text
stringlengths 9
354
| label
int64 0
1
|
---|---|
Biribiri loju un yi. Bonbo laguntan wo. Eni ti oba se ote si Yoruba ogiri alapa lo ma wo luwan pa ogiri alapa. Awon afibi su olore | 0 |
ọmọ yorùbá oní ìsọkúsọ 😅😂😂👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding… https://t.co/JWD5rxemXW | 0 |
Bólóògùn ìkà bá ṣe oògùn fún elòmíràn, tí ó sì fa ikú ẹlòmíì, bí àkàrá bá tú s'épo, olóògùn ní láti fi ẹ̀míi rẹ̀ dí i. #IdajoNileYoruba | 0 |
RT @user: #iroyin, #yoruba, Wahala ninu egbe oselu PDP ! Awon Adagunodo lawon o nii lo sipade… https://t.co/p8RjQ2IRWR | 0 |
RT @user: Yorùbá Idiom for today: """"""""Jẹ iyán níṣu"""""""" - To be greatly punished. #learnyoruba #yorubaidioms⠀⠀ #onlineyoruba #languagel… | 0 |
Ọmọ aṣòótọ́ Ìlọkọ ni í sun ilẹ̀ẹ́lẹ̀, purọ́ purọ́ wọn ni í gorí ẹṣin. | 0 |
Alabosi ni @user bi @user se ma gbemisoke ni adura Fayose lowuro, losan ati lale. https://t.co/nzKEmXhTDe | 0 |
Ìjà yìí kà ha tán bá'un. Owó a wá ńjà fún wá ń kọ́? #ASUU #NIGERIA | 0 |
... Bó wà nílé a ti pà'yá ẹ̀ jẹ. Òjó Abádìyẹ-sàba-lórí-ẹyin"""""""". #Oriki #Ojo | 0 |
.@user @user @user @user E te je je o! Be egbe @user ni gbo gbo yin jo wa. Rukerudo ti onlo larin eyin ololoselu, ti oba di bi o lo, oya, omo mekunu ni ema fi ori won fo agbon. Awon omo tiyin jaiye fami lete kin beto ni ilu oyinbo. Ete je je. | 0 |
Masanfani eda ni arakunrin Jose mourinho. Eri WA pe ako fun ni ikola Enu Rara Pelu Awon oro alufansa t'on jade loore koore. #TweetInYoruba | 0 |
Tí wọ́n bá ní """"""""ènìyàn fi kàsádà lé àgbọn"""""""", èyí túmọ̀ sí wípé, ẹnítọ̀hún wọ ìyá kò bá bàbá tan aṣọ #owe #yoruba #idahun #ipapanu @user | 0 |
Aare Orile ede Nijeria Dokita Goodluck Jonathan ko ni lakaye bi ogbon to peye lati se iboba. Gomina Ipinle Eko Babatunde Fashola lo so be | 0 |
Ọṣẹ ìwẹ̀ oní èròjà àtọwọ́dá ni àwọn èèyàn wa yàn láàyò, wọn gbàgbé pé erùpẹ̀ ni wá, ohun ìṣẹ̀dá t'ó ti ilẹ̀ wá l'ó yẹ ara wa. #Yoruba | 0 |
Ojú boro kó lafí ngbomo lówó èkùró Achieving something worthwhile isn't easily #AfricanProverbs #Yoruba | 0 |
A fẹ́ pupa láwọ̀ ṣá ní gbogbo ọ̀nà. Láìmọ̀ pé ó ńkó bá ara. #arabibo #bleach #omoyoruba #yobamoodua | 0 |
A ò mọ̀yí Ọlọ́run yóò ṣe"""", kò jẹ́ ká bínú kú. #Owe #Yoruba | 0 |
Ègún àfọwọ́fà pọ̀ ju ègún àfiṣe lọ. Àṣà ìgbàlódé l'onìgbà ń lò ti gba Mọ́ndé gbé Sátidé le wa lọ́ọ́. Kí wọ́n ba wọlé sí wa lára ni wọ́n fi parọ́ ayérayé fún wa nípa nǹkan ìbílẹ̀ wa. Ìgbésẹ̀ yìí fa ìfàsẹ́yìn fún wa nílẹ̀ adúláwò. #OgunIleAye #EgunIdile #Yoruba | 0 |
RT @user: Oko-ẹrú la sì wà ní orilẹ̀ Nàìjíríà. A kò tíì gba òmìnira kankan, ká má tan'rawa jẹ. Omi-Ìnira la gbà kìí ṣe òmìnira. | 0 |
RT @user: Ikú àgbágbìí tún ti mú ọ̀kan lára àwọn àwòrò ṣàṣà eré ìtàgé ilẹ̀ Yorùbá lọ ọ̀run àrèmabọ̀. Bàbá Jímọ̀ Àlíù tí gbogbo ènìyàn… | 0 |
Nǹkan bíntín tí ò tó nǹkan wá ń díjà sílẹ̀ láàárin ìlú méjì, mẹ́ta. Ìkólọ ogun ni akónilẹ́rú ń wá. #nigbatiwonde | 0 |
RT @user: @user @user @user B'ónílé ò f'ura olè ni yóò kòó. | 0 |
RT @user: """"""""Àwọn àgbà ló máa ń pòwe pé """"""""ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀!"""""""" Ìbínú àbíjù le kóni sínú ìyọnu. Lóòótọ́, ọmọ àlè… | 0 |
Pastor Alagba Ijo Suleiman ti eba ti e fe je opolo, ewa opolo ti oni eyin ninu. Efi Iyawo to ore wa sile, ewan tami oge lori @user https://t.co/9klG5aWxcd | 0 |
RT @user: @user iya Agba ti se fun mi ri ni kekere, """"""""ko si ba se le se ebolo ko ma run igbe"""""""" #Yoruba Odun se efo! | 0 |
... èéfín epo rọ̀bì nínú afẹ́fẹ́, ẹran ìgbẹ́ t'òun ẹja àpajù nínú ibú l'ó dá kún un, tí ojú ọjọ́ fi ń yípada. #IyipadaOjuOjo #Yoruba | 0 |
Ààrẹ ọ̀nà kakaǹfò kì í fọwọ́ rọrí sùn, wọn fọwọ́ rọrí sùn, ikú ò l’órúkọ méjì, ikú nikú ń jẹ́. #AareOnaKakanfo #Yoruba | 0 |
Kí ète wọn ba a r'ọrùn, wọ́n ṣe ìpèsè ohun amáyédẹrùn bíi ọ̀nà, tí ọkọ̀ wọn yóò rìn. À ń ná owóo wọn. #Nigbatiwonde | 0 |
@user Ile Naijiria padanu N76B lododun lori kiko anamon wole #TweetinYoruba | 0 |
Gbogbo ibi la ti ń bá ọ, bíi ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ Ìwọ lónìí, ìwọ lánàá bí ẹkún apọkọjẹ Wàá gbé dúdú, gbé pupa, | 0 |
RT @user: Omo to je igbadun gbagbe ile woni oso apo iya re koni .Omo ale yoruba ni o Femi Adeshina.A total disgrace to the yoruba rac… | 0 |
Egbe agbaboolu #barcelona fi di remi lale ana ni idije #Spanish #laliga #EdeYorubaDunLeti #yoruba #yorubanimi #yorubaculture #photo @user Somewhere in Nigeria https://t.co/vbdLu3kcXv | 0 |
2. #Parioweyii Bí ebí bá pa Ajé... #Ibeere #Owe #Yoruba | 0 |
Yoruba omo Oodua. Eni ba koju ote bo ile Yoruba ti e tan. Oruko rere San ju wura ati fadaka lo. @user @user @user oju ti yin | 0 |
Opuro ni Obasanjo ni se lo dobale ti ohun be wa ni odun 2003-Olusegun Osoba - YouTube http://t.co/5m6Xnf5UgQ"""""""" | 0 |
RT @user: Báa gún iyán, táa ro ọkà fún kòfẹ́kògbà, kò ní fẹ́, kò ní gbà, náà ni. #Yoruba #proverb #HopeWithYorubaProverbs | 0 |
Òwú ò sí ní'lé, abẹ́rẹ́ wọ́n lọ́jà"""" ni'gbe ahun t'áṣọ ọrùn rẹ̀ fi ń di àkísà. #Yoruba | 0 |
Ogun bẹ́ sílẹ̀, a ti iná bọ ilé, ọ̀gbìn jó mọ́ ilẹ̀ l'óko, àgbà àti ọmọdé kú ikú afináfọnṣu, ìlú di ahoro, koríko gbalẹ̀ padà.#nigbatiwonde | 0 |
Wahala dey o 😀😀😀. Abirun bawo? #lagos #abia #anambra #enugu #imo #ebonyi #yoruba #igbo @user Lagos, Nigeria https://t.co/Kj8ADy62FG | 0 |
Wọ́n ti pa ní mọ́ṣáláṣí, ṣọ́ọ̀ṣì, wọn ò yọ ẹlẹ́sìn kan sílẹ̀. Èmi ò rò pé ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ni tilẹ̀ yìí o. #bokoharam | 0 |
mọ̀jà mọ̀sá niyì ọdẹ. Ọdẹ tó mọ̀jà tí ò mọ̀sá, ẹranko burúkú ní í mú irú wọn jẹ. #owe | 0 |
Otito oro, omo iya isokuso ni. Ipade oloselu ni 🇳🇬 ko ja mo nkan nkan ju ki a gba ijoba #Yoruba https://t.co/1ieuxzPVOf | 0 |
Impeachmentì bá wo? Ẹ se ure! Kílóń jẹ́ #impeachment. Ẹ se ure! ♫ #ElemureOgunyemi | 0 |
Àwọn kan ò sanwó (bí ìyá Fẹlá), wọ́n bára wọn látimọ́lé, síbẹ̀ wọn ò bojú wẹ̀hìn fífẹ̀hónú wọn hàn síjọba. #IseleAtijo #Yoruba #Kirikiri | 0 |
1807 l'òfin ìfòpìnsówò ẹrú. Ká má tan 'raa wa jẹ, òwò ẹrú kòì tán ńlẹ̀, bẹbẹ ṣì ń lọ́ l'ówò ẹrú, òwò ẹrú ìgbàlódé la pèé. #RememberSlavery | 0 |
Agbanipa- hire killer (òkè àjà làwọn agbanipa bá wọ yàrá - the hire killer entered through the ceiling) #InYoruba #learnyoruba | 0 |
@user Èmi ò mọ ẹni tó dá irọ́ yìí sílẹ̀ o. Ara nkan tó nfa wàhálà fún èdè abínibí ní Afirika nìyẹn. | 0 |
Elo da Egbe tiyin sile, abi ewo ni soboloke, ariwo lenu fendo lori egbe elegbe, esa ti gbe apoti ibo, ede ti fi idi re omi. https://t.co/gAGA9xpvPw | 0 |
Ma see o Eewo ni. to difa fun eni ti baba e ku ti o jogun iya e | 0 |
Ìtesíwájú ète wọn ni a fi dá ilé-iṣẹ́ West African Company Limited, Company of African Merchants sí èbúté odò Ọya ní 1863. #Nigbatiwonde | 0 |
tí wọ́n wà ní Ìgbẹ́ìn. Láàárín ọjọ́ mélòó kan, àwọn ọmọ Ẹ̀gbá pa ẹgbẹ̀ta (600) Ajẹ́lẹ̀ ní Ẹ̀gbá. Nígbà tí Aláàfin gbọ́ èyí, ó rán àwọn ọmọ ogun, láti Ọ̀yọ́, Ẹ̀gbádò àti Ìbàràpàá lọ sí Ẹ̀gbá, kí wọ́n lọ jẹ Ẹ̀gbá run. Ṣùgbọ́n, nígbà tìí Kakanfò, Baálẹ̀ | 0 |
Irọ́ ni @user àti àwọn ilé isẹ́ oníròhìn bẹ́ẹ̀ máa ń pa nípa ilẹ̀ adúláwọ̀. Àfikún àti àsọdùn wọ́n pọ̀. #MediaImperialism #Ghana | 0 |
Èwo ni k'á fini joyè #Abobaku tí a ò le è bọ́bakú! Ẹyẹlé ì í bá onílé jẹ, b'ónílé mu kí ó dọjọ́ ikú kó yẹrí. #AbobakuOoni #Yoruba | 0 |
RT @user: @user @user ah! Enu yin lo ti ma gbo pe iya teacher ku | 0 |
#iroyin, #yoruba, Isu ogota ni Kehinde ji, ladajo ba ni ko loo lo odun mefa lewon: Tolulope… https://t.co/cIn2HlFYPK | 0 |
Bojúbojú ni èmi kà á sí wípé Abọ́bakú rọ́ gbẹ́. Àwọn kan ló wà nídìí ìròhìn irọ́. #AbobakuOoni #Yoruba | 0 |
Agba ofifo, empty barrel lo maa n pariwo. #emptybarrellomaanpariwo #ariwokonimusic #emptybarrel #akukoogbon #oluomoolu #Yoruba #asa #ede https://t.co/TTCYhS9HeM | 0 |
Ikú d'óró. Ikú ti pa ọ̀kan lára àwọn ògbóǹtarigi àgbáṣà àti èdè Yorùbá lárugẹ, bàbá Akínwùmí Ìṣọ̀lá ti di ẹni ilẹ̀. Ó di gbére, ó d'àrìnàk, ó dojú àlá. Sùn-un 're o!!! #Yoruba https://t.co/MxLr441wKt | 0 |
Wọ́n ti ní ká yéé mu kọfí mọ́n ní gbogbo ìgbà. Tíì 'gbóná náà ò kẹ̀rẹ̀. Àgàgà tó ba jẹ́ eléwé tútù. http://t.co/JMs3cRTk | 0 |
RT @user: """"""""@user: Ìyà yí pọ̀ #BrazilvsGermany"""""""" iya o to iya ni nje 'koni da fun eni to na mi' ese, adupe ni oye ki Brazi… | 0 |
ko ko ko la n rọfa aditi. Wi fun Twita. Dandan ni ki wọn gbọ,tulasi si ni ki wọn gba, tori oun ti a wi fun ọgbọ lọgbọ n gbọ #TwitterYoruba | 0 |
Onínáa mànàmáná! Kí la ṣe? :( #Nigeria | 0 |
Nígbàtí ìyáa Ríyìíkẹ́ bíi léèrè pé 'ẹja n bákàn', tí Ríyìíkẹ́ sì ní """"""""ẹja ni o""""""""... #Ejanbakan #idahun #Yorùbá #AkanloEde | 0 |
Kí ni ti Nàìjíríà ńbẹ̀? Mo mọ̀ wípé ejò lọ́wọ́ ń'nú ni ti Gambia, ebi tó kọjú s'ẹ́nìkan ẹ̀hìn l'ó kọ s'ẹ́lòmíì, àbí àwọn olóṣèlú kọ́! Ìran. https://t.co/AuP29Rs4lz | 0 |
.@user kan ni enu lasan bi ti aje akara ni o. Ojo lasan lasan ni! Sowore oludari @user lo so be http://t.co/v2WY0XszLS | 0 |
RT @user: @user @user Ko Si abo fun enikeni mo ni orile ede yi – Falana http://t.co/aVQW4XGh0c"""""""" | 0 |
Kódà bi ilé èjó ba fi èsùn ìwa òdáran kan e, sugbon ti won ba ti da e lebi, #Law2go #HumanRightsinNigeria #Section35 #Yoruba | 0 |
Bí irè irúgbìn GMO ṣe máa ń pọ̀ yamùrá ju t'ìṣẹ̀dá lọ, ni ó ń pa àǹfààní ilẹ̀ ọ̀gẹ́rẹ́. @user #YPARD10 #Agricultureinnigeria #IyipadaOjuOjo | 0 |
RT @user: @user sugbo o seni laani wipe owo ti won fi n mu awa odo ti se yepere ju bi o se ye lo. Oun lo se okunfa ai si is… | 0 |
Òjò ń rọ̀ inú orí ń dùn. Àfi bójò bá tún rọ̀ lọ́la, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, ooru ọ̀la ò ní ṣe é kó. | 0 |
Adìẹ KFC kò dùn mọ́n! https://t.co/pTdEMiv6hb https://t.co/sbWlaYcxPd | 0 |
@user """"""""The 10x rule"""""""", """"""""Wọ́n rò pé wèrè ni""""""""and"""""""" Ládépò ọmọ Àdánwò"""""""" and more if time permits me | 0 |
RT @user: Atoto Arere..Arakunrin kan dana sun iyawo re lori esun wipe o n bi obinrin...arabinrin naa ti wa ni baku'bala bayi ni … | 0 |
Àìní ìforítì àparò ló sọ ọ́ di aláṣọ pípọ́n. Translation: Patridge's lack of perseverance is what gave it its dirty garb. Usage: Perseverance is it; Lack of perseverance may deprive you of what ought to rightfully be yours. #Yoruba #proverb | 0 |
@user haha. ọmọ yìí má pamí o | 0 |
RT @user: Ẹ gbọ́ o. Eré ni àwàdà ni, àwọn ẹ̀fọn wọ̀nyí gan-an, ó dàbí pé ògùn ò rànwọ́n mọ́ o. A fí wọn, wọn ò kú. Nkan mà wá d ... | 0 |
Láká-ànláká ò ṣéé fi làjà; ọmọ eégún ò ṣéé gbé ṣeré. A limp is no great asset for a person wishing to stop a fight; a masquerader's child is no easy playmate. #Yoruba #Proverb #Owe #YorubaProverb #AfricanProverb | 0 |
#tweetinyoruba Awon a soju aiye ori Twitter. Oyinbo ni gbogbo won so lori ago. Won a wa si Twitter, won a ma pariwo Yoruba. | 0 |
Mẹ̀kúnnù yìí náà ni. Oríi mẹ̀kúnnù ni wọ́n fi ń fọ àgbọn. Wọn ò mọ̀ bí ebi ń pa ọmọ ẹnìkánànkan. #OminiraNigeria #Nigeria | 0 |
Bí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ kò bá tẹ́ wọn lọ́rùn, wọn ma yanjú ẹni náà ní ojúbọ ni. Àwọn ohun wọ̀nyìí tí wọ́n ń ṣe, ni láti dẹ́kun kí wọ́n yé kó àwọn èèyàn wọn tí wọ́n lọ ń tà sí oko ẹrú. | 0 |
Egbe Oloselu UPN tife tu mo Dokita Frederick Fasehun Lori o! Awon Alakoso egbe ni Wombia Adanikanje ni Dokita Fasehun http://t.co/y0PBxpJsUa | 0 |
RT @user: #LayajoOni ni Odun 2005 Iji lile(hurricane) Katrina se ose ni etido orilede America egberun eniyan ni o sofo emi ninu … | 0 |
RT @user: @user @user @user @user @user @user @user nikan lo le gbawa lowo awon agbaya wọn… | 0 |
Ẹ̀yin eléebi ṣé ẹ ti rí? Ìrẹsì tíò dáa fún jíjẹ ni Fáyọ̀ṣe há. Ó ga o @user @user http://t.co/zHwQY2JR0l #Thailand #Naija | 0 |
@user Broken calabash desert the river..... abinu eni dehin leyin mi #yoruba #Nigeria | 0 |
Ẹni tí bíńtín ò tó, púpọ̀ yóò jìnnà sí i. / Abundance will be far from whoever is not contented with a little. [Contentment is it; it makes for increase.] #Yoruba #proverb https://t.co/Zwq2uZhTAB | 0 |
Mo gbọ́ pé wọ́n pa èèyàn nítorí Gaàrí. #Nigeria :( | 0 |
Nigba ti eshinshin nje elegbo, ko s'eni to rii. Igba ti elegbo ba n je eshinshin, e wa n soro... Yoruba, e ji, e maa sun #sundayigboho #yoruba #igboho | 0 |
Àwòdì re ìbarà, wọ́n ṣe bí ẹyẹ́ kú. #Owe #Yoruba | 0 |
Eniti ko ni o, ko ni nkan kan. Eniti ko ri'se e, ko ri nkan kan. Eniti ko ri mi, ko ri'se Olurun. If you know, you know😃😂😆 #yoruba, #topealabi, #topealabimusic #rccglobal, #christian… https://t.co/7WrmqIwB6A | 0 |
Emadibo fun Ebele Nebu o!Otun ti un se oju anu! Tí ẹ̀dá bá fẹ́ gbàwìn ẹ̀bà ni wọ́n máa ńṣ'ojú àánú; tí wọ́n bá yó tán wọ́n á d'ọkọ olúwa wọn | 0 |
Lánàá wọ́n wá fi agbára kó ìlú òdìkejì, òní ìlú tìrẹ, b'ó dọ̀la, ó lè jẹ́ ìlú ọ̀rẹ́ẹ̀ rẹ. Hílàhílo, ìfòró-ẹ̀mí lójoojúmọ́. #OminiraNigeria | 0 |
RT @user: @user @user @user @user @user Nkan ti e hun so fun wa nipe kii awa omo Yoruba f'ipa ta ip… | 0 |
ìwé ìrìn àjò Olúfúnmiláyọ̀ ṣe. Olúfúnmiláyọ̀ pẹ̀lú àwọn aṣojú tí wọ́n lọ dúnà-dúrà lórí òmìnira Nàìjíríà. Ní àsìkò 1970, ó yí orúkọ rẹ̀ kúrò ní Ransome-Kuti, sí Aníkúlápò-Kútì Ní oṣù Èrèlé, 1977, àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà, ju Olúfúnmiláyọ̀ sílẹ̀ láti orí òkè, ní | 0 |
Aláàfin Aólẹ̀ wí fún Baṣọ̀run kí ó pèsè Kùránì náà. Ṣùgbọ́n, Baṣọ̀run sọ wípé, òhun ò mọ ibi tí Kùránì náà gbé wà. Ni inú bá bí Aólẹ̀, ló bá ké pè sí àwọn Alálẹ̀, tí í ṣe Ṣàǹgó, láti wá Kùránì náà jáde fún òhun, bí èèyàn ò bá ní wa. Àrá bá bẹ̀rẹ̀ sí ní lu àwọn | 0 |
RT @user: """"""""@user @user @user Egbe Oluburela ki Gomina Fashola lo ri iku Pa Fashola, Ajalu nla leyi http://… | 0 |
RT @user: Erín kú mọ̀ngúdú fi jẹ, ẹfọ̀n ku mọ̀ngúdú fi jẹ, mọ̀ngúdú wá kú kò rí ẹni tí yóò jẹ òun. #yoruba #proverb | 0 |
@user ... olè gbé e, olè gbà á. Ló bá tán! | 0 |
Ẹ̀pa ò bóró mọ́, ọ̀pọ̀ ìdílé ni ò ṣe orò ìdílé mọ́, ìran atẹfá ti da ikin Ifá rẹ̀ nu s'ódò tí omi ti wọ́ lọ. #IseseLagba #Iseseday #Yoruba | 0 |
Ta ló máa gbà wá lọ́wọ́ àwọn ìjọba òde òní? Àwọn oníṣẹ́ ọpọlọ ni wọ́n ń fi ìyà jẹ. Bí wọn kò t'akọ̀ròyìn mọ́lé, wọ́n á pa á lẹ́nu mọ́n. Olóòtú àti àwọn ayàwòrán eré nìjọba kan tún ń dá sẹ̀ríà fún nítorí iṣẹ́ ọpọlọ wọn. #DefendBakur #OminiraOroSiso | 0 |