diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ibikíbi tí ẹ bá wà, tí ẹ bá ti gbọ́ fèrè, ẹ wá péjọ sọ́dọ̀ wa. Ọlọrun wa yóo jà fún wa.”After the person with smooth cheeks has stated his or her case, he or she should remember that the person with blemished cheeks will have something to say.
Ibikibi ti e ba wa, ti e ba ti gbo fere, e wa pejo sodo wa. Olorun wa yoo ja fun wa.”After the person with smooth cheeks has stated his or her case, he or she should remember that the person with blemished cheeks will have something to say.
Kí ẹ gbadura kí ó má jẹ́ àkókò tí òtútù mú pupọ. Àwọn wolii yóo di àgbá òfo;nítorí kò sí ọ̀rọ̀ OLUWA ninu wọn.Bí wọ́n ti wí ni ọ̀rọ̀ yóo rí fún wọn.Òrẹ́hìn ní ńṣe ọmọ òkù pẹ̀lẹ́; ta ní jẹ́ ṣe ọmọ Ègùn lóore?
Ki e gbadura ki o ma je akoko ti otutu mu pupo. Awon wolii yoo di agba ofo;nitori ko si oro OLUWA ninu won.Bi won ti wi ni oro yoo ri fun won.Orehin ni nse omo oku pele; ta ni je se omo Egun loore?
Òtítọ́ ni ohun tí mò ń sọ yìí; n kò purọ́, nítorí Kristi ni ó ni mí. Ọkàn mi tí Ẹ̀mí ń darí sì jẹ́ mi lẹ́rìí pẹlu, pé, 87. Àwọn tò. ṣe àìgbàgbọ tí wọn
Otito ni ohun ti mo n so yii; n ko puro, nitori Kristi ni o ni mi. Okan mi ti Emi n dari si je mi lerii pelu, pe, 87. Awon to. se aigbagbo ti won
tún pe àwọn Àmì Wa ní irẹ.
tun pe awon Ami Wa ni ire.
Àwọn wọn yí ni ẹ̀rò iná.
Awon won yi ni ero ina.
ÌDÁ 12
IDA 12
88. Ẹyin onígbàgbọ òdodo! Ẹ má
88. Eyin onigbagbo ododo! E ma
ṣe ṣe ohun rere tí Allah ṣe ltọọ
se se ohun rere ti Allah se ltoo
fún yín ní ẹ má sì ṣe kọJá
fun yin ni e ma si se koJa
ẹnu ààlà. Dájúdájú Allah kò nífẹ̀ẹ
enu aala. Dajudaju Allah ko nifee
sí àwọn olùkọjá ààlà.
si awon olukoja aala.
89. Kí ẹ sì máa Jẹ nínú ohun tí
89. Ki e si maa Je ninu ohun ti
Allah pésé fún yín, ni ohun tí Ò tọ
Allah pese fun yin, ni ohun ti O to
ti ô sì dára. Kí ẹ sí páyà Allah ti
ti o si dara. Ki e si paya Allah ti
ẹ̀yin gbàgbọ.
eyin gbagbo.
90. Allah kì yòò gbá yín mú (fún
90. Allah ki yoo gba yin mu (fun
ìjẹníyà) nípa ìbúra yín tí ẹ ṣe
ijeniya) nipa ibura yin ti e se
lásán, ṣùgbòn Òun yòò gbá yín
lasan, sugbon Oun yoo gba yin
mú fún àwọn ìbúra ti ẹ
mu fun awon ibura ti e
mòn-ọn-mò ṣe. Ìtanràn rẹ̀ ni fifi
mon-on-mo se. Itanran re ni fifi
oúnjẹ bọ: aláìní mẹ̀wàá. pẹ̀lú
ounje bo: alaini mewaa. pelu
déédéé oúnjẹ tí ẹ fi n bọ àwọn ẹbí
deedee ounje ti e fi n bo awon ebi
yin, tàbí kí ẹ dáṣọ fún wọn, tàbí
yin, tabi ki e daso fun won, tabi
ki ẹ sọ ẹrú kan di òmìnira.
ki e so eru kan di ominira.
Ṣùgbọn ẹni tí kò ba lẹ̀ ṣe bẹ̀, ẹ̀yí
Sugbon eni ti ko ba le se be, eyi
tô kàn ni kí ô gba ààwẹ̀ fún ọjọ
to kan ni ki o gba aawe fun ojo
mẹta. Ìyẹn jẹ ìtanràn ìbúra yín
meta. Iyen je itanran ibura yin
nigbà tí ẹ bá búra.. Kí ẹ sì máa
nigba ti e ba bura.. Ki e si maa
mú ìbúra yín ṣẹ.. Bàyìí ni Allah
mu ibura yin se.. Bayii ni Allah
ṣe àlàyé àwọn Àmì Rẹ̀ fún yín, kí
se alaye awon Ami Re fun yin, ki
ẹ le máa dúpẹ.
e le maa dupe.
91. Ẹyin onígbàgbọ òdodo! Ọtí
91. Eyin onigbagbo ododo! Oti
mimu, tẹtẹ tita, ìbẹ̀rìṣà àti aje
mimu, tete tita, iberisa ati aje
dídá jẹ ohun ẹ̀gbiíin láti inú Iṣẹ
dida je ohun egbiiin lati inu Ise
ẹ̀ṣù, nítorí náà kí ẹ jìnnà sí
esu, nitori naa ki e jinna si
(òkòọkan) wọn kí ẹ le ṣe oríire. Ni
(okookan) won ki e le se oriire. Ni
Ó ṣe fún wọn! Wọ́n ń rìn ní ọ̀nà Kaini. Wọ́n tẹra mọ́ ọ̀nà ẹ̀tàn Balaamu nítorí ohun tí wọn yóo rí gbà. Wọ́n dá ọ̀tẹ̀ sílẹ̀ bíi Kora, wọ́n sì parun. Ṣọ́ra kí o má yipada sí ìwà ẹ̀ṣẹ̀,tí ó wù ọ́ ju ìjìyà lọ.Òní ni ọjọ́ pé tí ẹ óo jáde kúrò ní Ijipti, ninu oṣù Abibu. Ehudu rọ idà olójú meji kan tí kò gùn ju igbọnwọ kan lọ, ó fi bọ inú àkọ̀, ó so ó mọ́ itan rẹ̀ ọ̀tún lábẹ́ aṣọ. Saulu bá búra ní orúkọ OLUWA pé, “Bí OLUWA ti ń bẹ, ibi kan kò ní ṣẹlẹ̀ sí ọ nítorí èyí.”95. Nísinsinyìí ẹ ti wá bá wa ní
O se fun won! Won n rin ni ona Kaini. Won tera mo ona etan Balaamu nitori ohun ti won yoo ri gba. Won da ote sile bii Kora, won si parun. Sora ki o ma yipada si iwa ese,ti o wu o ju ijiya lo.Oni ni ojo pe ti e oo jade kuro ni Ijipti, ninu osu Abibu. Ehudu ro ida oloju meji kan ti ko gun ju igbonwo kan lo, o fi bo inu ako, o so o mo itan re otun labe aso. Saulu ba bura ni oruko OLUWA pe, “Bi OLUWA ti n be, ibi kan ko ni sele si o nitori eyi.”95. Nisinsinyii e ti wa ba wa ni
òkọọkan gẹgẹ bí A ti dá yín ní
okookan gege bi A ti da yin ni
ìgbà àkọkọ, ẹ sì fi àwọn ohun tí
igba akoko, e si fi awon ohun ti
A pésẹ̀ fun yín sílẹ̀ sẹyin yín, bẹ̀ẹ̀
A pese fun yin sile seyin yin, bee
ni À kò sì rí àwọn olùṣìpẹ yín tí ẹ
ni A ko si ri awon olusipe yin ti e
mú ní ẹgbẹ (pẹ̀lú Ọlọrun) nípa
mu ni egbe (pelu Olorun) nipa
àlámòri yín pẹ̀lu yín. Nísinsinyìí,
alamori yin pelu yin. Nisinsinyii,
ìpínyà ti wá dé sáàrin yín, ohun tí
ipinya ti wa de saarin yin, ohun ti
ẹ gbẹkẹ̀lé sì ti já yín kulẹ̀.
e gbekele si ti ja yin kule.
ÌDÁ 12
IDA 12
96. Dájúdájú Allah ni Ò fì mú kí
96. Dajudaju Allah ni O fi mu ki
(ọmùnú) hòrôò-ọkà, àti. hQrQ-
(omunu) horoo-oka, ati. hQrQ-
dàbínù tú jáde. Òun ni ô n mú
dabinu tu jade. Oun ni o n mu
alààyẹ̀ jáde láti inú òkú, Òun náà
alaaye jade lati inu oku, Oun naa
sì ni Ẹni tí O fi mú òkú jáde láti
si ni Eni ti O fi mu oku jade lati
inú alààyẹ. Éyí ni Allah; nígbà
inu alaaye. Eyi ni Allah; nigba
náà, nibo ni ẹ wá n ṣ£ri lọ?
naa, nibo ni e wa n s£ri lo?
97 Ônmú kí ojúmọ mọ; Ô sì ṣe
97 Onmu ki ojumo mo; O si se
òru ní ìsinmi, òòrùn àti òṣùpaá fún
oru ni isinmi, oorun ati osupaa fun
ìṣirò. (àkòkò)... Eyí ni ìpinnu
isiro. (akoko)... Eyi ni ipinnu
A lágbára, Olùmòọ ohun gbogbo.
A lagbara, Olumoo ohun gbogbo.
98, Òun ni Ẹni tò ṣe àwọn ìràwò
98, Oun ni Eni to se awon irawo
fun yín ki ẹ lẹ̀ tipasẹ̀ wọn mọ ọnà
fun yin ki e le tipase won mo ona
tú. tQ. nínú òkùnkùn birimù-
tu. tQ. ninu okunkun birimu-
birimù orí ilẹ̀ àti ti.. òkun.
birimu ori ile ati ti.. okun.
Dájúdájú A ti ṣe àlàyé àwọn Àmì
Dajudaju A ti se alaye awon Ami
lẹkùn-únrẹrẹ fún àwọn ẹ̀nìyàn ti
lekun-unrere fun awon eniyan ti
wỌn ní ìmọ.
wOn ni imo.
99, Òun náà ni Ẹni tí O dá yín
99, Oun naa ni Eni ti O da yin
láti ara ẹ̀mí kan ṣoṣo, bákan náà
lati ara emi kan soso, bakan naa
ni ibùgbé àti ibùwọ (n bẹ fún
ni ibugbe ati ibuwo (n be fun
yin). A ti ṣe àlàyé àwọn Àmì náà
yin). A ti se alaye awon Ami naa
lẹkùn-únrẹ̀rẹ fún àwọn ẹ̀nìyàn tí
lekun-unrere fun awon eniyan ti
wọn gbọ àgbọyé.
won gbo agboye.
ṣugbọn, ẹ bẹ̀rù idà,nítorí pé ìrúnú níí fa kí á fi idà pa eniyan,kí ẹ lè mọ̀ dájú pé ìdájọ́ ń bẹ.”“Wọ́n gbé, nítorí pé wọ́n ti ṣáko kúrò lọ́dọ̀ mi! Ìparun yóo kọlù wọ́n, nítorí pé wọ́n ń bá mi ṣọ̀tẹ̀! Ǹ bá rà wọ́n pada, ṣugbọn wọ́n ń parọ́ mọ́ mi. Ìrìbọmi tí Johanu ń ṣe, báwo ló ti jẹ́: ṣé láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun wá ni tabi láti ọ̀dọ̀ eniyan?”Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí bá ara wọn jiyàn, wọ́n ń wí pé, “Bí a bá sọ pé, ‘Láti ọ̀run ni,’ yóo bi wá pé, ‘Kí ló dé tí ẹ kò fi gbà á gbọ́?’ “Ó di ẹ̀ṣẹ̀ mi bí àjàgà,ó gbé e kọ́ mi lọ́rùn,ó sì sọ mí di aláìlágbára.OLUWA ti fi mí léàwọn tí n kò lè dojú kọ lọ́wọ́.Nítorí pé Ọlọrun sọ ọ́ di ẹni ńlá, gbogbo eniyan, gbogbo orílẹ̀-èdè ati gbogbo ẹ̀yà ń tẹríba fún un tìbẹ̀rùtìbẹ̀rù. A máa pa ẹni tí ó bá fẹ́, a sì máa dá ẹni tí ó fẹ́ sí. A máa gbé ẹni tí ó bá fẹ́ ga, a sì máa rẹ ẹni tí ó bá wù ú sílẹ̀. Ìdajì ẹ̀yà Manase ń gbé Baṣani, wọ́n pọ̀ pupọ; wọ́n tàn ká títí dé Baali Herimoni, Seniri, ati òkè Herimoni. It is out of regard for onlookers that one sings in praise of the dead; the dead did not prescribe a song before departing this life.
sugbon, e beru ida,nitori pe irunu nii fa ki a fi ida pa eniyan,ki e le mo daju pe idajo n be.”“Won gbe, nitori pe won ti sako kuro lodo mi! Iparun yoo kolu won, nitori pe won n ba mi sote! N ba ra won pada, sugbon won n paro mo mi. Iribomi ti Johanu n se, bawo lo ti je: se lati odo Olorun wa ni tabi lati odo eniyan?”Won wa bere si ba ara won jiyan, won n wi pe, “Bi a ba so pe, ‘Lati orun ni,’ yoo bi wa pe, ‘Ki lo de ti e ko fi gba a gbo?’ “O di ese mi bi ajaga,o gbe e ko mi lorun,o si so mi di alailagbara.OLUWA ti fi mi leawon ti n ko le doju ko lowo.Nitori pe Olorun so o di eni nla, gbogbo eniyan, gbogbo orile-ede ati gbogbo eya n teriba fun un tiberutiberu. A maa pa eni ti o ba fe, a si maa da eni ti o fe si. A maa gbe eni ti o ba fe ga, a si maa re eni ti o ba wu u sile. Idaji eya Manase n gbe Basani, won po pupo; won tan ka titi de Baali Herimoni, Seniri, ati oke Herimoni. It is out of regard for onlookers that one sings in praise of the dead; the dead did not prescribe a song before departing this life.
Ìran Isaaki ọmọ Abrahamu nìyí, Abrahamu ni baba Isaaki. Ẹnu olódodo dàbí orísun omi ìyè,ṣugbọn eniyan burúkú a máa fi ìwà ìkà sinu,a sì máa sọ̀rọ̀ rere jáde lẹ́nu.Ṣimei ń wí fún Dafidi bí ó ti ń ṣépè pé, “Kúrò lọ́dọ̀ mi! Kúrò lọ́dọ̀ mi! Ìwọ apànìyàn ati eniyan lásán! Kí ẹ gbadura pé kí n lè ṣe àlàyé bí ó ti yẹ.Gbogbo Israẹli láti Dani dé Beeriṣeba, ni wọ́n mọ̀ pé wolii OLUWA ni Samuẹli nítòótọ́. Nítorí náà, ẹ̀yin ará, kò sí ohunkohun mọ́ tí ó mú wa ní túlààsì pé kí á máa hùwà gẹ́gẹ́ bí àwọn tí ẹran-ara ń darí. Bí ẹnìkan bá ń lò yín bí ẹrú, tí ó ń jẹ yín run, tí ó fi okùn mu yín, tí ó ń ṣe fùkẹ̀ láàrin yín, tí ó ń gba yín létí, ẹ ṣetán láti gba irú ẹni bẹ́ẹ̀. N óo tún yín gbé dìde, ẹ óo sì di ọ̀tun, ẹ̀yin ọmọ Israẹli.Ẹ óo tún fi aro lu ìlù ayọ̀, ẹ óo sì jó ijó ìdùnnú.1e Atọrọohungbogbolọ́wọ́Ọlọ́run kì í kánjú.
Iran Isaaki omo Abrahamu niyi, Abrahamu ni baba Isaaki. Enu olododo dabi orisun omi iye,sugbon eniyan buruku a maa fi iwa ika sinu,a si maa soro rere jade lenu.Simei n wi fun Dafidi bi o ti n sepe pe, “Kuro lodo mi! Kuro lodo mi! Iwo apaniyan ati eniyan lasan! Ki e gbadura pe ki n le se alaye bi o ti ye.Gbogbo Israeli lati Dani de Beeriseba, ni won mo pe wolii OLUWA ni Samueli nitooto. Nitori naa, eyin ara, ko si ohunkohun mo ti o mu wa ni tulaasi pe ki a maa huwa gege bi awon ti eran-ara n dari. Bi enikan ba n lo yin bi eru, ti o n je yin run, ti o fi okun mu yin, ti o n se fuke laarin yin, ti o n gba yin leti, e setan lati gba iru eni bee. N oo tun yin gbe dide, e oo si di otun, eyin omo Israeli.E oo tun fi aro lu ilu ayo, e oo si jo ijo idunnu.1e AtoroohungbogbolowoOlorun ki i kanju.
Nígbà tí ó yá, Dafidi ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti ìlú Jerusalẹmu. Àwọn ará Jebusi tí wọn ń gbé ibẹ̀ nígbà náà wí fún Dafidi pé, “O kò lè wọ inú ìlú yìí wá, àwọn afọ́jú ati àwọn arọ lásán ti tó láti lé ọ dànù.” Wọ́n lérò pé Dafidi kò le ṣẹgun ìlú náà. Wọ́n ṣe àjọ̀dún Àgọ́ Àjọ, wọ́n rú ìwọ̀n ẹbọ sísun tí a ti ṣe ìlànà sílẹ̀ fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan. Bí adìẹ́ bá gbélẹ̀ a ya òpìpì.
Nigba ti o ya, Dafidi ati awon omo ogun re gbogun ti ilu Jerusalemu. Awon ara Jebusi ti won n gbe ibe nigba naa wi fun Dafidi pe, “O ko le wo inu ilu yii wa, awon afoju ati awon aro lasan ti to lati le o danu.” Won lero pe Dafidi ko le segun ilu naa. Won se ajodun Ago Ajo, won ru iwon ebo sisun ti a ti se ilana sile fun ojo kookan. Bi adie ba gbele a ya opipi.
Kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun wà pẹlu gbogbo yín.Anabu, Eṣitemoa, Animi, Jesu bá fi ọwọ́ kàn án lọ́wọ́, ibà náà sì fi í sílẹ̀. Ó bá dìde, ó bá tọ́jú oúnjẹ fún un.Iṣẹ́ ìsìn ti àwọn ọmọ Geriṣoni nìyí: Àgbà tí kò nítìjú, ojú kan ni ìbá ní; ojú kan náà a wà lọ́gangan iwájú-u rẹ̀.
Ki oore-ofe Olorun wa pelu gbogbo yin.Anabu, Esitemoa, Animi, Jesu ba fi owo kan an lowo, iba naa si fi i sile. O ba dide, o ba toju ounje fun un.Ise isin ti awon omo Gerisoni niyi: Agba ti ko nitiju, oju kan ni iba ni; oju kan naa a wa logangan iwaju-u re.
Ọ̀kan lára àwọn Kerubu náà na ọwọ́ sí inú iná tí ó wà láàrin wọn, ó bù ú sí ọwọ́ ọkunrin aláṣọ funfun náà. Ọkunrin náà gbà á, ó sì jáde.Ìsàlẹ̀ òkun di gbangba, ìpìlẹ̀ ayé sì ṣí sílẹ̀,nígbà tí OLUWA bá wọn wí,tí ó sì fi ibinu jágbe mọ́ wọn.Kí OLUWA máa ranti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba rẹ̀,kí ó má sì pa ẹ̀ṣẹ̀ ìyá rẹ̀ rẹ́.Bí a bá sì mọ̀ pé ó ń gbọ́ tiwa nípa ohunkohun tí a bá bèèrè, a mọ̀ pé à ń rí gbogbo ohun tí a bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ gbà.Ẹ̀yin tí ẹ ti di òkú nípa ẹ̀ṣẹ̀ yín, tí ẹ jẹ́ aláìkọlà nípa ti ara, ni Ọlọrun ti sọ di alààyè pẹlu Kristi. Ọlọrun ti dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá. Abrahamu nawọ́ mú ọ̀bẹ láti pa ọmọ rẹ̀. Wọ́n fún mi ní ọ̀pá kan, bí èyí tí wọ́n fi ń wọn aṣọ. Wọ́n sọ fún mi pé, “Dìde! Lọ wọn Tẹmpili Ọlọrun ati pẹpẹ ìrúbọ, kí o ka iye àwọn tí wọ́n n jọ́sìn níbẹ̀. Is it just morning now? The old person is grooming himself/herself.
Okan lara awon Kerubu naa na owo si inu ina ti o wa laarin won, o bu u si owo okunrin alaso funfun naa. Okunrin naa gba a, o si jade.Isale okun di gbangba, ipile aye si si sile,nigba ti OLUWA ba won wi,ti o si fi ibinu jagbe mo won.Ki OLUWA maa ranti ese awon baba re,ki o ma si pa ese iya re re.Bi a ba si mo pe o n gbo tiwa nipa ohunkohun ti a ba beere, a mo pe a n ri gbogbo ohun ti a beere lowo re gba.Eyin ti e ti di oku nipa ese yin, ti e je alaikola nipa ti ara, ni Olorun ti so di alaaye pelu Kristi. Olorun ti dari gbogbo ese wa ji wa. Abrahamu nawo mu obe lati pa omo re. Won fun mi ni opa kan, bi eyi ti won fi n won aso. Won so fun mi pe, “Dide! Lo won Tempili Olorun ati pepe irubo, ki o ka iye awon ti won n josin nibe. Is it just morning now? The old person is grooming himself/herself.
(A sọ ọ kalẹ̀
(A so o kale
1. Ni Orúkọ Allah, Olôore ọfẹ
1. Ni Oruko Allah, Oloore ofe
Alaàaánú jùlọ.
Alaaaanu julo.
2. Nígbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà bá ṣẹlẹ̀.
2. Nigba ti isele naa ba sele.
3. Kò sí irỌ nípa ṣíṣẹlẹ̀ rẹ̀.
3. Ko si irO nipa sisele re.
4. Yòò rẹ̀ àwọn kan sílẹ̀, YÒÒ sì
4. Yoo re awon kan sile, YOO si
gbé àwọn mìíràn ga.
gbe awon miiran ga.
53. Nígbà tí a bá mi ilẹ̀ ní mímì
53. Nigba ti a ba mi ile ni mimi
tìtì.
titi.
6. Tí àwọn òkòÒ yòò sì fQ
6. Ti awon okoO yoo si fQ
yángáyángá,
yangayanga,
7. Wọn yòò sì dàbí eruku tí é
7. Won yoo si dabi eruku ti e
fọnká.
fonka.
8. Ẹyin yÒÒ sì Jẹ ìpín oríṣi mẹta.
8. Eyin yOO si Je ipin orisi meta.
Báwo ni yòò ṣe dára tò fún àwọn
Bawo ni yoo se dara to fun awon
ẹ̀rò apá ọtún.
ero apa otun.
10. Àti àwọn ẹ̀rò apá òsì — Báwo
10. Ati awon ero apa osi — Bawo
ni yÒòò ti burú tô fún àwọn ẹ̀rò
ni yOoo ti buru to fun awon ero
apá òsì.
apa osi.
11. Àwọn tí ô gba iwájú ti gba
11. Awon ti o gba iwaju ti gba
iwájú.
iwaju.
12. Àwọn wọnyí ni ẹni ìsúnmọ
12. Awon wonyi ni eni isunmo
Ọlọrun.
Olorun.
13. Nínú Ọgbà onídẹ̀ra.
13. Ninu Ogba onidera.
14. Ọpọlọpọ nínú àwọn. ẹ̀rò
14. Opolopo ninu awon. ero