diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Ẹgbẹ́ Onímọ̀-nípa-ẹyẹ ṣe ìrìnàjò láti Kathmandu sí Chitwan ní àná. Pabambarì ni ìfojúrí ẹyẹ tí kò sí ní ibòmíràn lórí ilẹ̀ ayé, Spiny Babbler. | Egbe Onimo-nipa-eye se irinajo lati Kathmandu si Chitwan ni ana. Pabambari ni ifojuri eye ti ko si ni ibomiran lori ile aye, Spiny Babbler. |
Ẹyẹ náà ti ń dínkù látàrí ìgbẹ́ pípa fún iṣẹ́ ọ̀gbìn àti ìtẹ́lọ ìgbèríko di ìgboro. Bí a bá yọ ti agbègbè ààbò kúrò, nígbà mìíràn pípa ẹyẹ yìí fún oúnjẹ, ní òkè kékeré tí ó yí àfonífojì Kathmandu ká ti mú kí ẹyẹ Spiny Babbler dínkù ni iye. Síbẹ̀, ohun tí ó ń fa àdánù ní agbègbè kan náà lè mú wọn pọ̀ ní agbègbè mìíràn. Bí igbó ṣe ń dínkù látàrí ìgbẹ́ pípa àti igi gẹdú gígé jákèjádò orílẹ̀ èdè náà, igbó tí wọ́n fi ṣe ilé ti di ti nǹkan mìíràn. Àmọ́ ṣá ìgbà àti àkókò ni yóò sọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwọn ẹyẹ ìlú Nepal tí kò sí ní ibòmíràn. | Eye naa ti n dinku latari igbe pipa fun ise ogbin ati itelo igberiko di igboro. Bi a ba yo ti agbegbe aabo kuro, nigba miiran pipa eye yii fun ounje, ni oke kekere ti o yi afonifoji Kathmandu ka ti mu ki eye Spiny Babbler dinku ni iye. Sibe, ohun ti o n fa adanu ni agbegbe kan naa le mu won po ni agbegbe miiran. Bi igbo se n dinku latari igbe pipa ati igi gedu gige jakejado orile ede naa, igbo ti won fi se ile ti di ti nnkan miiran. Amo sa igba ati akoko ni yoo so ohun ti yoo sele si awon eye ilu Nepal ti ko si ni ibomiran. |
Fún ìyọsọ́tọ̀ tí wọ́n yọ òun nìkan láti yẹ ara rẹ̀ wò ní ilé ìtajà ìgbàlódé kan ní Serbia, gbajúgbajà ìràwọ̀ òṣèré orí-ìtàgé Roma fi ẹ̀sùn ìwà elẹ́yàmẹyà kan ilé ìtajà náà | Fun iyosoto ti won yo oun nikan lati ye ara re wo ni ile itaja igbalode kan ni Serbia, gbajugbaja irawo osere ori-itage Roma fi esun iwa eleyameya kan ile itaja naa |
Ìràwọ̀ òṣèré orí-ìtàgé ìlú Serbia Nataša Tasić Knežević, àwòrán láti ọwọ́ọ Dzenet Koko, a lò ó pẹ̀lú àṣẹ. | Irawo osere ori-itage ilu Serbia Natasa Tasic Knezevic, aworan lati owoo Dzenet Koko, a lo o pelu ase. |
Àwọn gbàgede ìtàkùrọ̀sọ ẹ̀rọ-alátagbà ìlú Serbia gbaná lẹ́yìn tí olórin àti òṣèré ìbílẹ̀ Nataša Tasić Knežević, tí ó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Roma fi ẹ̀sùn kan ilé ìtajà-ìgbàlóde kan tí ó wà ní ìgboro Novi Sad fún ìwà ìyàsọ́tọ̀ ẹ̀yà nínú ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ojú-ẹsẹ̀ kan lórí Facebook. | Awon gbagede itakuroso ero-alatagba ilu Serbia gbana leyin ti olorin ati osere ibile Natasa Tasic Knezevic, ti o je omo bibi ile Roma fi esun kan ile itaja-igbalode kan ti o wa ni igboro Novi Sad fun iwa iyasoto eya ninu igbohunsafefe oju-ese kan lori Facebook. |
Nínú fídíò náà, tí ó gbé-sórí-áfẹ́fẹ́ ní ọjọ́ 29, oṣù Ọ̀pẹ lẹ́yìn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣẹ̀, arábìnrin Tasić Knežević ṣàlàyé pé bí òun ṣe ń jáde síta nínú ilé ìtajà ńlá náà pẹ̀lú ọ̀pọ̀ àwọn òǹrajà mìíràn ni ẹ̀rọ adènà àfọwọ́rá dún. Bí àwọn ènìyàn yòókù ṣe ń jáde síta, àwọn ẹ̀ṣọ́-aláàbò ilé ìtajà náà ní kí ó dúró tí wọ́n sì tẹ̀síwajú láti yẹ ara rẹ̀ wò ní gbangba tí àwọn òǹwòran bẹ̀rẹ̀ sí í fi ṣe yẹ̀yẹ́. Ìwé orin, ìwé àti àpò-àpawómọ́-ìléwọ́ ni wọ́n rí nínú àpò-àgbékọ́yìn-in rẹ̀. | Ninu fidio naa, ti o gbe-sori-afefe ni ojo 29, osu Ope leyin ti isele naa se, arabinrin Tasic Knezevic salaye pe bi oun se n jade sita ninu ile itaja nla naa pelu opo awon onraja miiran ni ero adena afowora dun. Bi awon eniyan yooku se n jade sita, awon eso-alaabo ile itaja naa ni ki o duro ti won si tesiwaju lati ye ara re wo ni gbangba ti awon onworan bere si i fi se yeye. Iwe orin, iwe ati apo-apawomo-ilewo ni won ri ninu apo-agbekoyin-in re. |
Ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù Ṣẹẹrẹ ọdún 2019, fídíò náà dédé pòórá pẹ̀lú àlàyé ránpẹ́ nípa arábìnrin Knežević. Bíótilẹ̀jẹ́pé kòì tíì wá sí gbangba kí ó ṣàlàyé ohun tí ó ṣẹlẹ̀, àwọn ẹlòmíràn ń sọ pé fúnra rẹ̀ ni ó yọ ọ́ kí ọ̀ràn tó wà nílẹ̀ lè tán bọ̀rọ̀. Láàárín ọjọ́ díẹ̀, àwọn ènìyàn tí ó tó bíi ẹgbẹ̀rún 60 ti wo fídíò rẹ̀, tí wọ́n sì pín in lọ́nà 350, tí ó sì gba èsì tí ó tó 700. | Ni ibere osu Seere odun 2019, fidio naa dede poora pelu alaye ranpe nipa arabinrin Knezevic. Biotilejepe koi tii wa si gbangba ki o salaye ohun ti o sele, awon elomiran n so pe funra re ni o yo o ki oran to wa nile le tan boro. Laaarin ojo die, awon eniyan ti o to bii egberun 60 ti wo fidio re, ti won si pin in lona 350, ti o si gba esi ti o to 700. |
Ilé iṣẹ́ Ìkóròyìnjọ Orí-ayélujára Olómìnira Bulka ni ó kọ́kọ́ ro ìyìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣáájú àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn Bulka mìíràn. | Ile ise Ikoroyinjo Ori-ayelujara Olominira Bulka ni o koko ro iyin isele naa saaju awon ile-ise iroyin Bulka miiran. |
Akọrin-olóhùn-òkè ni arábìnrin Tasić Knežević ní Gbọ̀ngan Eré-ìtàgé ti orílẹ̀-èdè Serbia tí ó wà ní Novi Sad, ìlú kejì tí ó tóbi jù lọ ní orílẹ̀-èdè náà. Tẹ́lẹ̀ rí, ó ṣiṣẹ́ ní Belgrade Atelje 212. Ó tún jẹ́ akọrin-ṣeré àti àdánìkànkọrin tí ó gbajúmọ̀, ó sì máa ń kọ orin àdánìkànkọ nípa àṣà Roma tí ó jẹ́ orírun rẹ̀. | Akorin-olohun-oke ni arabinrin Tasic Knezevic ni Gbongan Ere-itage ti orile-ede Serbia ti o wa ni Novi Sad, ilu keji ti o tobi ju lo ni orile-ede naa. Tele ri, o sise ni Belgrade Atelje 212. O tun je akorin-sere ati adanikankorin ti o gbajumo, o si maa n ko orin adanikanko nipa asa Roma ti o je orirun re. |
Nínú fídíò náà, arábìnrin Knežević sọ pé alábòójútó ilé ìtajà náà bẹ̀bẹ̀ lẹ́yìn tí òun ṣe àròyé nípa ìwọ̀sí náà, ṣùgbọ́n pé inú òun kò dùn sí bí àwọn èrò tí ó pé jọ lé òun lórí ṣe yẹ̀yẹ́ òun. Ó ní ọkùnrin àgbàlagbà kan pariwo pé kí wọ́n “kó pàǹtí yẹn jáde”, ìyẹn túmọ̀ sí wípé kí àwọn òṣìṣẹ́ ó ju òun jáde síta nínú ilé ìtajà náà nítorí pé òun jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ Rome. | Ninu fidio naa, arabinrin Knezevic so pe alaboojuto ile itaja naa bebe leyin ti oun se aroye nipa iwosi naa, sugbon pe inu oun ko dun si bi awon ero ti o pe jo le oun lori se yeye oun. O ni okunrin agbalagba kan pariwo pe ki won “ko panti yen jade”, iyen tumo si wipe ki awon osise o ju oun jade sita ninu ile itaja naa nitori pe oun je omo ibile Rome. |
“Ta ni ó ń kọrin níbẹ̀ yẹn” jẹ́ eré Yugoslavia ayé ìgbà 1980 tí ó sì di ipò ẹgbẹ́-ìmùlẹ̀ láàárín àwọn Balkan. Nínú ìtàn náà, wọ́n ṣèṣì fẹ̀sùn olè kan àwọn olórin Roma méjì, orí ni ó kó wọn yọ lọ́wọ́ ìjìyà láìsí ìdájọ́. | “Ta ni o n korin nibe yen” je ere Yugoslavia aye igba 1980 ti o si di ipo egbe-imule laaarin awon Balkan. Ninu itan naa, won sesi fesun ole kan awon olorin Roma meji, ori ni o ko won yo lowo ijiya laisi idajo. |
Ilé-iṣẹ́ tí ó ni ilé ìtajà-ìgbàlóde Maxi, Delez Srbija, ṣe àgbéjáde àkọsílẹ̀ ìtúúbá lọ́jọ́ kan náà, ó sọ pé àwọn “gbàgbọ́ pé èyí á wà bí ìṣẹ̀lẹ̀ ìyàsọ́tọ̀ tí ó mú ìfura ẹni tí kò yẹ dání pé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ò ní wáyé mọ́ lọ́jọ́ iwájú. Ilé-iṣẹ́ náà fi kún un pé àwọn á ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn òṣìṣẹ́ wọn lórí bí a ṣe ń hùwà bí wọ́n bá fura sí olè jíjà. | Ile-ise ti o ni ile itaja-igbalode Maxi, Delez Srbija, se agbejade akosile ituuba lojo kan naa, o so pe awon “gbagbo pe eyi a wa bi isele iyasoto ti o mu ifura eni ti ko ye dani pe iru isele bee o ni waye mo lojo iwaju. Ile-ise naa fi kun un pe awon a se idanilekoo fun awon osise won lori bi a se n huwa bi won ba fura si ole jija. |
Ní ọjọ́ kejì, Miloš Nikolić tí ó jẹ́ adarí ọ́fíìsì tí ó ń ṣe àfikún Novi Sad mọ́ Roma sọ̀rọ̀ tako ìṣẹ̀lẹ̀ náà. Ó ní; “gbogbo ìwádìí tí wọ́n ṣe fi hàn pé àwọn ará Roma lọ́kùnrin lóbìnrin ni ẹ̀yà tí a yà sọ́tọ̀ jù lọ ní orílẹ̀-èdèe wa. A ní láti ṣiṣẹ́ pọ̀ láti yí i padà!” | Ni ojo keji, Milos Nikolic ti o je adari ofiisi ti o n se afikun Novi Sad mo Roma soro tako isele naa. O ni; “gbogbo iwadii ti won se fi han pe awon ara Roma lokunrin lobinrin ni eya ti a ya soto ju lo ni orile-edee wa. A ni lati sise po lati yi i pada!” |
Ní 31 oṣù Ọpẹ, Igbá-kejì Alákòóso Ìgbìmọ̀ Ìjọba àti Ààrẹ Àjọ-tí-ó-ń-fètò-sí Ìmúdọ́gba Akọ-àtabo ní àwùjọ, Zorana Mihajlović náà sọ̀rọ̀ tako àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìtajà Maxi pé “ìwà ìbanilórúkọjẹ́ ni wọ́n hù àti pé wọ́n jẹ̀bi”. Kò sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí ó yẹ kí wọ́n ṣe sí ìyàsọ́tọ̀ àwọn ọmọ Roma ní Serbia… | Ni 31 osu Ope, Igba-keji Alakooso Igbimo Ijoba ati Aare Ajo-ti-o-n-feto-si Imudogba Ako-atabo ni awujo, Zorana Mihajlovic naa soro tako awon osise ile itaja Maxi pe “iwa ibanilorukoje ni won hu ati pe won jebi”. Ko soro nipa awon ohun ti o ye ki won se si iyasoto awon omo Roma ni Serbia… |
Bíótilẹ̀jẹ́pé ó dàbí ẹni pé arábìnrin Knežević ti yọ ara rẹ̀ kúrò lórí Facebook, bóyá láti lè jẹ́ kí ọ̀ràn náà ó silẹ̀, ó fi àlàyé-nípa-ara rẹ̀ orí Twitter sílẹ̀. Ní alẹ́ ọjọ́ tí ó ṣíwájú Ọdún Tuntun, ó fi àtẹ̀jáde ṣókí sọ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà. | Biotilejepe o dabi eni pe arabinrin Knezevic ti yo ara re kuro lori Facebook, boya lati le je ki oran naa o sile, o fi alaye-nipa-ara re ori Twitter sile. Ni ale ojo ti o siwaju Odun Tuntun, o fi atejade soki so nipa isele naa. |
Ẹ̀yin ọ̀rẹ́ẹ̀ mi ọ̀wọ́n, ìṣẹ̀lẹ̀ tí kò dùn mọ́ni nínú kan ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ mélòó kan sẹ́yìn, ṣùgbọ́n mo nírètí pé irú ìṣẹ̀lẹ̀ náà á pín pẹ̀lú ọdun 2018 àti pé irú ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ ò ní wáyé mọ́. Ẹ jẹ́ kí a jẹ́ ènìyàn ẹlẹ́ran ara, ohun tí ó dára jù ní ayé yìí nìyẹn. | Eyin oree mi owon, isele ti ko dun moni ninu kan sele ni ojo meloo kan seyin, sugbon mo nireti pe iru isele naa a pin pelu odun 2018 ati pe iru isele bee o ni waye mo. E je ki a je eniyan eleran ara, ohun ti o dara ju ni aye yii niyen. |
Ilé-iṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Ìbílẹ̀ Fagilé Ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn ajìjàǹgbara LGBT lẹ́yìn ìhalẹ̀mọ́ sí olóòtú | Ile-ise Agbohunsafefe Ibile Fagile Iforoworo pelu awon ajijangbara LGBT leyin ihalemo si olootu |
Ilé-iṣẹ́ Echo ti Moscow ní Yaroslavl tí ó jẹ́ ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Echo ti Moscow ìsopọ̀ tí ó ti dá dúró fún ìgbà pípẹ́ ní Russia fagi lé ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn ajìjàǹgbara LGBT lẹ́yìn tí wọ́n gba ìhalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn tí ó kórìíra-ìbálòpọ̀-láàárín-akọ-àti-akọ, olóòtú ilé-iṣẹ́ náà Lyudmila Shabuyeva sọ̀rọ̀ nínú àkọsílẹ̀ Facebook kan: | Ile-ise Echo ti Moscow ni Yaroslavl ti o je eka ile-ise Agbohunsafefe Echo ti Moscow isopo ti o ti da duro fun igba pipe ni Russia fagi le iforoworo pelu awon ajijangbara LGBT leyin ti won gba ihale lati odo awon ti o koriira-ibalopo-laaarin-ako-ati-ako, olootu ile-ise naa Lyudmila Shabuyeva soro ninu akosile Facebook kan: |
Ní àná, a gba ìhàlẹ̀ kan tí ó ń lérí mọ́ àwa àti àwọn àlejòo wa tí a bá tẹ̀síwajú pẹ̀lú ètò ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ọ wa nípa LGBT. | Ni ana, a gba ihale kan ti o n leri mo awa ati awon alejoo wa ti a ba tesiwaju pelu eto iforoworoo wa nipa LGBT. |
Mò ń fagi lé ètò náà. | Mo n fagi le eto naa. |
Gẹ́gẹ́ bí ìwé ìròyìn tí ò sí ní abẹ́ ìṣàkóso ìjọba Novaya Gazeta ti ṣe sọ, ó yẹ kí ètò náà tí yóò ṣe àfihàn àwọn ajìjàǹgbara LGBT ní Yaroslavl wáyé ní òwúrọ̀ Ọjọ́rú 23, ní oṣù Ṣẹẹrẹ. Àwọn ajìjàǹgbara yìí kan náà ṣẹ̀ṣẹ̀ fi ẹ̀hónú hàn ní gbàgede ìlú láti tako ìfìyàjẹ àwọn aṣe-ìbálòpọ̀-akọ-àti-akọ ní Russia, pàápàá jùlọ ní orílẹ̀ Chechnya. Ilé-iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ náà pè wọ́n láti fi ọ̀rọ̀ wá wọn lẹ́nu wò nípa ìfẹ̀hónúhàn àti ìrírí wọn fún jíjáde sí gbangba gẹ́gẹ́ bíi aṣe-ìbálòpọ̀-akọ-àti-akọ ní ẹ̀ka-ìlúu Russia. | Gege bi iwe iroyin ti o si ni abe isakoso ijoba Novaya Gazeta ti se so, o ye ki eto naa ti yoo se afihan awon ajijangbara LGBT ni Yaroslavl waye ni owuro Ojoru 23, ni osu Seere. Awon ajijangbara yii kan naa sese fi ehonu han ni gbagede ilu lati tako ifiyaje awon ase-ibalopo-ako-ati-ako ni Russia, paapaa julo ni orile Chechnya. Ile-ise agbohunsafefe naa pe won lati fi oro wa won lenu wo nipa ifehonuhan ati iriri won fun jijade si gbangba gege bii ase-ibalopo-ako-ati-ako ni eka-iluu Russia. |
Ìkéde Shebuyeva àkọ́kọ́ nípa ètò náà fa ẹgbẹlẹmùkù èébú ìkórìíra-ìbálòpọ̀-láàárín-akọ́-àti-akọ nínú àwọn èsì, tí èsì sì wá láti ọ̀dọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ọba kan bákan náà, ṣùgbọ́n ìyẹn ò mú ọkàn-an rẹ̀ kúrò, ó sọ fún Novaya Gazeta. | Ikede Shebuyeva akoko nipa eto naa fa egbelemuku eebu ikoriira-ibalopo-laaarin-ako-ati-ako ninu awon esi, ti esi si wa lati odo awon osise oba kan bakan naa, sugbon iyen o mu okan-an re kuro, o so fun Novaya Gazeta. |
Ṣùgbọ́n ní alẹ́ ọjọ́ tí ètò náà ku ọ̀la, Shabuyeva sọ̀rọ̀ pé òun gba ìpè àjèjì láti orí òpó ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ kan tí kò ṣe é dámọ̀, ẹni náà sì sọ fún òun pé bí òun bá tẹ̀síwajú pẹ̀lú ètò náà bí ó ṣe ti pinnu, wọ́n máa fi igi ìgbábọ́ọ̀lù-afọwọ́jù pàdé àwọn àlejò rẹ ní ìta ilé-iṣẹ́ náà. Òun náà sì lè kojúu wàhálà, onípè àjèjì náà léríléka. Nítorí ìbẹ̀rù fún ààbò àwọn àlejòo rẹ̀, Shabuyeva fagilé ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò náà tí ó sì fi ètò mìíràn rọ́pòo rẹ̀. | Sugbon ni ale ojo ti eto naa ku ola, Shabuyeva soro pe oun gba ipe ajeji lati ori opo ero-ibanisoro kan ti ko se e damo, eni naa si so fun oun pe bi oun ba tesiwaju pelu eto naa bi o se ti pinnu, won maa fi igi igbaboolu-afowoju pade awon alejo re ni ita ile-ise naa. Oun naa si le kojuu wahala, onipe ajeji naa lerileka. Nitori iberu fun aabo awon alejoo re, Shabuyeva fagile iforowanilenuwo naa ti o si fi eto miiran ropoo re. |
Ìfẹ̀hónúhàn tí ó wáyé ní gbàgede ìlú wà lára ìkéde gbogboògbò saveLGBTinRussia tí wọ́n fi ń polongo ìyà tí ó rorò tí wọ́n fi ń jẹ àwọn ènìyàn aṣe-ìbálòpọ̀-akọ-àti-akọ ní orílẹ̀ Chechnya. Àwọn ìwọ́de àti ìfẹ̀hónúhàn irú èyí wáyé ní àwọn ìlú mìíràn ní Russia. | Ifehonuhan ti o waye ni gbagede ilu wa lara ikede gbogboogbo saveLGBTinRussia ti won fi n polongo iya ti o roro ti won fi n je awon eniyan ase-ibalopo-ako-ati-ako ni orile Chechnya. Awon iwode ati ifehonuhan iru eyi waye ni awon ilu miiran ni Russia. |
Ìlú ń ké pe àwọn ọmọ rẹ̀ (àwọn ọmọ ìlú) láti dojú ìjà kọ ìwà elẹ́yàmẹyà àti ìtẹ̀mọ́lẹ̀ ní Russia òde-òní. Jẹ́ kí ìpèe rẹ̀ ta ọ́ jí! | Ilu n ke pe awon omo re (awon omo ilu) lati doju ija ko iwa eleyameya ati itemole ni Russia ode-oni. Je ki ipee re ta o ji! |
[àmì náà ń sọ pé: Ẹ̀KA ÌṢÈDÁJỌ́ TI ORÍLẸ̀-ÈDÈE RUSSIA Ò RÍ ÀWỌN AṢE-ÌBÁLÒPỌ̀-AKỌ-ÀTI-AKỌ NÍ CHECHYA. WỌ́N WÀ NÍBẸ̀: NÍNÚ ÀWỌN ỌGBÀ Ẹ̀WỌ̀N ÀTI IBOJÌ-ÒKÚ. | [ami naa n so pe: EKA ISEDAJO TI ORILE-EDEE RUSSIA O RI AWON ASE-IBALOPO-AKO-ATI-AKO NI CHECHYA. WON WA NIBE: NINU AWON OGBA EWON ATI IBOJI-OKU. |
Ẹ̀TANÚ ÌBÁLÒPỌ̀-LÁÀÁRÍN-AKỌ-ÀTI-AKỌ = ÌJỌBA AFIPÁMÚNI | ETANU IBALOPO-LAAARIN-AKO-ATI-AKO = IJOBA AFIPAMUNI |
Nínú oṣù Igbe 2017, Novaya Gazeta jábọ̀ pé àwọn aláṣẹ ní Chechnya, ti ìlú oníjọba Ìmọ́lẹ̀ tí ó ń rí ìdààmú jù ní gúúsù Russia tí ajagun fẹ̀yìntì Ramzan Kadyrov, ń ṣe olóríi rẹ̀, ń ṣe ìpolongo tí ó rorò tí ó ń tako ìtẹ̀mọ́lẹ̀ àwọn ènìyàn tí í ṣe LGBT tí ó ń gbé nínúu rẹ̀. Ìròyìn tí ó jáde ní àìpẹ́ sọ pé “ìfọ̀mọ́” náà le gidi gan-an ni, pẹ̀lú ikú èèyàn méjì ó kéré tán àti ogunlọ́gọ̀ àwọn tí ó wà ní àtìmọ́lé tí ó lòdì sí òfin. | Ninu osu Igbe 2017, Novaya Gazeta jabo pe awon alase ni Chechnya, ti ilu onijoba Imole ti o n ri idaamu ju ni guusu Russia ti ajagun feyinti Ramzan Kadyrov, n se olorii re, n se ipolongo ti o roro ti o n tako itemole awon eniyan ti i se LGBT ti o n gbe ninuu re. Iroyin ti o jade ni aipe so pe “ifomo” naa le gidi gan-an ni, pelu iku eeyan meji o kere tan ati ogunlogo awon ti o wa ni atimole ti o lodi si ofin. |
Wọ́n fagi lé ìfìwépè Adarí iléeṣẹ́ tó ń ṣètò Ìṣàjò-papọ̀-wa-ọkọ̀-kí-n-wa-ọkọ̀ sí iléeṣẹ́ tẹlifíṣàn Russia lẹ́yìn tí olóòtú ètò rí i pé obìnrin ni | Won fagi le ifiwepe Adari ileese to n seto Isajo-papo-wa-oko-ki-n-wa-oko si ileese telifisan Russia leyin ti olootu eto ri i pe obinrin ni |
Àgékúrò àwòrán adarí iléeṣẹ́ náà, Irina Reyder ní ọ́fíìsì iléeṣẹ́ BlaBlaCar ti Russia. Àwòrán láti orí Ojú ewé. | Agekuro aworan adari ileese naa, Irina Reyder ni ofiisi ileese BlaBlaCar ti Russia. Aworan lati ori Oju ewe. |
Irina Reyder tí ó jẹ́ adarí iléeṣẹ́ BlaBlaCar ní Russia ní wọ́n fagi lé ìfìwépè òun sí ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ kan pẹ̀lú iléeṣẹ́ amóhùnmáwòrán-an ti ìjọba, Channel One lẹ́yìn tí olóòtú náà rí i pé obìnrin ni òun. | Irina Reyder ti o je adari ileese BlaBlaCar ni Russia ni won fagi le ifiwepe oun si iforoworo kan pelu ileese amohunmaworan-an ti ijoba, Channel One leyin ti olootu naa ri i pe obinrin ni oun. |
Reyder kọ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà sójú ìwé Facebook rẹ̀. Ó ní òun gbọ́ ọ̀rọ̀ inú ìpè olóòtú ètò náà pẹ̀lú aṣojú ilé iṣẹ́ BlaBlaCar fún ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwùjọ tí òun sì gba ohùn-un wọn sílẹ̀: | Reyder ko nipa isele naa soju iwe Facebook re. O ni oun gbo oro inu ipe olootu eto naa pelu asoju ile ise BlaBlaCar fun ibanisoro pelu awujo ti oun si gba ohun-un won sile: |
(Olóòtú ètò “Ojúmọ́ Ire”): Báyìí ni a ṣe gbèrò láti ṣe é; akọ̀ròyìn-in wa á máa wa ọkọ̀ bí yóò ṣe máa fi ọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ lẹ́nu alámọ̀dájúu yín. | (Olootu eto “Ojumo Ire”): Bayii ni a se gbero lati se e; akoroyin-in wa a maa wa oko bi yoo se maa fi oro wa oro lenu alamodajuu yin. |
(Aṣojú iléeṣẹ́ BlaBlaCar fún ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwùjọ): Bẹ́ẹ̀ ni, Ìyẹn dára | (Asoju ileese BlaBlaCar fun ibanisoro pelu awujo): Bee ni, Iyen dara |
Ta ni yóò wá jẹ́ alámọ̀dájú náà? | Ta ni yoo wa je alamodaju naa? |
Adarí iléeṣẹ́ wa ni, Irina Reyder | Adari ileese wa ni, Irina Reyder |
Ẹ̀n… Ẹ ti fìgbà kan ní ọkùnrin tó dára ní ipò náà, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? | En… E ti figba kan ni okunrin to dara ni ipo naa, abi bee ko? |
Bẹ́ẹ̀ ni, a ti ní Alexey Lazorenko gẹ́gẹ́ bí Adarí, Irina Reyder ni nísẹ̀yín. | Bee ni, a ti ni Alexey Lazorenko gege bi Adari, Irina Reyder ni niseyin. |
Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ̀ nípa àyípadà tí ó wáyé nínú ìdarí iléeṣẹ́ yín lọ́dún tó kọjá. Ṣùgbọ́n Irina kò ní le è wúlò gẹ́gẹ́ bí alámọ̀dájú, ó nírú ẹni tí àwọn olùgbọ́ọ wa máa ń nífẹ̀ẹ́ sí. Fún àpẹẹrẹ, tí a bá ní agbẹjọ́rò gidi kan. Ó ń láti jẹ́ ọkùnrin. Tàbí ẹni tí ó mọ̀ nípa ọkọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ – ọkùnrin ni, kó má jẹ̀ ẹ́ obìnrin. Bóyá kí ìwọ Sergey ó ṣe ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ náà? | Bee ni, mo mo nipa ayipada ti o waye ninu idari ileese yin lodun to koja. Sugbon Irina ko ni le e wulo gege bi alamodaju, o niru eni ti awon olugboo wa maa n nifee si. Fun apeere, ti a ba ni agbejoro gidi kan. O n lati je okunrin. Tabi eni ti o mo nipa oko lopolopo – okunrin ni, ko ma je e obinrin. Boya ki iwo Sergey o se iforoworo naa? |
Lẹ́yìn tí aṣojú iléeṣẹ́ náà fún ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwùjọ, Sergey sọ fún olóòtú ètò náà pé kò sí alámọ̀dájú ọkùnrin kankan ní iléeṣẹ́ naa, ó ní olóòtú ètò náà ṣe ìlérí láti padà wá lẹ́yìn tí ó bá ti bá olóòtú àgbà ètòo wọn sọ ọ́. Nínú ìpè kan lẹ́yìn ìgbà náà, wọ́n sọ fún aṣojú iléeṣẹ́ BlaBlaCar pé ètò náà ti yí padà, pé àwọn á máa ṣe ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn oníbàáràa wọn dípò wọn. | Leyin ti asoju ileese naa fun ibanisoro pelu awujo, Sergey so fun olootu eto naa pe ko si alamodaju okunrin kankan ni ileese naa, o ni olootu eto naa se ileri lati pada wa leyin ti o ba ti ba olootu agba etoo won so o. Ninu ipe kan leyin igba naa, won so fun asoju ileese BlaBlaCar pe eto naa ti yi pada, pe awon a maa se iforoworo pelu awon onibaaraa won dipo won. |
“Kí lẹ rò? Ṣé àwọn alámọ̀dájú tuntun yìí á mọ̀ dájú dánu? Reyder ń béèrè ìbéèrè ìkẹ́gàn náà lọ́wọ́ àwọn èèyàn-an rẹ̀. | “Ki le ro? Se awon alamodaju tuntun yii a mo daju danu? Reyder n beere ibeere ikegan naa lowo awon eeyan-an re. |
Nínú èsì kan sí TJournal, tí ó jẹ́ iléeṣẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti ìròyìn ẹ̀rọ alátagbà àti orí ayélujára. Ẹ̀ka ìròyìn Channel One ò fi òtítọ́ ìtàkùrọ̀sọ yìí pamọ́, ṣùgbọ́n wọ́n tẹnu mọ́ ọn pé ọ̀rọ̀ náà kò ṣègbè lẹ́yìn akọ. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àlàyé wọn kò fìdí èyí múlẹ̀ tó: | Ninu esi kan si TJournal, ti o je ileese onimo-ero ati iroyin ero alatagba ati ori ayelujara. Eka iroyin Channel One o fi otito itakuroso yii pamo, sugbon won tenu mo on pe oro naa ko segbe leyin ako. Bi o tile je pe alaye won ko fidi eyi mule to: |
Akọ̀ròyìn méjì, ọkùnrin àti obìnrin kan ń gbèrò láti ṣàfihàn ìyàtọ̀ tí ó wà nínúu bí ọkùnrin àti obìnrin ṣe ń hùwà sí ìfowópamọ́. Akọ̀ròyìn lóbìnrin á ní láti fọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú alámọ̀dájú ọkùnrin kan nígbà tí Akọ̀ròyìn lọ́kùnrin á ní ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn obìnrin. Nítorí pé èròńgbà Akọ̀ròyìn obìnrin yẹn ni láti wo bí wọ́n ṣe ń tọ́jú owó bí wọ́n bá gbé ọkọ̀, a nílò láti bá aṣojú iléeṣẹ́ tó ń ṣètò ìrìnnà-papọ̀-wa-ọkọ̀-kí-n-wa-ọkọ̀ kan sọ̀rọ̀ (bẹ́ẹ̀ ni, nítorí àlàkalẹ̀ ètò náà ni, kì í ṣe nítorí àìfẹ́dọ̀ọ́gba akọ àtabo, ó ní láti jẹ́ ọkùnrin). | Akoroyin meji, okunrin ati obinrin kan n gbero lati safihan iyato ti o wa ninuu bi okunrin ati obinrin se n huwa si ifowopamo. Akoroyin lobinrin a ni lati foroworo pelu alamodaju okunrin kan nigba ti Akoroyin lokunrin a ni iforoworo pelu awon obinrin. Nitori pe erongba Akoroyin obinrin yen ni lati wo bi won se n toju owo bi won ba gbe oko, a nilo lati ba asoju ileese to n seto irinna-papo-wa-oko-ki-n-wa-oko kan soro (bee ni, nitori alakale eto naa ni, ki i se nitori aifedoogba ako atabo, o ni lati je okunrin). |
Channel One ò sọ bí ìyàtọ̀ ṣe wà láàárín bí ọkùnrin àti obìnrin ṣe ń ronú sí ìfowópamọ́. Ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ náà kò yí àwọn èèyàn lọ́kàn padà, wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ tako ìhùwàsí iléeṣẹ́ tẹlifíṣàn yìí. | Channel One o so bi iyato se wa laaarin bi okunrin ati obinrin se n ronu si ifowopamo. Sugbon oro naa ko yi awon eeyan lokan pada, won si n soro tako ihuwasi ileese telifisan yii. |
Adarí iléeṣẹ́ BlaBlaCar, Irina Reyder sọ pé wọ́n fagi lé ìfìwépè òun wá sórí ètò Ojúmọ́ Ire lórí Channel One lẹ́yìn tí olóòtú rí i pé obìnrin ni òún jẹ́. Ó yani lẹ́nu pé àwọn ohun kan ṣì wà nínú ìyírí àwọn Channel One tí a kò mọ̀. | Adari ileese BlaBlaCar, Irina Reyder so pe won fagi le ifiwepe oun wa sori eto Ojumo Ire lori Channel One leyin ti olootu ri i pe obinrin ni oun je. O yani lenu pe awon ohun kan si wa ninu iyiri awon Channel One ti a ko mo. |
Pẹ̀lú ọ̀rọ̀ burúkú tí Channel One gbọ́ lórí ayélujára, Russia sì ní iṣẹ́ ńlá láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìbádọ́gbà akọ àti abo. Russia wà ní ipò 75 nínú àwọn orílẹ̀-èdè 149 tí Àjọ tó-ń-ṣètò-ọrọ̀-Ajé Lágbàáyé ṣàyẹ̀wò fún lọ́dún 2018 nínú Ìjábọ̀ Àlàfo tó wà láàárín Akọ àti Abo Lágbàáyé, ó ń ṣe dáadáa ní ti ìbádọ́gbà nínú rírí ètò ìlera àti ètò ẹ̀kọ́ lò fún àwọn obìnrin, ṣùgbọ́n wọ́n ń fà sẹ́yìn nínú ètò ìṣòfin láti jà fún ẹ̀tọ́ọ wọn. Àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ abo ní Russia máa ń sábàá lo gbàgede ẹ̀rọ alátagbà àti ẹ̀fẹ̀ láti tan ìmọ́lẹ̀ sí ìhùwàsí àti ìṣe àwọn tí ó ń ṣègbè lẹ́yìn ẹ̀yà ènìyàn kan. | Pelu oro buruku ti Channel One gbo lori ayelujara, Russia si ni ise nla lati se lori oro ibadogba ako ati abo. Russia wa ni ipo 75 ninu awon orile-ede 149 ti Ajo to-n-seto-oro-Aje Lagbaaye sayewo fun lodun 2018 ninu Ijabo Alafo to wa laaarin Ako ati Abo Lagbaaye, o n se daadaa ni ti ibadogba ninu riri eto ilera ati eto eko lo fun awon obinrin, sugbon won n fa seyin ninu eto isofin lati ja fun etoo won. Awon ajafetoo abo ni Russia maa n sabaa lo gbagede ero alatagba ati efe lati tan imole si ihuwasi ati ise awon ti o n segbe leyin eya eniyan kan. |
100 ọjọ́ fún Alaa: Ẹbí ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọ Íjípìtì ń ka ọjọ́ fún ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n | 100 ojo fun Alaa: Ebi ajafuneto omo Ijipiti n ka ojo fun idasilee re ninu ewon |
Lẹ́yìn tí ó ti lo ọdún 5 nínú ẹ̀wọ̀n, akọbúlọ́ọ̀gù ọmọ Íjípìtì àti ajàfúnẹ̀tọ́ Alaa Abd El Fattah yóò gba ìdásílẹ̀ nínú ẹ̀wọ̀n ní ọjọ́ 7, oṣù Ẹrẹ́nà, ọdún 2019. Ní ọjọ́ 8 oṣù Ọ̀pẹ, ẹbíi rẹ̀ ti ṣe àgbékalẹ̀ ìpolongo –“100 ọjọ́ fún Alaa” kí àtìmọ́lée rẹ̀ ó ba wá s'ópin ní mọnawáà. | Leyin ti o ti lo odun 5 ninu ewon, akobuloogu omo Ijipiti ati ajafuneto Alaa Abd El Fattah yoo gba idasile ninu ewon ni ojo 7, osu Erena, odun 2019. Ni ojo 8 osu Ope, ebii re ti se agbekale ipolongo –“100 ojo fun Alaa” ki atimolee re o ba wa s'opin ni monawaa. |
Ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀ nínú oṣù Ẹrẹ́nà kì í ṣe ìsààmì òpin ìgbà Alaa ní ẹ̀wọ̀n, ṣùgbọ́n ìṣíkúrò sí ipò tí ó jẹ́ àṣekágbá àtìmọ́lée rẹ̀. Lẹ́yìn ìdásílẹ̀ẹ rẹ̀, Alaa yóò máa wá sun oorun alẹ́ ní àgọ́ ọlọ́pàá ìbílẹ̀ẹ rẹ̀ fún àfikún ọdún márùn-ún gbáko. Abẹ́ ìṣọ́ ọlọ́pàá ni yóò wà fún àkókò yìí. | Idasilee re ninu osu Erena ki i se isaami opin igba Alaa ni ewon, sugbon isikuro si ipo ti o je asekagba atimolee re. Leyin idasilee re, Alaa yoo maa wa sun oorun ale ni ago olopaa ibilee re fun afikun odun marun-un gbako. Abe iso olopaa ni yoo wa fun akoko yii. |
A fi ọwọ́ọ ṣìgún òfin mú Alaa a sì mú u kúrò ní ilé ẹbíi rẹ̀ nínú oṣù Belu ọdún 2013. Ọdún kan kọjá, nínú oṣù Èrèlé ọdún 2015, a gbé e re ilé ẹjọ́ a sì rán an ní ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún fún “àgbékalẹ̀” ìyíde kiri ìfẹ̀hànnúhàn lábẹ́ òfin ìyíde kiri ìfẹ̀hànnúhàn ọdún 2013 tí kò fi àyè gba ìyíde láìgbàṣẹ. Ní tòótọ́ ni ó kópa nínú ìyíde kiri tí ó ń tako ẹjọ́ tí àwọn ológun dá mẹ́kúnnú ní ọjọ́ 26 oṣù Belu ọdún 2013, Alaa kò kó ipa nínú àgbékalẹ̀ẹ rẹ̀. Ilé ẹjọ́ Cassation ti Íjípìtì fi ẹsẹ ẹ̀wọ̀n-ọn rẹ̀ múlẹ̀ nínú oṣù Belu ọdún 2017. | A fi owoo sigun ofin mu Alaa a si mu u kuro ni ile ebii re ninu osu Belu odun 2013. Odun kan koja, ninu osu Erele odun 2015, a gbe e re ile ejo a si ran an ni ewon odun marun-un fun “agbekale” iyide kiri ifehannuhan labe ofin iyide kiri ifehannuhan odun 2013 ti ko fi aye gba iyide laigbase. Ni tooto ni o kopa ninu iyide kiri ti o n tako ejo ti awon ologun da mekunnu ni ojo 26 osu Belu odun 2013, Alaa ko ko ipa ninu agbekalee re. Ile ejo Cassation ti Ijipiti fi ese ewon-on re mule ninu osu Belu odun 2017. |
Omar Robert Hamilton, olùkùu Alaa, to àwọn ète ìpolongo náà lẹ́sẹẹsẹ lóríi Twitter: | Omar Robert Hamilton, olukuu Alaa, to awon ete ipolongo naa leseese lorii Twitter: |
Láti mú kí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ àti ọmọ àgbáyé ó fi ọkàn sí ìdájọ́ àti fún ìdásílẹ̀ẹ Alaa ní ọjọ́ 17 oṣù Ẹrẹ́nà. | Lati mu ki awon omo ibile ati omo agbaye o fi okan si idajo ati fun idasilee Alaa ni ojo 17 osu Erena. |
Láti gbé ìrò (‘ìṣọ́nikiri’ tàbí ‘ìdásílẹ̀-lẹ́wọ̀n-kọ́jọ́-ìdásílẹ̀-tó-pé’) sínú làákàyè àwọn ènìyàn gbogbo. Lẹ́yìn ìdásílẹ̀, Alaa ṣì tún ní láti sun ọrùn alẹ́ nínú àgọ́ ọlọ́pàá ìbílẹ̀ẹ rẹ̀ fún “ọdún márùn-ún”. A ní láti ṣe iṣẹ́ ìpìlẹ̀ fún ìtako èyí. | Lati gbe iro (‘isonikiri’ tabi ‘idasile-lewon-kojo-idasile-to-pe’) sinu laakaye awon eniyan gbogbo. Leyin idasile, Alaa si tun ni lati sun orun ale ninu ago olopaa ibilee re fun “odun marun-un”. A ni lati se ise ipile fun itako eyi. |
Gbogbo olórí orílẹ̀-èdè Íjípìtì ni ó ti ṣe ìwádìí tàbí rán Alaa ní ẹ̀wọ̀n ní ojú ayée rẹ̀. Ní ọdún 2006, a fi ọwọ́ọ ṣìgún òfin mú u fún ipa tí ó kó nínú ìyíde kiri ìfẹ̀hànnúhàn tí kò fa ìdíwọ́ fún ẹnikẹ́ni. Ní ọdún 2011, ó lo oṣù méjì ní ẹ̀wọ̀n, àkókò yìí ni ìyàwóo rẹ̀ bí àkọ́bíi rẹ̀, Khaled. Ní ọdún 2013, a mú u a sì fi sínú àhámọ́ fún ọjọ́ 115 láì ṣe ìgbẹ́jọ́. | Gbogbo olori orile-ede Ijipiti ni o ti se iwadii tabi ran Alaa ni ewon ni oju ayee re. Ni odun 2006, a fi owoo sigun ofin mu u fun ipa ti o ko ninu iyide kiri ifehannuhan ti ko fa idiwo fun enikeni. Ni odun 2011, o lo osu meji ni ewon, akoko yii ni iyawoo re bi akobii re, Khaled. Ni odun 2013, a mu u a si fi sinu ahamo fun ojo 115 lai se igbejo. |
Ó ti pẹ́ tí Alaa ti ń ṣiṣẹ́ lóríi ìjìnlẹ̀ ìmọ̀-ẹ̀rọ àti òṣèlú pẹ̀lú ìyàwóo rẹ̀, Manal Hassan. Ìdílé gbajúgbajà ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni ó ti wà, adájọ́ ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọnìyàn Ahmed Seif El Islam, ni bàbáa Alaa, ẹni tí a ti rán lọ ní ẹ̀wọ̀n láì mọye ìgbà ní abẹ́ àṣẹ Hosni Mubarak. Ẹ̀gbọ́n-bìrin méjèèjì Abd El Fattah, Mona àti Sanaa Seif, jẹ́ agbèjà ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn bákan náà tí wọ́n sì ti ṣe ìpolongo alátakò ìjìyà mẹ́kúnnú lọ́wọ́ọ àwọn ológun ní ìlú náà. Ní ọdún 2016, Sanaa lo oṣù mẹ́fà ní ẹ̀wọ̀n nítorí wípé ó sọ̀rọ̀ àfojúdi sí alaṣẹ ìjọba. | O ti pe ti Alaa ti n sise lorii ijinle imo-ero ati oselu pelu iyawoo re, Manal Hassan. Idile gbajugbaja ajafuneto omoniyan ni o ti wa, adajo ajafuneto omoniyan Ahmed Seif El Islam, ni babaa Alaa, eni ti a ti ran lo ni ewon lai moye igba ni abe ase Hosni Mubarak. Egbon-birin mejeeji Abd El Fattah, Mona ati Sanaa Seif, je agbeja eto omoniyan bakan naa ti won si ti se ipolongo alatako ijiya mekunnu lowoo awon ologun ni ilu naa. Ni odun 2016, Sanaa lo osu mefa ni ewon nitori wipe o soro afojudi si alase ijoba. |
Àdánwòo Alaa jọ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Íjípìtì tí ó wà ní ẹ̀yin gádà nítorí akitiyan wọn nípa ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn. Ẹgbẹ́ ajàfúnẹ̀tọ́ ọmọnìyàn sọ wípé, àwọn tí ìjọba rán ní ẹ̀wọ̀n ní Íjípìtì á tó 60,000. Gbogbo ẹni tí ìjọba bá fi ọwọ́ọ ṣìgún òfin mú ní Íjípìtì ní í jẹ ìyà oró, ìfarasin, àtìmọ́lé ọjọ́ pípẹ́ àti àdánìkangbé inúu túbú. | Adanwoo Alaa jo ti opolopo omo orile-ede Ijipiti ti o wa ni eyin gada nitori akitiyan won nipa eto omoniyan. Egbe ajafuneto omoniyan so wipe, awon ti ijoba ran ni ewon ni Ijipiti a to 60,000. Gbogbo eni ti ijoba ba fi owoo sigun ofin mu ni Ijipiti ni i je iya oro, ifarasin, atimole ojo pipe ati adanikangbe inuu tubu. |
Dídarapọ̀ mọ́n ìpolongo | Didarapo mon ipolongo |
Ní inú ìwé tí a kọ sí àwọn àlejò tí ó wá sí RightsCon, àpérò tó dá lórí ẹ̀tọ́ irinṣẹ́ ẹ̀rọ-ayárabíaṣá tí ó wáyé ní Toronto nínú oṣù Èbìbì ọdún 2018, Alaa rọ àwọn alátìlẹ́yìn láti “ṣe àtúnṣe sí ìjọba àwa-arawa ti wọn”. | Ni inu iwe ti a ko si awon alejo ti o wa si RightsCon, apero to da lori eto irinse ero-ayarabiasa ti o waye ni Toronto ninu osu Ebibi odun 2018, Alaa ro awon alatileyin lati “se atunse si ijoba awa-arawa ti won”. |
Èyí ti fi ìgbà pípẹ́ jẹ́ ìdáhùn mi sí ìbéèrè náà “báwo ni a ṣe lè ṣe ìrànwọ́?” Mo ṣì ní ìgbàgbọ́ wípé [àtúnṣe ìjọba àwa-arawa] ni ìdáhùn kan ṣoṣo. Kì í ṣe ibi tí ò ń gbé nìkan, ṣiṣẹ́, san owó orí àti ṣe àkóso ibi tí ó ti ní ipa, àmọ́ ìfàsẹ́yìn fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn nínú ibi tí ìjọba àwa-arawa ti fi ẹsẹ̀ rinlẹ̀ lè di lílò fún ìrúfin ẹ̀tọ́ ní àwọn agbègbè tí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn kò fi bẹ́ẹ̀ fi ẹsẹ̀ múlẹ̀. Mo mọ̀ wípé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní òde òní jẹ́ ẹ̀rí wípé àtúnṣe pọ̀ láti ṣe. Mo ń retí ìmísí ọ̀nà tí ẹ ó gbà tún un ṣe. | Eyi ti fi igba pipe je idahun mi si ibeere naa “bawo ni a se le se iranwo?” Mo si ni igbagbo wipe [atunse ijoba awa-arawa] ni idahun kan soso. Ki i se ibi ti o n gbe nikan, sise, san owo ori ati se akoso ibi ti o ti ni ipa, amo ifaseyin fun eto omoniyan ninu ibi ti ijoba awa-arawa ti fi ese rinle le di lilo fun irufin eto ni awon agbegbe ti eto omoniyan ko fi bee fi ese mule. Mo mo wipe awon isele ti o n sele ni ode oni je eri wipe atunse po lati se. Mo n reti imisi ona ti e o gba tun un se. |
Kí ẹni tí ó bá fẹ́ darapọ̀ mọ́ ìpolongo “100 ọjọ́ fún Alaa” ó fi “àròkọ, àwòrán tàbí ìṣe ìlọ́wọ́sí ìpolongo” ṣọwọ́ tí a lè tún tẹ̀ jáde sórí ibùdó-ìtàkùn-àgbáyé ìpolongo náà: | Ki eni ti o ba fe darapo mo ipolongo “100 ojo fun Alaa” o fi “aroko, aworan tabi ise ilowosi ipolongo” sowo ti a le tun te jade sori ibudo-itakun-agbaye ipolongo naa: |
Ìpolongo orísun-ọ̀fẹ́ – a óò máa tẹ àwọn ọgbọ́n àtinúdá tuntun síta, àmọ́ a nílò láti gba èrò tuntun àti agbára tuntun wọlé bákan náà. Torí ìdí èyí máa bá wa ronú! | Ipolongo orisun-ofe – a oo maa te awon ogbon atinuda tuntun sita, amo a nilo lati gba ero tuntun ati agbara tuntun wole bakan naa. Tori idi eyi maa ba wa ronu! |
Bí ìgbà gbogbo, àmì ìpolongo ni FreeAlaa – jọ̀wọ́ darapọ̀ mọ́ wa fún ìpalẹ̀mọ́ ìdásílẹ̀ẹ Alaa.Nígbà náà ni Eliakimu ati Ṣebina ati Joa sọ fún Rabuṣake pé, “Jọ̀wọ́, èdè Aramaiki ni kí o fi bá wa sọ̀rọ̀, nítorí pé àwa náà gbọ́ Aramaiki. Má fi èdè Juda bá wa sọ̀rọ̀ kí àwọn ará wa tí ó wà lórí odi má baà gbọ́.”Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn meji náà gbọ́, wọ́n tẹ̀lé Jesu. Àwọn ọmọ Senaa jẹ́ egbejidinlogun ó lé ọgbọ̀n (3,630)Gbogbo àwọn oníṣòwò ati àwọn tí wọn ń ta oríṣìíríṣìí nǹkan sùn sí ẹ̀yìn odi Jerusalẹmu bíi ẹ̀ẹ̀kan tabi ẹẹmeji. “Ọjọ́ meje ni ẹ óo fi jẹ burẹdi tí kò ní ìwúkàrà ninu. Láti ọjọ́ kinni ni kí ẹ ti mú gbogbo ìwúkàrà kúrò ninu ilé yín, nítorí pé bí ẹnikẹ́ni bá jẹ burẹdi tí ó ní ìwúkàrà ninu láti ọjọ́ kinni títí di ọjọ́ keje, a kò ní ka irú ẹni bẹ́ẹ̀ kún àwọn eniyan Israẹli mọ́. Dafidi bá kọ orin arò fún Saulu, ati Jonatani, ọmọ rẹ̀, Ẹ̀yin ọmọde, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń ṣe òdodo ni olódodo, bí Jesu ti jẹ́ olódodo. Má sọ pé, “Bí lágbájá ti ṣe sí mi,bẹ́ẹ̀ ni èmi náà yóo ṣe sí i,n óo san ẹ̀san ohun tí ó ṣe fún un.”Ó tún gbé igba ọdún ó lé meje (207) sí i láyé lẹ́yìn tí ó bí Serugi, ó sì tún bí àwọn ọmọ mìíràn lọkunrin ati lobinrin.Má bá àwọn ọ̀mùtí kẹ́gbẹ́;tabi àwọn wọ̀bìà, tí wọn ń jẹ ẹran ní àjẹkì;Àgbaǹgbá ṣe bẹ́ẹ̀, ó làwo lórí san-san. | Bi igba gbogbo, ami ipolongo ni FreeAlaa – jowo darapo mo wa fun ipalemo idasilee Alaa.Nigba naa ni Eliakimu ati Sebina ati Joa so fun Rabusake pe, “Jowo, ede Aramaiki ni ki o fi ba wa soro, nitori pe awa naa gbo Aramaiki. Ma fi ede Juda ba wa soro ki awon ara wa ti o wa lori odi ma baa gbo.”Nigba ti awon omo-eyin meji naa gbo, won tele Jesu. Awon omo Senaa je egbejidinlogun o le ogbon (3,630)Gbogbo awon onisowo ati awon ti won n ta orisiirisii nnkan sun si eyin odi Jerusalemu bii eekan tabi eemeji. “Ojo meje ni e oo fi je buredi ti ko ni iwukara ninu. Lati ojo kinni ni ki e ti mu gbogbo iwukara kuro ninu ile yin, nitori pe bi enikeni ba je buredi ti o ni iwukara ninu lati ojo kinni titi di ojo keje, a ko ni ka iru eni bee kun awon eniyan Israeli mo. Dafidi ba ko orin aro fun Saulu, ati Jonatani, omo re, Eyin omode, e ma se je ki enikeni tan yin je. Enikeni ti o ba n se ododo ni olododo, bi Jesu ti je olododo. Ma so pe, “Bi lagbaja ti se si mi,bee ni emi naa yoo se si i,n oo san esan ohun ti o se fun un.”O tun gbe igba odun o le meje (207) si i laye leyin ti o bi Serugi, o si tun bi awon omo miiran lokunrin ati lobinrin.Ma ba awon omuti kegbe;tabi awon wobia, ti won n je eran ni ajeki;Agbangba se bee, o lawo lori san-san. |
Mo sì ti fi ẹ̀mí Ọlọrun kún inú rẹ̀, mo ti fún un ní òye ati ọgbọ́n ati ìmọ̀ iṣẹ́ ọnà, Ewúrẹ́ kì í bíni ká lọ sísọ̀ àgùntàn lọ jẹ̀. | Mo si ti fi emi Olorun kun inu re, mo ti fun un ni oye ati ogbon ati imo ise ona, Ewure ki i bini ka lo siso aguntan lo je. |
Òkìkí Jesu sì kàn ká gbogbo ìgbèríko ibẹ̀.Ọbẹ ṣìlò-ó ḿbáni ṣeré a ní kò mú; bí eré bí eré ó ńpani lọ́wọ́. | Okiki Jesu si kan ka gbogbo igberiko ibe.Obe silo-o mbani sere a ni ko mu; bi ere bi ere o npani lowo. |
Àwọn Farisi bá jáde lọ láti gbèrò nípa rẹ̀, bí wọn óo ṣe lè pa á.An elephant's bone: it sticks in the wolf's mouth. | Awon Farisi ba jade lo lati gbero nipa re, bi won oo se le pa a.An elephant's bone: it sticks in the wolf's mouth. |
ó ranṣẹ pada ó ní, “Ẹ sọ fún ọ̀gá yín pé OLUWA ní kí ó má jẹ́ kí iṣẹ́ tí ọba Asiria rán sí i pé OLUWA kò lè gbà á dẹ́rùbà á. Àwọn ọmọ Israẹli ṣọ̀fọ̀ Mose fún ọgbọ̀n ọjọ́ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu, wọ́n sì parí ṣíṣe òkú rẹ̀.ìgbàgbọ. | o ranse pada o ni, “E so fun oga yin pe OLUWA ni ki o ma je ki ise ti oba Asiria ran si i pe OLUWA ko le gba a deruba a. Awon omo Israeli sofo Mose fun ogbon ojo ni petele Moabu, won si pari sise oku re.igbagbo. |
192. Àti pé, dájúdájú Olúwa rẹ- | 192. Ati pe, dajudaju Oluwa re- |
Oun ni Alaágbára, Aláàánú. | Oun ni Alaagbara, Alaaanu. |
ÌDÁ l1I | IDA l1I |
193. Dájúdájú, ìṣípayá lòyí láti | 193. Dajudaju, isipaya loyi lati |
òdọ Olúwa gbogbo àgbáyé. | odo Oluwa gbogbo agbaye. |
194. Ẹmí náà tò ṣe é fọkàn tán lò | 194. Emi naa to se e fokan tan lo |
wá pẹ̀lú rẹ̀. | wa pelu re. |
195. Sí inú ọkan rẹ, kí o lẹ̀ jẹ | 195. Si inu okan re, ki o le je |
òkan nínú àwọn Olùkìlòẹ, | okan ninu awon Olukiloe, |
196. Ní ẹ̀dẹ̀ Larubawa tò. já | 196. Ni ede Larubawa to. ja |
197. Dájúdájú A sì ti sọ nípa rẹ̀ | 197. Dajudaju A si ti so nipa re |
nínú àwọn Iwé mímọ àwọn ẹni | ninu awon Iwe mimo awon eni |
ìṣíwájú. | isiwaju. |
198. Ṣé kò ha ti tô ní Àmì fún | 198. Se ko ha ti to ni Ami fun |
wọn pé àwọn onímọẹ̀ nínú àwọn | won pe awon onimoe ninu awon |
ọmọ Israẹli mọ ọn? | omo Israeli mo on? |
199. To bá ṣe pé a sọ Ọ kalẹ̀ fún | 199. To ba se pe a so O kale fun |
ẹni tí kì í ṣe Larubawa ni, | eni ti ki i se Larubawa ni, |
200. Tí ô sì ti kà á fún wọn, | 200. Ti o si ti ka a fun won, |
síbẹ̀síbẹ̀ wọn ìbá tí gbà á gbọ. | sibesibe won iba ti gba a gbo. |
201. Lénà báyìí ni Àwa jẹ kí ô | 201. Lena bayii ni Awa je ki o |
(àìgbàgbọ) wọ ọkàn àwọn ẹlẹ̀ṣẹ̀. | (aigbagbo) wo okan awon elese. |
202. Wọn kò ní gbà á gbọ títí tí | 202. Won ko ni gba a gbo titi ti |
wọn yòò fi rí ìyà olôrò. | won yoo fi ri iya oloro. |
203. Ṣùgbọn yòò dé bá wọn léòjijì | 203. Sugbon yoo de ba won leojiji |
nígbà ti wọn kò mọ. | nigba ti won ko mo. |
204. Nígbà náà wọn yòò wí pé, | 204. Nigba naa won yoo wi pe, |
Njẹ a lẹ̀ lọ wa lára bí? | Nje a le lo wa lara bi? |
Ṣugbọn ó yọ Lọti tí ó jẹ́ olódodo eniyan, tí ọkàn rẹ̀ bàjẹ́ nítorí ìwàkiwà àwọn tí ń ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara wọn. Òní ọ̀wẹ̀, ọ̀la àro; iṣẹ́ oníṣẹ́ ò jẹ́ ká ráàyè ṣe tẹni. | Sugbon o yo Loti ti o je olododo eniyan, ti okan re baje nitori iwakiwa awon ti n se ifekufee ara won. Oni owe, ola aro; ise onise o je ka raaye se teni. |
“Ẹ̀yin aláìmọ̀kan, ẹ óo ti pẹ́ tó ninu àìmọ̀kan yín?Àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn yóo ti ní inú dídùn pẹ́ tó ninu ẹ̀gàn pípa wọn,tí àwọn òmùgọ̀ yóo sì kórìíra ìmọ̀?Àwọn Farisi sọ fún un pé, “Ò ń jẹ́rìí ara rẹ, ẹ̀rí rẹ kò jámọ́ nǹkankan.” Bákan náà ni àwọn ọlọ́ṣà tí wọ́n kàn mọ́ agbelebu pẹlu rẹ̀ fi ń ṣe ẹlẹ́yà.Àwọn akóniṣiṣẹ́ Farao bẹ̀rẹ̀ sí na àwọn tí wọ́n fi ṣe olórí láàrin àwọn ọmọ Israẹli. Wọn á máa bi wọ́n pé “Kí ló dé tí bíríkì tí ẹ mọ lónìí kò fi tó iye tí ó yẹ kí ẹ mọ?”The lump that attacks the head is shamed, the boil is shamed, and the hardened tissue on the buttocks is shames also. | “Eyin alaimokan, e oo ti pe to ninu aimokan yin?Awon peganpegan yoo ti ni inu didun pe to ninu egan pipa won,ti awon omugo yoo si koriira imo?Awon Farisi so fun un pe, “O n jerii ara re, eri re ko jamo nnkankan.” Bakan naa ni awon olosa ti won kan mo agbelebu pelu re fi n se eleya.Awon akonisise Farao bere si na awon ti won fi se olori laarin awon omo Israeli. Won a maa bi won pe “Ki lo de ti biriki ti e mo lonii ko fi to iye ti o ye ki e mo?”The lump that attacks the head is shamed, the boil is shamed, and the hardened tissue on the buttocks is shames also. |
“O kò gbọdọ̀ bá obinrin lòpọ̀, nígbà tí ó bá ń ṣe nǹkan oṣù rẹ̀ lọ́wọ́. Nígbà náà ni Hagai tún bi wọ́n pé, “Ǹjẹ́ bí ẹnìkan bá di aláìmọ́ nítorí pé ó farakan òkú, tí ó sì fọwọ́ kan ọ̀kan ninu àwọn ohun tí a kà sílẹ̀ wọnyi ǹjẹ́ kò ní di aláìmọ́?” Wọ́n dáhùn pé: “Dájúdájú, yóo di aláìmọ́.” Nígbà tí àwọn eṣú náà ti jẹ gbogbo koríko ilẹ̀ náà tán, mo ní, “OLUWA Ọlọrun, jọ̀wọ́ dáríjì àwọn eniyan rẹ. Báwo ni àwọn ọmọ Jakọbu yóo ṣe là, nítorí pé wọ́n kéré níye?”Èyí yóo jẹ́ ìlànà ayérayé fun yín, kí wọ́n lè máa ṣe ètùtù fún àwọn ọmọ Israẹli ní ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.” Mose sì ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún un.OLUWA tún sọ fún mi lẹẹkeji pé, Ọjọ́ ńlá OLUWA súnmọ́lé, ó súnmọ́ etílé, ó ń bọ̀ kíákíá. Ọjọ́ náà yóo burú tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn akikanju ọkunrin yóo kígbe lóhùn rara. Nísàlẹ̀ àwọn yàrá wọnyi, ọ̀nà kan wà ní apá ìlà oòrùn bí eniyan bá ti ń bọ̀ láti ibi gbọ̀ngàn ìta. Tẹ́lẹ̀ rí òun ni àwọn eniyan kà kún, tí idán tí ó ń pa ń yà wọ́n lẹ́nu. kúrò lòrí ilẹ̀ wa. Àwa kò ha ti fún | “O ko gbodo ba obinrin lopo, nigba ti o ba n se nnkan osu re lowo. Nigba naa ni Hagai tun bi won pe, “Nje bi enikan ba di alaimo nitori pe o farakan oku, ti o si fowo kan okan ninu awon ohun ti a ka sile wonyi nje ko ni di alaimo?” Won dahun pe: “Dajudaju, yoo di alaimo.” Nigba ti awon esu naa ti je gbogbo koriko ile naa tan, mo ni, “OLUWA Olorun, jowo dariji awon eniyan re. Bawo ni awon omo Jakobu yoo se la, nitori pe won kere niye?”Eyi yoo je ilana ayeraye fun yin, ki won le maa se etutu fun awon omo Israeli ni eekan lodun, nitori ese won.” Mose si se gege bi ase ti OLUWA pa fun un.OLUWA tun so fun mi leekeji pe, Ojo nla OLUWA sunmole, o sunmo etile, o n bo kiakia. Ojo naa yoo buru tobee ti awon akikanju okunrin yoo kigbe lohun rara. Nisale awon yara wonyi, ona kan wa ni apa ila oorun bi eniyan ba ti n bo lati ibi gbongan ita. Tele ri oun ni awon eniyan ka kun, ti idan ti o n pa n ya won lenu. kuro lori ile wa. Awa ko ha ti fun |
wọn ní ààyẹ̀ ỌWỌ tí O ní | won ni aaye OWO ti O ni |
ìfòkànbalẹ̀ (Makka) gbé bí? Nínú | ifokanbale (Makka) gbe bi? Ninu |
wá ní ìpẹ̀sẹ̀ láti dọ Wa; Ṣùgbọn | wa ni ipese lati do Wa; Sugbon |