diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
3S. Kò ri bẹ̀! A ô gbé e sọ sínú
3S. Ko ri be! A o gbe e so sinu
6. Kí ni yòò mú ọ mọ ohun to n
6. Ki ni yoo mu o mo ohun to n
jẹ 'Hutamah'?
je 'Hutamah'?
7. Ohun náà ni iná tí Allah, ti a
7. Ohun naa ni ina ti Allah, ti a
dá kalẹ̀.
da kale.
8. Éyí tí yòò ru bo àwọn ọkàn
8. Eyi ti yoo ru bo awon okan
mọỌljẹ̀.
moOlje.
9, Dájúdájú yòò mu wQn lôámi
9, Dajudaju yoo mu wQn loami
dárudáru.
darudaru.
10. Nínú àwọn opò tí a mọ ga.
10. Ninu awon opo ti a mo ga.
Ẹ fetí sí orin arò tí mò ń kọ le yín lórí, ẹ̀yin ìdílé Israẹli:The person who plants a hundred yam seedlings and says he planted two hundred, after he has eaten a hundred truths, he will come to eat a hundred lies.
E feti si orin aro ti mo n ko le yin lori, eyin idile Israeli:The person who plants a hundred yam seedlings and says he planted two hundred, after he has eaten a hundred truths, he will come to eat a hundred lies.
Àwọn kan tí wọ́n yàn bá dìde, wọ́n kó àwọn tí àwọn ọmọ ogun kó lẹ́rú ati ẹrù wọn, wọ́n wọ àwọn tí wọ́n wà ní ìhòòhò láṣọ; wọ́n fún wọn ní bàtà, wọ́n pèsè oúnjẹ ati nǹkan mímu fún wọn, wọ́n sì fi òróró sí ọgbẹ́ wọn. Wọ́n gbé gbogbo àwọn tí àárẹ̀ ti mú gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn arakunrin wọn ní Jẹriko, ìlú ọlọ́pẹ. Lẹ́yìn náà wọ́n pada lọ sí Samaria.Usi ni ó bí Isiraya. Isiraya sì bí ọmọ mẹrin: Mikaeli, Ọbadaya, Joẹli, ati Iṣaya; wọ́n di marun-un, àwọn maraarun ni wọ́n sì jẹ́ ìjòyè. Ẹni tí ọ̀ṣọ́ bá wù kó ṣòwò; ẹni ajé yalé-e rẹ̀ ló gbọ́n.
Awon kan ti won yan ba dide, won ko awon ti awon omo ogun ko leru ati eru won, won wo awon ti won wa ni ihooho laso; won fun won ni bata, won pese ounje ati nnkan mimu fun won, won si fi ororo si ogbe won. Won gbe gbogbo awon ti aare ti mu gun ketekete lo si odo awon arakunrin won ni Jeriko, ilu olope. Leyin naa won pada lo si Samaria.Usi ni o bi Isiraya. Isiraya si bi omo merin: Mikaeli, Obadaya, Joeli, ati Isaya; won di marun-un, awon maraarun ni won si je ijoye. Eni ti oso ba wu ko sowo; eni aje yale-e re lo gbon.
Nígbà tí ó gba ọmú lẹ́nu rẹ̀, ó mú un lọ́wọ́ lọ sí Ṣilo. Nígbà tí ó ń lọ, ó mú akọ mààlúù ọlọ́dún mẹta kan lọ́wọ́, ati ìyẹ̀fun ìwọ̀n efa kan, ati ọtí waini ẹ̀kún ìgò aláwọ kan. Ó sì mú Samuẹli lọ sí Ṣilo ní ilé OLUWA, ọmọde ni Samuẹli nígbà náà. jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400).Ọ̀nà òmùgọ̀ níí dára lójú tirẹ̀,ṣugbọn ọlọ́gbọ́n a máa fetí sí ìmọ̀ràn.Ibi tí a ti ńwo olókùnrùn la ti ńwo ara ẹni.
Nigba ti o gba omu lenu re, o mu un lowo lo si Silo. Nigba ti o n lo, o mu ako maaluu olodun meta kan lowo, ati iyefun iwon efa kan, ati oti waini ekun igo alawo kan. O si mu Samueli lo si Silo ni ile OLUWA, omode ni Samueli nigba naa. je egbaa metadinlogbon o le irinwo (54,400).Ona omugo nii dara loju tire,sugbon ologbon a maa feti si imoran.Ibi ti a ti nwo olokunrun la ti nwo ara eni.
Ó ní òun óo sọ wọ́n di ẹni àríbẹ̀rù fún gbogbo ìjọba ayé. Wọn óo di ẹni ẹ̀gàn, ẹni ẹ̀sín, ẹni yẹ̀yẹ́ ati ẹni tí a fi ń ṣẹ́ èpè ní gbogbo ibi tí òun óo tì wọ́n lọ. Ó ba dè mí bí ẹranko ìjàkùmọ̀,ó lúgọ bíi kinniun,Ẹni tí ó bá fi Tẹmpili búra, ohun tí ó wà ninu rẹ̀ ati Ọlọrun tí ó ń gbé inú rẹ̀ ni ó fi búra pẹlu. Jakọbu bá Rakẹli náà lòpọ̀, ó sì fẹ́ràn rẹ̀ ju Lea lọ, ó sì sin Labani fún ọdún meje sí i.baba Nuni, baba Joṣua.Kalebu ní ẹnikẹ́ni tí ó bá gbógun ti ìlú Kiriati Seferi tí ó sì ṣẹgun rẹ̀, ni òun óo fi Akisa, ọmọbinrin òun fún kí ó fi ṣe aya. Àwọn ọ̀tá yí mi ká bí akọ mààlúù,wọ́n yí mi ká bí akọ mààlúù Baṣani tó lágbára.“Protruding twig, do not poke me in the eye”; one must keep one's eyes on the twig from a distance.
O ni oun oo so won di eni ariberu fun gbogbo ijoba aye. Won oo di eni egan, eni esin, eni yeye ati eni ti a fi n se epe ni gbogbo ibi ti oun oo ti won lo. O ba de mi bi eranko ijakumo,o lugo bii kinniun,Eni ti o ba fi Tempili bura, ohun ti o wa ninu re ati Olorun ti o n gbe inu re ni o fi bura pelu. Jakobu ba Rakeli naa lopo, o si feran re ju Lea lo, o si sin Labani fun odun meje si i.baba Nuni, baba Josua.Kalebu ni enikeni ti o ba gbogun ti ilu Kiriati Seferi ti o si segun re, ni oun oo fi Akisa, omobinrin oun fun ki o fi se aya. Awon ota yi mi ka bi ako maaluu,won yi mi ka bi ako maaluu Basani to lagbara.“Protruding twig, do not poke me in the eye”; one must keep one's eyes on the twig from a distance.
Nítorí pé ó mọ iṣẹ́ ọwọ́ wọn,á bì wọ́n ṣubú lóru, wọn á sì parun.Ṣalumu, Amaraya, ati Josẹfu.Kí ni anfaani tí ọlọ́gbọ́n ní tí ó fi ju òmùgọ̀ lọ? Kí sì ni anfaani tí talaka rí ninu pé ó mọ̀ ọ́n ṣe ní àwùjọ eniyan. Ó pàṣẹ fún wọn pé, “Ẹ lọ fara pamọ́ lẹ́yìn ìlú náà, ẹ má jìnnà sí i pupọ, ṣugbọn ẹ wà ní ìmúrasílẹ̀. Àwọn mẹ̀kúnnù ati àwọn eniyan pataki pataki jọ wà níbẹ̀,àwọn ẹrú sì bọ́ lọ́wọ́ oluwa wọn. Ṣé o kò rí àwọn ohun tí wọn ń ṣe ninu àwọn ìlú Juda ati ní ìgboro Jerusalẹmu ni? 58. (Gẹ̀gẹ bí) ojúure láti ọdọ
Nitori pe o mo ise owo won,a bi won subu loru, won a si parun.Salumu, Amaraya, ati Josefu.Ki ni anfaani ti ologbon ni ti o fi ju omugo lo? Ki si ni anfaani ti talaka ri ninu pe o mo on se ni awujo eniyan. O pase fun won pe, “E lo fara pamo leyin ilu naa, e ma jinna si i pupo, sugbon e wa ni imurasile. Awon mekunnu ati awon eniyan pataki pataki jo wa nibe,awon eru si bo lowo oluwa won. Se o ko ri awon ohun ti won n se ninu awon ilu Juda ati ni igboro Jerusalemu ni? 58. (Gege bi) ojuure lati odo
Olúwa rẹ. Eyi ni àṣeyọrí tò ga.
Oluwa re. Eyi ni aseyori to ga.
59. A sì ti ṣe é (Al-Kur'an) ní
59. A si ti se e (Al-Kur'an) ni
ìròrún lôrí ahọn rẹ, kí wọn baà lò
irorun lori ahon re, ki won baa lo
máa kíyẹ̀sara.
maa kiyesara.
60. Nitori náà máa wòye, àwọn
60. Nitori naa maa woye, awon
náà fì wòye.
naa fi woye.
Ẹbọ tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ ìwọ Ọlọrun ni ẹ̀mí ìròbìnújẹ́,ọkàn ìròbìnújẹ́ ati ìrònúpìwàdà ni ìwọ kì yóo gàn.Ẹṣin kì í já kó já èkejì-i rẹ̀.
Ebo ti o se itewogba lodo iwo Olorun ni emi irobinuje,okan irobinuje ati ironupiwada ni iwo ki yoo gan.Esin ki i ja ko ja ekeji-i re.
Àwọn ẹyẹ ìwò ń gbé oúnjẹ ati ẹran wá fún un ní ojoojumọ, ní àràárọ̀ ati ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́, ó sì ń mu omi odò náà. Èrè kí ni ó wà ninu ère? Ère irin lásánlàsàn, tí eniyan ṣe, tí ń kọ́ni ní irọ́ pípa. Nítorí ẹni tí ó ṣe wọ́n gbẹ́kẹ̀lé iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀, ère tí ó gbẹ́ tán tí kò lè sọ̀rọ̀! ìbá wúwo ju yanrìn etí òkun lọ.Ìdí nìyí tí mo fi ń fi ìtara sọ̀rọ̀.nítorí bí mo bá pẹ́ kí n tó wá, kí o lè mọ̀ bí ó ti yẹ láti darí ètò ilé Ọlọrun, èyí tíí ṣe ìjọ Ọlọrun alààyè, òpó ati ààbò òtítọ́. Ó bá sọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí gbogbo ayé, kí ẹ máa waasu ìyìn rere fún gbogbo ẹ̀dá. ati gbogbo àwọn ọba Tire, ati àwọn ọba Sidoni, ati gbogbo àwọn ọba erékùṣù tí ó wà ní òdìkejì òkun. One shows deference to the dog's owner, and the dog thinks the deference is to it.
Awon eye iwo n gbe ounje ati eran wa fun un ni ojoojumo, ni araaro ati ni irole irole, o si n mu omi odo naa. Ere ki ni o wa ninu ere? Ere irin lasanlasan, ti eniyan se, ti n koni ni iro pipa. Nitori eni ti o se won gbekele ise owo re, ere ti o gbe tan ti ko le soro! iba wuwo ju yanrin eti okun lo.Idi niyi ti mo fi n fi itara soro.nitori bi mo ba pe ki n to wa, ki o le mo bi o ti ye lati dari eto ile Olorun, eyi tii se ijo Olorun alaaye, opo ati aabo otito. O ba so fun won pe, “E lo si gbogbo aye, ki e maa waasu iyin rere fun gbogbo eda. ati gbogbo awon oba Tire, ati awon oba Sidoni, ati gbogbo awon oba erekusu ti o wa ni odikeji okun. One shows deference to the dog's owner, and the dog thinks the deference is to it.
O ní ìfaradà. O ti farada ìyà nítorí orúkọ mi, o kò sì jẹ́ kí àárẹ̀ mú ọ. Mo sọkún títí àárẹ̀ mú mi,ọ̀nà ọ̀fun mi gbẹ,ojú mi sì di bàìbàì,níbi tí mo ti dúró, tí mò ń wo ojú ìwọ Ọlọrun mi.Jesu ń rìn kiri ní apá ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí wọn ń pè ní Ọ̀dẹ̀dẹ̀ Solomoni ninu Tẹmpili. Wọ́n jíṣẹ́ fún un pé Balaki ní, “Mo bẹ̀ ọ́, má jẹ́ kí ohunkohun dí ọ lọ́wọ́ láti wá sọ́dọ̀ mi. Wọ́n ń kígbe pé,“Ọ̀dọ́ Aguntan tí a ti pa ni ó tọ́ síláti gba agbára, ọrọ̀, ọgbọ́n, ipá, ọlá, ògo ati ìyìn.”Ẹni a wí fún ko gbọ́; ẹni a fọ̀ fún kó gbà; èyí tí ò gbọ́ yó filẹ̀ bora.
O ni ifarada. O ti farada iya nitori oruko mi, o ko si je ki aare mu o. Mo sokun titi aare mu mi,ona ofun mi gbe,oju mi si di baibai,nibi ti mo ti duro, ti mo n wo oju iwo Olorun mi.Jesu n rin kiri ni apa odede ti won n pe ni Odede Solomoni ninu Tempili. Won jise fun un pe Balaki ni, “Mo be o, ma je ki ohunkohun di o lowo lati wa sodo mi. Won n kigbe pe,“Odo Aguntan ti a ti pa ni o to silati gba agbara, oro, ogbon, ipa, ola, ogo ati iyin.”Eni a wi fun ko gbo; eni a fo fun ko gba; eyi ti o gbo yo file bora.
À ń kọ àwọn nǹkan wọnyi si yín kí ayọ̀ wa lè kún.“Nítorí náà, mò ń ba yín rojọ́,n óo sì tún bá arọmọdọmọ yín rojọ́ pẹlu.”OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.Ọlọrun fi òpin sí igbe kinniun,ati bíbú tí kinniun ń bú ramúramù,ó sì wọ́ àwọn ẹgbọ̀rọ̀ kinniun léyín.Nígbà tí wọ́n dé agbègbè odò Jọdani, tí ó wà ní ilẹ̀ Kenaani, àwọn ẹ̀yà Reubẹni, ẹ̀yà Gadi, ati ìdajì ẹ̀yà Manase tẹ́ pẹpẹ kan lẹ́bàá Jọdani, pẹpẹ náà tóbi pupọ. Bí ẹ bá gba Mose gbọ́, ẹ̀ bá gbà mí gbọ́, nítorí èmi ni ọ̀rọ̀ ìwé tí ó kọ bá wí. Láti inú ilẹ̀ ni OLUWA Ọlọrun ti mú kí oríṣìíríṣìí igi hù jáde ninu ọgbà náà, tí wọ́n dùn ún wò, tí wọ́n sì dára fún jíjẹ. Igi ìyè wà láàrin ọgbà náà, ati igi ìmọ̀ ibi ati ire. Whoever people speak to should listen; whoever people instruct should accept instruction; the one who does not listen will be covered by the earth.
A n ko awon nnkan wonyi si yin ki ayo wa le kun.“Nitori naa, mo n ba yin rojo,n oo si tun ba aromodomo yin rojo pelu.”OLUWA lo so bee.Olorun fi opin si igbe kinniun,ati bibu ti kinniun n bu ramuramu,o si wo awon egboro kinniun leyin.Nigba ti won de agbegbe odo Jodani, ti o wa ni ile Kenaani, awon eya Reubeni, eya Gadi, ati idaji eya Manase te pepe kan lebaa Jodani, pepe naa tobi pupo. Bi e ba gba Mose gbo, e ba gba mi gbo, nitori emi ni oro iwe ti o ko ba wi. Lati inu ile ni OLUWA Olorun ti mu ki orisiirisii igi hu jade ninu ogba naa, ti won dun un wo, ti won si dara fun jije. Igi iye wa laarin ogba naa, ati igi imo ibi ati ire. Whoever people speak to should listen; whoever people instruct should accept instruction; the one who does not listen will be covered by the earth.
Lẹ́yìn náà, ó yipada, ó wọn ìhà àríwá, ó jẹ́ ẹẹdẹgbẹta (500) igbọnwọ (mita 250), gẹ́gẹ́ bí ọ̀pá rẹ̀. Kí ẹnikẹ́ni tí ó bá fara kan ibùsùn rẹ̀ fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóo jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́. Ojoojumọ ni wọ́n ń kìlọ̀ fún un, ṣugbọn kò gbọ́. Nítorí náà, wọ́n lọ sọ fún Hamani, wọ́n fẹ́ mọ̀ bóyá ohun tí Modekai sọ ni yóo ṣẹ, nítorí ó sọ fún wọn pé Juu ni òun. Ẹ gbọ́ igbe àwọn olùṣọ́-aguntanati ẹkún ẹ̀dùn ti àwọn oluwa agbo ẹran;nítorí OLUWA ń ba ibùjẹ ẹran wọn jẹ́.Ṣugbọn Jesu sọ pé, “Kò sí ẹni tí ó bá ti dá ọwọ́ lé lílo ẹ̀rọ-ìroko, tí ó bá tún ń wo ẹ̀yìn tí ó yẹ fún ìjọba Ọlọrun.”Ṣugbọn ìwọ OLUWA ti mú kí orílẹ̀-èdè náà pọ̀ sí i,OLUWA, o ti bukun orílẹ̀-èdè náà,gbogbo ààlà ilẹ̀ náà ni o ti bì sẹ́yìn,o sì ti buyì kún ara rẹ.27. Dajúdájú, Allah kì í tijú láti
Leyin naa, o yipada, o won iha ariwa, o je eedegbeta (500) igbonwo (mita 250), gege bi opa re. Ki enikeni ti o ba fara kan ibusun re fo aso re, ki o si we, yoo je alaimo titi di irole. Ojoojumo ni won n kilo fun un, sugbon ko gbo. Nitori naa, won lo so fun Hamani, won fe mo boya ohun ti Modekai so ni yoo se, nitori o so fun won pe Juu ni oun. E gbo igbe awon oluso-aguntanati ekun edun ti awon oluwa agbo eran;nitori OLUWA n ba ibuje eran won je.Sugbon Jesu so pe, “Ko si eni ti o ba ti da owo le lilo ero-iroko, ti o ba tun n wo eyin ti o ye fun ijoba Olorun.”Sugbon iwo OLUWA ti mu ki orile-ede naa po si i,OLUWA, o ti bukun orile-ede naa,gbogbo aala ile naa ni o ti bi seyin,o si ti buyi kun ara re.27. Dajudaju, Allah ki i tiju lati
máa fi àpẹjúwe lélẹ, bí ô kéré bí
maa fi apejuwe lele, bi o kere bi
ẹ̀fọn tàbí jù bẹ̀ẹ̀ lọ.. Ní ti àwọn tí
efon tabi ju bee lo.. Ni ti awon ti
wọn gbàgbọ, wQn mọ wí. pé:
won gbagbo, wQn mo wi. pe:
dájúdájú òdodo ni (àpẹ̀júwe yìí)
dajudaju ododo ni (apejuwe yii)
lati ọdọ Olúwa wọn; ṣùgbọn ní ti
lati odo Oluwa won; sugbon ni ti
àwọn tí wQn ṣe àìgbàgbọ, wọn
awon ti wQn se aigbagbo, won
yòò sọ pé: 'Kí ni Allah gbà lérò
yoo so pe: 'Ki ni Allah gba lero
pẹlú àpẹjúwe yìí? ẹ̀pọlọpọ. yÒÒ
pelu apejuwe yii? epolopo. yOO
ṣínà nípasẹ̀ rẹ̀, ẹpọòlọpọ sì ni Oun
sina nipase re, epoolopo si ni Oun
yoò tọ sọnà nípasẹ̀ rẹ̀. Bẹ̀ẹ̀ kò sí
yoo to sona nipase re. Bee ko si
ẹni ti yòò ti ipasẹ̀ rẹ̀ ṣinà bí kò ṣe
eni ti yoo ti ipase re sina bi ko se
àwọn aláìgbọràn,
awon alaigboran,
28. Àwọn tò n yẹ majẹ̀mu Allah
28. Awon to n ye majemu Allah
lẹhìn ìfidímúlẹ̀ rẹ̀. Tí wọn sì n já
lehin ifidimule re. Ti won si n ja
ohun tí Allah pàṣẹ ìsopọ rẹ̀, ti
ohun ti Allah pase isopo re, ti
wọn sì nì ṣe ìbàjẹ lòrí ilẹ̀. Àwọn
won si ni se ibaje lori ile. Awon
wọnyi ni ẹni òfò.
wonyi ni eni ofo.
29. Bawo ni ẹ̀yin YyéÒò ṣe
29. Bawo ni eyin YyeOo se
ṣàìgbàgbọ sí Allah? Nígbà tí ẹ̀yin
saigbagbo si Allah? Nigba ti eyin
ti JẸ òkú rí, Òún sì sọ yin di
ti JE oku ri, Oun si so yin di
alààyé.. Lẹ̀hìn náà Òun yòò sọ
alaaye.. Lehin naa Oun yoo so
yin di oku, lẹhìn náà Oun yòò tún
yin di oku, lehin naa Oun yoo tun
sọ yin di alààyẹ̀.. Lẹ̀hìn náà, ọdọ
so yin di alaaye.. Lehin naa, odo
rẹ̀ ni a 0 dá a yín padà sí.
re ni a 0 da a yin pada si.
30. Òun lẹni tí Ò dá ohun gbogbo
30. Oun leni ti O da ohun gbogbo
tí n bẹ ní ayé nítorí yín.. Lẹhìn
ti n be ni aye nitori yin.. Lehin
náà Ò yí ìhà sí òkẹ̀ òrun, Ô sì dá
naa O yi iha si oke orun, O si da
wọn pé ní ìpele méje.. Àti pé
won pe ni ipele meje.. Ati pe
Òun ni Olùmò ohun gbogbo.
Oun ni Olumo ohun gbogbo.
ÌDÁ 4
IDA 4
31. Nígba tí Olúwa rẹ̀ sì wí fún
31. Nigba ti Oluwa re si wi fun
Bí n kò bá ṣe iṣẹ́ Baba mi, ẹ má ṣe gbà mí gbọ́. wọn á ní kí ó pe, “Ṣiboleti.” Tí kò bá le pè é dáradára, tí ó bá wí pé, “Siboleti,” wọn á kì í mọ́lẹ̀, wọn á sì pa á létí odò Jọdani náà. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe pa ọ̀kẹ́ meji ati ẹgbaa (42,000) eniyan, ninu àwọn ará Efuraimu ní ọjọ́ náà.Jesu ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́ ninu ilé ìpàdé kan ní Ọjọ́ Ìsinmi. Jagunjagun ni OLUWA, OLUWA sì ni orúkọ rẹ̀.Ó sọ fún iranṣẹ rẹ̀ pé, “Jẹ́ kí á lọ sí ọ̀kan ninu àwọn ìlú wọnyi, kí á sì sùn ní Gibea tabi ní Rama.”
Bi n ko ba se ise Baba mi, e ma se gba mi gbo. won a ni ki o pe, “Siboleti.” Ti ko ba le pe e daradara, ti o ba wi pe, “Siboleti,” won a ki i mole, won a si pa a leti odo Jodani naa. Bee ni won se pa oke meji ati egbaa (42,000) eniyan, ninu awon ara Efuraimu ni ojo naa.Jesu n ko awon eniyan lekoo ninu ile ipade kan ni Ojo Isinmi. Jagunjagun ni OLUWA, OLUWA si ni oruko re.O so fun iranse re pe, “Je ki a lo si okan ninu awon ilu wonyi, ki a si sun ni Gibea tabi ni Rama.”
(A sọ ọ kal
(A so o kal
1. Ní Orúkọ Allah, Olôore ọfẹ,
1. Ni Oruko Allah, Oloore ofe,
Alaàanú jùlọ.
Alaaanu julo.
2. Àwọn tí wọn n ṣe àìgbàgbò, tí
2. Awon ti won n se aigbagbo, ti
wỌn sì n darí àwọn ẹ̀nìyàn kúrò
wOn si n dari awon eniyan kuro
lôjú ẹ̀nà Allah- O máa fì sọ iṣẹ
loju ena Allah- O maa fi so ise
wọn di asán.
won di asan.
3. Ṣùgbọn ní ti àwọn to gbàgbọ ti
3. Sugbon ni ti awon to gbagbo ti
wọỌn sì n ṣe IṢẹ rere, tí wọn tún gba
woOn si n se ISe rere, ti won tun gba
ohun tí a sọòkalẹ̀ fún Muhammad
ohun ti a sookale fun Muhammad
gbọ- òdodo sì ni lati òdọ Olúwa
gbo- ododo si ni lati odo Oluwa
wọn- Òun yòò pa àìṣedéédé wọn
won- Oun yoo pa aisedeede won
rẹ̀, yÒò sì tún ònà wọn ṣe.
re, yOo si tun ona won se.
4. EÉyí jẹ̀ bẹ̀ẹ̀, nítorí pé àwọn
4. EEyi je bee, nitori pe awon
aláìgbàgbọ tẹ̀lé irọ nígbà tí àwọn té
alaigbagbo tele iro nigba ti awon te
gbàgbọ lOdodo tẹ̀lé òtítọ láti ẹdẹ̀
gbagbo lOdodo tele otito lati ede
Olúwa wọn. Báyìí ni Allah ṣe n ṣe
Oluwa won. Bayii ni Allah se n se
àfiwé àwọn ẹ̀nìyàn (láti kọ. wọn
afiwe awon eniyan (lati ko. won
lẹkọọ).
lekoo).
3.. Nígbà tí ẹ bá pàdé àwọn
3.. Nigba ti e ba pade awon
aláìgbàgbọ (lôjú ogun) ẹ lù wọn ní
alaigbagbo (loju ogun) e lu won ni
ọrùn, nígbà tí ẹ bá ti borí wọn, ẹ dẹ̀
orun, nigba ti e ba ti bori won, e de
wọn ní ṣẹkẹṣẹkẹ̀- lẹhìn náà, (ẹ lò tú
won ni sekeseke- lehin naa, (e lo tu
wọn sílẹ̀) gẹgẹ bí ojú-àánú tàbí kí ẹ
won sile) gege bi oju-aanu tabi ki e
gba ìtanràn- títí tí ogun yòôò fi parí.
gba itanran- titi ti ogun yooo fi pari.
Ìyẹn (ni òfin). Bí Allah bá fẹ̀ ni,
Iyen (ni ofin). Bi Allah ba fe ni,
Òun ìbá ti fìyà jẹ wQn fúnra Rẹ̀,
Oun iba ti fiya je wQn funra Re,
Ṣùgbọn Oun (ti pinnu) láti fi apá
Sugbon Oun (ti pinnu) lati fi apa
kan yín dán apá kejì wò. Ní ti àwọn
kan yin dan apa keji wo. Ni ti awon
tí a pa sôjú ẹ̀nà Allah- Òun kì yôò
ti a pa soju ena Allah- Oun ki yoo
Jẹ kí iṣẹ wọn pasán.
Je ki ise won pasan.
Nisinsinyii, a ti tún un gbìn sinu aṣálẹ̀,ninu ilẹ̀ gbígbẹ níbi tí kò sí omi.Ẹnìkejì ní, ‘Mo ra mààlúù fún ẹ̀rọ-ìroko. Mò ń lọ dán an wò, dákun, yọ̀ǹda mi.’ Ẹ̀rù kì í ba igbó, bẹ́ẹ̀ni kì í ba odò; ẹ̀rù kì í ba ọlọ lójú ata.
Nisinsinyii, a ti tun un gbin sinu asale,ninu ile gbigbe nibi ti ko si omi.Enikeji ni, ‘Mo ra maaluu fun ero-iroko. Mo n lo dan an wo, dakun, yonda mi.’ Eru ki i ba igbo, beeni ki i ba odo; eru ki i ba olo loju ata.
Bí ẹni tí ó ya ilé yìí sọ́tọ̀ fún OLUWA bá fẹ́ rà á pada, yóo san iye tí ilé náà bá tó, yóo sì tún fi ìdámárùn-ún iye owó rẹ̀ lé e. Nígbà tí ó bá san owó ilé náà pada, ilé yóo di tirẹ̀.Ní àkókò yìí, OLUWA ya àwọn ẹ̀yà Lefi sọ́tọ̀ láti máa gbé Àpótí Majẹmu OLUWA, ati láti máa dúró níwájú OLUWA láti ṣe iṣẹ́ ìsìn, ati láti máa yin orúkọ rẹ̀, títí di òní olónìí. Nígbà tí ó bá wa ní Asọsi, ó wọnú ọkọ̀ wa, a bá lọ sí Mitilene. No carver of mortars can do a thing to the banana stem.
Bi eni ti o ya ile yii soto fun OLUWA ba fe ra a pada, yoo san iye ti ile naa ba to, yoo si tun fi idamarun-un iye owo re le e. Nigba ti o ba san owo ile naa pada, ile yoo di tire.Ni akoko yii, OLUWA ya awon eya Lefi soto lati maa gbe Apoti Majemu OLUWA, ati lati maa duro niwaju OLUWA lati se ise isin, ati lati maa yin oruko re, titi di oni olonii. Nigba ti o ba wa ni Asosi, o wonu oko wa, a ba lo si Mitilene. No carver of mortars can do a thing to the banana stem.
Nígbà tí Pilatu gbọ́ bẹ́ẹ̀, ó mú Jesu jáde, ó wá jókòó lórí pèpéle ìdájọ́ níbìkan tí wọn ń pè ní “Pèpéle olókùúta,” tí ń jẹ́ “Gabata” ní èdè Heberu. “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni tíì sọ fún Ọlọrun pé,‘Mo ti jìyà rí, n kò sì ní gbẹ̀ṣẹ̀ mọ́.Just as the talk turns to the partridge it shows up to raid the farm
Nigba ti Pilatu gbo bee, o mu Jesu jade, o wa jokoo lori pepele idajo nibikan ti won n pe ni “Pepele olokuuta,” ti n je “Gabata” ni ede Heberu. “Nje enikeni tii so fun Olorun pe,‘Mo ti jiya ri, n ko si ni gbese mo.Just as the talk turns to the partridge it shows up to raid the farm
Ṣé òkú ni o óo ṣe iṣẹ́ ìyanu hàn?Ṣé àwọn òkú lè dìde kí wọ́n máa yìn ọ́?“Bí èdè-àìyedè kan bá bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ọmọ meji, tí wọ́n bá lọ sí ilé ẹjọ́, tí àwọn adájọ́ sì dá ẹjọ́ náà fún wọn, tí wọ́n dá ẹni tí ó jàre láre, tí wọ́n sì dá ẹni tí ó jẹ̀bi lẹ́bi, Nígbà tí ó di òwúrọ̀, bí wọ́n ti ń kọjá lọ, wọ́n rí i tí igi ọ̀pọ̀tọ́ àná ti gbẹ patapata láti orí dé gbòǹgbò. Ṣugbọn níbi èrè aiṣododo nìkan ni ojú ati ọkàn yín ń wà,níbi kí ẹ máa pa aláìṣẹ̀, kí ẹ máa ni eniyan lára,kí ẹ sì máa hùwà ìkà.Nítorí pé ọpọlọpọ àwọn ará Juda ni wọ́n ti bá a dá majẹmu, nítorí àna Ṣekanaya ọmọ Ara ni: ọmọ rẹ̀ ọkunrin, Jehohanani, ló fẹ́ ọmọbinrin Meṣulamu, ọmọ Berekaya. kí ó ṣe oore kan fún wọn, kí ó fi Paulu ranṣẹ sí Jerusalẹmu. Èrò wọn ni láti dènà dè é, kí wọ́n baà lè pa á. Wọn kì í ṣe ti ayé, gẹ́gẹ́ bí èmi kì í tíí ṣe ti ayé. “Tabi ọba wo ni yóo lọ ko ọba mìíràn lójú ogun tí kò ní kọ́kọ́ jókòó kí ó gba ìmọ̀ràn bí òun yóo bá lè ko ẹni tí ó ní ọ̀kẹ́ kan ọmọ-ogun lójú? Mo dùbúlẹ̀, mo sùn, mo sì jí,nítorí OLUWA ni ó ń gbé mi ró.“Èmi OLUWA fi ara mi búra pé, ní ilẹ̀ Babiloni, ní ilẹ̀ ọba tí ó fi í sórí oyè ọba tí kò náání, tí ó sì da majẹmu rẹ̀, níbẹ̀ ni yóo kú sí. ẹni tí kì í ṣe ojuṣaaju fún àwọn ìjòyè,tí kì í sì í ka ọlọ́rọ̀ sí ju talaka lọ,nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo wọn.Háà! Asiria!Orílẹ̀-èdè tí mò ń lò bíi kùmọ̀, ati bíi ọ̀pánígbà tí inú bá bí mi.gègé ni wọ́n ṣẹ́ tí wọ́n fi yàn wọ́n, nítorí pé, bí àwọn alámòójútó ìsìn ati alámòójútó iṣẹ́ ilé Ọlọrun ṣe wà ninu àwọn ìran Eleasari, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n wà ninu ti Itamari. Alabojuto ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fi wọ́n sábẹ́ àkóso Josẹfu, wọ́n sì wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n náà fún ìgbà díẹ̀.Ohun tí mo bẹ̀rù jù ti dé bá mi,ohun tí ń fò mí láyà ti ṣẹlẹ̀ sí mi.Ṣugbọn ìwọ, OLUWA, ni Ọlọrun aláàánú ati olóore;o kì í tètè bínú, o sì kún fún ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́.Tí ó bá di ìgbà náà, ẹ̀ka igi OLUWA yóo di ohun ẹwà ati iyì. Èso ilẹ̀ náà yóo sì di ohun ògo ati àmúyangàn fún àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n bá kù. OLUWA, ranti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wa,Ṣe akiyesi ẹ̀sín wa.Ó dá wọn lóhùn, ó ní, “Kí ni mo ṣe lẹ́gbẹ̀ẹ́ èyí tí ẹ̀yin ṣe? Ohun tí ẹ̀yin ará Efuraimu ṣe, tí ẹ rò pé ohun kékeré ni yìí, ó ju gbogbo ohun tí àwọn ará Abieseri ṣe, tí ẹ kà kún nǹkan bàbàrà lọ. Ẹ̀bẹ̀ là ḿbẹ òṣìkà pé kó tún ìlú-u rẹ̀ ṣe.
Se oku ni o oo se ise iyanu han?Se awon oku le dide ki won maa yin o?“Bi ede-aiyede kan ba be sile laarin awon omo meji, ti won ba lo si ile ejo, ti awon adajo si da ejo naa fun won, ti won da eni ti o jare lare, ti won si da eni ti o jebi lebi, Nigba ti o di owuro, bi won ti n koja lo, won ri i ti igi opoto ana ti gbe patapata lati ori de gbongbo. Sugbon nibi ere aisododo nikan ni oju ati okan yin n wa,nibi ki e maa pa alaise, ki e maa ni eniyan lara,ki e si maa huwa ika.Nitori pe opolopo awon ara Juda ni won ti ba a da majemu, nitori ana Sekanaya omo Ara ni: omo re okunrin, Jehohanani, lo fe omobinrin Mesulamu, omo Berekaya. ki o se oore kan fun won, ki o fi Paulu ranse si Jerusalemu. Ero won ni lati dena de e, ki won baa le pa a. Won ki i se ti aye, gege bi emi ki i tii se ti aye. “Tabi oba wo ni yoo lo ko oba miiran loju ogun ti ko ni koko jokoo ki o gba imoran bi oun yoo ba le ko eni ti o ni oke kan omo-ogun loju? Mo dubule, mo sun, mo si ji,nitori OLUWA ni o n gbe mi ro.“Emi OLUWA fi ara mi bura pe, ni ile Babiloni, ni ile oba ti o fi i sori oye oba ti ko naani, ti o si da majemu re, nibe ni yoo ku si. eni ti ki i se ojusaaju fun awon ijoye,ti ki i si i ka oloro si ju talaka lo,nitori ise owo re ni gbogbo won.Haa! Asiria!Orile-ede ti mo n lo bii kumo, ati bii opanigba ti inu ba bi mi.gege ni won se ti won fi yan won, nitori pe, bi awon alamoojuto isin ati alamoojuto ise ile Olorun se wa ninu awon iran Eleasari, bee naa ni won wa ninu ti Itamari. Alabojuto ogba ewon naa fi won sabe akoso Josefu, won si wa ni ogba ewon naa fun igba die.Ohun ti mo beru ju ti de ba mi,ohun ti n fo mi laya ti sele si mi.Sugbon iwo, OLUWA, ni Olorun alaaanu ati oloore;o ki i tete binu, o si kun fun ife ti ki i ye, ati otito.Ti o ba di igba naa, eka igi OLUWA yoo di ohun ewa ati iyi. Eso ile naa yoo si di ohun ogo ati amuyangan fun awon omo Israeli ti won ba ku. OLUWA, ranti ohun ti o sele si wa,Se akiyesi esin wa.O da won lohun, o ni, “Ki ni mo se legbee eyi ti eyin se? Ohun ti eyin ara Efuraimu se, ti e ro pe ohun kekere ni yii, o ju gbogbo ohun ti awon ara Abieseri se, ti e ka kun nnkan babara lo. Ebe la mbe osika pe ko tun ilu-u re se.
Olùfẹ́ mi dàbí àpò òjíá,bí ó ti sùn lé mi láyà.Sibẹ Ọlọrun wá ẹ̀sùn sí ọ lẹ́sẹ̀,ó sọ ọ́ di ọ̀tá rẹ̀,A snake sees a tight hole and crawls into it; has its mother hands to pull it out?
Olufe mi dabi apo ojia,bi o ti sun le mi laya.Sibe Olorun wa esun si o lese,o so o di ota re,A snake sees a tight hole and crawls into it; has its mother hands to pull it out?
O óo pe àwọn orílẹ̀-èdè tí o kò mọ̀ rí,àwọn orílẹ̀-èdè tí kò mọ̀ ọ́ rí yóo sáré wá sọ́dọ̀ rẹ,nítorí OLUWA Ọlọrun rẹ,ati nítorí Ẹni Mímọ́ Israẹli, tí ó ṣe ọ́ lógo.”Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, òun náà mú burẹdi, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun níwájú gbogbo wọn, ó bù ú, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí jẹ ẹ́. Bí Abrahamu ti gba Ọlọrun gbọ́, tí Ọlọrun wá gbà á gẹ́gẹ́ bí olódodo, Nítorí pé gbogbo rẹ̀ tòfin-tòfin ni,èyí òfin, tọ̀hún ìlànà.Díẹ̀ níhìn-ín, díẹ̀ lọ́hùn-ún.”The younger person does not give the older person history lectures.
O oo pe awon orile-ede ti o ko mo ri,awon orile-ede ti ko mo o ri yoo sare wa sodo re,nitori OLUWA Olorun re,ati nitori Eni Mimo Israeli, ti o se o logo.”Nigba ti o ti so bayii tan, oun naa mu buredi, o dupe lowo Olorun niwaju gbogbo won, o bu u, o ba bere si je e. Bi Abrahamu ti gba Olorun gbo, ti Olorun wa gba a gege bi olododo, Nitori pe gbogbo re tofin-tofin ni,eyi ofin, tohun ilana.Die nihin-in, die lohun-un.”The younger person does not give the older person history lectures.
“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ Kenaani tí mo fun yín, gbogbo ilẹ̀ náà ni yóo jẹ́ tiyín. Àwọn ààlà ilẹ̀ yín nìwọ̀nyí.’ OLUWA, tẹ́tí sí adura èmi iranṣẹ rẹ, tí mo bẹ̀rù orúkọ rẹ, kí o sì jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lónìí, kí n sì rí ojurere ọba.”Èmi ni agbọ́tí ọba ní àkókò náà.Ní ọjọ́ kan ṣoṣo, Peka, ọmọ Remalaya, ọba Israẹli, pa ọ̀kẹ́ mẹfa (120,000) ninu àwọn ọmọ ogun Juda; tí gbogbo wọn sì jẹ́ akọni. Ọlọrun jẹ́ kí àwọn nǹkan wọnyi ṣẹlẹ̀ sí wọn nítorí pé wọ́n ti kọ OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn sílẹ̀. Bí ẹnìkan bá bá aya arakunrin baba rẹ̀ lòpọ̀, ohun ìtìjú ni ó ṣe sí arakunrin baba rẹ̀. Àwọn mejeeji yóo sì fi orí ara wọn ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ wọn, wọn yóo kú láì bímọ. Lẹ́yìn tí wọ́n ti wà fún ọpọlọpọ ọjọ́, láì jẹun, Paulu dìde dúró láàrin wọn, ó ní, “Ẹ̀yin eniyan, ẹ̀ bá ti gbọ́ tèmi kí ẹ má ṣíkọ̀ ní Kirete. Irú ewu ati òfò yìí ìbá tí sí. Sì sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé nígbà tí ẹnìkan bá kú láìní ọmọkunrin, àwọn ọmọbinrin rẹ̀ yóo jogún ilẹ̀ ìní rẹ̀. Dafidi sì sọ fún Akiṣi pé, “Bí mo bá rí ojurere rẹ, jọ̀wọ́ fún mi ní ààyè ní ọ̀kan ninu àwọn ìletò agbègbè yìí kí n máa gbé. Kí ló dé tí èmi iranṣẹ rẹ yóo máa gbé inú ìlú kan náà pẹlu rẹ?” Nítorí ta ni a lè fi wé ọ ní ọ̀run, OLUWA?Ta ni ó dàbí OLUWA láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run?You are described as the child of the elephant that swallows coconuts, and you rejoice; are you the one who swallows coconuts?
“Pase fun awon omo Israeli pe, ‘Nigba ti e ba de ile Kenaani ti mo fun yin, gbogbo ile naa ni yoo je tiyin. Awon aala ile yin niwonyi.’ OLUWA, teti si adura emi iranse re, ti mo beru oruko re, ki o si je ki n se aseyori lonii, ki n si ri ojurere oba.”Emi ni agboti oba ni akoko naa.Ni ojo kan soso, Peka, omo Remalaya, oba Israeli, pa oke mefa (120,000) ninu awon omo ogun Juda; ti gbogbo won si je akoni. Olorun je ki awon nnkan wonyi sele si won nitori pe won ti ko OLUWA Olorun awon baba won sile. Bi enikan ba ba aya arakunrin baba re lopo, ohun itiju ni o se si arakunrin baba re. Awon mejeeji yoo si fi ori ara won ru ebi ese won, won yoo ku lai bimo. Leyin ti won ti wa fun opolopo ojo, lai jeun, Paulu dide duro laarin won, o ni, “Eyin eniyan, e ba ti gbo temi ki e ma siko ni Kirete. Iru ewu ati ofo yii iba ti si. Si so fun awon omo Israeli pe nigba ti enikan ba ku laini omokunrin, awon omobinrin re yoo jogun ile ini re. Dafidi si so fun Akisi pe, “Bi mo ba ri ojurere re, jowo fun mi ni aaye ni okan ninu awon ileto agbegbe yii ki n maa gbe. Ki lo de ti emi iranse re yoo maa gbe inu ilu kan naa pelu re?” Nitori ta ni a le fi we o ni orun, OLUWA?Ta ni o dabi OLUWA laarin awon eda orun?You are described as the child of the elephant that swallows coconuts, and you rejoice; are you the one who swallows coconuts?
Ó sọ fún mi pé, “Kọ ọ́ sílẹ̀: àwọn tí a pè sí àsè igbeyawo ti Ọ̀dọ́ Aguntan náà ṣe oríire.” Ó tún sọ fún mi pé, “Òdodo ọ̀rọ̀ Ọlọrun ni ọ̀rọ̀ wọnyi.” Wò ó! N óo kó ìpayà bá ọ,láti ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn tí wọ́n yí ọ ká;èmi OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.Gbogbo yín ni yóo fọ́nká,tí olukuluku yóo sì yà sí ọ̀nà tirẹ̀,kò sì ní sí ẹni tí yóo kó àwọn tí ń sá fún ogun jọ.Abrahamu bá dìde, ó tẹríba níwájú wọn, Ejò-ó rí ihò tó há ó kó wọ̀ ọ́; ìyá-a rẹ̀-ẹ́ lọ́wọ́ àti fà á yọ?
O so fun mi pe, “Ko o sile: awon ti a pe si ase igbeyawo ti Odo Aguntan naa se oriire.” O tun so fun mi pe, “Ododo oro Olorun ni oro wonyi.” Wo o! N oo ko ipaya ba o,lati odo gbogbo awon ti won yi o ka;emi OLUWA Olorun awon omo ogun ni mo so bee.Gbogbo yin ni yoo fonka,ti olukuluku yoo si ya si ona tire,ko si ni si eni ti yoo ko awon ti n sa fun ogun jo.Abrahamu ba dide, o teriba niwaju won, Ejo-o ri iho to ha o ko wo o; iya-a re-e lowo ati fa a yo?
Bí ẹnìkan bá bi yín ní nǹkankan, ẹ dá a lóhùn pé, ‘Oluwa nílò wọn.’ Lẹsẹkẹsẹ wọn yóo jẹ́ kí ẹ mú wọn wá.”Àjàkálẹ̀ àrùn ń lọ níwájú rẹ̀,ìyọnu sì ń tẹ̀lé e lẹ́yìn pẹ́kípẹ́kí.Miriamu ati Aaroni sọ̀rọ̀ òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ ọmọbinrin ará Kuṣi ní iyawo. One can only remonstrate with a wicked person to urge him or her to improve his or her town.
Bi enikan ba bi yin ni nnkankan, e da a lohun pe, ‘Oluwa nilo won.’ Lesekese won yoo je ki e mu won wa.”Ajakale arun n lo niwaju re,iyonu si n tele e leyin pekipeki.Miriamu ati Aaroni soro odi si Mose nitori pe o fe omobinrin ara Kusi ni iyawo. One can only remonstrate with a wicked person to urge him or her to improve his or her town.
Mo bá bèèrè pé, “Ta ni ẹni tí ó gbọ́n, tí òye nǹkan yìí yé? Ta ni OLUWA ti bá sọ̀rọ̀, kí ó kéde rẹ̀? Kí ló dé tí ilẹ̀ náà fi parun, tí ó sì dàbí aṣálẹ̀ tóbẹ́ẹ̀, tí ẹnikẹ́ni kò fi gba ibẹ̀ kọjá?”Ní ọjọ́ náà ọba yóo pa ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀ ati fún gbogbo àwọn ará ìlú. Ìdajì yòókù, tí ó jẹ́ ìpín àwọn ọmọ Israẹli tí kò lọ sójú ogun, Ṣugbọn jẹ́ kí inú gbogbo àwọn tí ó sá di ọ́ ó dùn,kí wọn ó máa kọrin ayọ̀ títí lae.Dáàbò bò wọ́n,kí àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ sì máa yọ̀ ninu rẹ.Ọ̀pọ̀ àwọn eniyan péjọ pọ̀ sọ́dọ̀ rẹ̀. Ó bá yíjú pada sí wọn, ó ní, 34. Bíi kò bá ṣe pé kí àwọn
Mo ba beere pe, “Ta ni eni ti o gbon, ti oye nnkan yii ye? Ta ni OLUWA ti ba soro, ki o kede re? Ki lo de ti ile naa fi parun, ti o si dabi asale tobee, ti enikeni ko fi gba ibe koja?”Ni ojo naa oba yoo pa odo ako maaluu kan fun ebo imukuro ese fun ara re ati fun gbogbo awon ara ilu. Idaji yooku, ti o je ipin awon omo Israeli ti ko lo soju ogun, Sugbon je ki inu gbogbo awon ti o sa di o o dun,ki won o maa korin ayo titi lae.Daabo bo won,ki awon ti o feran oruko re si maa yo ninu re.Opo awon eniyan pejo po sodo re. O ba yiju pada si won, o ni, 34. Bii ko ba se pe ki awon
ẹ̀nìyàn má baà di irú kan náà ni,
eniyan ma baa di iru kan naa ni,