text
stringlengths 9
354
| label
int64 0
1
|
---|---|
.@user ipo giga ti e fi parowa pe ema gbe omo karo ojire si ninu ipolongo ibo aare Nijeria ni odun 2019 da? Se agba ofifo lasan lasan ni? Koda @user ti wa di eni awati ninu ipolongi yin, se apere bi ijoba @user se ma ri re? Ile lapoti joko de idi. Be efe ka ta omo wa lopo | 0 |
Ọ̀lẹ ni ó ń di olè | 0 |
Wọ́n sọ̀rọ̀ bú ẹni tí ò gbààwẹ̀. Ẹ ó máa gbọ́ """"""""ajọ̀sán"""""""". Bí wọ́n bá rí i níbi gbé ń jẹun, wọ́n á ní """"""""lọ́sàn-án ààwẹ̀!"""""""" #AlayeOro #Yoruba | 0 |
Áwù, aṣọ kù lọ́jà, èwo ni ti bóńfò, èwo n taṣọ pénpé kí ẹ dá, Kò balẹ̀ le fi ṣe Àbí ẹ ò mọ̀ pé aṣọ àbúròo yín lẹ wọ̀? | 0 |
@user @user Eleyi ti j'efo riro...#TweetinYoruba | 0 |
RT @user: ☺ agbara lo koja ni wa'ju ile oba ti o ko ba""""""""@user: @user hahaha ko ní se bee mó"""""""" | 0 |
RT @user: Ose o.eni ba f'oju agbara wo kudeti,omi ni n gbe'ru won lo """"""""@user: Ajírorín, ajíbọ́jú ni mí. Ọ̀bùn èèyàn ní í fo ... | 0 |
Ẹ̀wá wo bí agbèrò ṣe fọ́ kọ̀ndọ́ kan lójú l'Óṣòdí t'ẹ́jẹ̀ ń dà ṣuuruṣu nítorí ìyẹn ò fún un lówó oríta. @user @user #lagos | 0 |
àyà wọn. Èyí tí à ń pè ní Igbá-Ọmú. Ní àsìkò ọdúnrún mọ́kàndínlógún, àṣà wíwọ ìró àti bùbá dé, láti lè bo ara ati àyà obìnrin pátápátá. Èyí wáyé láti ara àwọn ọmọ Yorùbá ti wọ́n kàwé lókè òkun àti ìfagbára múni ìjọba Britain. Wọ́n ní, kò bójú mú fún kìrìsìtẹ́nì láti | 0 |
Ìdíwọ́ díẹ̀ wà ní #Westest kí á tó dé #Charleboy. Kòtò títì tí wọ́n ń dí ló fà á @user http://t.co/Ti68Yel8p1 | 0 |
What animal is knows to be very cunning in Yorùbá folktale? Ẹranko wo ni ó ní ọgbọ́n ète láàárín àwọn ẹranko nínú àwọn ìtàn Yorùbá? | 0 |
Omo ti a ba bawi, ti o ba warunki...O ma parun lojiji ni. #yoruba | 0 |
Akaba yìí kan náà ni ó jágbọ́n idà tí ó mú tó láti bẹ́ orí ọ̀tá péú lọ́wọ́ kan bí èlé ṣe ń bẹ ajá Ògún. #OgunDahomeyAtiEgba | 0 |
RT @user: Ojú á tún'ra rí; òwe àkàlà. #EsinOro🐎 #Yoruba | 0 |
RT @user: @user Ki la gbe ki le n ju? | 0 |
.@user ti aro wipe o gbon, ase bintin lopolo re. Oni ti a o ba dibo fun GEJ Niger Delta yio no wa ni pasan http://t.co/EInnW5uTLb | 0 |
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyínká ní ìjọba wa ń ṣe bíi ọmọdé #CNN #Amanpour #BringBackOurGirls @user http://t.co/XWpV9msiEe | 0 |
@user @user Àtapa ni oyin yóò ta ẹni bá 'ru igi oyin'. #Yoruba #AkanloEde | 0 |
Ṣé ẹ mọ̀ wípé àwọn èròjà tóyìnbó fi ńṣe ìpara àti ọṣẹ ìbóra wọ̀nyí ló ńfa jẹjẹrẹ orí àwọ̀? #arabibo #omoyoruba #yobamoodua #bleach | 0 |
Sugbon Oorun osan oni yii ko mu owo ero wa rara, nise ni o n gbona lala | 0 |
RT @user: @user o gba ojo iku niyen | 0 |
Àṣẹ̀hìnwá àṣẹ̀hìnbọ̀, ohun tí wọ́n sọ fún wa wípé àwọn fẹ́ ṣe kọ́ ni wọ́n ṣe. #Nigbatiwonde | 0 |
@user mo gbọ́. Lánàá ẹ ní n yọ mo sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ ṣe bẹ́ẹ̀ kò yí padà. Mo pa #Data pa #Data, kò sí àtúnṣe. | 0 |
Arun Ebola: Iyawo Aare Damuuu Patience Jonathan ofe gba owo mo o https://t.co/B7oOGJn46y | 0 |
RT @user: Èpè ò jà b'ẹ́nìkan ò rọ̀ ọ́. #EsinOro #Yoruba | 0 |
RT @user: @user Keke ologere la wa na o ma gun ni ilu eko. Latari pe ko si epo petrol. | 0 |
@user: Emenike Iyalaya e ....."""" Rọra àwé #idanoripapa | 0 |
Kí àkóso okòwò adú ba di ti wọn ni wọ́n fi f'ogun bá wa jà.1861 ni Britain gba Èkó lọ́wọ́ Elékòó, Ọba Dòsùmú. #Nigbatiwonde | 0 |
@user epele. Afi bi ere afi bi awada. Eti un fi pelepele sun mo ewon re o! Gbo gbo ere asala ti esa ti di ofo. Ipade si koootuuu! | 0 |
̣Provérbio Yorùbá *Iná l'ọmọ aráyé le pa; Kò S'ẹni tó lè pa èéfín* """""""" humanos só podem apagar o fogo, ninguém pode apagar a fumaça """""""" #cultura #candomblé #yoruba https://t.co/cRpvi8HLPL | 0 |
Ọmọge aláìlójútì. Ilé sílé sílé lọ́ ti ń ká wọn láṣọ s'ókè. Ẹ ṣọ́ ṣe #Ife #AyajoOlolufe | 0 |
Gbajúmọ̀ ọ̀rọ̀ Yorùbá yìí; MÁ SỌ MÍ DI ẸDUN ARINLẸ̀, jáde láti inú àrà tí Ẹdun ń dá. Ẹdun yára sáré, àti wípé, kò sí àrà tí wọ́n kò lè dá lórí igi. Ṣùgbọ́n, tí wọ́n bá dé orí ilẹ̀, wọ́n ma di ọ̀lẹ ni. Ó sì yára láti ṣe wọ́n ní jàm̀bá lórí ilẹ̀. | 0 |
RT @user: @user @user @user @user @user @user Oniro ni yin e ko si Mon tin en se pelu eyin… | 0 |
Ẹ ò rí nǹkan ṣe síi àwọn #OPC tí ó fọ́ ọmọlọ́mọ lójú, tí ẹ sì ba ọmúu rẹ̀ jẹ́. - #AjataOja | 0 |
RT @user: @user @user @user ,to bà ya ni sin yi....wan atun ni awon o sò bè ô! | 0 |
Wọ́n sinmi sí abẹ igi ràbàtà kan. Oǹgbẹ ń gbẹ wọ́n, kò s'ómi fún wọn láti mu, ẹkún àwọn ọmọ yìí gba igbó kan. #ItanOdoIyewa | 0 |
Be eyankan lobi eranko yi! Se awon Hausa ati Fulani nikan lodibo fun @user ni odun 2015 ni? Ti aba se ofintoto ko seni to ran were nise o https://t.co/gjTGIpK2am | 0 |
♪ ... Àánú rẹ ló ṣe mi o, ló jẹ́ kí n bá ọ dámọràn, pé k'ó o bíbejì k'o tó bó'ra ♪ ~ Àyìnlá Ọmọwúrà. #Yoruba #music #Orin | 0 |
Àwọn aṣojú wa ní 🇳🇬 nù un. Kòkòrò ẹ̀wà tí í ba ẹ̀wà jẹ́. https://t.co/MAFpo38Tz3 | 0 |
Ìjà kékeré kan ló wáyé láàrínín ìjòyè Aláàfin Ṣàngó méjì, ìjà yìí ló sì dàlú Ọ̀yọ́ rú #worldsangofestival #Sango #Oyo | 0 |
#yoruba mom b like """"""""shy wa jesi olonje Iya."""""""" N u mistakenly say beni Then gbam she says """"""""too ba like iwe bi o shy like onje o ba ti gbe first. WO awon egbe ee ti wo university."""""""". Child """""""" momi mo ti yoo."""""""" | 0 |
Òlè ò ráyé wá o, ibi ọmọlọ́mọ ni alápámáṣiṣẹ́ já gbà. | 0 |
RT @user: Dójú tì - To disgrace/embarrass ⠀ Àpẹẹrẹ: """"""""Ọ̀rẹ́ rẹ̀ dójú tì í"""""""" - His friend disgraced him. ⠀ #learnyoruba #yorubaidiom… | 0 |
Èèrà kò fẹ́ pòòròpóòrò dénú; ọmọ aráyé ò fẹ́ ká jẹ̀bà nínú àwo tanganran. #owe #Yorùbá | 0 |
RT @user: @user kilo de ti awon omo orile ede Liberia o le fidi mole ki won ye pin aisan na kiri? Awon akobani ekute ile | 0 |
RT @user: @user @user @user Gbogbo aniyan ati ishaluwala ologbo ogbeni @user ko ju ati je eran dindin lo. Amo o… | 0 |
Kaada fun Osi. 👉 Yorùbátv ẸGBẸ ỌMỌ OLÚWA BÍ GBOGBO ÀGBÁYÉ Ojú òpó ìkànsíraẹni 🇳🇬🇹🇬🇧🇯🇧🇷🇨🇴🇨🇺🇬🇭🇨🇮______________________________□ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #hausa… https://t.co/r4PmWiv6X4 | 0 |
Ẹbọ ní ńpa ẹlẹ́bọ, èpè ní ńpa elépè, àsàsí ní ńpa alásàsí ♥ #owe #yoruba #proverb #yobamoodua ♥ | 0 |
Eniyan o ton ra re bi Iya beji.... ejo, ewo ninu yin ni tan Aaare @user https://t.co/EUVwduTyeO | 0 |
Àwọn dìndìnrìn kan á ní a ò ní ìtàn àkọsílẹ̀; òwe, oríkì, ìjálá, ìyèrè Ifá ńkọ́? Àwọn wọ̀nyí kún fún ìtàn-an wa | 0 |
Àánú #BarcaFc tó ń jẹ́ #Messi ló ṣe #ManCity pa o! @user #IdanOriPapa #UEFA | 0 |
#Naija gba wèrè bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ṣá o. | 0 |
😂😅😂😅😅😅😅😢 Alai ni nkan se □ Yoruba TV 🥰😘🔥 #yoruba #yorubatv #yorubaweddings #ebi #asoebi #nigerianwedding #hausa #igbo #yoruba #oodua #oduduwa #ondo #oyo #lagos #kogi #edo #delta #ogun… https://t.co/ZpsTCWmV91 | 0 |
RT @user: Ṣé bí ọ̀rọ̀-ọ́ bá dé ojú rẹ̀ tán, ìgbín pàápàá a máa pòṣé. #EsinOro🐎 | 0 |
Njẹ́ ọ̀rọ̀ wa ni Afirika lè lójútùú láí-láí bí? Ogun níwá, rògbòdìyàn lẹ́hìn. Orígun mẹ́rẹ̀rin ilẹ̀ adúláwọ̀ wa polúkúrúmusu. Èé ṣe? | 0 |
Kínni àǹfààní orógbó? A pa á, kò láwẹ́, a bù ú jẹ, ó korò. Igi rẹ̀ ò ṣe é dáná, bẹ́ẹ̀ ewé rẹ̀ kò ṣe é pọ́n ẹ̀kọ ọmọ #orogbo #oroyoruba #yoruba | 0 |
Òkúta, igi tàbí nǹkan míì ni a fi ń pààlè iye t'ọ́jà jẹ́ s'órí ọ́jà. Ta ló jẹ́ pààlè s'órí ọjà lóde ònìí tí ọ̀ṣà ò ní gbé e lọ́jà lọ. #Asa | 0 |
Ẹ jẹ́ k'á ka Yorùbá: Apanilẹ́kún Jayé Episode 4 Kí ló fa àìbalẹ̀ ọkàn fún Tèmídùn lẹ́yìn tí ọkọ rẹ̀ kú? Find out at https://t.co/Z9qPNwXq8L Someone said I interpreted the emotions well😊😊😊 #Yoruba #YorubaBooks #ReadingShow | 0 |
Agogo ti dún o. Wọ́n ti lù wá ní gbànjo. $35 #TwitterIPO | 0 |
Aasa wu Obo, faari wu Inaki, Ohun ti o daa naa wu Ole | 0 |
Ajílẹ̀ àti àwọn èròjà tí a fi p'èèlò irúgbìn àtọwọ́dá GMO tí ó wà nínú oúnjẹ tí à ń jẹ lóde òní yóò la inú omi kọjá, a ó lò ó, àṣẹ̀yìnwá-àṣẹ̀yìnbọ̀ yóò fa àìsàn tí yóò mú kí àrùn rọrùn sí wa l'ágọ̀ọ́ ara. #EarthDay https://t.co/5sZwhQWJUn | 0 |
Láwòlé sùn, gbogbo ọ̀táa ìlú mi yó d'ọ̀tá ayé. Ayé tó ṣe ilá tí ilá fi kó yó ṣe wọ́n po lọ̀kànkan èjèèjì. Àṣẹ́ gùn ún. #Osetura gbé e lọ. | 0 |
RT @user: Ìtàkùn tó ní kí erin má wọ odò, t'òun t'erin ló ńlọ. / A creeping plant that insists the elephant will not enter the r… | 0 |
Ọdẹ tó bá ṣiyèméjì, òun lẹranko ńpa. / An indecisive hunter easily gets killed by an animal (in the forest). [Be decisive; indecision can come with intolerable risks.] #Yoruba #proverb | 0 |
Aláàfin lé olórí àwọn ẹ̀ṣọ́; Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ kúrò l'Áàfin, èyí bí Ẹlẹ́mọ̀ṣọ́ nínú, ó pinu láti dojú ìjà kọ kábíyèsí.#Ogbomoso | 0 |
Níbo ni """"""""bìlísì"""""""" ti wá? Bá wo ni ọ̀rọ̀ yìí ṣe wọ inú èdè Yorùbá? #AyaloEde #Yoruba #learnYoruba #OroAyalo https://t.co/7vVWUejUrX | 0 |
pàápàá ẹni tó jẹ́ pé ikú ọ̀hún gan-an ní nlépa, k'óun báà lè rí """"""""alujana"""""""" wọ̀. Bẹ́ẹ̀ ọ̀run àpáàdì ni tààrà fún irú ẹni bẹ́ẹ̀. #BokoHaram | 0 |
Síbẹ̀, ìpinnu yìí kì í di múmú ṣẹ bí ọdún ṣe ń jó lọ. Díẹ̀díẹ̀, lẹ́yọkọ̀ọ̀kan ni wọn yóò gbé ìpinnu ọdún tuntun yẹ̀ tì. | 0 |
“@user: Waa pa mi. ;)RT @user: """"""""@user: Eke nseke f'eke. @user: Irọ́ ńparọ́ fún rọ́...""""""""""""""""#owe #yoruba”Àṣẹ mà á pà míì | 0 |
Ara ìjọba wa ni àléébù t'ó jù ú wà, ìjọba la óò fi ẹ̀sùn kàn kí a tó ó f'ẹ̀sùn kan alẹ́nulọ́rọ̀. @user #IjobaWaKala #Nigeria | 0 |
RT @user: """"""""@user @user Eniyan mejo miran ni won ti pa ni Ipinle Bayelsa http://t.co/AFNgDSR8Rj"""""""" | 0 |
RT @user: Ìgbé ò léegun sùgbón ení bátèé á tiro #TweetYoruba | 0 |
the offender must make restitution from the best of their own field or vineyard. #Yoruba ẸKISODU 22:5 “Bí ẹnìkan bá jẹ́ kí ẹran ọ̀sìn rẹ̀ jẹ oko olóko, tabi ọgbà àjàrà ẹlòmíràn, tabi tí ó bá da ẹran wọ inú oko olóko tí wọ́n sì jẹ nǹkan ọ̀gbìn inú rẹ̀, | 0 |
@user agbo wipe asofin @user ati awon elegbe re fe so ara won di Olorun ni orilede Nigeria #TweetInYoruba | 0 |
Awon alatileyin Oloogbe Segun Agagu binu fi @user sile l'Ondo, ni won ba darapo mo @user - Alaroye | 0 |
RT @user: Ado Oloro Dun Ni Ilu Kano Lonii: Ado oloro iku kan ni awon onise bi kan ti won fura si gege bi Boko Haram gbin... http://t.co/L… | 0 |
@user @user hahaha. Àwọn oní yẹ̀yẹ́. | 0 |
Ẹ gbọ́ àriyànjiyàn ìlera ààrẹ nílé ọtí. Àwọn kan fẹ́ kí Buhari kú. Ọmọ Nàìjá kí ló dé! 😦 https://t.co/vYK0WVH2pZ | 0 |
Pẹ̀lú gbogbo ìṣòro tí abala àwọn tó ń ṣe ohun tí ó tan mọ́ ìrìnnà ọkọ̀, bóyá ayọ́kẹ́lẹ́; akérò; afàyàfà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ń fà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, síbẹ̀ àwọn kan tún yàn iṣẹ́ yìí láàyò láti ṣe. #KiEpoRobiKogbaWole #Ogogoro #Yoruba #Oko | 0 |
RT @user: Ẹni tó ńsáré tó ńwo ẹ̀hìn, ó di dandan, kó fi ẹsẹ̀ kọ. / Whoever keeps looking back while running, will certainly stum… | 0 |
A fi ọ́ jọba ò ńṣàwúre o fẹ́ jẹ Ọlọ́run ni? | 0 |
@user @user ohun to wa seni laanu ni wipe awon ti a gbemi le lati sooto, ohun ti awon naa o je ko je ki won gbon #naija | 0 |
Chelsea ti fi owo osi juwe Ile fun akonimoogba Roberto Di Matteo, leyin ti o fi idi remi pelu ami ayo meta, ni orileede Italy lanaa | 0 |
Gbogbo ohun tó ń múnú bí wa nípa ẹlòmíràn lè mú wa ní kíkún nípa ara wa(irú ẹni tí a jẹ́)"""""""". - Carl Jung #TranslatedQuotes #AnyQuoteInYoruba #RandomQuotes #RandomThoughts #Quotes #YorubaTranslator #IyaYoruba https://t.co/ujzz43kPeR | 0 |
RT @user: Ti a ba wi fun omo eni agbo RT""""""""@user: Orí ọ̀kẹ́rẹ́ koko láwo http://t.co/K3WmXYDk3P"""""""" | 0 |
RT @user: Iru wahala wo le 'yi bayi iwo olorun. Kilode. | 0 |
Àgùtàn tó bá bá ajá rìn á jẹ ìgbẹ́, ajá tó bá bá ewúrẹ́ rìn á jẹ èpo iṣu. /#Yoruba A sheep that moves with dogs will eat faeces and a dog that moves with goats will eat yam peelings. [Be mindful of your close associates] Good morning!! | 0 |
Tọmọdé tàgbà sí í ṣọ̀tẹ̀ Aláàfin Ṣàngó, wọ́n ní Aláàfin ńta epo s'íjà ọ̀hún, pé Ṣàngó n'igi wọ́rọ́kọ́ tí ńdáná rú #worldsangofestival | 0 |
...nílé ayé yìí yóò jèrè ìwàa rẹ̀ nílùú mìíìn tó bá lọ. Ẹlòmíì tẹ́ ẹ rí tó ń ṣiwèrè kiri níbí, iṣẹ́ ọwọ́ ẹ̀ tó ṣe láyé tó ti kúrò ló ń jìyà ẹsẹ̀ẹ rẹ̀. Béèyàn bá ti kú nílé ayé níbí, ó ń ṣí awọ lọ síbòmìíìn ni. Ó lè lọ s'Ámẹ̀ríkà, ó lè lọ sí India... | 0 |
Aago yii ti baje saa, ara e lo dojuti lai se emi. Mo gbodo ra omiran ni kiamosa | 0 |
Bí ẹyẹkẹ́yẹ bá gbìdánwò láti fi enu ṣán Ìjàpá pẹ́rẹ́n, yóò ba ẹnu ara rẹ̀ jẹ́ lásán ni nítorí ahun ẹ̀hìn rẹ̀ t'ó le bí òkúta. #Yoruba | 0 |
Ìbàdí ọmọge yín là ń wò l’òfẹ́ lófò, Gbogbo ọmú rè é níta, ẹ jọ̀wọ́ ẹ bòdíi yín o, ó ti súu wá í wò. | 0 |
Wón ti jẹun yó, wọ́n wá ń wá bẹ́kùnbẹ́kùn. Ó máà ṣe o. Imúu bàbá ẹnìkan ni wọ́n fi ìkúùkù gé báyìí! https://t.co/15oaZozCW8 | 0 |
RT @user: @user @user @user @user @user Oro ofutu fete lasan li olugbafo Atiku nso lenu o. | 0 |
Mo ya aago ọwọ́ obìnrin Kan tí mo bá wọ kẹ̀kẹ́ Marwa ní Allen. Pándukú aago ni. | 0 |
Mo ṣe bí ẹ ní èdè abínibí ni ẹ óò máa lò l'áyàájọ́ òní? Gẹ̀ẹ́sì ti ṣe há jẹ́? K'á s'ọ̀rọ̀ k'á bá a bẹ́ẹ̀ niyì ọmọlúwàbí. https://t.co/yl235qs3CR | 0 |
Ṣèbí wọ́n ní """"""""Ìjàkajì lorò Ọ̀fà"""""""". Àwọn ọmọ Ọ̀fà ọ̀hún náà wá dà ? :)) | 0 |
@user Sùgbón a tún le so wípé """"""""wèrè l'a fi ń wo wèrè"""""""" 😁 #TweetYoruba | 0 |
Àmọ́, àjọ àgbà ilé-èkọ́ ifácitì ti láwọn ò ní gbà ní tàwọn, àfi bí ìjọba bá gba tàwọn. Wọ́n ní ìyanṣẹ́ lódì ńtẹ̀síwájú #Education #Nigeria | 0 |
RT @user: A ń r'ojú jẹ́ ẹ̀kọ ọ̀bùn, ọ̀bùn tún ń pọ́n ẹ̀kọ rẹ̀ kere!! Gbàgbé òsì....! | 0 |
Subsets and Splits