diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Àwa ìbá jẹ kí òrùlé ilé àwọn tú
Awa iba je ki orule ile awon tu
ṣàìgbàgbọ nínú Ọba Oníkẹ̀ẹ jẹ
saigbagbo ninu Oba Onikee je
kìkí fàdákà àti àtẹ̀gùn (fàdákà) tí
kiki fadaka ati ategun (fadaka) ti
wỌn yòò máaa fi gùn ún pẹ̀lú;
wOn yoo maaa fi gun un pelu;
35. TÍ àwọn ilé wọn yòò ní
35. TI awon ile won yoo ni
ìlẹ̀kùn (fàdákà). àti. ibùsùn
ilekun (fadaka). ati. ibusun
(fàdákà) tí wọn yôò máa rògbọkú
(fadaka) ti won yoo maa rogboku
lé lôrí,
le lori,
36. (Àti àwọn ohun àlò mìíràn) tú
36. (Ati awon ohun alo miiran) tu
jẹ ti ẹwà. Ṣùgbọn gbogbo ìyẹn kò
je ti ewa. Sugbon gbogbo iyen ko
JẸ. kiní kan, bíkòṣe. ìgbádùn
JE. kini kan, bikose. igbadun
(ránpẹ€) ti ayé yìí. Ayé t0 sì n bọ
(ranpe€) ti aye yii. Aye t0 si n bo
lọdò Olúwa rẹ jẹ ti àwọn olùpáyà
lodo Oluwa re je ti awon olupaya
(Rẹ̀).
(Re).
ÌDÁ 4
IDA 4
37. Ẹnikẹni tô bá ṣẹrí kúrò níbi
37. Enikeni to ba seri kuro nibi
ìrántí Ọba Oníkẹ̀ẹ̀, àwa yôòò yan
iranti Oba Onikee, awa yooo yan
ẹ̀ṣù fún un gẹgẹ bí alájọṣepọ.
esu fun un gege bi alajosepo.
38. Dájúdájú wọn máa n ṣẹ wọn
38. Dajudaju won maa n se won
lôòrí kúrò ní ojú ọnà (Allah),
loori kuro ni oju ona (Allah),
ṣùgbọn wọn n rò pé ẹni ìtỌsọnà ni
sugbon won n ro pe eni itOsona ni
àwọn.
awon.
39. Títíi tí irú ẹni náà yòò fi dé
39. Titii ti iru eni naa yoo fi de
òdò Wa, yòò sì wí (fún alábàárìn
odo Wa, yoo si wi (fun alabaarin
rẹ̀) pé, "O má ṣe o! ìbá lẹ̀ ṣe é ṣe
re) pe, "O ma se o! iba le se e se
kí àlàfo tò jìnnà bí ìlà-oòrùn si
ki alafo to jinna bi ila-oorun si
ìwọ-oòrùn wà láàrin ẹ̀mi pẹ̀lú rẹ!
iwo-oorun wa laarin emi pelu re!
Irú alájọṣepọ burúkú wo ni ẹ̀yí!'
Iru alajosepo buruku wo ni eyi!'
40. Nitorí pé ẹ ti rékọjá ààlà,
40. Nitori pe e ti rekoja aala,
àjọpín nínú ìyà náà kì yòò ṣe yín
ajopin ninu iya naa ki yoo se yin
lánfàní lúnìí.
lanfani lunii.
Ó ní Ijipti tí Hesekaya gbára lé dàbí kí eniyan fi ìyè ṣe ọ̀pá ìtẹ̀lẹ̀, ìyè tí yóo dá, tí yóo sì gún ẹnikẹ́ni tí ó bá gbára lé e lọ́wọ́. Bẹ́ẹ̀ ni Farao ọba Ijipti jẹ́ sí gbogbo àwọn tí ó bá gbára lé e. Ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá yà sọ́tọ̀ pé ó gbọdọ̀ jẹ́ pípa láàrin àwọn eniyan, ẹnìkan kò gbọdọ̀ rà á pada, pípa ni wọ́n gbọdọ̀ pa á.Ẹ ṣọ́ra yín, ẹ sì ṣọ́ agbo tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi yín ṣe alabojuto lórí rẹ̀, kí ẹ máa bọ́ ìjọ Ọlọrun tí ó fi ẹ̀jẹ̀ Ọmọ rẹ̀ ṣe ní tirẹ̀. Nítorí mo sọ fun yín pé láti àkókò yìí lọ, n kò tún ní mu ninu èso àjàrà mọ́ títí ìgbà tí ìjọba Ọlọrun yóo fi dé.”Lẹsẹkẹsẹ ọmọdebinrin náà dìde, ó bá ń rìn, nítorí ọmọ ọdún mejila ni. Ìyàlẹ́nu ńlá ni ó jẹ́ fún gbogbo wọn. Ológo ni ọ́, ọlá rẹ sì pọ̀,ó ju ti àwọn òkè tí ó kún fún ẹran lọ.Wọ́n bá pe Rebeka, wọ́n bi í pé, “Ṣé o óo máa bá ọkunrin yìí lọ?” Ó dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, n óo lọ.”Ẹni tí ó bá ṣẹgun, tí ó forí tì í, tí ó ń ṣe iṣẹ́ mi títí dé òpin, òun ni n óo fún ní àṣẹ lórí àwọn orílẹ̀-èdè, ọ̀pá irin ni yóo fi jọba lórí wọn, bí ìkòkò amọ̀ ni yóo fọ́ wọn túútúú. Irú àṣẹ tí mo gbà lọ́dọ̀ Baba mi ni n óo fún un. N óo tún fún un ní ìràwọ̀ òwúrọ̀. Ẹlòmíràn ni kí o jẹ́ kí ó yìn ọ́, má yin ara rẹ,jẹ́ kí ó ti ẹnu ẹlòmíràn jáde,kí ó má jẹ́ láti ẹnu ìwọ alára.Má sẹ̀ẹ́ kí ọ̀ràn má pọ̀.
O ni Ijipti ti Hesekaya gbara le dabi ki eniyan fi iye se opa itele, iye ti yoo da, ti yoo si gun enikeni ti o ba gbara le e lowo. Bee ni Farao oba Ijipti je si gbogbo awon ti o ba gbara le e. Enikeni ti won ba ya soto pe o gbodo je pipa laarin awon eniyan, enikan ko gbodo ra a pada, pipa ni won gbodo pa a.E sora yin, e si so agbo ti Emi Mimo fi yin se alabojuto lori re, ki e maa bo ijo Olorun ti o fi eje Omo re se ni tire. Nitori mo so fun yin pe lati akoko yii lo, n ko tun ni mu ninu eso ajara mo titi igba ti ijoba Olorun yoo fi de.”Lesekese omodebinrin naa dide, o ba n rin, nitori omo odun mejila ni. Iyalenu nla ni o je fun gbogbo won. Ologo ni o, ola re si po,o ju ti awon oke ti o kun fun eran lo.Won ba pe Rebeka, won bi i pe, “Se o oo maa ba okunrin yii lo?” O dahun pe, “Bee ni, n oo lo.”Eni ti o ba segun, ti o fori ti i, ti o n se ise mi titi de opin, oun ni n oo fun ni ase lori awon orile-ede, opa irin ni yoo fi joba lori won, bi ikoko amo ni yoo fo won tuutuu. Iru ase ti mo gba lodo Baba mi ni n oo fun un. N oo tun fun un ni irawo owuro. Elomiran ni ki o je ki o yin o, ma yin ara re,je ki o ti enu elomiran jade,ki o ma je lati enu iwo alara.Ma see ki oran ma po.
Ẹ má mú ẹbọ asán wá fún mi mọ́;ohun ìríra ni turari jẹ́ fún mi.Àjọ̀dún ìbẹ̀rẹ̀ oṣù titun, ọjọ́ ìsinmi, ati pípe àpéjọ.Ara mi kò gba ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ̀ ń dàpọ̀ mọ́ ẹ̀sìn mọ́.gbogbo oniruuru àṣá, Òun ati àwọn ará ilé rẹ̀ gba ìrìbọmi. Lẹ́yìn náà, ó bẹ̀ wá pé, bí a bá gbà pé òun jẹ́ onigbagbọ nítòótọ́, kí á máa bọ̀ ní ilé òun kí á máa bá àwọn gbé. Ó tẹnu mọ́ ọn títí a fi gbà.Láti òní lọ, nígbà tí o bá dá oko, ilẹ̀ kò ní fi gbogbo agbára rẹ̀ so èso fún ọ mọ́, ìsáǹsá ati alárìnká ni o óo sì jẹ́ lórí ilẹ̀ ayé.”Àṣaálẹ́ ni kí o fi ọ̀dọ́ aguntan keji rúbọ, pẹlu ẹbọ ohun jíjẹ ati ọtí waini fún ìtasílẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ti òwúrọ̀. Ẹbọ olóòórùn dídùn ni, àní ẹbọ tí a fi iná sun sí OLUWA. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì jẹ ẹ́ yóo jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, nítorí pé, ó ti ba ohun mímọ́ OLUWA jẹ́, a óo yọ ọ́ kúrò láàrin àwọn eniyan rẹ̀.àfi Kalebu ọmọ Jefune ni yóo rí i. Òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ ni òun óo sì fún ní ilẹ̀ tí ó ti fi ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ̀, nítorí pé, ó fi tọkàntọkàn tẹ̀lé òun. No wise man ever ties water in a knot in his cloth; no knowledgeable person can tell the number of grains of sand on the earth.
E ma mu ebo asan wa fun mi mo;ohun irira ni turari je fun mi.Ajodun ibere osu titun, ojo isinmi, ati pipe apejo.Ara mi ko gba ese ti e n dapo mo esin mo.gbogbo oniruuru asa, Oun ati awon ara ile re gba iribomi. Leyin naa, o be wa pe, bi a ba gba pe oun je onigbagbo nitooto, ki a maa bo ni ile oun ki a maa ba awon gbe. O tenu mo on titi a fi gba.Lati oni lo, nigba ti o ba da oko, ile ko ni fi gbogbo agbara re so eso fun o mo, isansa ati alarinka ni o oo si je lori ile aye.”Asaale ni ki o fi odo aguntan keji rubo, pelu ebo ohun jije ati oti waini fun itasile gege bii ti owuro. Ebo olooorun didun ni, ani ebo ti a fi ina sun si OLUWA. Enikeni ti o ba si je e yoo jiya ese re, nitori pe, o ti ba ohun mimo OLUWA je, a oo yo o kuro laarin awon eniyan re.afi Kalebu omo Jefune ni yoo ri i. Oun ati awon omo re ni oun oo si fun ni ile ti o ti fi ese re te, nitori pe, o fi tokantokan tele oun. No wise man ever ties water in a knot in his cloth; no knowledgeable person can tell the number of grains of sand on the earth.
Wọ́n ti mú ayọ̀ ati ìdùnnú kúrò ní ilẹ̀ ọlọ́ràá Moabu;mo ti mú kí ọtí waini tán níbi tí wọ́n ti ń ṣe é,kò sí ẹni tí ó ń ṣe ọtí waini pẹlu ariwo ayọ̀ mọ́, ariwo tí wọn ń pa kì í ṣe ti ayọ̀.It is time to get out of here, the gatekeeper of Atadi; his home was burglarized, his wife was taken from him, the divining string he was going to use to investigate matters was snatched by a dog, his son who ran after the dog to retrieve the divining string fell into a well; the gatekeeper of Atadi then spoke up and said, “It is time to get out of here.”
Won ti mu ayo ati idunnu kuro ni ile oloraa Moabu;mo ti mu ki oti waini tan nibi ti won ti n se e,ko si eni ti o n se oti waini pelu ariwo ayo mo, ariwo ti won n pa ki i se ti ayo.It is time to get out of here, the gatekeeper of Atadi; his home was burglarized, his wife was taken from him, the divining string he was going to use to investigate matters was snatched by a dog, his son who ran after the dog to retrieve the divining string fell into a well; the gatekeeper of Atadi then spoke up and said, “It is time to get out of here.”
Wọ́n ti gbẹ́ kòtò jíjìn ní ìlú Ṣitimu; ṣugbọn n óo jẹ wọ́n níyà. Ọmọdé ní ẹẹ́ta lọ́wọ́, ó ní kí Èṣù wá ká ṣeré owó; ẹẹ́ta-á ha tó Èṣùú sú epo lá?
Won ti gbe koto jijin ni ilu Sitimu; sugbon n oo je won niya. Omode ni eeta lowo, o ni ki Esu wa ka sere owo; eeta-a ha to Esuu su epo la?
Ó kó wọn gba ọ̀nà tààrà jáde,lọ sí ìlú tí wọ́n lè máa gbé.Kí ògo yìí wà fún un ninu ìjọ ati ninu Kristi Jesu láti ìrandíran títí laelae. Amin.Jahasi, Kedemotu, ati Mefaati; OLUWA sì dá Mose lóhùn pé, “N óo mú kí ẹwà mi kọjá níwájú rẹ; n óo sì pe orúkọ mímọ́ mi lójú rẹ, èmi ni OLUWA, èmi a máa yọ́nú sí àwọn tí ó bá wù mí, èmi a sì máa ṣàánú fún àwọn tí mo bá fẹ́.” Ó bá wí fún un pé, “Pada lọ sùn. Bí olúwarẹ̀ bá tún pè ọ́, dá a lóhùn pé, ‘Máa wí OLUWA, iranṣẹ rẹ ń gbọ́.’ ” Samuẹli bá pada lọ sùn.O ti rí i, OLUWA, má dákẹ́.OLUWA, má jìnnà sí mi.Kí ẹni tí ń jalè má jalè mọ́. Kàkà bẹ́ẹ̀ kí ó kúkú gbìyànjú láti fi ọwọ́ ara rẹ̀ ṣe iṣẹ́ rere, kí òun náà lè ní ohun tí yóo fún àwọn aláìní. Meṣulamu, Abija, ati Mijamini, Wọ́n lọ ń gbé Geruti Kimhamu, tí ó wà lẹ́bàá Bẹtilẹhẹmu. Wọ́n pinnu láti kó lọ sí ilẹ̀ Ijipti nítorí ẹ̀rù àwọn ará Kalidea ń bà wọ́n; “We might see each other again” who sold his dog for twenty cowries; he said if that is how things are sold, they might well see each other again.
O ko won gba ona taara jade,lo si ilu ti won le maa gbe.Ki ogo yii wa fun un ninu ijo ati ninu Kristi Jesu lati irandiran titi laelae. Amin.Jahasi, Kedemotu, ati Mefaati; OLUWA si da Mose lohun pe, “N oo mu ki ewa mi koja niwaju re; n oo si pe oruko mimo mi loju re, emi ni OLUWA, emi a maa yonu si awon ti o ba wu mi, emi a si maa saanu fun awon ti mo ba fe.” O ba wi fun un pe, “Pada lo sun. Bi oluware ba tun pe o, da a lohun pe, ‘Maa wi OLUWA, iranse re n gbo.’ ” Samueli ba pada lo sun.O ti ri i, OLUWA, ma dake.OLUWA, ma jinna si mi.Ki eni ti n jale ma jale mo. Kaka bee ki o kuku gbiyanju lati fi owo ara re se ise rere, ki oun naa le ni ohun ti yoo fun awon alaini. Mesulamu, Abija, ati Mijamini, Won lo n gbe Geruti Kimhamu, ti o wa lebaa Betilehemu. Won pinnu lati ko lo si ile Ijipti nitori eru awon ara Kalidea n ba won; “We might see each other again” who sold his dog for twenty cowries; he said if that is how things are sold, they might well see each other again.
Bí òfé ti ńfò la ti ḿmọ̀ ọ́ lákọ ẹyẹ.
Bi ofe ti nfo la ti mmo o lako eye.
OLUWA wí fún Mose pé, “Mo dá majẹmu kan, n óo ṣe iṣẹ́ ìyanu níwájú àwọn eniyan náà, irú èyí tí ẹnikẹ́ni kò rí rí ní gbogbo ayé tabi láàrin orílẹ̀-èdè kankan. Gbogbo àwọn eniyan tí ẹ̀ ń gbé ààrin wọn yóo sì rí iṣẹ́ OLUWA, nítorí ohun tí n óo ṣe fún wọn yóo bani lẹ́rù jọjọ.kí ó má jẹ́ pé, nígbà tí ẹ bá jẹun, tí ẹ yó tán, tí ẹ ti kọ́ àwọn ilé dáradára, tí ẹ sì ń gbé inú wọn, Ààrẹ àgòrò tó bá gbójú, tòun tolúwa rẹ̀ lẹgbẹ́ra.
OLUWA wi fun Mose pe, “Mo da majemu kan, n oo se ise iyanu niwaju awon eniyan naa, iru eyi ti enikeni ko ri ri ni gbogbo aye tabi laarin orile-ede kankan. Gbogbo awon eniyan ti e n gbe aarin won yoo si ri ise OLUWA, nitori ohun ti n oo se fun won yoo bani leru jojo.ki o ma je pe, nigba ti e ba jeun, ti e yo tan, ti e ti ko awon ile daradara, ti e si n gbe inu won, Aare agoro to ba gboju, toun toluwa re legbera.
bí agbára mi ṣe rí nígbà tí Mose rán wa jáde láti lọ ṣe amí, bẹ́ẹ̀ náà ni ó wà títí di òní olónìí, mo tún lágbára láti jagun ati láti wọlé ati láti jáde. Nítorí ọ̀rọ̀ OLUWA dúró ṣinṣin;òtítọ́ sì ni ó fi ń ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.wọ́n gbé e jù sinu kànga kan tí kò ní omi ninu.When the wife has got to know the husband, the marriage broker makes way.
bi agbara mi se ri nigba ti Mose ran wa jade lati lo se ami, bee naa ni o wa titi di oni olonii, mo tun lagbara lati jagun ati lati wole ati lati jade. Nitori oro OLUWA duro sinsin;otito si ni o fi n se gbogbo ise re.won gbe e ju sinu kanga kan ti ko ni omi ninu.When the wife has got to know the husband, the marriage broker makes way.
Ìwẹ̀fà náà bá pàṣẹ pé kí ọkọ̀ dúró. Òun ati Filipi bá sọ̀kalẹ̀, wọ́n lọ sinu odò, Filipi bá rì í bọmi. “Ojú àna-à mi ò sunwọ̀n”; kò ju kó gba ọmọ ẹ̀ lọ.
Iwefa naa ba pase pe ki oko duro. Oun ati Filipi ba sokale, won lo sinu odo, Filipi ba ri i bomi. “Oju ana-a mi o sunwon”; ko ju ko gba omo e lo.
Nígbà tí ẹ bá gbúròó ogun ati ìrúkèrúdò, ẹ má jẹ́ kí ó dẹ́rùbà yín. Nítorí dandan ni kí nǹkan wọnyi kọ́kọ́ ṣẹlẹ̀. Ṣugbọn òpin kò níí tíì dé.”Nítorí mo mọ̀ pé láìpẹ́ n óo bọ́ àgọ́ ara mi sílẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Oluwa wa Jesu Kristi ti fihàn mí. “Nítorí náà, ẹ pa àwọn àṣẹ mi mọ́, kí ẹ má sì ṣe èyíkéyìí ninu àwọn ohun ìríra wọnyi, tí àwọn tí wọ́n ṣáájú yín ṣe, kí ẹ má fi wọ́n ba ara yín jẹ́. Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.”Nítorí pé Mose ti fún àwọn ẹ̀yà meji ati ààbọ̀ ní ìpín tiwọn ní òdìkejì odò Jọdani, ṣugbọn kò pín ilẹ̀ fún àwọn ẹ̀yà Lefi. Yọ mí kúrò ninu ìhámọ́,kí n lè yin orúkọ rẹ lógo.Àwọn olódodo yóo yí mi ká,nítorí ọpọlọpọ oore tí o óo ṣe fún mi.Mo nawọ́ kó ọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,bí ẹni nawọ́ kó ọmọ ẹyẹ.Mo kó gbogbo ayé,bí ẹni kó ẹyin ẹyẹ tí ó kọ ẹyin rẹ̀ sílẹ̀, tí ó fò lọ,kò sí ẹnìkan tí ó lè ṣe nǹkankan,kò sí ẹnìkan tí ó lanu sọ̀rọ̀,bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò gbin.”Gbogbo àwọn tí ó jókòó ní ìgbìmọ̀ tẹjú mọ́ ọn, wọ́n rí ojú rẹ̀ tí ó dàbí ojú angẹli.Òjò-ó pọnmi fún ọ̀lẹ, kò ṣẹ́gi fún ọ̀lẹ.
Nigba ti e ba gburoo ogun ati irukerudo, e ma je ki o deruba yin. Nitori dandan ni ki nnkan wonyi koko sele. Sugbon opin ko nii tii de.”Nitori mo mo pe laipe n oo bo ago ara mi sile, gege bi Oluwa wa Jesu Kristi ti fihan mi. “Nitori naa, e pa awon ase mi mo, ki e ma si se eyikeyii ninu awon ohun irira wonyi, ti awon ti won saaju yin se, ki e ma fi won ba ara yin je. Emi ni OLUWA Olorun yin.”Nitori pe Mose ti fun awon eya meji ati aabo ni ipin tiwon ni odikeji odo Jodani, sugbon ko pin ile fun awon eya Lefi. Yo mi kuro ninu ihamo,ki n le yin oruko re logo.Awon olododo yoo yi mi ka,nitori opolopo oore ti o oo se fun mi.Mo nawo ko oro awon orile-ede,bi eni nawo ko omo eye.Mo ko gbogbo aye,bi eni ko eyin eye ti o ko eyin re sile, ti o fo lo,ko si enikan ti o le se nnkankan,ko si enikan ti o lanu soro,bee ni enikeni ko gbin.”Gbogbo awon ti o jokoo ni igbimo teju mo on, won ri oju re ti o dabi oju angeli.Ojo-o ponmi fun ole, ko segi fun ole.
OLUWA Ọlọrun sọ fún Mose pé, “Àkókò ń tó bọ̀ tí o óo kú, pe Joṣua, kí ẹ̀yin mejeeji wá sinu àgọ́ àjọ kí n lè fi ohun tí yóo ṣe lé e lọ́wọ́.” Mose ati Joṣua bá wọ inú àgọ́ àjọ lọ. Ọmọ ọdún mẹjọ ni Josaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanlelọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jedida ọmọ Adaya ará Bosikati. “Má ṣe fi èyíkéyìí ninu àwọn nǹkan tí a dárúkọ wọnyi ba ara rẹ jẹ́, nítorí pé, nǹkan wọnyi ni àwọn orílẹ̀-èdè tí mò ń lé jáde kúrò níwájú yín fi ba ara wọn jẹ́. “We might see each other again” who sells his dog for twenty cowries and spent the money on pounded yams to eat.
OLUWA Olorun so fun Mose pe, “Akoko n to bo ti o oo ku, pe Josua, ki eyin mejeeji wa sinu ago ajo ki n le fi ohun ti yoo se le e lowo.” Mose ati Josua ba wo inu ago ajo lo. Omo odun mejo ni Josaya nigba ti o joba, o si wa lori oye ni Jerusalemu fun odun mokanlelogbon. Oruko iya re ni Jedida omo Adaya ara Bosikati. “Ma se fi eyikeyii ninu awon nnkan ti a daruko wonyi ba ara re je, nitori pe, nnkan wonyi ni awon orile-ede ti mo n le jade kuro niwaju yin fi ba ara won je. “We might see each other again” who sells his dog for twenty cowries and spent the money on pounded yams to eat.
A footloose person will part with his valuables for little or nothing. “Ojú ò fẹ́rakù” is an expression people use on parting from one another; it means, literally; “Our eyes are not giving up the sight of one another.”
A footloose person will part with his valuables for little or nothing. “Oju o feraku” is an expression people use on parting from one another; it means, literally; “Our eyes are not giving up the sight of one another.”
Nítorí náà OLUWA, èmi bẹ̀ Ọ́, fi agbára ńlá rẹ hàn gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ pé, Ṣé ó ṣeéṣe kí ará Kuṣi yí àwọ̀ ara rẹ̀ pada?Àbí kí àmọ̀tẹ́kùn fọ tóótòòtóó ara rẹ̀ dànù?Bí ó bá ṣeéṣe, á jẹ́ wí pé ẹ̀yin náà lè hùwà rere;ẹ̀yin tí ibi ṣíṣe ti mọ́ lára.OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn kò dẹ́kun láti máa rán wolii sí wọn, nítorí pé àánú àwọn eniyan rẹ̀ ati ibùgbé rẹ̀ ń ṣe é. Ó ń wo ọpọlọpọ nǹkan, ṣugbọn kò ṣe akiyesi wọn.Etí rẹ̀ là sílẹ̀,ṣugbọn kò gbọ́ràn.”Bí ayá bá mojú ọkọ, alárìnnà a yẹsẹ̀.
Nitori naa OLUWA, emi be O, fi agbara nla re han gege bi ileri re pe, Se o seese ki ara Kusi yi awo ara re pada?Abi ki amotekun fo tootootoo ara re danu?Bi o ba seese, a je wi pe eyin naa le huwa rere;eyin ti ibi sise ti mo lara.OLUWA Olorun awon baba won ko dekun lati maa ran wolii si won, nitori pe aanu awon eniyan re ati ibugbe re n se e. O n wo opolopo nnkan, sugbon ko se akiyesi won.Eti re la sile,sugbon ko gboran.”Bi aya ba moju oko, alarinna a yese.
Bí a kò bá jìyà tó kún agbọ̀n; a ò lè jẹ oore tó kún ahá.
Bi a ko ba jiya to kun agbon; a o le je oore to kun aha.
wọ́n sì tẹ̀lé ìwà àwọn eniyan tí OLUWA lé jáde kúrò fún wọn, ati àwọn àṣàkaṣà tí àwọn ọba Israẹli kó wá. Joṣua to òkúta mejila mìíràn jọ láàrin odò Jọdani lọ́gangan ibi tí àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Majẹmu dúró sí; àwọn òkúta náà wà níbẹ̀ títí di òní olónìí. Ó pada lọ bá àwọn arakunrin rẹ̀, ó wí fún wọn pé, “Ọmọ náà kò sí níbẹ̀? Mo gbé! Ibo ni n óo yà sí?”The kite cannot swoop down and carry off a goat.
won si tele iwa awon eniyan ti OLUWA le jade kuro fun won, ati awon asakasa ti awon oba Israeli ko wa. Josua to okuta mejila miiran jo laarin odo Jodani logangan ibi ti awon alufaa ti won gbe Apoti Majemu duro si; awon okuta naa wa nibe titi di oni olonii. O pada lo ba awon arakunrin re, o wi fun won pe, “Omo naa ko si nibe? Mo gbe! Ibo ni n oo ya si?”The kite cannot swoop down and carry off a goat.
Kí Ọlọrun orísun alaafia mu yín ṣẹgun Satani ní kíákíá. Kí oore-ọ̀fẹ́ Oluwa wa Jesu kí ó wà pẹlu yín.It is by its flight that the parrot proves itself a formidable bird.
Ki Olorun orisun alaafia mu yin segun Satani ni kiakia. Ki oore-ofe Oluwa wa Jesu ki o wa pelu yin.It is by its flight that the parrot proves itself a formidable bird.
A child has three cowries in hand and challenges Èṣù to a game played for money; will three solitary cowries suffice for Èṣù to purchase palm-oil to lick?
A child has three cowries in hand and challenges Esu to a game played for money; will three solitary cowries suffice for Esu to purchase palm-oil to lick?
People who come into some money for the first time are wont to overestimate their sudden worth. Èṣù is the unpredictable god in the Yorùbà pantheon, his favorite food is palm-oil.
People who come into some money for the first time are wont to overestimate their sudden worth. Esu is the unpredictable god in the Yoruba pantheon, his favorite food is palm-oil.
Isó inú ẹ̀kú, à-rá-mọ́ra.
Iso inu eku, a-ra-mora.
“Gbogbo yín wá sọ́dọ̀ mi, ẹ sì wí pé, ‘Ẹ jẹ́ kí á rán àwọn eniyan lọ ṣiwaju wa, láti lọ ṣe amí ilẹ̀ náà, kí wọ́n lè wá jábọ̀ fún wa, kí á lè mọ ọ̀nà tí ó yẹ kí á tọ̀, ati àwọn ìlú tí ó yẹ kí á wọ̀.’Nígbà tí ó yá, tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu ń pọ̀ sí i, ìkùnsínú bẹ̀rẹ̀ láàrin àwọn tí ó ń sọ èdè Giriki ati àwọn tí ó ń sọ èdè Heberu, nítorí wọ́n ń fojú fo àwọn opó àwọn tí ń sọ èdè Giriki dá, nígbà tí wọ́n bá ń pín àwọn nǹkan ní ojoojumọ. Nítorí Ọlọrun kò jẹ́ kábàámọ̀ pé òun fún ẹnìkan ní ẹ̀bùn kí ó wá gbà á pada. Àwọn ẹran náà ń gun ara wọn níwájú àwọn ọ̀pá wọnyi, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bí ọmọ tí àwọ̀ wọn dàbí adíkálà ati àwọn tí wọ́n ní funfun tóótòòtóó.Moabu, ṣebí ò ń fi Israẹli ṣe yẹ̀yẹ́?Ṣé o bá a láàrin àwọn ọlọ́ṣà ni,tí ó fi jẹ́ pé nígbàkúùgbà tí o bá ń sọ̀rọ̀ rẹ̀, ń ṣe ni o máa ń mi orí rẹ?Mo ti rán Tukikọsi lọ sí Efesu. Ọlọgbọ́n kan ò ta kókó omi sáṣọ; ọ̀mọ̀ràn kan ò mọ oye erùpẹ̀ ilẹ̀.
“Gbogbo yin wa sodo mi, e si wi pe, ‘E je ki a ran awon eniyan lo siwaju wa, lati lo se ami ile naa, ki won le wa jabo fun wa, ki a le mo ona ti o ye ki a to, ati awon ilu ti o ye ki a wo.’Nigba ti o ya, ti awon omo-eyin Jesu n po si i, ikunsinu bere laarin awon ti o n so ede Giriki ati awon ti o n so ede Heberu, nitori won n foju fo awon opo awon ti n so ede Giriki da, nigba ti won ba n pin awon nnkan ni ojoojumo. Nitori Olorun ko je kabaamo pe oun fun enikan ni ebun ki o wa gba a pada. Awon eran naa n gun ara won niwaju awon opa wonyi, won ba bere si bi omo ti awo won dabi adikala ati awon ti won ni funfun tootootoo.Moabu, sebi o n fi Israeli se yeye?Se o ba a laarin awon olosa ni,ti o fi je pe nigbakuugba ti o ba n soro re, n se ni o maa n mi ori re?Mo ti ran Tukikosi lo si Efesu. Ologbon kan o ta koko omi saso; omoran kan o mo oye erupe ile.
Ẹ̀yin ìdílé Aaroni, ẹ gbẹ́kẹ̀lé OLUWA,òun ni olùrànlọ́wọ́ ati aláàbò yín.“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin eniyan mi, n óo sọ̀rọ̀,Israẹli, n óo takò yín.Èmi ni Ọlọrun, Ọlọrun yín.Olùṣọ́-aguntan mi tí kò bá níláárí gbé! Tí ó ń fi agbo ẹran sílẹ̀. Idà ni yóo ṣá a ní apá, yóo sì bá a ní ojú ọ̀tún, apá rẹ̀ óo rọ patapata, ojú ọ̀tún rẹ̀ óo sì fọ́ patapata.”Reueli bá bi àwọn ọmọ rẹ̀ léèrè pé, “Níbo ni ará Ijipti ọ̀hún wà? Kí ló dé tí ẹ fi sílẹ̀? Ẹ lọ pè é wọlé, kí ó wá jẹun.”Ní àkókò náà, Israẹli yóo ṣìkẹta Ijipti ati Asiria, wọn yóo sì jẹ́ ibukun lórí ilẹ̀ fún àwọn ará Ijipti, àwọn eniyan mi.Wò ó, ẹni tí ń pa Israẹli mọ́kò ní tòògbé, bẹ́ẹ̀ ni kò ní sùn.Àwọn ohun tí o gbọ́ láti ẹnu mi níwájú ọpọlọpọ ẹlẹ́rìí, ni kí o fi lé àwọn olóòótọ́ eniyan lọ́wọ́, àwọn tí ó tó láti kọ́ àwọn ẹlòmíràn.Ìmàlé sọ̀rọ̀ òjò-ó kù, ó ní Ọlọ́runún jẹ́rì-í òun.
Eyin idile Aaroni, e gbekele OLUWA,oun ni oluranlowo ati alaabo yin.“E gbo, eyin eniyan mi, n oo soro,Israeli, n oo tako yin.Emi ni Olorun, Olorun yin.Oluso-aguntan mi ti ko ba nilaari gbe! Ti o n fi agbo eran sile. Ida ni yoo sa a ni apa, yoo si ba a ni oju otun, apa re oo ro patapata, oju otun re oo si fo patapata.”Reueli ba bi awon omo re leere pe, “Nibo ni ara Ijipti ohun wa? Ki lo de ti e fi sile? E lo pe e wole, ki o wa jeun.”Ni akoko naa, Israeli yoo siketa Ijipti ati Asiria, won yoo si je ibukun lori ile fun awon ara Ijipti, awon eniyan mi.Wo o, eni ti n pa Israeli moko ni toogbe, bee ni ko ni sun.Awon ohun ti o gbo lati enu mi niwaju opolopo elerii, ni ki o fi le awon oloooto eniyan lowo, awon ti o to lati ko awon elomiran.Imale soro ojo-o ku, o ni Olorunun jeri-i oun.
Ibi tí oyín gbé ńhó, tí àdó ńhó, ìfun ò dákẹ́ lásán.
Ibi ti oyin gbe nho, ti ado nho, ifun o dake lasan.
Lea bá sọ pé, “Oríire.” Ó bá sọ ọmọ náà ní Gadi. Ó ń dún bí ejò tí ó ń sálọ;nítorí pé àwọn ọ̀tá rẹ̀ ń bọ̀ tagbára tagbára,wọ́n ń kó àáké bọ̀ wá bá a,bí àwọn tí wọn ń gé igi.OLUWA bá bá mi sọ̀rọ̀, Mose fún ẹ̀yà Gadi ní ìpín tiwọn, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn. Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, Oluwa?Ta ni kò ní fi ògo fún orúkọ rẹ?Nítorí ìwọ nìkan ni ó pé,nítorí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo wá,wọn yóo júbà níwájú rẹ,nítorí òdodo rẹ farahàn gbangba.”Ìjiyàn kan wà láàrin àwọn ọmọ-ẹ̀yìn pé ta ni ó jẹ́ ẹni pataki jùlọ. Yàtọ̀ sí pé ọ̀jọ̀gbọ́n náà gbọ́n, ó tún kọ́ àwọn eniyan ní ìmọ̀. Ó wádìí àwọn òwe fínnífínní, ó sì tò wọ́n lẹ́sẹẹsẹ. Ó sọ̀rọ̀, wọ́n yọ́,ó fẹ́ afẹ́fẹ́, omi sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣàn.The pot is no shelter for the snail; all it does is trap the snail.
Lea ba so pe, “Oriire.” O ba so omo naa ni Gadi. O n dun bi ejo ti o n salo;nitori pe awon ota re n bo tagbara tagbara,won n ko aake bo wa ba a,bi awon ti won n ge igi.OLUWA ba ba mi soro, Mose fun eya Gadi ni ipin tiwon, gege bi iye idile won. Ta ni ko ni beru re, Oluwa?Ta ni ko ni fi ogo fun oruko re?Nitori iwo nikan ni o pe,nitori gbogbo awon orile-ede yoo wa,won yoo juba niwaju re,nitori ododo re farahan gbangba.”Ijiyan kan wa laarin awon omo-eyin pe ta ni o je eni pataki julo. Yato si pe ojogbon naa gbon, o tun ko awon eniyan ni imo. O wadii awon owe finnifinni, o si to won leseese. O soro, won yo,o fe afefe, omi si bere si san.The pot is no shelter for the snail; all it does is trap the snail.
Ṣugbọn ilẹ̀ ran obinrin náà lọ́wọ́. Ilẹ̀ lanu, ó fa omi tí Ẹranko Ewèlè náà tu jáde lẹ́nu mu. Ìdájọ́ ńlá ń bẹ fún ayé, nítorí àwọn ohun ìkọsẹ̀. Dandan ni kí àwọn ohun ìkọsẹ̀ dé, ṣugbọn ẹnikẹ́ni tí ohun ìkọsẹ̀ bá ti ọ̀dọ̀ rẹ̀ wá, ó gbé!“Ọ̀rọ̀ náà rí bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ ninu Ìwé Orin Dafidi pé, ‘Kí ibùgbé rẹ̀ di ahoro,kí ẹnikẹ́ni má gbé ibẹ̀.’Ati pé,‘Kí á fi ipò rẹ̀ fún ẹlòmíràn.’Ojú tí Rebeka náà gbé sókè, ó rí Isaaki, ó sọ̀kalẹ̀ lórí ràkúnmí. Bí ẹnikẹ́ni bá gbé òkú wọn, kí ó fọ aṣọ rẹ̀, yóo sì jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́; ohun àìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fun yín.Ẹni tí ń ṣọ́ ilé ẹ̀wọ̀n náà bá bèèrè iná, ó pa kuuru wọ inú iyàrá, ó ń gbọ̀n láti orí dé ẹsẹ̀. Ó wólẹ̀ níwájú Paulu ati Sila. Gba-n-gba là ńṣe gbàǹgbà; bẹ́ṣín bá kú, ìta gbangba là ńsin í sí.
Sugbon ile ran obinrin naa lowo. Ile lanu, o fa omi ti Eranko Ewele naa tu jade lenu mu. Idajo nla n be fun aye, nitori awon ohun ikose. Dandan ni ki awon ohun ikose de, sugbon enikeni ti ohun ikose ba ti odo re wa, o gbe!“Oro naa ri bi o ti wa ni akosile ninu Iwe Orin Dafidi pe, ‘Ki ibugbe re di ahoro,ki enikeni ma gbe ibe.’Ati pe,‘Ki a fi ipo re fun elomiran.’Oju ti Rebeka naa gbe soke, o ri Isaaki, o sokale lori rakunmi. Bi enikeni ba gbe oku won, ki o fo aso re, yoo si je alaimo titi di irole; ohun aimo ni won je fun yin.Eni ti n so ile ewon naa ba beere ina, o pa kuuru wo inu iyara, o n gbon lati ori de ese. O wole niwaju Paulu ati Sila. Gba-n-gba la nse gbangba; besin ba ku, ita gbangba la nsin i si.
Ṣugbọn ní tèmi, OLUWA, ìwọ ni mò ń gbadura síní àkókò tí ó bá yẹ, Ọlọrun,ninu ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,ninu agbára ìgbàlà rẹ, Ọlọrun dá mi lóhùn.Nígbà náà ni OLUWA tún bá Jobu sọ̀rọ̀ láti inú ìjì líle, ó ní,Yóo gbé ọwọ́ rẹ̀ mejeeji lé e lórí, yóo jẹ́wọ́ gbogbo àìṣedéédé ati ìrékọjá ati ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli lórí rẹ̀, yóo sì kó wọn lé e lórí, yóo fà á lé ẹnìkan tí ó ti múra sílẹ̀ lọ́wọ́, láti fà á lọ sinu aṣálẹ̀. Ṣugbọn nígbà tí àwọn kan ninu àwọn ará Kipru ati Kirene dé Antioku, wọ́n bá àwọn ará Giriki sọ̀rọ̀, wọ́n ń waasu Oluwa Jesu fún wọn. One cannot be bedeviled by two hills; if one ascends a hill, one descends a hill.
Sugbon ni temi, OLUWA, iwo ni mo n gbadura sini akoko ti o ba ye, Olorun,ninu opo ife re ti ki i ye,ninu agbara igbala re, Olorun da mi lohun.Nigba naa ni OLUWA tun ba Jobu soro lati inu iji lile, o ni,Yoo gbe owo re mejeeji le e lori, yoo jewo gbogbo aisedeede ati irekoja ati ese awon omo Israeli lori re, yoo si ko won le e lori, yoo fa a le enikan ti o ti mura sile lowo, lati fa a lo sinu asale. Sugbon nigba ti awon kan ninu awon ara Kipru ati Kirene de Antioku, won ba awon ara Giriki soro, won n waasu Oluwa Jesu fun won. One cannot be bedeviled by two hills; if one ascends a hill, one descends a hill.
Ó ti kúrò ní agbègbè Rimoni,ó ti dé sí Aiati;ó kọjá ní Migironi,ó kó ẹrù ogun rẹ̀ jọ sí Mikimaṣi.Sibẹsibẹ, ninu ìnira wọn, ó ṣàánú wọn,nígbà tí ó gbọ́ igbe wọn.Aṣọ ìkélé tí ó wà ninu Tẹmpili ya sí meji láti òkè dé ilẹ̀. Ilẹ̀ mì tìtì. Àwọn òkè sán. Ọkunrin ọlọ́rọ̀ yìí ní ọpọlọpọ agbo mààlúù, ati agbo aguntan. Má jẹ́ kí abanijẹ́ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ lórí ilẹ̀ náà;jẹ́ kí oníwà ipá ko àgbákò kíákíá.“OLUWA Ọlọrun, fi ojurere wo àwa iranṣẹ rẹ, àní àwọn ọmọ Israẹli, eniyan rẹ, kí o sì gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ wọn nígbàkúùgbà tí wọ́n bá ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. A kì í tún ṣe ọmọ-ọwọ́ mọ́, tí ìgbì yóo máa bì sọ́tùn-ún, sósì, tabi tí afẹ́fẹ́ oríṣìíríṣìí ẹ̀kọ́ àrékérekè àwọn tí wọn ń lo ọgbọ́n-ẹ̀wẹ́ láti fi tan eniyan jẹ yóo máa fẹ́ káàkiri. OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ìgbà ayé Jehoiakimu ọmọ Josaya, ọba Juda; ó ní, A favor has turned to mud in Awẹ́ towń the vulture did a favor and went bald.
O ti kuro ni agbegbe Rimoni,o ti de si Aiati;o koja ni Migironi,o ko eru ogun re jo si Mikimasi.Sibesibe, ninu inira won, o saanu won,nigba ti o gbo igbe won.Aso ikele ti o wa ninu Tempili ya si meji lati oke de ile. Ile mi titi. Awon oke san. Okunrin oloro yii ni opolopo agbo maaluu, ati agbo aguntan. Ma je ki abanije fi ese mule lori ile naa;je ki oniwa ipa ko agbako kiakia.“OLUWA Olorun, fi ojurere wo awa iranse re, ani awon omo Israeli, eniyan re, ki o si gbo adura ati ebe won nigbakuugba ti won ba ke pe o fun iranlowo. A ki i tun se omo-owo mo, ti igbi yoo maa bi sotun-un, sosi, tabi ti afefe orisiirisii eko arekereke awon ti won n lo ogbon-ewe lati fi tan eniyan je yoo maa fe kaakiri. OLUWA ba Jeremaya soro ni igba aye Jehoiakimu omo Josaya, oba Juda; o ni, A favor has turned to mud in Awe town the vulture did a favor and went bald.
One should be careful about doing favors, lest they come back to haunt one. Compare Oore tí igúnnugún ṣe . . . Awẹ́ is a town near Ọ̀yọ́; the proverb obviously refers to an incident in which someone did a favor and reaped disaster. The reference to the vulture recalls the folktale in which the bird volunteered to carry a sacrifice to heaven to end a draught and got caught in the downpour resulting from his successful mission on its return.
One should be careful about doing favors, lest they come back to haunt one. Compare Oore ti igunnugun se . . . Awe is a town near Oyo; the proverb obviously refers to an incident in which someone did a favor and reaped disaster. The reference to the vulture recalls the folktale in which the bird volunteered to carry a sacrifice to heaven to end a draught and got caught in the downpour resulting from his successful mission on its return.
“Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ óo la odò Jọdani kọjá sí òdìkejì lónìí, ẹ óo sì gba ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n pọ̀ jù yín lọ, tí wọ́n sì lágbára jù yín lọ. Àwọn ìlú wọn tóbi, tí odi tí wọ́n mọ yí wọn ká sì ga kan ojú ọ̀run. Olóòlà kì í kọ àfín.
“E gbo, eyin omo Israeli, e oo la odo Jodani koja si odikeji lonii, e oo si gba ile awon orile-ede ti won po ju yin lo, ti won si lagbara ju yin lo. Awon ilu won tobi, ti odi ti won mo yi won ka si ga kan oju orun. Oloola ki i ko afin.
Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya, Dafidi bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni o ti ń bọ̀?”Ọdọmọkunrin náà dáhùn pé, “Láti inú àgọ́ àwọn ọmọ Israẹli ni mo ti sá àsálà.”Bí wọ́n ti rí i tí ó yọ lókèèrè, kí ó tilẹ̀ tó súnmọ́ ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn láti pa á. Ṣugbọn OLUWA wà pẹlu Josẹfu, ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kìí yẹ̀ hàn sí i, ó jẹ́ kí ó bá ojurere alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà pàdé. “Nígbà tí àwọn eniyan rẹ bá ṣẹ̀ ọ́, (nítorí pé kò sí ẹni tí kì í dẹ́ṣẹ̀), tí o bá bínú sí wọn, tí o sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá ṣẹgun wọn, tí wọ́n sì kó wọn lẹ́rú lọ sí ilẹ̀ mìíràn, kì báà jẹ́ ibi tí ó jìnnà tabi tòsí, “Nítorí náà, lójú gbogbo ọmọ Israẹli, lójú ìjọ eniyan OLUWA, ati ní etígbọ̀ọ́ Ọlọrun wa, mò ń kìlọ̀ fun yín pé kí ẹ máa pa gbogbo òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́, kí ẹ̀yin ati arọmọdọmọ yín baà lè máa gbé ilẹ̀ yìí títí lae.Ẹ gbọdọ̀ pa àwọn òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́ dáradára, kí ẹ sì máa tẹ̀lé àwọn òfin ati àwọn ìlànà rẹ̀, tí ó fi lélẹ̀ fun yín. “Wolii tí yóo máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ ati ẹ̀tàn ni àwọn eniyan wọnyi ń fẹ́, tí yóo sì máa waasu pé, ‘Ẹ óo ní ọpọlọpọ waini ati ọtí líle.’Onígbàjámọ̀ ńfárí fún ọ, ò ńfọwọ́ kàn án wò; èwo ló máa kù fún ọ níbẹ̀.
Leyin naa, ni akoko ijoba Atasasesi, oba Pasia, okunrin kan wa, oruko re n je Esira, omo Seraaya, omo Asaraya, omo Hilikaya, Dafidi beere lowo re pe, “Nibo ni o ti n bo?”Odomokunrin naa dahun pe, “Lati inu ago awon omo Israeli ni mo ti sa asala.”Bi won ti ri i ti o yo lokeere, ki o tile to sunmo odo won, won dite mo on lati pa a. Sugbon OLUWA wa pelu Josefu, o si fi ife re ti kii ye han si i, o je ki o ba ojurere alabojuto ogba ewon naa pade. “Nigba ti awon eniyan re ba se o, (nitori pe ko si eni ti ki i dese), ti o ba binu si won, ti o si je ki awon ota segun won, ti won si ko won leru lo si ile miiran, ki baa je ibi ti o jinna tabi tosi, “Nitori naa, loju gbogbo omo Israeli, loju ijo eniyan OLUWA, ati ni etigboo Olorun wa, mo n kilo fun yin pe ki e maa pa gbogbo ofin OLUWA Olorun yin mo, ki eyin ati aromodomo yin baa le maa gbe ile yii titi lae.E gbodo pa awon ofin OLUWA Olorun yin mo daradara, ki e si maa tele awon ofin ati awon ilana re, ti o fi lele fun yin. “Wolii ti yoo maa so asotele iro ati etan ni awon eniyan wonyi n fe, ti yoo si maa waasu pe, ‘E oo ni opolopo waini ati oti lile.’Onigbajamo nfari fun o, o nfowo kan an wo; ewo lo maa ku fun o nibe.
Ẹ pe gbogbo àwọn àgbààgbà ẹ̀yà yín wá sọ́dọ̀ mi, ati gbogbo àwọn olórí ninu yín, kí àwọn náà lè máa gbọ́ bí mo ti ń sọ ọ̀rọ̀ yìí, kí ẹ sì pe ọ̀run ati ayé láti ṣe ẹlẹ́rìí wọn. Dájúdájú Allah kì í tQ àwọn
E pe gbogbo awon agbaagba eya yin wa sodo mi, ati gbogbo awon olori ninu yin, ki awon naa le maa gbo bi mo ti n so oro yii, ki e si pe orun ati aye lati se elerii won. Dajudaju Allah ki i tQ awon
ÌDÁ 6
IDA 6
52. Àti pé ní tòôtọ ni A ti ṣe
52. Ati pe ni tooto ni A ti se
àlàyé ọrọ náà fún wọn, kí wọn
alaye oro naa fun won, ki won
baà le máa rántí.
baa le maa ranti.
53. Àwọn tí a ti fún ní Ìwé náà
53. Awon ti a ti fun ni Iwe naa
ṣáájú rẹ̀ — wọn gbà 4 gbọ.
saaju re — won gba 4 gbo.
54. Nígbà ti A bá sì kà a fún
54. Nigba ti A ba si ka a fun
wọn, wọn á wí pé, 'Àwá gbà á
won, won a wi pe, 'Awa gba a
gbọ, Ôô jẹ òdodo lati ọdọ Olúwa
gbo, Oo je ododo lati odo Oluwa
wa.. Dájúdájú Àwá ti ju ara wa
wa.. Dajudaju Awa ti ju ara wa
sílẹ̀ (fún Allah) tẹlẹ̀tẹlẹ̀.
sile (fun Allah) teletele.
55. Àwọn wọnyí ni A 0 san ní
55. Awon wonyi ni A 0 san ni
ẹ̀san wọn ní ẹ̀ẹ̀mejì, nípa ìfaradà
esan won ni eemeji, nipa ifarada
wọn, WỌQn sì tún n fi rere ti ibi
won, WOQn si tun n fi rere ti ibi
sẹhìn, bákan náà ni wQn tún n ná
sehin, bakan naa ni wQn tun n na
nínú ohun tí A pẹ̀sẹ̀ fún wọn.
ninu ohun ti A pese fun won.
56. Nígbà tí wọn bá sì gbọ ẹ̀rọ
56. Nigba ti won ba si gbo ero
asán, wọn á yípadà kúrò nibẹ̀,
asan, won a yipada kuro nibe,
wọn yOoò sì wi pé, 'ẹ̀san iṣẹ tiwa
won yOoo si wi pe, 'esan ise tiwa
n bẹ fún wa, ẹ̀san iṣẹ ti yín sì n
n be fun wa, esan ise ti yin si n
bẹ fún yín.. Àlàáfíà kò máa bá
be fun yin.. Alaafia ko maa ba
yin, àwa kò ní ohunkohun ṣe pẹ̀lú
yin, awa ko ni ohunkohun se pelu
àwọn aláímòkan.
awon alaimokan.
57. Dajúdájú ìwọ Annabi kì yúôò
57. Dajudaju iwo Annabi ki yuoo
le tọ) gbogbo àwọn tí ìwọ fẹ̀ràn
le to) gbogbo awon ti iwo feran
sọnà; ṣùgbọn Allah A máa tọ ẹni
sona; sugbon Allah A maa to eni
tô bá wù Ú sọnà; Òun sì ti mọ
to ba wu U sona; Oun si ti mo
àwọn tí yôòò gba ìmọnà tààrà jùlọ.
awon ti yooo gba imona taara julo.
58. Wọn yòò sì wí pé; 'Bí àwá bá
58. Won yoo si wi pe; 'Bi awa ba
tẹ̀lé ìlànà náà pẹ̀lú rẹ, a 0 mú wa
tele ilana naa pelu re, a 0 mu wa
Gbogbo eniyan ló kà á kún; ati àwọn eniyan yẹpẹrẹ ati àwọn eniyan pataki wọn. Wọ́n ní, “Eléyìí ní agbára Ọlọrun tí à ń pè ní ‘Agbára ńlá.’ ” Ó ṣe fún Arieli, Jerusalẹmu, ìlú tí ń jẹ́ pẹpẹ Ọlọrun!Ìlú tí Dafidi pàgọ́ sí.Ẹ ṣe ọdún kan tán, ẹ tún ṣe òmíràn sí i,ẹ máa ṣe àwọn àjọ̀dún ní gbogbo àkókò wọn.Àwọn yàrá ti gbọ̀ngàn ìta gùn ní aadọta igbọnwọ (mita 25), ṣugbọn àwọn tí wọ́n wà níwájú tẹmpili jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 50). Reubẹni ni àkọ́bí Jakọbu, (Ṣugbọn nítorí pé Reubẹni fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn obinrin baba rẹ̀, baba rẹ̀ gba ipò àgbà lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì gbé e fún àwọn ọmọ Josẹfu. Ninu àkọsílẹ̀ ìdílé, a kò kọ orúkọ rẹ̀ sí ipò àkọ́bí. Ọjọ́ ibinu ni ọjọ́ náà yóo jẹ́, ọjọ́ ìpọ́njú ati ìrora, ọjọ́ ìyọnu ati ìparun, ọjọ́ òkùnkùn ati ìbànújẹ́, ọjọ́ ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri. Mo bá ra aṣọ funfun náà, bí OLUWA ti wí, mo lọ́ ọ mọ́ ìdí. O kò gbọdọ̀ fi ọmọ ìyá, tabi ọmọ baba iyawo rẹ ṣe aya níwọ̀n ìgbà tí aya rẹ tí í ṣe ẹ̀gbọ́n rẹ̀ bá wà láàyè.The suffering that the babaláwo is experiencing is not something that leads to death; the hard times that the babaláwo is going through is one that leads to riches; the vicissitudes that now befall the babaláwo are ones that leave room for taking a bite of kola-nut.
Gbogbo eniyan lo ka a kun; ati awon eniyan yepere ati awon eniyan pataki won. Won ni, “Eleyii ni agbara Olorun ti a n pe ni ‘Agbara nla.’ ” O se fun Arieli, Jerusalemu, ilu ti n je pepe Olorun!Ilu ti Dafidi pago si.E se odun kan tan, e tun se omiran si i,e maa se awon ajodun ni gbogbo akoko won.Awon yara ti gbongan ita gun ni aadota igbonwo (mita 25), sugbon awon ti won wa niwaju tempili je ogorun-un (100) igbonwo (mita 50). Reubeni ni akobi Jakobu, (Sugbon nitori pe Reubeni fe okan ninu awon obinrin baba re, baba re gba ipo agba lowo re, o si gbe e fun awon omo Josefu. Ninu akosile idile, a ko ko oruko re si ipo akobi. Ojo ibinu ni ojo naa yoo je, ojo iponju ati irora, ojo iyonu ati iparun, ojo okunkun ati ibanuje, ojo ikuukuu ati okunkun biribiri. Mo ba ra aso funfun naa, bi OLUWA ti wi, mo lo o mo idi. O ko gbodo fi omo iya, tabi omo baba iyawo re se aya niwon igba ti aya re ti i se egbon re ba wa laaye.The suffering that the babalawo is experiencing is not something that leads to death; the hard times that the babalawo is going through is one that leads to riches; the vicissitudes that now befall the babalawo are ones that leave room for taking a bite of kola-nut.
OLUWA bá yí ìpinnu rẹ̀ pada, ó ní, “Ohun tí o rí kò ní ṣẹlẹ̀.”Ǹjẹ́ bí ẹnìkan bá mú ẹran tí a fi rúbọ, tí ó ti di mímọ́, tí ó dì í mọ́ ìṣẹ́tí ẹ̀wù rẹ̀, tí ó sì fi ẹ̀wù náà kan burẹdi, tabi àsáró, tabi waini, tabi òróró, tabi oúnjẹ-kóúnjẹ, ṣé ọ̀kan kan ninu àwọn oúnjẹ yìí lè tipa bẹ́ẹ̀ di mímọ́?” Àwọn alufaa bá dáhùn pé, “Rárá.”Àwọn tí wọ́n fi ṣe olórí láàrin àwọn ọmọ Israẹli bá ké tọ Farao lọ, wọ́n ní, “Kí ló dé tí o fi ń ṣe báyìí sí àwa iranṣẹ rẹ? Láti agogo mejila ọ̀sán ni òkùnkùn ti bo gbogbo ilẹ̀ títí di agogo mẹta ọ̀sán. Ǹ bá gbọ́ èsì tí yóo fún mi,ati ọ̀rọ̀ tí yóo sọ fún mi.Wọ́n gba ìhà gúsù gòkè lọ sí Heburoni, níbi tí àwọn ẹ̀yà Ahimani, ati ti Ṣeṣai ati ti Talimai, àwọn òmìrán ọmọ Anaki ń gbé. (A ti tẹ Heburoni dó ní ọdún meje ṣáájú Soani ní ilẹ̀ Ijipti.) kí ẹ lè bá mi jẹ, kí ẹ sì bá mi mu ninu ìjọba mi, kí ẹ sì jókòó lórí ìtẹ́ láti máa ṣe ìdájọ́ ẹ̀yà Israẹli mejila. Nítorí n óo wà pẹlu rẹ. Kò sí ẹni tí yóo fọwọ́ kàn ọ́ láti ṣe ọ́ níbi. Nítorí mo ní eniyan pupọ ninu ìlú yìí.” His or her mouth is the same one that proposes two hundred and proposes three hundred.
OLUWA ba yi ipinnu re pada, o ni, “Ohun ti o ri ko ni sele.”Nje bi enikan ba mu eran ti a fi rubo, ti o ti di mimo, ti o di i mo iseti ewu re, ti o si fi ewu naa kan buredi, tabi asaro, tabi waini, tabi ororo, tabi ounje-kounje, se okan kan ninu awon ounje yii le tipa bee di mimo?” Awon alufaa ba dahun pe, “Rara.”Awon ti won fi se olori laarin awon omo Israeli ba ke to Farao lo, won ni, “Ki lo de ti o fi n se bayii si awa iranse re? Lati agogo mejila osan ni okunkun ti bo gbogbo ile titi di agogo meta osan. N ba gbo esi ti yoo fun mi,ati oro ti yoo so fun mi.Won gba iha gusu goke lo si Heburoni, nibi ti awon eya Ahimani, ati ti Sesai ati ti Talimai, awon omiran omo Anaki n gbe. (A ti te Heburoni do ni odun meje saaju Soani ni ile Ijipti.) ki e le ba mi je, ki e si ba mi mu ninu ijoba mi, ki e si jokoo lori ite lati maa se idajo eya Israeli mejila. Nitori n oo wa pelu re. Ko si eni ti yoo fowo kan o lati se o nibi. Nitori mo ni eniyan pupo ninu ilu yii.” His or her mouth is the same one that proposes two hundred and proposes three hundred.
Ẹ kọ orin titun sí OLUWA;gbogbo ayé, ẹ kọ orin sí OLUWA.Jesu tún bi í ní ẹẹkẹta pé, “Simoni ọmọ Johanu, ǹjẹ́ o fẹ́ràn mi?”Ó dun Peteru nítorí Jesu bi í ní ẹẹkẹta pé, “Ǹjẹ́ o fẹ́ràn mi?” Ó wá sọ fún Jesu pé, “Oluwa, o mọ ohun gbogbo, o mọ̀ pé mo fẹ́ràn rẹ.”Jesu sọ fún un pé, “Máa bọ́ àwọn aguntan mi. Jákèjádò Juda ni Hesekaya ti ṣe ètò yìí, ó ṣe ohun tí ó dára, tí ó tọ́, tí ó sì jẹ́ òtítọ́ lójú OLUWA Ọlọrun rẹ̀. Wọn óo gbé àwọn eniyan tí wọn ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún sọ síta ní òkú ní ìgboro Jerusalẹmu, nígbà tí ìyàn ati ogun bá pa wọ́n tán. Kò ní sí ẹni tí yóo sin òkú wọn, ati ti àwọn iyawo wọn, ati ti àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin. N óo da ibi tí wọ́n ṣe lé wọn lórí.”Tó bá di ìgbà náà, ìlú marun-un yóo wà ní ilẹ̀ Ijipti, tí wọn yóo máa sọ èdè Kenaani; wọ́n óo búra láti jẹ́ ti OLUWA àwọn ọmọ ogun.Orúkọ ọ̀kan ninu wọn yóo máa jẹ́ ìlú Oòrùn. Kí OLUWA ṣe ilé ọkọ tí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín bá tún ní, ní ilé rẹ̀.” Ó bá kí wọn, ó fi ẹnu kò wọ́n lẹ́nu, ó dágbére fún wọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí sọkún. Olukuluku orílẹ̀-èdè a máa rìn ní ọ̀nà tí oriṣa rẹ̀ là sílẹ̀, ṣugbọn ọ̀nà OLUWA tí Ọlọrun wa là sílẹ̀ ni àwa yóo máa tọ̀ títí laelae.Wọ́n bá dáhùn pé, “Àwọn tí wọ́n kù ninu àwọn ara Bẹnjamini gbọdọ̀ ní ogún tiwọn, kí odidi ẹ̀yà kan má baà parun patapata ní Israẹli. Èmi náà yóo máa pàtẹ́wọ́, inú tí ń bí mi yóo sì rọ̀, èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”Ní ọjọ́ kinni oṣù kejila, ọdún kejila tí a ti wà ní ìgbèkùn, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀. Ẹ kò mọ ọ̀nà alaafia, kò sí ìdájọ́ òdodo ní ọ̀nà yín.Ẹ ti mú kí ọ̀nà yín wọ́,ẹni tó bá ba yín rìn kò ní ní alaafia.Ìjà ní ńpa onítìjú; ogun ní ḿpa alágbára.
E ko orin titun si OLUWA;gbogbo aye, e ko orin si OLUWA.Jesu tun bi i ni eeketa pe, “Simoni omo Johanu, nje o feran mi?”O dun Peteru nitori Jesu bi i ni eeketa pe, “Nje o feran mi?” O wa so fun Jesu pe, “Oluwa, o mo ohun gbogbo, o mo pe mo feran re.”Jesu so fun un pe, “Maa bo awon aguntan mi. Jakejado Juda ni Hesekaya ti se eto yii, o se ohun ti o dara, ti o to, ti o si je otito loju OLUWA Olorun re. Won oo gbe awon eniyan ti won n so asotele fun so sita ni oku ni igboro Jerusalemu, nigba ti iyan ati ogun ba pa won tan. Ko ni si eni ti yoo sin oku won, ati ti awon iyawo won, ati ti awon omo won lokunrin ati lobinrin. N oo da ibi ti won se le won lori.”To ba di igba naa, ilu marun-un yoo wa ni ile Ijipti, ti won yoo maa so ede Kenaani; won oo bura lati je ti OLUWA awon omo ogun.Oruko okan ninu won yoo maa je ilu Oorun. Ki OLUWA se ile oko ti enikookan yin ba tun ni, ni ile re.” O ba ki won, o fi enu ko won lenu, o dagbere fun won, won si bere si sokun. Olukuluku orile-ede a maa rin ni ona ti orisa re la sile, sugbon ona OLUWA ti Olorun wa la sile ni awa yoo maa to titi laelae.Won ba dahun pe, “Awon ti won ku ninu awon ara Benjamini gbodo ni ogun tiwon, ki odidi eya kan ma baa parun patapata ni Israeli. Emi naa yoo maa patewo, inu ti n bi mi yoo si ro, emi OLUWA ni mo so bee.”Ni ojo kinni osu kejila, odun kejila ti a ti wa ni igbekun, OLUWA ba mi soro. E ko mo ona alaafia, ko si idajo ododo ni ona yin.E ti mu ki ona yin wo,eni to ba ba yin rin ko ni ni alaafia.Ija ni npa onitiju; ogun ni mpa alagbara.
Bẹ́ẹ̀ ni alufaa yóo ṣe ètùtù fún un nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá, nítorí pé ó ṣe ọ̀kan ninu àwọn ohun tí OLUWA pa láṣẹ pé ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ ṣe, OLUWA yóo sì dáríjì í. Ìyẹ̀fun yòókù yóo di ti alufaa, gẹ́gẹ́ bí ti ẹbọ ohun jíjẹ.”Nítorí bí kíkọ̀ tí Ọlọrun kọ̀ wọ́n sílẹ̀ bá mú kí aráyé bá Ọlọrun rẹ́, kí ni yóo ṣẹlẹ̀ nígbà tí Ọlọrun bá gbà wọ́n mọ́ra? Ǹjẹ́ òkú pàápàá kò ní jí dìde?Nítòótọ́,ìwọ ni Ọlọrun tí ó ń fi ara pamọ́,Ọlọrun Israẹli, Olùgbàlà.Ọjọ́ kan ṣoṣo là ńtẹ́; ojoojúmọ́ lojú ńtini.
Bee ni alufaa yoo se etutu fun un nitori ese ti o da, nitori pe o se okan ninu awon ohun ti OLUWA pa lase pe enikeni ko gbodo se, OLUWA yoo si dariji i. Iyefun yooku yoo di ti alufaa, gege bi ti ebo ohun jije.”Nitori bi kiko ti Olorun ko won sile ba mu ki araye ba Olorun re, ki ni yoo sele nigba ti Olorun ba gba won mora? Nje oku paapaa ko ni ji dide?Nitooto,iwo ni Olorun ti o n fi ara pamo,Olorun Israeli, Olugbala.Ojo kan soso la nte; ojoojumo loju ntini.
Ṣugbọn OLUWA sọ fún wolii Ṣemaaya, eniyan Ọlọrun pé, Ilẹ̀ tiwọn bẹ̀rẹ̀ láti Mahanaimu, títí dé gbogbo ilẹ̀ Baṣani, gbogbo ilẹ̀ ìjọba Ogu, ọba Baṣani, ati gbogbo àwọn ìlú Jairi tí ó wà ní Baṣani, gbogbo ìlú wọn jẹ́ ọgọta. Nígbà tí Reu di ẹni ọdún mejilelọgbọn ni ó bí Serugi. Gbogbo ẹni tí ó bá ń gbé inú rẹ̀ kò ní máa dẹ́ṣẹ̀. Ẹni tí ó bá ń dẹ́ṣẹ̀ kò ì tíì rí i, kò sì tíì mọ̀ ọ́n.Má jẹ́rìí lòdì sí aládùúgbò rẹ láìnídìí,má sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn ti ẹnu rẹ jáde.Dafidi wí fún ọdọmọkunrin ará Amaleki náà pé, “Ìwọ ni o fa èyí sí orí ara rẹ. Ìwọ ni o dá ara rẹ lẹ́bi, nípa jíjẹ́wọ́ pé, ìwọ ni o pa ọba, ẹni tí OLUWA fi àmì òróró yàn.”Ọjọ́ ìrántí ni ọjọ́ yìí yóo jẹ́ fún yín, ní ọdọọdún ni ẹ óo sì máa ṣe àjọ̀dún rẹ̀ fún OLUWA; àwọn arọmọdọmọ yín yóo sì máa ṣe àjọ̀dún yìí bí ìlànà, gẹ́gẹ́ bí ohun ìrántí títí lae.ó tẹjú mọ́ Jesu bí ó ti ń kọjá lọ, ó ní, “Wo ọ̀dọ́ aguntan Ọlọrun.”Ẹ bi í pé, ṣé kò mọ̀ pé wíwá tí mo wá láti gbógun ti ìlú yìí ati láti pa á run kò ṣẹ̀yìn OLUWA? OLUWA ni ó sọ fún mi pé kí n lọ gbógun ti ilẹ̀ yìí, kí n sì pa á run.”Ṣugbọn mo kìlọ̀ fún wọn, mo sì sọ fún wọn pé, “Kí ló dé tí ẹ fi ń dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ odi? Bí ẹ bá tún ṣe bẹ́ẹ̀ n óo jẹ yín níyà.” Láti ìgbà náà ni wọn kò wá ní ọjọ́ ìsinmi mọ́. Àwọn ọmọ Jẹriko jẹ́ ojilelọọdunrun ó lé marun-un (345)Nígbà náà ni ìkùukùu bo àgọ́ àjọ náà, ògo OLUWA sì kún inú rẹ̀. oúnjẹ tí ó wà lórí tabili rẹ̀ ati bí àwọn ìjòyè rẹ̀ ti jókòó, àwọn iranṣẹ rẹ̀, ìwọṣọ ati ìṣesí wọn, àwọn agbọ́tí rẹ̀ ati ìwọṣọ wọn, ati ẹbọ sísun tí ó ń rú ní ilé OLUWA, ẹnu yà á lọpọlọpọ.125. Nígbà tí Àmì kan bá dé wá bá
Sugbon OLUWA so fun wolii Semaaya, eniyan Olorun pe, Ile tiwon bere lati Mahanaimu, titi de gbogbo ile Basani, gbogbo ile ijoba Ogu, oba Basani, ati gbogbo awon ilu Jairi ti o wa ni Basani, gbogbo ilu won je ogota. Nigba ti Reu di eni odun mejilelogbon ni o bi Serugi. Gbogbo eni ti o ba n gbe inu re ko ni maa dese. Eni ti o ba n dese ko i tii ri i, ko si tii mo on.Ma jerii lodi si aladuugbo re lainidii,ma si je ki oro etan ti enu re jade.Dafidi wi fun odomokunrin ara Amaleki naa pe, “Iwo ni o fa eyi si ori ara re. Iwo ni o da ara re lebi, nipa jijewo pe, iwo ni o pa oba, eni ti OLUWA fi ami ororo yan.”Ojo iranti ni ojo yii yoo je fun yin, ni odoodun ni e oo si maa se ajodun re fun OLUWA; awon aromodomo yin yoo si maa se ajodun yii bi ilana, gege bi ohun iranti titi lae.o teju mo Jesu bi o ti n koja lo, o ni, “Wo odo aguntan Olorun.”E bi i pe, se ko mo pe wiwa ti mo wa lati gbogun ti ilu yii ati lati pa a run ko seyin OLUWA? OLUWA ni o so fun mi pe ki n lo gbogun ti ile yii, ki n si pa a run.”Sugbon mo kilo fun won, mo si so fun won pe, “Ki lo de ti e fi n duro legbee odi? Bi e ba tun se bee n oo je yin niya.” Lati igba naa ni won ko wa ni ojo isinmi mo. Awon omo Jeriko je ojileloodunrun o le marun-un (345)Nigba naa ni ikuukuu bo ago ajo naa, ogo OLUWA si kun inu re. ounje ti o wa lori tabili re ati bi awon ijoye re ti jokoo, awon iranse re, iwoso ati isesi won, awon agboti re ati iwoso won, ati ebo sisun ti o n ru ni ile OLUWA, enu ya a lopolopo.125. Nigba ti Ami kan ba de wa ba
wọn, wọn á wí pé, 'Àwa kò ní
won, won a wi pe, 'Awa ko ni
gbàgbọ titi ti a 0 fi fún wa ní irú
gbagbo titi ti a 0 fi fun wa ni iru
ohun tí a ti fún àwọn Òjíṣẹ Allah".
ohun ti a ti fun awon Ojise Allah".
Allah lô mò ibi tí Òun yòò gbé iṣẹ
Allah lo mo ibi ti Oun yoo gbe ise