diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
àti òrun ni òrùlé, tí Ò sì fi sọ omi | ati orun ni orule, ti O si fi so omi |
kalẹ̀ láti ojú-òrin wa, tí O: sì fì | kale lati oju-orin wa, ti O: si fi |
tipasẹ̀ rẹ̀ mú ẹ̀so jade wá ní ìpẹ̀sẹ̀ | tipase re mu eso jade wa ni ipese |
fún yín. Nítorí náà, ẹ má ṣe bá | fun yin. Nitori naa, e ma se ba |
A Ilah wá ẹgbẹ̀ra nígbà ti ẹ̀yin mọ | A Ilah wa egbera nigba ti eyin mo |
(wi pé kò ní). | (wi pe ko ni). |
24. Ti ẹ̀yin bá n bẹ nínú iyéméjì | 24. Ti eyin ba n be ninu iyemeji |
nipa ohun tí a ti sọ kalẹ̀ fún | nipa ohun ti a ti so kale fun |
ẹrúsìn Wa, nígbà náà ẹ mú orí | erusin Wa, nigba naa e mu ori |
òrọ kan bí irú rẹ̀ wá, kí ẹ sì pe | oro kan bi iru re wa, ki e si pe |
àwọn olùrànljỌWỌ yin yàtọ sí | awon oluranljOWO yin yato si |
Allah, tí ẹ bá jẹ olòtìítọ. | Allah, ti e ba je olotiito. |
25. Ṣùgbọn bí ẹ̀yin kò ba lẹ̀ ṣe é, | 25. Sugbon bi eyin ko ba le se e, |
ẹ kò tilẹ̀ ni lò ṣe € ni. Tí ô bá rí | e ko tile ni lo se € ni. Ti o ba ri |
bẹ̀, ẹ bẹ̀rù ima tí ìkòná rẹ̀ jẹ | be, e beru ima ti ikona re je |
ẹ̀nìyàn àti òkúta, tí a sì ti pẹ̀sẹ̀ | eniyan ati okuta, ti a si ti pese |
sílẹ̀ fún àwọn aláìgbàgbọ. | sile fun awon alaigbagbo. |
26. Ki o sì fún àwọn ti. wọn | 26. Ki o si fun awon ti. won |
gbàgbọ ti wọn sì n) ṣe isẹ rere ní | gbagbo ti won si n) se ise rere ni |
ìro ìdùnnú wí pé àwọn ọgbà ìdẹ̀ra | iro idunnu wi pe awon ogba idera |
ti àwọn akérémọdò n ṣàn laábẹ rẹ̀ | ti awon akeremodo n san laabe re |
n bẹ fún wọn. Nígbàkúùgbà tí a | n be fun won. Nigbakuugba ti a |
bá pẹ̀sẹ̀ fún wọn nínú àwọn ẹ̀so | ba pese fun won ninu awon eso |
lati inú rẹ̀ (ọgbà ìdẹ̀ra náà), wọn 4 | lati inu re (ogba idera naa), won 4 |
sọ pé: eléyìí ni ohun tí wọn ti | so pe: eleyii ni ohun ti won ti |
pẹ̀sẹ̀ fún wa tẹlẹ̀ rí; A ô sì tún | pese fun wa tele ri; A o si tun |
máa fún wọn ní ìpésẹ̀ tí O Jọ ara | maa fun won ni ipese ti O Jo ara |
wọn, àti pẹ̀ àwọn aya/ọkọ tí ô mọ | won, ati pe awon aya/oko ti o mo |
ni bẹ fún wọn nibẹ̀, ibẹ̀ ni wọn | ni be fun won nibe, ibe ni won |
yòò máa gbé. | yoo maa gbe. |
Wọ́n ti kú, wọn kò ní wà láàyè mọ́,ẹ̀mí wọn kò ní dìde mọ́ ní isà òkú.Nítorí bẹ́ẹ̀ ni o ṣe jẹ wọ́n níyà,o sì pa wọ́n run,o sì ti sọ gbogbo ìrántí wọn di ohun ìgbàgbé.Nígbà tí Hamani rí i pé Modekai kọ̀, kò foríbalẹ̀ fún òun, inú bí i pupọ. Ibùsùn tí ẹni náà bá dùbúlẹ̀ lé lórí di aláìmọ́, ohunkohun tí ó bá sì fi jókòó di aláìmọ́ pẹlu. Ó wọn apá ìlà oòrùn pẹlu ọ̀pá rẹ̀, ó jẹ́ ẹẹdẹgbẹta (500) igbọnwọ (mita 250), gẹ́gẹ́ bí ọ̀pá rẹ̀. People killed by folly are innumerable; people killed by wisdom are few. | Won ti ku, won ko ni wa laaye mo,emi won ko ni dide mo ni isa oku.Nitori bee ni o se je won niya,o si pa won run,o si ti so gbogbo iranti won di ohun igbagbe.Nigba ti Hamani ri i pe Modekai ko, ko foribale fun oun, inu bi i pupo. Ibusun ti eni naa ba dubule le lori di alaimo, ohunkohun ti o ba si fi jokoo di alaimo pelu. O won apa ila oorun pelu opa re, o je eedegbeta (500) igbonwo (mita 250), gege bi opa re. People killed by folly are innumerable; people killed by wisdom are few. |
OLUWA Ọlọrun ṣe ọgbà kan sí Edẹni, ní ìhà ìlà oòrùn, ó fi eniyan tí ó mọ sinu rẹ̀. Ṣugbọn bí ẹ kò bá gba ohun tí ó kọ gbọ́, báwo ni ẹ óo ti ṣe gba ọ̀rọ̀ mi gbọ́?”Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli gbọ́ pé àwọn ẹ̀yà Reubẹni, ẹ̀yà Gadi ati ìdajì ẹ̀yà Manase ti tẹ́ pẹpẹ kan sí ìhà ibi tí ó jẹ́ ti àwọn ọmọ Israẹli, ní agbègbè odò Jọdani, ní àtiwọ ilẹ̀ Kenaani, Ṣé a lè sọ̀rọ̀ ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ninu ibojì?Àbí ẹnìkan lè sọ̀rọ̀ òtítọ́ rẹ ninu ìparun?Kí ẹni ibi má baà lè ṣe àkóso,kí ó má baà kó àwọn eniyan sinu ìgbèkùn.It is only when one pleads with the Ègùn person (from Porto Novo or Àjàṣẹ́ in present-day Benin Republic)that he draws his knife. | OLUWA Olorun se ogba kan si Edeni, ni iha ila oorun, o fi eniyan ti o mo sinu re. Sugbon bi e ko ba gba ohun ti o ko gbo, bawo ni e oo ti se gba oro mi gbo?”Nigba ti awon omo Israeli gbo pe awon eya Reubeni, eya Gadi ati idaji eya Manase ti te pepe kan si iha ibi ti o je ti awon omo Israeli, ni agbegbe odo Jodani, ni atiwo ile Kenaani, Se a le soro ife re ti ki i ye ninu iboji?Abi enikan le soro otito re ninu iparun?Ki eni ibi ma baa le se akoso,ki o ma baa ko awon eniyan sinu igbekun.It is only when one pleads with the Egun person (from Porto Novo or Ajase in present-day Benin Republic)that he draws his knife. |
Said of people who redouble their efforts belatedly, just when they are supposed to break off. The Ègùn serve the Yoruba as favourite butts of jokes. | Said of people who redouble their efforts belatedly, just when they are supposed to break off. The Egun serve the Yoruba as favourite butts of jokes. |
Láti ìgbà náà ni Pilatu ti ń wá ọ̀nà láti dá Jesu sílẹ̀. Ṣugbọn àwọn Juu ń kígbe pé, “Bí o bá dá ọkunrin yìí sílẹ̀, ìwọ kì í ṣe ọ̀rẹ́ Kesari, gbogbo ẹni tí ó bá fi ara rẹ̀ jọba lòdì sí Kesari.”Fear of the snake keeps one from stepping on the young of the snake. | Lati igba naa ni Pilatu ti n wa ona lati da Jesu sile. Sugbon awon Juu n kigbe pe, “Bi o ba da okunrin yii sile, iwo ki i se ore Kesari, gbogbo eni ti o ba fi ara re joba lodi si Kesari.”Fear of the snake keeps one from stepping on the young of the snake. |
Ní ọjọ́ keji a kúrò níbẹ̀, a dé òdìkejì erékùṣù Kiosi. Ní ọjọ́ kẹta a dé Samosi. Ní ọjọ́ kẹrin a dé Miletu. Nítorí náà ni àwọn ẹ̀yà Lefi kò fi ní ìpín tabi ogún pẹlu àwọn arakunrin wọn. OLUWA ni ìpín wọn gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín ti wí fún wọn.)“Nígbà tí ẹnìkan bá ya ilé rẹ̀ sọ́tọ̀ fún OLUWA, alufaa yóo wò ó bóyá ó dára tabi kò dára; iyekíye tí alufaa bá pè é ni iye rẹ̀. Ni gbogbo wọn patapata láìku ẹnìkan bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àwáwí. Ekinni sọ fún un pé, ‘Mo ra ilẹ̀ kan, mo sì níláti lọ wò ó. Mo tọrọ àforíjì, yọ̀ǹda mi.’ Ẹ̀rù kì í ba orí kó sá wọnú. | Ni ojo keji a kuro nibe, a de odikeji erekusu Kiosi. Ni ojo keta a de Samosi. Ni ojo kerin a de Miletu. Nitori naa ni awon eya Lefi ko fi ni ipin tabi ogun pelu awon arakunrin won. OLUWA ni ipin won gege bi OLUWA Olorun yin ti wi fun won.)“Nigba ti enikan ba ya ile re soto fun OLUWA, alufaa yoo wo o boya o dara tabi ko dara; iyekiye ti alufaa ba pe e ni iye re. Ni gbogbo won patapata laiku enikan ba bere si se awawi. Ekinni so fun un pe, ‘Mo ra ile kan, mo si nilati lo wo o. Mo toro aforiji, yonda mi.’ Eru ki i ba ori ko sa wonu. |
Ó dá a lóhùn, ó ní, “A kò ní wọ̀ ní ìlú àjèjì, lọ́dọ̀ àwọn tí kì í ṣe ọmọ Israẹli, kàkà bẹ́ẹ̀, a óo kọjá lọ sí Gibea.” Ṣugbọn a fa àjàrà náà tu pẹlu ibinu,a sì jù ú sílẹ̀.Afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn mú kí ó gbẹ,gbogbo èso rẹ̀ sì rẹ̀ dànù.Igi rẹ̀ tí ó lágbára gbẹ, iná sì jó o.33. 'Àti pé ẹni tí kò bá jẹ ìpẹ̀ | O da a lohun, o ni, “A ko ni wo ni ilu ajeji, lodo awon ti ki i se omo Israeli, kaka bee, a oo koja lo si Gibea.” Sugbon a fa ajara naa tu pelu ibinu,a si ju u sile.Afefe ila oorun mu ki o gbe,gbogbo eso re si re danu.Igi re ti o lagbara gbe, ina si jo o.33. 'Ati pe eni ti ko ba je ipe |
olùpẹ̀pẹ sọdọ Allah kò lẹ̀ lọ mọ | olupepe sodo Allah ko le lo mo |
Ọn lọwọ láyé, bákan náà ni kò ní | On lowo laye, bakan naa ni ko ni |
si.. aláàbò kan fún un lẹhìn Rẹ̀. | si.. alaabo kan fun un lehin Re. |
Irú àwọn wọnyí lô wà nínú ìṣìnà | Iru awon wonyi lo wa ninu isina |
tô hàn gbangba. | to han gbangba. |
34. Wọn kò ha rí i pé, Allah, Ẹni | 34. Won ko ha ri i pe, Allah, Eni |
toô dá àwọn ọrun àti ayé, tí kò si | too da awon orun ati aye, ti ko si |
káàárẹ̀. nípa. dídá. wọn, ÒÔ ni | kaaare. nipa. dida. won, OO ni |
agbara láti sọ okú di alààyẹ̀? Bẹ̀ẹ̀, | agbara lati so oku di alaaye? Bee, |
nítòòtọ, O. ní agbára lòrí ohun | nitooto, O. ni agbara lori ohun |
35. Àti pé ní ọjọ tí a ô darí àwọn | 35. Ati pe ni ojo ti a o dari awon |
tí kò gbàgbọ lọ síbi iná, (a O sọ | ti ko gbagbo lo sibi ina, (a O so |
fún wọn pé:), 'Njẹ òtítọ ha kọ ni | fun won pe:), 'Nje otito ha ko ni |
ẹ̀yí bí?" Wọn yòò wí pé, 'B$ẹ̀ ni, | eyi bi?" Won yoo wi pe, 'B$e ni, |
a fi Olúwa wa ṣẹ̀rí (pé òtítọ ni). | a fi Oluwa wa seri (pe otito ni). |
Òun yòò wí pé, 'Nígbà náà ẹ tQ | Oun yoo wi pe, 'Nigba naa e tQ |
ìyà wò nítorí pé ẹ ṣàìgbàgbọ.' | iya wo nitori pe e saigbagbo.' |
36. Nítori náà, ṣe sùúrú, gẹgẹ bi | 36. Nitori naa, se suuru, gege bi |
àwọn Òjíṣẹ tô ní ìpinnu ọkàn té | awon Ojise to ni ipinnu okan te |
lágbára; má sì kánjú nípa wọn. | lagbara; ma si kanju nipa won. |
Ní ọjọ tí wọn bá rí ohun tí a fi | Ni ojo ti won ba ri ohun ti a fi |
ṣẹ̀rù bà wọn, yòò dà bí i pé wọn | seru ba won, yoo da bi i pe won |
kò lò ju wákàtí kan lọ (láyé) lòjú | ko lo ju wakati kan lo (laye) loju |
wọn. A ti ṣe (ìkìlọ yí); a kò sì ni | won. A ti se (ikilo yi); a ko si ni |
pa ẹnikẹni run bíkòṣe. àwọn | pa enikeni run bikose. awon |
aláìgbọràn. | alaigboran. |
OLUWA ni agbára ati orin mi, ó ti gbà mí là, òun ni Ọlọrun mi,n óo máa yìn ín.Òun ni Ọlọrun àwọn baba ńlá mi;n óo máa gbé e ga.Ẹ̀tẹ́ bá ọ̀lẹ. | OLUWA ni agbara ati orin mi, o ti gba mi la, oun ni Olorun mi,n oo maa yin in.Oun ni Olorun awon baba nla mi;n oo maa gbe e ga.Ete ba ole. |
ÌDÁ 3 | IDA 3 |
44. Dajúdájú igi Sakuum | 44. Dajudaju igi Sakuum |
45. NI yòò Jẹ oúnjẹ àwọn ẹlẹ̀ṣẹ̀, | 45. NI yoo Je ounje awon elese, |
46. Ti ô dà bí bàbà yíyọ, yôò máa | 46. Ti o da bi baba yiyo, yoo maa |
hô nínú ikùn wọn, | ho ninu ikun won, |
47. Bí omi gbígbúôná. | 47. Bi omi gbigbuona. |
48. (A ô pa wọn láṣẹ pé) Ẹ mú | 48. (A o pa won lase pe) E mu |
un, kí ẹ sì wọ ọ lọ sí inú iná tÒô n | un, ki e si wo o lo si inu ina tOo n |
Jò bùlàbùlà; | Jo bulabula; |
49, Lẹ̀hìn náà, ẹ fi ìyà omi | 49, Lehin naa, e fi iya omi |
gbigbòôná pá a lòrí. | gbigboona pa a lori. |
50. (A o si sọ Wi pé) tọ ọ wò! | 50. (A o si so Wi pe) to o wo! |
Dájúdájú, ìwọ ka ara rẹ̀ kún | Dajudaju, iwo ka ara re kun |
alagbára, ẹni àpọnlé. | alagbara, eni aponle. |
51. Dajúdájú, ẹ̀yí ni ohun tí ẹ n | 51. Dajudaju, eyi ni ohun ti e n |
ṣe iyẹ̀méjì sí." | se iyemeji si." |
52. Dájúdájú àwọn olùpayà Allah | 52. Dajudaju awon olupaya Allah |
yòò wà nínú ààyẹ̀ ìfòkànbaljẹ̀. | yoo wa ninu aaye ifokanbalje. |
53. Àti àwọn ọgbà pẹ̀lú omi | 53. Ati awon ogba pelu omi |
ìṣẹlẹ̀rú. | iseleru. |
54. Wọn yòò wọ asọ àrán tò fẹlẹ | 54. Won yoo wo aso aran to fele |
àti ẹ̀yí toô nípọn, wọn yòò wà ní | ati eyi too nipon, won yoo wa ni |
ìdojukojú. | idojukoju. |
55. (Bi yòò ṣe rí) nìyẹn. A o sì fi | 55. (Bi yoo se ri) niyen. A o si fi |
àwọn obìnrin, ẹlẹyinjúẹgẹ ṣe aya | awon obinrin, eleyinjuege se aya |
fún wọn. | fun won. |
56. Wọn yòò máa bẹ̀ẹ̀rẹ̀. fún | 56. Won yoo maa beere. fun |
ìfàyàbalẹ̀. | ifayabale. |
57. Wọn kì yòò tọ ikú mìíràn wò | 57. Won ki yoo to iku miiran wo |
níbẹ̀ yàtò sí ikú àkẹk6. Òun yòò sì | nibe yato si iku akek6. Oun yoo si |
gbà wQn là lọwọ iná tô n jò | gba wQn la lowo ina to n jo |
bùlàbùlà, | bulabula, |
Bí ó bá jẹ́ pé o fẹ́ ẹbọ ni, ǹ bá mú wá fún ọ;ṣugbọn o ò tilẹ̀ fẹ́ ẹbọ sísun.Yóo yí ọkàn àwọn baba pada sọ́dọ̀ àwọn ọmọ wọn, yóo sì yí ti àwọn ọmọ, pada sọ́dọ̀ àwọn baba wọn; kí n má baà fi ilẹ̀ náà gégùn-ún.” Kí Ọlọrun alaafia, ẹni tí ó jí Jesu Oluwa wa dìde ninu òkú, Jesu, Olú olùṣọ́-aguntan, ẹni tí ó kú, kí ó baà lè fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ṣe èdìdì majẹmu ayérayé, kí ó mu yín pé ninu gbogbo ohun rere kí ẹ lè ṣe ìfẹ́ rẹ̀, kí ó lè máa ṣe ohun tí ó wù ú ninu yín nípasẹ̀ Jesu Kristi ẹni tí ògo wà fún lae ati laelae. Amin.OLUWA ní, “Ìwọ Jeremaya ní tìrẹ, má bẹ̀bẹ̀ fún àwọn eniyan wọnyi, má sọkún nítorí wọn, tabi kí o gbadura fún wọn. Má sì bẹ̀ mí nítorí wọn, nítorí n kò ní gbọ́. Ó sàn kí ojú ẹni rí nǹkan, ju kí á máa fi ọkàn lépa rẹ̀ lọ. Asán ati ìmúlẹ̀mófo ni èyí pẹlu.Níbẹ̀, àwọn ẹlẹ́wọ̀n ń gbé pọ̀ pẹlu ìrọ̀rùn,wọn kò sì gbọ́ ohùn akóniṣiṣẹ́ mọ́.Èmi ati gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu mi nìkan ni a óo wọ ìlú náà. Nígbà tí wọ́n bá jáde sí wa láti bá wa jà bí i ti àkọ́kọ́, a óo sá fún wọn. Wariness is the elders' most efficacious juju. | Bi o ba je pe o fe ebo ni, n ba mu wa fun o;sugbon o o tile fe ebo sisun.Yoo yi okan awon baba pada sodo awon omo won, yoo si yi ti awon omo, pada sodo awon baba won; ki n ma baa fi ile naa gegun-un.” Ki Olorun alaafia, eni ti o ji Jesu Oluwa wa dide ninu oku, Jesu, Olu oluso-aguntan, eni ti o ku, ki o baa le fi eje re se edidi majemu ayeraye, ki o mu yin pe ninu gbogbo ohun rere ki e le se ife re, ki o le maa se ohun ti o wu u ninu yin nipase Jesu Kristi eni ti ogo wa fun lae ati laelae. Amin.OLUWA ni, “Iwo Jeremaya ni tire, ma bebe fun awon eniyan wonyi, ma sokun nitori won, tabi ki o gbadura fun won. Ma si be mi nitori won, nitori n ko ni gbo. O san ki oju eni ri nnkan, ju ki a maa fi okan lepa re lo. Asan ati imulemofo ni eyi pelu.Nibe, awon elewon n gbe po pelu irorun,won ko si gbo ohun akonisise mo.Emi ati gbogbo awon eniyan ti won wa pelu mi nikan ni a oo wo ilu naa. Nigba ti won ba jade si wa lati ba wa ja bi i ti akoko, a oo sa fun won. Wariness is the elders' most efficacious juju. |
OLUWA tún pe Mose, ó ní, “Dìde kúrò níhìn-ín, ìwọ ati àwọn eniyan tí o kó wá láti ilẹ̀ Ijipti, ẹ lọ sí ilẹ̀ tí mo ti búra fún Abrahamu, ati fún Isaaki, ati fún Jakọbu pé n óo fún arọmọdọmọ wọn. Á pa àwọn alágbára run láìṣe ìwádìí wọn,á sì fi àwọn ẹlòmíràn dípò wọn.Ninu ìdílé Nebo: Jeieli, Matitaya, Sabadi, Sebina, Jadai, Joẹli, ati Benaaya.Kinniun alágbára a máa kú,nítorí àìrí ẹran pa jẹ,àwọn ọmọ abo kinniun a sì fọ́nká.Àwọn alufaa kò bèèrè pé, ‘OLUWA dà?’Àwọn tí wọn ń ṣe àmójútó òfin kò mọ̀ mí,àwọn olórí ń dìtẹ̀ sí mi,àwọn wolii ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní orúkọ oriṣa Baali,wọ́n sì ń tẹ̀lé àwọn oriṣa lásánlàsàn.Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. Iṣẹ́ tí ó fi rán wa, tí à ń jẹ́ fun yín nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ni Ọlọrun, kò sí òkùnkùn ninu rẹ̀ rárá. Ẹni àìgbọ́n pa ló pọ̀; ẹni ọgbọ́n pa ò tó ǹkan. | OLUWA tun pe Mose, o ni, “Dide kuro nihin-in, iwo ati awon eniyan ti o ko wa lati ile Ijipti, e lo si ile ti mo ti bura fun Abrahamu, ati fun Isaaki, ati fun Jakobu pe n oo fun aromodomo won. A pa awon alagbara run laise iwadii won,a si fi awon elomiran dipo won.Ninu idile Nebo: Jeieli, Matitaya, Sabadi, Sebina, Jadai, Joeli, ati Benaaya.Kinniun alagbara a maa ku,nitori airi eran pa je,awon omo abo kinniun a si fonka.Awon alufaa ko beere pe, ‘OLUWA da?’Awon ti won n se amojuto ofin ko mo mi,awon olori n dite si mi,awon wolii n so asotele ni oruko orisa Baali,won si n tele awon orisa lasanlasan.E dupe lowo OLUWA, nitori pe o seun,nitori pe ife re ti ki i ye wa titi lae. Ise ti o fi ran wa, ti a n je fun yin niyi: pe imole ni Olorun, ko si okunkun ninu re rara. Eni aigbon pa lo po; eni ogbon pa o to nkan. |
Mo bá tún gbọ́ tí gbogbo ẹ̀dá tí ó wà lọ́run ati ní orílẹ̀ ayé, ati nísàlẹ̀ ilẹ̀, ati lórí òkun, ati ohun gbogbo tí ń bẹ ninu òkun, ń wí pé,“Ìyìn, ọlá, ògo, ati agbára ni ti ẹnití ó jókòó lórí ìtẹ́ ati Ọ̀dọ́ Aguntan lae ati laelae.”N óo sọ ọ́ di eniyan pataki, ohunkohun tí o bá sọ, n óo ṣe é. Jọ̀wọ́ wá bá mi ṣépè lé àwọn eniyan wọnyi.”His hand is being severed, yet he is slipping on a ring. | Mo ba tun gbo ti gbogbo eda ti o wa lorun ati ni orile aye, ati nisale ile, ati lori okun, ati ohun gbogbo ti n be ninu okun, n wi pe,“Iyin, ola, ogo, ati agbara ni ti eniti o jokoo lori ite ati Odo Aguntan lae ati laelae.”N oo so o di eniyan pataki, ohunkohun ti o ba so, n oo se e. Jowo wa ba mi sepe le awon eniyan wonyi.”His hand is being severed, yet he is slipping on a ring. |
Ní àkókò òtútù-nini, ó tó àkókò Àjọ̀dún Ìyàsímímọ́ Tẹmpili tí wọn ń ṣe ní Jerusalẹmu, Mo ti rì sinu irà jíjìn,níbi tí kò ti sí ohun ìfẹsẹ̀tẹ̀;mo ti bọ́ sinu ibú,omi sì ti bò mí mọ́lẹ̀.Mo mọ iṣẹ́ rẹ, ati làálàá rẹ, ati ìfaradà rẹ. Mo mọ̀ pé o kò jẹ́ gba àwọn eniyan burúkú mọ́ra. O ti dán àwọn tí wọn ń pe ara wọn ní aposteli, tí wọn kì í ṣe aposteli wò, o ti rí i pé òpùrọ́ ni wọ́n. N óo fún Dedani mu, ati Tema, ati Busi ati gbogbo àwọn tí wọn ń gé ẹsẹ̀ irun wọn. Lẹ́yìn náà ó fara han àwọn mọkanla bí wọ́n ti ń jẹun. Ó bá wọn wí fún aigbagbọ ati ọkàn líle wọn, nítorí wọn kò gba àwọn tí wọ́n rí i, tí wọ́n sọ pé ó ti jinde gbọ́. “Bí ó bá ṣeéṣe láti wọn ìbànújẹ́ mi,tí a bá sì le gbé ìdààmú mi lé orí ìwọ̀n,Mo ní ìrètí láti wá sọ́dọ̀ rẹ láìpẹ́, ṣugbọn mò ń kọ ìwé yìí, Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ fún ohun tí a fi igi gbẹ́, pé kí ó dìde; ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ fún òkúta tí kò lè sọ̀rọ̀, pé kí ó gbéra nílẹ̀. Ǹjẹ́ eléyìí lè rí ìran kankan? Wò ó! Wúrà ati fadaka ni wọ́n yọ́ lé e, kò sì ní èémí ninu rárá.Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, odò náà gbẹ nítorí àìrọ̀ òjò ní ilẹ̀ náà.Bí iwájú àwọn tí mo rí lẹ́bàá odò Kebari ti rí gan-an ni iwájú wọn rí. Olukuluku ń rìn lọ siwaju tààrà.Nítorí náà, ẹni tí ó bá mọ rere í ṣe tí kò ṣe é, ẹ̀ṣẹ̀ ni ó ń gbà.Nígbà tí mo ro ohun tí ó dé bá mi,ẹ̀rù bà mí, mo sì wárìrì.Àwọn ará Amoni ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún Usaya, òkìkí rẹ̀ kàn káàkiri títí dé agbègbè ilẹ̀ Ijipti, nítorí pé ó di alágbára gan-an.Nípa igbagbọ ni Isaaki fi súre fún Jakọbu ati Esau tí ó sì sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí wọn. Dìde, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san èrè iṣẹ́ àwọn agbéraga fún wọn!Only coolness come out of the fish's mouth. | Ni akoko otutu-nini, o to akoko Ajodun Iyasimimo Tempili ti won n se ni Jerusalemu, Mo ti ri sinu ira jijin,nibi ti ko ti si ohun ifesete;mo ti bo sinu ibu,omi si ti bo mi mole.Mo mo ise re, ati laalaa re, ati ifarada re. Mo mo pe o ko je gba awon eniyan buruku mora. O ti dan awon ti won n pe ara won ni aposteli, ti won ki i se aposteli wo, o ti ri i pe opuro ni won. N oo fun Dedani mu, ati Tema, ati Busi ati gbogbo awon ti won n ge ese irun won. Leyin naa o fara han awon mokanla bi won ti n jeun. O ba won wi fun aigbagbo ati okan lile won, nitori won ko gba awon ti won ri i, ti won so pe o ti jinde gbo. “Bi o ba seese lati won ibanuje mi,ti a ba si le gbe idaamu mi le ori iwon,Mo ni ireti lati wa sodo re laipe, sugbon mo n ko iwe yii, E gbe! Eyin ti e n so fun ohun ti a fi igi gbe, pe ki o dide; eyin ti e n so fun okuta ti ko le soro, pe ki o gbera nile. Nje eleyii le ri iran kankan? Wo o! Wura ati fadaka ni won yo le e, ko si ni eemi ninu rara.Leyin igba die, odo naa gbe nitori airo ojo ni ile naa.Bi iwaju awon ti mo ri lebaa odo Kebari ti ri gan-an ni iwaju won ri. Olukuluku n rin lo siwaju taara.Nitori naa, eni ti o ba mo rere i se ti ko se e, ese ni o n gba.Nigba ti mo ro ohun ti o de ba mi,eru ba mi, mo si wariri.Awon ara Amoni n san isakole fun Usaya, okiki re kan kaakiri titi de agbegbe ile Ijipti, nitori pe o di alagbara gan-an.Nipa igbagbo ni Isaaki fi sure fun Jakobu ati Esau ti o si so ohun ti yoo sele si won. Dide, iwo onidaajo aye;san esan ere ise awon agberaga fun won!Only coolness come out of the fish's mouth. |
Ṣebí àwọn ni wọ́n máa ń sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí orúkọ rere tí a fi ń pè yín!Kí ni n óo mú wá fún OLUWA, tí n óo fi rẹ ara mi sílẹ̀ níwájú Ọlọrun, ẹni gíga? Ṣé kí n wá siwaju rẹ̀ pẹlu ẹbọ sísun ni tabi pẹlu ọ̀dọ́ mààlúù ọlọ́dún kan? “Èyí ni òfin Nasiri, ṣugbọn bí Nasiri kan bá ṣe ìlérí ju ẹbọ tí òfin là sílẹ̀ lọ, ó gbọdọ̀ mú ìlérí náà ṣẹ.” Nígbà tí ó wọ́ ọ kúrò lójú ọ̀nà tán, gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí sá tẹ̀lé Joabu, wọ́n ń lépa Ṣeba lọ.“Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ kí o sì wí pé, OLUWA Ọlọrun ní,Abimeleki tún wí fún un pé, “Wo gbogbo ilẹ̀ yìí, èmi ni mo ni ín, yan ibi tí ó bá wù ọ́ láti gbé.” Ọ̀pá gbóńgbó ní nṣíwájú agbọ́ọni. | Sebi awon ni won maa n soro egan si oruko rere ti a fi n pe yin!Ki ni n oo mu wa fun OLUWA, ti n oo fi re ara mi sile niwaju Olorun, eni giga? Se ki n wa siwaju re pelu ebo sisun ni tabi pelu odo maaluu olodun kan? “Eyi ni ofin Nasiri, sugbon bi Nasiri kan ba se ileri ju ebo ti ofin la sile lo, o gbodo mu ileri naa se.” Nigba ti o wo o kuro loju ona tan, gbogbo awon eniyan bere si sa tele Joabu, won n lepa Seba lo.“Iwo omo eniyan, so asotele ki o si wi pe, OLUWA Olorun ni,Abimeleki tun wi fun un pe, “Wo gbogbo ile yii, emi ni mo ni in, yan ibi ti o ba wu o lati gbe.” Opa gbongbo ni nsiwaju agbooni. |