diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
páyà,. Allah tí ẹ̀yin bá jẹ̀
paya,. Allah ti eyin ba je
onígbàgbọ òdodo.
onigbagbo ododo.
59, Àti nígbà tí ẹ̀yin bá pe ìpẹ̀ fún
59, Ati nigba ti eyin ba pe ipe fun
ìrun kíkí, wọn yòò mú un ní
irun kiki, won yoo mu un ni
nìkan yẹ̀yẹ àti àwàdà. Éyí jẹ bẹ̀
nikan yeye ati awada. Eyi je be
nítorí pé wọn Jẹ ẹ̀nìyàn tí kò ṣe
nitori pe won Je eniyan ti ko se
làákàyẹ̀.
laakaye.
60. Sọ pé, 'Ẹyin oníwéé, ṣé ẹ̀yin
60. So pe, 'Eyin oniwee, se eyin
n wá ẹ̀sùn sí wa lẹ̀sẹ̀ nítorí pé
n wa esun si wa lese nitori pe
àwa gba Allah àti ohun tí a
awa gba Allah ati ohun ti a
sọòkalẹ̀ fún wa àti ẹ̀yí tí a ti sòkalẹ̀
sookale fun wa ati eyi ti a ti sokale
ṣíiwájú gbọ? Taàbí (ô ha jẹ) nítori
siiwaju gbo? Taabi (o ha je) nitori
pé ọpọlọpọ nínú yín jẹ aláìgbọràn
pe opolopo ninu yin je alaigboran
(si Ọlọrun)?'
(si Olorun)?'
61. Sọ pé, 'Emi kì yòò ha fún yín
61. So pe, 'Emi ki yoo ha fun yin
ní ìré nípa àwọn tí ẹ̀san wọn burú
ni ire nipa awon ti esan won buru
lọdọ Allah ju ẹ̀yíinì lọ? Àwọn ni
lodo Allah ju eyiini lo? Awon ni
Allah fi gégùn-ún tí Ò sì ti bínú
Allah fi gegun-un ti O si ti binu
sí, tí O sì sọ nínú wọn di òbọ àti
si, ti O si so ninu won di obo ati
ẹlẹdẹ̀ ti wọn sì n sin ẹ̀ṣù.
elede ti won si n sin esu.
Dájúdájú àwọn wọnyí lô wà ní
Dajudaju awon wonyi lo wa ni
Ipò tô burú jù àti pé wỌn ti sọnù
Ipo to buru ju ati pe wOn ti sonu
Jìnnà kúrò ní ojú ọnà tààrà.
Jinna kuro ni oju ona taara.
62. Àti pé nígbà tí wọn wá bá
62. Ati pe nigba ti won wa ba
yín, wọn ha wí pé: 'Àwa
yin, won ha wi pe: 'Awa
gbàgbọ.?" Nígbà tí ô sì JẸ pé wọn
gbagbo.?" Nigba ti o si JE pe won
wọlé pẹ̀lú àìgbàgbọ wọn sì jáde
wole pelu aigbagbo won si jade
pẹ̀lú rẹ̀. Àti pé Allah mò jùlọ nípa
pelu re. Ati pe Allah mo julo nipa
ohun tí wọn fi pamọ.
ohun ti won fi pamo.
63. Ìwọ yòò rí ẹ̀pòlọpò nínú wọn, ti
63. Iwo yoo ri epolopo ninu won, ti
wọn n yára lọ sí ìdi ẹ̀ṣẹ̀ àti ìkọjá ààlà
won n yara lo si idi ese ati ikoja aala
àti jíjẹ ohun ẹ̀ẹ̀wọ.
ati jije ohun eewo.
Nígbà tí Jesu di ọmọ ọdún mejila, wọ́n lọ sí àjọ yìí gẹ́gẹ́ bí ìṣe wọn. Mo bá bèèrè pé, ‘Kí ni kí n ṣe Oluwa?’ Oluwa bá dá mi lóhùn pé, ‘Dìde kí o máa lọ sí Damasku. Níbẹ̀ a óo sọ fún ọ gbogbo nǹkan tí a ti ṣètò fún ọ láti ṣe.’ Bí ẹlẹ́rẹ̀kẹ́ régérégé bá ro ẹjọ́-ọ tirẹ̀ tán, kó rántí pé ẹlẹ́rẹ̀kẹ́ mẹ́kí á rí rò.
Nigba ti Jesu di omo odun mejila, won lo si ajo yii gege bi ise won. Mo ba beere pe, ‘Ki ni ki n se Oluwa?’ Oluwa ba da mi lohun pe, ‘Dide ki o maa lo si Damasku. Nibe a oo so fun o gbogbo nnkan ti a ti seto fun o lati se.’ Bi elereke regerege ba ro ejo-o tire tan, ko ranti pe elereke meki a ri ro.
Ọdún jubili ni ọdún tí ó gbẹ̀yìn aadọta ọdún yìí yóo jẹ́ fun yín. Ninu ọdún náà, ẹ kò gbọdọ̀ gbin ohunkohun, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ kórè ohun tí ó bá dá hù fúnra rẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ ká àjàrà tí ó bá so ninu ọgbà àjàrà tí ẹ kò tọ́jú. tí kò ní rí ìlọ́po-ìlọ́po gbà ní ayé yìí, yóo sì ní ìyè ainipẹkun ní ayé tí ń bọ̀.”pẹlu òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀. Ẹ óo máa rú ẹbọ wọnyi kún ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ ati ẹbọ ohun mímu ojoojumọ.Nígbà tí ó wí báyìí tán, ó tún dúró ní ilẹ̀ Galili.A chicken has no knees for cases.
Odun jubili ni odun ti o gbeyin aadota odun yii yoo je fun yin. Ninu odun naa, e ko gbodo gbin ohunkohun, bee ni e ko gbodo kore ohun ti o ba da hu funra re; bee ni e ko gbodo ka ajara ti o ba so ninu ogba ajara ti e ko toju. ti ko ni ri ilopo-ilopo gba ni aye yii, yoo si ni iye ainipekun ni aye ti n bo.”pelu obuko kan fun ebo imukuro ese. E oo maa ru ebo wonyi kun ebo sisun ati ebo ohun jije ati ebo ohun mimu ojoojumo.Nigba ti o wi bayii tan, o tun duro ni ile Galili.A chicken has no knees for cases.
awọ àgbò tí wọ́n ṣe ní àwọ̀ pupa ati awọ ewúrẹ́, igi akasia, If one spends three years flapping one's arms, how many years will one take to fly?
awo agbo ti won se ni awo pupa ati awo ewure, igi akasia, If one spends three years flapping one's arms, how many years will one take to fly?
Afẹ́fẹ́ ńda ológìì láàmú; oníyẹ̀fun rọra.
Afefe nda ologii laamu; oniyefun rora.
Yóo ya ọjà tí ó ń tà ati èrè tí ó bá jẹ sọ́tọ̀ fún OLUWA, kò ní máa to èrè rẹ̀ jọ, tabi kí ó máa kó o pamọ́; ṣugbọn yóo máa lò wọ́n láti pèsè oúnjẹ ati aṣọ fún àwọn tí ó bá ń sin OLUWA. Ní ìgbà kan, Jesu ń lé ẹ̀mí èṣù kan tí ó yadi jáde. Nígbà tí ẹ̀mí Èṣù náà ti jáde tán ọkunrin odi náà sọ̀rọ̀, ẹnu wá ya àwọn eniyan. Wọn yóo mú ẹwà ati ọlá àwọn orílẹ̀-èdè wá sí inú rẹ̀. Ariwo ta lóde nítorí kò sí ọtí waini,oòrùn ayọ̀ ti wọ̀;ayọ̀ di àwátì ní ilẹ̀ náà.Ó sọ èyí, ó fi ṣe àkàwé irú ikú tí yóo kú.Àríyànjiyàn nípa ẹ̀sìn oriṣa wọn, ati nípa ẹnìkan tí ń jẹ́ Jesu ni ohun tí wọn ń jà sí. Jesu yìí ti kú, ṣugbọn Paulu ní ó wà láàyè. kí ó sọ fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin, ati gbogbo àwọn eniyan Israẹli pé: “Nígbà tí ẹnìkan ninu àwọn eniyan Israẹli tabi àlejò tí ó wà láàrin wọn bá mú ohun ìrúbọ rẹ̀ wá, kì báà ṣe pé láti fi san ẹ̀jẹ́ kan ni, tabi gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àtinúwá, láti fi rú ẹbọ sísun sí OLUWA, Ó wọn ẹnu ọ̀nà náà láti ẹ̀yìn àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ kan títí dé ẹ̀yìn yàrá ẹ̀gbẹ́ keji, ìbú rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ mẹẹdọgbọn (mita 12½), láti ìlẹ̀kùn kinni sí ekeji. Ní òkè àpótí yìí ni àwọn kerubu ògo Ọlọrun wà, tí òjìji wọn bo ìtẹ́ àánú. N kò lè sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan yìí fínnífínní ní àkókò yìí. Àwọn ìtẹ́ mẹrinlelogun ni wọ́n yí ìtẹ́ náà ká. Àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun sì jókòó lórí ìtẹ́ mẹrinlelogun náà. Wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n dé adé wúrà. 33. (Ibrahim) sọ pé, '. Ṣùgbọn
Yoo ya oja ti o n ta ati ere ti o ba je soto fun OLUWA, ko ni maa to ere re jo, tabi ki o maa ko o pamo; sugbon yoo maa lo won lati pese ounje ati aso fun awon ti o ba n sin OLUWA. Ni igba kan, Jesu n le emi esu kan ti o yadi jade. Nigba ti emi Esu naa ti jade tan okunrin odi naa soro, enu wa ya awon eniyan. Won yoo mu ewa ati ola awon orile-ede wa si inu re. Ariwo ta lode nitori ko si oti waini,oorun ayo ti wo;ayo di awati ni ile naa.O so eyi, o fi se akawe iru iku ti yoo ku.Ariyanjiyan nipa esin orisa won, ati nipa enikan ti n je Jesu ni ohun ti won n ja si. Jesu yii ti ku, sugbon Paulu ni o wa laaye. ki o so fun Aaroni ati awon omo re okunrin, ati gbogbo awon eniyan Israeli pe: “Nigba ti enikan ninu awon eniyan Israeli tabi alejo ti o wa laarin won ba mu ohun irubo re wa, ki baa se pe lati fi san eje kan ni, tabi gege bi ore atinuwa, lati fi ru ebo sisun si OLUWA, O won enu ona naa lati eyin awon yara egbe kan titi de eyin yara egbe keji, ibu re je igbonwo meedogbon (mita 12½), lati ilekun kinni si ekeji. Ni oke apoti yii ni awon kerubu ogo Olorun wa, ti ojiji won bo ite aanu. N ko le soro nipa awon nnkan yii finnifinni ni akoko yii. Awon ite merinlelogun ni won yi ite naa ka. Awon agbaagba merinlelogun si jokoo lori ite merinlelogun naa. Won wo aso funfun, won de ade wura. 33. (Ibrahim) so pe, '. Sugbon
Lutu n bẹ níbẹ̀... Wọn wí pé,
Lutu n be nibe... Won wi pe,
Àwa. mọ àmòdájú ẹni tí n bẹ
Awa. mo amodaju eni ti n be
níbẹ̀. Dájúdájú Àwa yòò gbà á là
nibe. Dajudaju Awa yoo gba a la
àti ìdílé rẹ̀, àyàfi aya rẹ̀, ẹni tí O ti
ati idile re, ayafi aya re, eni ti O ti
Jẹ ọkan nínú àwọn tí yúò ṣẹ̀kù
Je okan ninu awon ti yuo seku
lẹhin.
lehin.
34. Nígbà tí àwọn òjíṣẹ Wa sì wá
34. Nigba ti awon ojise Wa si wa
bá Lutu, ô dààmú nítorí wọn, ÒÔ sì
ba Lutu, o daamu nitori won, OO si
di aláìlágbára mọ nípa wọn. Wọn
di alailagbara mo nipa won. Won
sì wí pé, 'Má bẹ̀rù, má sì ṣe
si wi pe, 'Ma beru, ma si se
banújẹ dájúdájú Àwa Yyòò. gba
banuje dajudaju Awa Yyoo. gba
ìwọ àti ìdílé rẹ̀ là, àyàfi aya rẹ̀ ẹni
iwo ati idile re la, ayafi aya re eni
tô J€ òkan nínú àwọn tí yúòò ṣẹkù
to J€ okan ninu awon ti yuoo seku
lẹhìn.
lehin.
35. Dájúdájú Àwa yòò sọ ìyà kan
35. Dajudaju Awa yoo so iya kan
kalẹ̀ láti ẹ̀run. wá sôrí àwọn
kale lati erun. wa sori awon
ẹ̀nìyàn ìlú yìí, nítorí pé wọn ti
eniyan ilu yii, nitori pe won ti
balẹ̀jẹ jìnnà.
baleje jinna.
36. Àwá sì ti fi Àmì tô hàn
36. Awa si ti fi Ami to han
gbangba sílẹ̀. níbẹ̀ fún àwọn
gbangba sile. nibe fun awon
ẹ̀nìyàn tí òrò yé yékéyéké.
eniyan ti oro ye yekeyeke.
37. A si rán. arákùnrin àwọn ara
37. A si ran. arakunrin awon ara
Madiani,. Ṣuaibu sí wọn. Ò wi
Madiani,. Suaibu si won. O wi
pé; "Ẹ máa jọsìn fún Allah kí ẹ sì
pe; "E maa josin fun Allah ki e si
máa ní ìrẹ̀tí Ọjọ ìkẹhìn, kí ẹ má sì
maa ni ireti Ojo ikehin, ki e ma si
ṣe hùwà ẹ̀ṣẹ̀ lòrí ilẹ̀, ki ẹ má ṣe
se huwa ese lori ile, ki e ma se
wa di òbìjlẹ̀jẹ."
wa di obijleje."
38. Ṣùgbọn wọn pẹ̀ é lòpùrọ.
38. Sugbon won pe e lopuro.
Nitorí náà ìmìtìtì ilẹ̀ kọlù wọn,
Nitori naa imititi ile kolu won,
wọn sì wà ní ìdojúbolẹ̀ nínú ilé
won si wa ni idojubole ninu ile
wọn.
won.
Ṣebí Ìwé Mímọ́ ti sọ pé láti inú ìdílé Dafidi, ní Bẹtilẹhẹmu ìlú Dafidi, ni Mesaya yóo ti wá?” Ọpọlọpọ àwọn obinrin àjèjì ni Solomoni fẹ́, lẹ́yìn ọmọ Farao, ọba Ijipti, tí ó kọ́kọ́ fẹ́, ó tún fẹ́ ará Moabu ati ará Amoni, ará Edomu ati ará Sidoni, ati ará Hiti. “Ẹni tí ó bá kọ̀tí kò ṣàánú ọ̀rẹ́ rẹ̀kò ní ìbẹ̀rù Olodumare.Samsoni lọ sí Timna, ó rí ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin ará Filistia níbẹ̀. Èyí pẹlu yóo jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,tí adájọ́ gbọdọ̀ jẹ mí níyà fún;nítorí yóo jẹ́ aiṣootọ sí Ọlọrun ọ̀run. OLUWA, gbogbo ọba ayé ni yóo máa yìn ọ́,nítorí pé wọ́n ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ.tỌwò nínú ìkẹ Rẹ̀, àti kí àwọn
Sebi Iwe Mimo ti so pe lati inu idile Dafidi, ni Betilehemu ilu Dafidi, ni Mesaya yoo ti wa?” Opolopo awon obinrin ajeji ni Solomoni fe, leyin omo Farao, oba Ijipti, ti o koko fe, o tun fe ara Moabu ati ara Amoni, ara Edomu ati ara Sidoni, ati ara Hiti. “Eni ti o ba koti ko saanu ore reko ni iberu Olodumare.Samsoni lo si Timna, o ri okan ninu awon omobinrin ara Filistia nibe. Eyi pelu yoo je ese,ti adajo gbodo je mi niya fun;nitori yoo je aisooto si Olorun orun. OLUWA, gbogbo oba aye ni yoo maa yin o,nitori pe won ti gbo oro enu re.tOwo ninu ike Re, ati ki awon
ọkọ ojú omi lẹ̀ máa lọ pẹ̀lú àṣẹ
oko oju omi le maa lo pelu ase
Rẹ̀.. Kí ẹ sì tún lò máa wá ojú
Re.. Ki e si tun lo maa wa oju
rere Rẹ̀, kí ẹ sì tún lẹ̀ máa dúpẹ.
rere Re, ki e si tun le maa dupe.
48. Dájúdájú Àwa ti rán àwọn
48. Dajudaju Awa ti ran awon
ÒJÍṢẸ ṣíwájú rẹ̀ sí àwọn ẹ̀nìyàn
OJISE siwaju re si awon eniyan
wọn, wọn sì mú àwọn Àmì tò
won, won si mu awon Ami to
hàn gbangba wá bá wọn... Lẹ̀hìn
han gbangba wa ba won... Lehin
náà Àwa jẹ àwọn tò jẹ̀bi níyà. OÔ
naa Awa je awon to jebi niya. OO
sì ti di dandan fún Wa láti rán
si ti di dandan fun Wa lati ran
àwọn olùgbàgbọ òdodo lọwọ.
awon olugbagbo ododo lowo.
49. Allah ni Ẹni tí ÒÔ fi rán aféfẹ
49. Allah ni Eni ti OO fi ran afefe
láti kò ẹ̀ṣú-ÒJÒ jọ... Lẹhìn náà,
lati ko esu-OJO jo... Lehin naa,
Òun yòò tàn án ká sôjú ẹ̀run bí ô
Oun yoo tan an ka soju erun bi o
ti wù Ú, Òun yÒò sì ṣe wỌn ní
ti wu U, Oun yOo si se wOn ni
ìpele-ìpele, ẹ̀yin yòò sì máa rí òjò
ipele-ipele, eyin yoo si maa ri ojo
tí yòò máa tú jáde láti ààrin rẹ̀
ti yoo maa tu jade lati aarin re
wá, nígbà tí Òun bá sì jẹ kí ô rò
wa, nigba ti Oun ba si je ki o ro
fún àwọn tò bá wù Ú nínú àwọn
fun awon to ba wu U ninu awon
ẹrúsìn Rẹ̀. Sì kíyòsi i, wọn ô máa
erusin Re. Si kiyosi i, won o maa
yọ ṣẹ̀ṣẹ̀.
yo sese.
50. Bí ô tilẹ̀ j€ pé, ṣíwájú kí Á tô
50. Bi o tile j€ pe, siwaju ki A to
sò ọ kalẹ̀ fún wọn, ni wọn ti sọ
so o kale fun won, ni won ti so
ìrẹ̀tí nù.
ireti nu.
51. Nítorí náà, kíyési àwọn Àmì
51. Nitori naa, kiyesi awon Ami
ìkẹ Allah, bí ò ti ṣe n sọ ilẹ̀ di
ike Allah, bi o ti se n so ile di
alààyẹ̀ lẹhin ikú rẹ̀, dájúdájú bẹ̀ẹ̀
alaaye lehin iku re, dajudaju bee
gẹgẹ ni Òun yòò ṣe jí òkú dìde.
gege ni Oun yoo se ji oku dide.
Òun sì ni Alágbára lòrí ohun
Oun si ni Alagbara lori ohun
Ọba bi ayaba Ẹsita pé, “Ẹsita, kí ló dé? Kí ni ẹ̀dùn ọkàn rẹ? A óo fún ọ, títí dé ìdajì ìjọba mi.”“Nígbà tí ibìkan bá lé lára eniyan, tabi tí ara eniyan bá wú tí ọ̀gangan ibẹ̀ sì ń dán, tí ó bá jọ ẹ̀tẹ̀ ní ara rẹ̀, kí wọ́n mú olúwarẹ̀ tọ Aaroni, alufaa wá; tabi kí wọ́n mú un wá sí ọ̀dọ̀ ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Aaroni, tí ó jẹ́ alufaa. Ṣugbọn OLUWA bínú sí Mose ati Aaroni, ó ní, “Nítorí pé ẹ kò gbà mí gbọ́, ẹ kò sì fi títóbi agbára mi hàn níwájú àwọn eniyan náà, ẹ̀yin kọ́ ni yóo kó wọn dé ilẹ̀ tí mo ti ṣèlérí láti fún wọn.”Onímọ-tara-ẹni-nìkan ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀,láti tako ìdájọ́ òtítọ́.Ebi kò ní pa wọ́n mọ́, bẹ́ẹ̀ ni òùngbẹ kò ní gbẹ wọ́n mọ́. Oòrùn kò ní pa wọ́n mọ́, ooru kankan kò sì ní mú wọn mọ́. Nígbà tí wọ́n gbọ́ ohun tí ó bá wá, inú wọn dùn, wọ́n bá ṣe ìlérí láti fún un ní owó. Judasi wá ń wá àkókò tí ó wọ̀ láti fi Jesu lé wọn lọ́wọ́.Lẹ́yìn wọn, Sadoku, ọmọ Imeri, ṣe àtúnṣe ibi tí ó kọjú sí ilé tirẹ̀.Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣemaaya, ọmọ Ṣekanaya, olùṣọ́ ẹnu ọ̀nà ìhà ìlà oòrùn, ṣe àtúnṣe ọ̀dọ̀ tirẹ̀.Aaroni bá na ọwọ́ rẹ̀ sí orí gbogbo omi ilẹ̀ Ijipti, ọ̀pọ̀lọ́ bá wọ́ jáde, wọ́n sì bo gbogbo ilẹ̀ Ijipti. Dájúdájú, kò sí ẹni tí ó le ra ara rẹ̀ pada,tabi tí ó lè san owó ìràpadà ẹ̀mí rẹ̀ fún Ọlọrun;Jesu bá tún sọ pé, “Ọkàn mí dàrú nisinsinyii. Kí ni ǹ bá wí? Ọkàn kan ń sọ pé kí n wí pé, ‘Baba, yọ mí kúrò ninu àkókò yìí.’ Ṣugbọn nítorí àkókò yìí gan-an ni mo ṣe wá sí ayé. gẹ́gẹ́ bí ìyìn rere tí a fi lé mi lọ́wọ́, ìyìn rere Ọlọrun Ológo, tí ìyìn yẹ fún.Wọ́n bá bèèrè pé, “Ẹ̀yà wo ninu Israẹli ni kò wá siwaju OLUWA ní Misipa?” Wọ́n rí i pé ẹnikẹ́ni kò wá ninu àwọn ará Jabeṣi Gileadi sí àjọ náà. Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Kiṣi, baba Saulu sọnù. Kiṣi bá sọ fún Saulu ọmọ rẹ̀ pé, “Mú ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ lẹ́yìn, kí ẹ lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà wá.” “Ìwọ ọmọ eniyan, gbọ́ bí àwọn ọmọ Israẹli ti ń wí pé, Ìran ọjọ́ iwájú ni ò ń rí, o sì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ gbọọrọ. Àwọn tí ó mọ̀ ọ́ yóo gbẹ́kẹ̀lé ọ;nítorí ìwọ, OLUWA, kìí kọ àwọn tí ń wá ọ sílẹ̀.Kí wọn máa ṣe rere, kí wọn jẹ́ ọlọ́rọ̀ ninu iṣẹ́ rere, kí wọn fẹ́ràn láti máa ṣe ọrẹ ati láti máa mú ninu ohun ìní wọn fún àwọn ẹlòmíràn, Ẹ máa fi akọ mààlúù kan ati àgbò kan tí kò ní àbààwọ́n rú ẹbọ sísun olóòórùn dídùn sí OLÚWA. Mo fà wọ́n mọ́ra pẹlu okùn àánú ati ìdè ìfẹ́,mo dàbí ẹni tí ó tú àjàgà kúrò ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ wọn,mo sì bẹ̀rẹ̀, mo gbé oúnjẹ kalẹ̀ níwájú wọn.Nígbà tí Jesu rí bí inú rẹ̀ ti bàjẹ́, ó ní, “Yóo ṣòro fún àwọn olówó láti wọ ìjọba Ọlọrun. The wind is making life difficult for the seller of liquid corn starch; corn flour seller, you had better watch out!
Oba bi ayaba Esita pe, “Esita, ki lo de? Ki ni edun okan re? A oo fun o, titi de idaji ijoba mi.”“Nigba ti ibikan ba le lara eniyan, tabi ti ara eniyan ba wu ti ogangan ibe si n dan, ti o ba jo ete ni ara re, ki won mu oluware to Aaroni, alufaa wa; tabi ki won mu un wa si odo okan ninu awon omo Aaroni, ti o je alufaa. Sugbon OLUWA binu si Mose ati Aaroni, o ni, “Nitori pe e ko gba mi gbo, e ko si fi titobi agbara mi han niwaju awon eniyan naa, eyin ko ni yoo ko won de ile ti mo ti seleri lati fun won.”Onimo-tara-eni-nikan ya ara re soto,lati tako idajo otito.Ebi ko ni pa won mo, bee ni oungbe ko ni gbe won mo. Oorun ko ni pa won mo, ooru kankan ko si ni mu won mo. Nigba ti won gbo ohun ti o ba wa, inu won dun, won ba se ileri lati fun un ni owo. Judasi wa n wa akoko ti o wo lati fi Jesu le won lowo.Leyin won, Sadoku, omo Imeri, se atunse ibi ti o koju si ile tire.Leyin re ni Semaaya, omo Sekanaya, oluso enu ona iha ila oorun, se atunse odo tire.Aaroni ba na owo re si ori gbogbo omi ile Ijipti, opolo ba wo jade, won si bo gbogbo ile Ijipti. Dajudaju, ko si eni ti o le ra ara re pada,tabi ti o le san owo irapada emi re fun Olorun;Jesu ba tun so pe, “Okan mi daru nisinsinyii. Ki ni n ba wi? Okan kan n so pe ki n wi pe, ‘Baba, yo mi kuro ninu akoko yii.’ Sugbon nitori akoko yii gan-an ni mo se wa si aye. gege bi iyin rere ti a fi le mi lowo, iyin rere Olorun Ologo, ti iyin ye fun.Won ba beere pe, “Eya wo ninu Israeli ni ko wa siwaju OLUWA ni Misipa?” Won ri i pe enikeni ko wa ninu awon ara Jabesi Gileadi si ajo naa. Awon ketekete Kisi, baba Saulu sonu. Kisi ba so fun Saulu omo re pe, “Mu okan ninu awon iranse leyin, ki e lo wa awon ketekete naa wa.” “Iwo omo eniyan, gbo bi awon omo Israeli ti n wi pe, Iran ojo iwaju ni o n ri, o si n so asotele ohun ti yoo sele ni ojo gbooro. Awon ti o mo o yoo gbekele o;nitori iwo, OLUWA, kii ko awon ti n wa o sile.Ki won maa se rere, ki won je oloro ninu ise rere, ki won feran lati maa se ore ati lati maa mu ninu ohun ini won fun awon elomiran, E maa fi ako maaluu kan ati agbo kan ti ko ni abaawon ru ebo sisun olooorun didun si OLUWA. Mo fa won mora pelu okun aanu ati ide ife,mo dabi eni ti o tu ajaga kuro ni ereke won,mo si bere, mo gbe ounje kale niwaju won.Nigba ti Jesu ri bi inu re ti baje, o ni, “Yoo soro fun awon olowo lati wo ijoba Olorun. The wind is making life difficult for the seller of liquid corn starch; corn flour seller, you had better watch out!
Bí a bá ńretí òfò, ká fi ohun tọrẹ.
Bi a ba nreti ofo, ka fi ohun tore.
Ẹ kò gbọdọ̀ ro ire kàn wọ́n tabi kí ẹ wá ìtẹ̀síwájú wọn títí lae.Adìẹ ò lórúnkún ẹjọ́.
E ko gbodo ro ire kan won tabi ki e wa itesiwaju won titi lae.Adie o lorunkun ejo.