t…
0
🎵""""""""Ọmọ tí babá bí, tó gún bàbá rẹ̀ lọ́bẹ kò jẹ̀bi ẹ jẹ́ á fura. Ọmọ tí bàbá bí ò jẹ́ hùwà èpè."""""""" #Orin #AyinlaAdegators #FathersDay #Yoruba
0
RT @user: Oníṣẹ́-ìròyìn ní Nàìjíríà: 1.Agbébọnrìn pa Lawrence Okojie ń Benin ń'nú oṣù Agẹmọ 2017. 2.Ọmọẹgbẹ́ ọkùnrin 7 dìgbòlu oníròyìn…
0
RT @user: Mo ṣàkíyèsí kan. Bí mo bá túwíìtì nípa ìṣẹ̀ṣe, ara àwọn kan kì í gbà á, wọ́n á ṣíra tẹ àìbárìn, wọn kò tẹ̀lé mi mọ́. Òtítọ́…
0