diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
òpọlọpọ wọn ni kò mọ.
opolopo won ni ko mo.
59. Mélòòmélòọ ni àwọn ìlú tí A
59. Meloomeloo ni awon ilu ti A
ti parun, nígbà tí wọn yọ ayọòpọrọ
ti parun, nigba ti won yo ayooporo
nípa ìṣẹ̀mí tí A ṣe ní ìrọrùn fún
nipa isemi ti A se ni irorun fun
wọn. Éyí sì ni àwọn ibùgbé wọn
won. Eyi si ni awon ibugbe won
tô jẹ pé ìwọnba ni àwọn tô n
to je pe iwonba ni awon to n
gbé ibẹ̀ lẹhìn wọn. Àwa sì ni
gbe ibe lehin won. Awa si ni
Olùjogún.
Olujogun.
60. Olúwa rẹ kò ní pa ìlú kan run
60. Oluwa re ko ni pa ilu kan run
láìjẹ pé O ti rán òjíṣẹ kan sí olú-
laije pe O ti ran ojise kan si olu-
ìlú náà, tí yòò máa ka àwọn Àmì
ilu naa, ti yoo maa ka awon Ami
Wa fún wọn; Àwa kò sì ní pa
Wa fun won; Awa ko si ni pa
àwọn ìlú kan run láìjẹ pé àwọn
awon ilu kan run laije pe awon
ẹ̀nìyàn ibẹ̀ jẹ alábòsí.
eniyan ibe je alabosi.
61. Ohunkòhun tí a bá.. fún yín
61. Ohunkohun ti a ba.. fun yin
nínú ayé kàn jẹ ìgbádùn ti ayé yìí
ninu aye kan je igbadun ti aye yii
àti sọ rẹ̀ fún ìgbà diẹ̀ ni; ohun tò
ati so re fun igba die ni; ohun to
n bẹ lọdọ Allah lô dára jù, òun ni
n be lodo Allah lo dara ju, oun ni
yòò sì wà títí láé. Ẹyin kì yòò ha
yoo si wa titi lae. Eyin ki yoo ha
gbọ àgbọyé bí?
gbo agboye bi?
ÌDÁ 7
IDA 7
62. Njé ẹni tí A bá ṣe àdéhùn rere
62. Nje eni ti A ba se adehun rere
kan, ti 0 sì ri àmúṣẹ rẹ̀, ha dàbi
kan, ti 0 si ri amuse re, ha dabi
ẹni tí A ṣe ìgbádùn ti ayé yìí fún
eni ti A se igbadun ti aye yii fun
ṣùgbọn tò jẹ pé lọjò Àjíìde yòò
sugbon to je pe lojo Ajiide yoo
wà lára àwọn tí A ô kòjọ (fún
wa lara awon ti A o kojo (fun
ìdájọ ìyà níwájú Allah)?
idajo iya niwaju Allah)?
Nítorí mo mọ̀ dájú pé gẹ́rẹ́ tí mo bá kú tán, ìṣekúṣe ni ẹ óo máa ṣe, ẹ óo sì yipada kúrò ní ọ̀nà tí mo ti pa láṣẹ fun yín, ibi ni yóo sì ba yín ní ọjọ́ iwájú, nítorí pé ẹ óo ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA. Iṣẹ́ ọwọ́ yín yóo sì mú un bínú.”Onílé ńrelé wọ́n ní oǹdè ńsá; oǹdè ò sá, ilé ẹ̀ ló lọ.
Nitori mo mo daju pe gere ti mo ba ku tan, isekuse ni e oo maa se, e oo si yipada kuro ni ona ti mo ti pa lase fun yin, ibi ni yoo si ba yin ni ojo iwaju, nitori pe e oo se ohun ti o buru loju OLUWA. Ise owo yin yoo si mu un binu.”Onile nrele won ni onde nsa; onde o sa, ile e lo lo.
“Ẹ kò gbọdọ̀ dán OLUWA Ọlọrun yín wò, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ṣe ní Masa. Ẹ dìde, ẹ máa lọ, nítorí pé ìhín yìí kì í ṣe ibi ìsinmi; nítorí pé ẹ ti hùwà ìríra tí ń mú ìparun ńlá báni.“Ìwọ Solomoni, ọmọ mi, mọ Ọlọrun àwọn baba rẹ, kí o sì fi gbogbo ọkàn rẹ sìn ín tìfẹ́tìfẹ́, nítorí OLUWA a máa wádìí ọkàn, ó sì mọ gbogbo èrò ati ète eniyan. Bí o bá wá OLUWA, o óo rí i, ṣugbọn bí o bá kọ̀ ọ́ sílẹ̀, yóo ta ọ́ nù títí lae. ó sì sọ Josẹfu sinu ọgbà ẹ̀wọ̀n. Ibi tí wọn ń ti àwọn tí ọba bá sọ sí ẹ̀wọ̀n mọ́ ni wọ́n tì í mọ́. bí wọ́n bá ronupiwada ní ilẹ̀ tí wọ́n kó wọn lẹ́rú lọ, tí wọ́n sì rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ọ, tí wọ́n bá jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá, ati ìwà burúkú tí wọ́n hù, Ninu ilẹ̀ wọn ni ìdajì Gileadi wà ati Aṣitarotu ati Edirei, àwọn ìlú ńláńlá ilẹ̀ ìjọba Ogu, ọba Baṣani; Mose pín wọn fún àwọn ìdajì ìdílé Makiri, ọmọ Manase, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.“Sọ fún Rehoboamu ọmọ Solomoni, ọba Juda, ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọn ń gbé Juda ati Bẹnjamini pé, Ó ní, “Àwọn ọrọ̀ ilẹ̀ Ijipti ati àwọn ẹrù ilẹ̀ Etiopia,ati àwọn ọkunrin Seba tí wọn ṣígbọnlẹ̀,wọn óo tọ̀ ọ́ wá, wọn óo di tìrẹ,wọn óo sì máa tẹ̀lé ọ.Wọn óo wá, pẹlu ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ lẹ́sẹ̀ wọn,wọn óo sì wólẹ̀ fún ọ.Wọn óo máa bẹ̀ ọ́ pé,‘Lọ́dọ̀ rẹ nìkan ni Ọlọrun wà,kò tún sí Ọlọrun mìíràn.Kò sí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn rẹ.’ ”Ọjọ́ kan là ḿbàjẹ́, ọjọ́ gbogbo lara ńtini.
“E ko gbodo dan OLUWA Olorun yin wo, gege bi e ti se ni Masa. E dide, e maa lo, nitori pe ihin yii ki i se ibi isinmi; nitori pe e ti huwa irira ti n mu iparun nla bani.“Iwo Solomoni, omo mi, mo Olorun awon baba re, ki o si fi gbogbo okan re sin in tifetife, nitori OLUWA a maa wadii okan, o si mo gbogbo ero ati ete eniyan. Bi o ba wa OLUWA, o oo ri i, sugbon bi o ba ko o sile, yoo ta o nu titi lae. o si so Josefu sinu ogba ewon. Ibi ti won n ti awon ti oba ba so si ewon mo ni won ti i mo. bi won ba ronupiwada ni ile ti won ko won leru lo, ti won si rawo ebe si o, ti won ba jewo ese ti won da, ati iwa buruku ti won hu, Ninu ile won ni idaji Gileadi wa ati Asitarotu ati Edirei, awon ilu nlanla ile ijoba Ogu, oba Basani; Mose pin won fun awon idaji idile Makiri, omo Manase, gege bi iye idile won.“So fun Rehoboamu omo Solomoni, oba Juda, ati gbogbo awon omo Israeli ti won n gbe Juda ati Benjamini pe, O ni, “Awon oro ile Ijipti ati awon eru ile Etiopia,ati awon okunrin Seba ti won sigbonle,won oo to o wa, won oo di tire,won oo si maa tele o.Won oo wa, pelu sekeseke lese won,won oo si wole fun o.Won oo maa be o pe,‘Lodo re nikan ni Olorun wa,ko tun si Olorun miiran.Ko si Olorun miiran leyin re.’ ”Ojo kan la mbaje, ojo gbogbo lara ntini.
pé bóyá mo lè ti ipa bẹ́ẹ̀ mú àwọn eniyan mi jowú yín, kí n lè gba díẹ̀ ninu wọn là. Kí ó gbé ìyẹ̀fun náà tọ alufaa wá, kí alufaa bu ẹ̀kúnwọ́ kan ninu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìrántí, kí ó sì fi rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ sí OLUWA, ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ ni. Ijó ní ḿbọ́ṣọ, ìjà ní ḿbọ́ ẹ̀wù.
pe boya mo le ti ipa bee mu awon eniyan mi jowu yin, ki n le gba die ninu won la. Ki o gbe iyefun naa to alufaa wa, ki alufaa bu ekunwo kan ninu re gege bi ebo iranti, ki o si fi ru ebo sisun lori pepe si OLUWA, ebo imukuro ese ni. Ijo ni mboso, ija ni mbo ewu.
Àwọn àgbààgbà ìjọ eniyan náà bá bèèrè pé, “Níbo ni a óo ti rí aya fún àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù, níwọ̀n ìgbà tí a ti pa àwọn obinrin ẹ̀yà Bẹnjamini run.” Àwọn eniyan bá dáhùn pé,“Nítorí náà ni ìdájọ́ òtítọ́ fi jìnnà sí wa,tí òdodo kò sì fi dé ọ̀dọ̀ wà.Ìmọ́lẹ̀ ni à ń retí, ṣugbọn òkùnkùn ló ṣú,ìtànṣán oòrùn ni à ń retí, ṣugbọn ìkùukùu ni ó bolẹ̀.Máa pa wọ́n lọ ní ọwọ́ ọ̀tún, ati ní ọwọ́ òsì, níbikíbi tí ó bá sá ti kọjú sí. Ṣugbọn olukuluku yóo jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀,ati lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, kò sì ní sí ẹni tí yóo dẹ́rùbà wọ́n;nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ó sọ bẹ́ẹ̀.Tó bá di ìgbà náà, wọn yóo tẹ́ pẹpẹ kan fún OLUWA láàrin ilẹ̀ Ijipti, ọ̀wọ̀n OLUWA kan yóo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ ààlà ilẹ̀ rẹ̀. Bí wọ́n ti ń lọ, Naomi yíjú pada sí àwọn mejeeji, ó ní, “Ẹ̀yin mejeeji, ẹ pada sí ilé ìyá yín. Kí OLUWA ṣàánú fun yín, bí ẹ ti ṣàánú fún èmi ati àwọn òkú ọ̀run. Gbogbo ohun tí ó ṣe ninu iṣẹ́ ìsìn ilé OLUWA, gẹ́gẹ́ bí òfin ati àṣẹ Ọlọ́run, ati wíwá tí ó wá ojurere Ọlọrun, gbogbo rẹ̀ ni ó ṣe tọkàntọkàn, ó sì dára fún un.OLUWA wí fun mi pé, “Sọ fún wọn pé,‘Kí omijé máa ṣàn lójú mi tọ̀sán-tòru,kí ó má dáwọ́ dúró,nítorí ọgbẹ́ ńlá tí a fi tagbára tagbára ṣá eniyan mi.The liar's mouth does not bleed.
Awon agbaagba ijo eniyan naa ba beere pe, “Nibo ni a oo ti ri aya fun awon ti won seku, niwon igba ti a ti pa awon obinrin eya Benjamini run.” Awon eniyan ba dahun pe,“Nitori naa ni idajo otito fi jinna si wa,ti ododo ko si fi de odo wa.Imole ni a n reti, sugbon okunkun lo su,itansan oorun ni a n reti, sugbon ikuukuu ni o bole.Maa pa won lo ni owo otun, ati ni owo osi, nibikibi ti o ba sa ti koju si. Sugbon olukuluku yoo jokoo labe ajara re,ati labe igi opoto re, ko si ni si eni ti yoo deruba won;nitori pe OLUWA awon omo ogun ni o so bee.To ba di igba naa, won yoo te pepe kan fun OLUWA laarin ile Ijipti, owon OLUWA kan yoo si wa legbeegbe aala ile re. Bi won ti n lo, Naomi yiju pada si awon mejeeji, o ni, “Eyin mejeeji, e pada si ile iya yin. Ki OLUWA saanu fun yin, bi e ti saanu fun emi ati awon oku orun. Gbogbo ohun ti o se ninu ise isin ile OLUWA, gege bi ofin ati ase Olorun, ati wiwa ti o wa ojurere Olorun, gbogbo re ni o se tokantokan, o si dara fun un.OLUWA wi fun mi pe, “So fun won pe,‘Ki omije maa san loju mi tosan-toru,ki o ma dawo duro,nitori ogbe nla ti a fi tagbara tagbara sa eniyan mi.The liar's mouth does not bleed.
Jesu tún bi í lẹẹkeji pé, “Simoni ọmọ Johanu, ǹjẹ́ o fẹ́ràn mi?”Ó tún dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni Oluwa, o mọ̀ pé mo fẹ́ràn rẹ.”Jesu wí fún un pé, “Máa tọ́jú àwọn aguntan mi.” “Simoni! Simoni! Ṣọ́ra o! Satani ti gba àṣẹ láti dán gbogbo yín wò, bí ìgbà tí eniyan bá ń fẹ́ fùlùfúlù kúrò lára ọkà. Nígbà tí wọ́n dé àfonífojì Eṣikolu, wọn gé ṣiiri àjàrà kan tí ó ní èso. Ṣiiri àjàrà yìí tóbi tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé àwọn meji ni wọ́n fi ọ̀pá gbé e. Wọ́n sì mú èso pomegiranate ati èso ọ̀pọ̀tọ́ wá pẹlu. Paulu gbé ààrin wọn fún ọdún kan ati oṣù mẹfa, ó ń kọ́ wọn ní ọ̀rọ̀ Ọlọrun.Ǹ bá ro ẹjọ́ mi níwájú rẹ̀,gbogbo ẹnu ni ǹ bá fi ṣàròyé.Fi inú ṣìkà, fi òde ṣòótọ́; ẹni tí ḿbini kò níí ṣàì bini.
Jesu tun bi i leekeji pe, “Simoni omo Johanu, nje o feran mi?”O tun da a lohun pe, “Bee ni Oluwa, o mo pe mo feran re.”Jesu wi fun un pe, “Maa toju awon aguntan mi.” “Simoni! Simoni! Sora o! Satani ti gba ase lati dan gbogbo yin wo, bi igba ti eniyan ba n fe fulufulu kuro lara oka. Nigba ti won de afonifoji Esikolu, won ge siiri ajara kan ti o ni eso. Siiri ajara yii tobi tobee ti o fi je pe awon meji ni won fi opa gbe e. Won si mu eso pomegiranate ati eso opoto wa pelu. Paulu gbe aarin won fun odun kan ati osu mefa, o n ko won ni oro Olorun.N ba ro ejo mi niwaju re,gbogbo enu ni n ba fi saroye.Fi inu sika, fi ode sooto; eni ti mbini ko nii sai bini.
Èmi ni àwọn tí ń jókòó lẹ́nu ibodèfi ń ṣe ọ̀rọ̀ sọ;àwọn ọ̀mùtí sì ń fi mí ṣe orin kọ. Paulu bá kígbe pè é, ó ní, “Má ṣe ara rẹ léṣe, nítorí gbogbo wa wà níhìn-ín.”“Àwọn tí wọ́n jẹ́ aláìmọ́ fun yín ninu gbogbo àwọn ohun tí ń rìn lórí ilẹ̀ ni: asín, ati èkúté, ati àwọn oríṣìíríṣìí aláǹgbá ńlá, Ó bi iranṣẹ Abrahamu náà pé, “Ta ni ó ń rìn ninu pápá lọ́ọ̀ọ́kán tí ó ń bọ̀ wá pàdé wa yìí?” Iranṣẹ náà dá a lóhùn pé, “Olúwa mi ni.” Rebeka bá mú ìbòjú rẹ̀, ó dà á bojú.Nítorí náà, ó di dandan láti yan ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ti ń bá wa rìn ni gbogbo àkókò tí Jesu Olúwa ń wọlé, tí ó sì jáde láàrín wa. “Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́ ohun ìkọsẹ̀ fún ọ̀kan ninu àwọn kéékèèké wọnyi tí ó gbà mí gbọ́, ó sàn fún un kí á so ọlọ ńlá mọ́ ọn lọ́rùn, kí á sọ ọ́ sinu ibú òkun. Inú wá bí Ẹranko Ewèlè yìí sí obinrin náà. Ó wá lọ gbógun ti àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù, tí wọn ń pa àṣẹ Ọlọrun mọ́, tí wọn ń jẹ́rìí igbagbọ ninu Jesu. Ó ṣí ọ̀rọ̀ rẹ̀ payá fún Jakọbu,ó sì fi òfin ati ìlànà rẹ̀ han Israẹli.Asán ninu asán, ọ̀jọ̀gbọ́n ní, asán ni gbogbo rẹ̀.The oil pot is ever found in a sitting position.
Emi ni awon ti n jokoo lenu ibodefi n se oro so;awon omuti si n fi mi se orin ko. Paulu ba kigbe pe e, o ni, “Ma se ara re lese, nitori gbogbo wa wa nihin-in.”“Awon ti won je alaimo fun yin ninu gbogbo awon ohun ti n rin lori ile ni: asin, ati ekute, ati awon orisiirisii alangba nla, O bi iranse Abrahamu naa pe, “Ta ni o n rin ninu papa loookan ti o n bo wa pade wa yii?” Iranse naa da a lohun pe, “Oluwa mi ni.” Rebeka ba mu iboju re, o da a boju.Nitori naa, o di dandan lati yan okan ninu awon okunrin wonyi ti n ba wa rin ni gbogbo akoko ti Jesu Oluwa n wole, ti o si jade laarin wa. “Enikeni ti o ba je ohun ikose fun okan ninu awon keekeeke wonyi ti o gba mi gbo, o san fun un ki a so olo nla mo on lorun, ki a so o sinu ibu okun. Inu wa bi Eranko Ewele yii si obinrin naa. O wa lo gbogun ti awon omo re yooku, ti won n pa ase Olorun mo, ti won n jerii igbagbo ninu Jesu. O si oro re paya fun Jakobu,o si fi ofin ati ilana re han Israeli.Asan ninu asan, ojogbon ni, asan ni gbogbo re.The oil pot is ever found in a sitting position.
Lẹ́yìn èyí mo tún rí Tẹmpili tí ó ṣí sílẹ̀ ní ọ̀run. Àgọ́-Ẹ̀rí wà ninu rẹ̀. Jesu sọ fún wọn pé, “Àwọn ọba àwọn orílẹ̀-èdè alaigbagbọ a máa jẹ ọlá lórí wọn. Àwọn aláṣẹ wọn ni wọ́n ń pè ní olóore wọn. Ilẹ̀ tiwọn ni Jaseri ati gbogbo ìlú Gileadi, ati ìdajì ilẹ̀ àwọn ará Amoni, títí dé Aroeri tí ó wà ní ìlà oòrùn Raba; ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọkunrin wọnyi kó oriṣa wọn lé ọkàn, wọ́n sì gbé ẹrù ẹ̀ṣẹ̀ tí ń múni kọsẹ̀ siwaju wọn. Ṣé wọ́n rò pé n óo dá wọn lóhùn tí wọ́n bá wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi?Wọn yóo gé igi inú igbó rẹ̀ lulẹ̀.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé igbó náà dí,nítorí pé igi ibẹ̀ pọ̀ bí eṣú, tí wọn kò sì lóǹkà.Iranṣẹbinrin Lea bí ọmọkunrin kan fún Jakọbu. Only one day brings disgrace to a person; the shame is felt every day.
Leyin eyi mo tun ri Tempili ti o si sile ni orun. Ago-Eri wa ninu re. Jesu so fun won pe, “Awon oba awon orile-ede alaigbagbo a maa je ola lori won. Awon alase won ni won n pe ni oloore won. Ile tiwon ni Jaseri ati gbogbo ilu Gileadi, ati idaji ile awon ara Amoni, titi de Aroeri ti o wa ni ila oorun Raba; o ni: “Iwo omo eniyan, awon okunrin wonyi ko orisa won le okan, won si gbe eru ese ti n muni kose siwaju won. Se won ro pe n oo da won lohun ti won ba wadii oro lowo mi?Won yoo ge igi inu igbo re lule.Bi o tile je pe igbo naa di,nitori pe igi ibe po bi esu, ti won ko si lonka.Iransebinrin Lea bi omokunrin kan fun Jakobu. Only one day brings disgrace to a person; the shame is felt every day.
Ìdí òwò ni òwòó gbé tà.
Idi owo ni owoo gbe ta.
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí wí fún ara wọn pé, “Ẹ wò ó, alálàá ni ó ń bọ̀ yìí! Ní ọjọ́ kẹta, ọdọmọkunrin kan wá, láti inú àgọ́ Saulu, ó ti fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì ku erùpẹ̀ sí orí, láti fi ìbànújẹ́ hàn. Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ Dafidi, ó wólẹ̀, ó dojúbolẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì kí i tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀. Olórìṣà-á gbé ààjà sókè, wọ́n ní ire ni; bí ire ni, bí ibi ni, wọn ò mọ̀.
Won bere si wi fun ara won pe, “E wo o, alalaa ni o n bo yii! Ni ojo keta, odomokunrin kan wa, lati inu ago Saulu, o ti fa aso re ya, o si ku erupe si ori, lati fi ibanuje han. Nigba ti o de odo Dafidi, o wole, o dojubole niwaju re, o si ki i towotowo. Olorisa-a gbe aaja soke, won ni ire ni; bi ire ni, bi ibi ni, won o mo.
Ṣugbọn a óo máa sọ òtítọ́ pẹlu ìfẹ́, a óo máa dàgbà ninu rẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà, ninu Kristi tíí ṣe orí. OLUWA Ọlọrun, ìwọ ni o yà wọ́n sọ́tọ̀ láàrin gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé, pé kí wọ́n jẹ́ ìní rẹ, gẹ́gẹ́ bí o ti sọ fún wọn láti ẹnu Mose, iranṣẹ rẹ, nígbà tí ó kó àwọn baba ńlá wa jáde ní ilẹ̀ Ijipti.”Jesu bá tún kígbe tòò, ó mí kanlẹ̀, ó bá dákẹ́.Nítorí tiwọn, ó ranti majẹmu tí ó dá,ó sì yí ìpinnu rẹ̀ pada nítorí ọ̀pọ̀ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.Jẹ́ kí ẹ̀yinná dà lé wọn lórí;jẹ́ kí wọn já sí kòtò, kí wọn má lè yọ.Ṣugbọn ọkunrin talaka yìí kò ní nǹkankan, àfi ọmọ aguntan kékeré kan tí ó rà, tí ó sì ń tọ́jú títí tí ó fi dàgbà ninu ilé rẹ̀, pẹlu àwọn ọmọ rẹ̀. Ninu oúnjẹ tí òun pàápàá ń jẹ ni ó ti ń fún un jẹ, igbá tí ọkunrin yìí fi ń mu omi ni ó fi ń bu omi fún ọmọ aguntan rẹ̀ mu. A sì máa gbé e jókòó lórí ẹsẹ̀, bí ẹni pé ọmọ rẹ̀ gan-an ni. Wọ́n sọdá sí òdìkejì odòwọ́n sùn ní Geba di ọjọ́ keji.Àwọn ará Rama ń wárìrì,àwọn ará Gibea, ìlú Saulu sá lọ.Wọn óo máa gbé ibẹ̀ láìbẹ̀rù; wọn óo kọ́ ilé, wọn óo sì ṣe ọgbà àjàrà, wọn óo máa gbé láìbẹ̀rù nígbà tí mo bá ṣe ìdájọ́ gbogbo àwọn tí wọ́n yí wọn ká, tí wọ́n sì ti kẹ́gàn wọn. Wọn óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA Ọlọrun wọn.” It is from aloft that the bird sounds off.
Sugbon a oo maa so otito pelu ife, a oo maa dagba ninu re ni gbogbo ona, ninu Kristi tii se ori. OLUWA Olorun, iwo ni o ya won soto laarin gbogbo awon orile-ede aye, pe ki won je ini re, gege bi o ti so fun won lati enu Mose, iranse re, nigba ti o ko awon baba nla wa jade ni ile Ijipti.”Jesu ba tun kigbe too, o mi kanle, o ba dake.Nitori tiwon, o ranti majemu ti o da,o si yi ipinnu re pada nitori opo ife re ti ki i ye.Je ki eyinna da le won lori;je ki won ja si koto, ki won ma le yo.Sugbon okunrin talaka yii ko ni nnkankan, afi omo aguntan kekere kan ti o ra, ti o si n toju titi ti o fi dagba ninu ile re, pelu awon omo re. Ninu ounje ti oun paapaa n je ni o ti n fun un je, igba ti okunrin yii fi n mu omi ni o fi n bu omi fun omo aguntan re mu. A si maa gbe e jokoo lori ese, bi eni pe omo re gan-an ni. Won soda si odikeji odowon sun ni Geba di ojo keji.Awon ara Rama n wariri,awon ara Gibea, ilu Saulu sa lo.Won oo maa gbe ibe laiberu; won oo ko ile, won oo si se ogba ajara, won oo maa gbe laiberu nigba ti mo ba se idajo gbogbo awon ti won yi won ka, ti won si ti kegan won. Won oo wa mo nigba naa pe emi ni OLUWA Olorun won.” It is from aloft that the bird sounds off.
“Múra gírí bí ọkunrin,mo ní ìbéèrè láti bi ọ́, o óo sì dá mi lóhùn.Agbára Oluwa hàn ninu iṣẹ́ wọn. Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n gbàgbọ́, tí wọ́n sì yipada sí Oluwa.“Lẹ́yìn ìgbà tí ó bá ti parí ṣíṣe ètùtù fún ibi mímọ́ náà, ati fún Àgọ́ Àjọ náà, ati pẹpẹ náà, yóo fa ààyè ewúrẹ́ náà kalẹ̀. If it has been three years since the leopard took ill, is it a monkey that one sends to ask its condition?
“Mura giri bi okunrin,mo ni ibeere lati bi o, o oo si da mi lohun.Agbara Oluwa han ninu ise won. Opolopo eniyan ni won gbagbo, ti won si yipada si Oluwa.“Leyin igba ti o ba ti pari sise etutu fun ibi mimo naa, ati fun Ago Ajo naa, ati pepe naa, yoo fa aaye ewure naa kale. If it has been three years since the leopard took ill, is it a monkey that one sends to ask its condition?
Wọ́n bá mú ọmọ ewúrẹ́ kan ninu agbo, wọ́n pa á, wọ́n sì ti ẹ̀wù Josẹfu bọ inú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀. Timoti alábàáṣiṣẹ́ mi ki yín. Bẹ́ẹ̀ náà ni Lukiusi ati Jasoni ati Sosipata, àwọn ìbátan wa. The kite looks long at the tortoise; the eagle looks long at the tortoise; what can the hawk, father of the kite, do to the tortoise?
Won ba mu omo ewure kan ninu agbo, won pa a, won si ti ewu Josefu bo inu eje re. Timoti alabaasise mi ki yin. Bee naa ni Lukiusi ati Jasoni ati Sosipata, awon ibatan wa. The kite looks long at the tortoise; the eagle looks long at the tortoise; what can the hawk, father of the kite, do to the tortoise?
Àwọn ọkunrin náà ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Joṣua pa fún wọn. Wọ́n gbé òkúta mejila láti inú odò Jọdani, gẹ́gẹ́ bí iye ẹ̀yà tí ó wà ninu àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ fún Joṣua. Wọ́n gbé wọn lọ́wọ́ lọ sí ibi tí wọ́n sùn ní alẹ́ ọjọ́ náà, wọ́n sì tò wọ́n jọ sibẹ. Bí a kò bá ṣe bí ẹlẹ́dẹ̀ lọ́nà Ìkòròdú, a ò lè ṣe bí Adégbọrọ̀ lọ́jà ọba.
Awon okunrin naa se gege bi ase ti Josua pa fun won. Won gbe okuta mejila lati inu odo Jodani, gege bi iye eya ti o wa ninu awon omo Israeli, gege bi OLUWA ti so fun Josua. Won gbe won lowo lo si ibi ti won sun ni ale ojo naa, won si to won jo sibe. Bi a ko ba se bi elede lona Ikorodu, a o le se bi Adegboro loja oba.
Àwọn ọmọ Israẹli ṣe oríṣìíríṣìí nǹkan níkọ̀kọ̀, tí OLUWA Ọlọrun wọn kò fẹ́. Wọ́n kọ́ àwọn pẹpẹ ìrúbọ sinu àwọn ìlú wọn: wọ́n kọ́ sinu ilé ìṣọ́, títí kan àwọn ìlú olódi. One cowrie makes a miser of one; two cowries make a spendthrift of one.
Awon omo Israeli se orisiirisii nnkan nikoko, ti OLUWA Olorun won ko fe. Won ko awon pepe irubo sinu awon ilu won: won ko sinu ile iso, titi kan awon ilu olodi. One cowrie makes a miser of one; two cowries make a spendthrift of one.
Bí ajá rójú ẹkùn, a pa rọ́rọ́.
Bi aja roju ekun, a pa roro.
Ó wu OLUWA láti gbé òfin rẹ̀ gaati láti ṣe é lógo nítorí òdodo rẹ̀.Bí ẹ bá wí lọ́kàn yín pé,“Kí ló dé tí irú èyí fi dé bá wa?”Ẹ̀ṣẹ̀ yín ni ó pọ̀, ni a fi ká aṣọ ní ìdí yín,tí a sì jẹ yín níyà.Bákan náà, àwọn alufaa tí wọ́n jẹ́ aṣaaju ati àwọn eniyan yòókù pàápàá ṣe aiṣootọ sí OLUWA, wọ́n tẹ̀lé ìwà ìríra àwọn orílẹ̀-èdè tí ó yí wọn ká, wọ́n sì sọ ilé tí OLUWA ti yà sí mímọ́ ní Jerusalẹmu di aláìmọ́. Ní ọjọ́ kan, nígbà tí ọpọlọpọ eniyan tún wà lọ́dọ̀ Jesu, tí wọn kò rí nǹkan jẹ, ó pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, Ten eyes are not like one's own.
O wu OLUWA lati gbe ofin re gaati lati se e logo nitori ododo re.Bi e ba wi lokan yin pe,“Ki lo de ti iru eyi fi de ba wa?”Ese yin ni o po, ni a fi ka aso ni idi yin,ti a si je yin niya.Bakan naa, awon alufaa ti won je asaaju ati awon eniyan yooku paapaa se aisooto si OLUWA, won tele iwa irira awon orile-ede ti o yi won ka, won si so ile ti OLUWA ti ya si mimo ni Jerusalemu di alaimo. Ni ojo kan, nigba ti opolopo eniyan tun wa lodo Jesu, ti won ko ri nnkan je, o pe awon omo-eyin re, o wi fun won pe, Ten eyes are not like one's own.
Seeing something oneself is far better than hearing a report of it from ten people. Compare Ojú olójú . . .
Seeing something oneself is far better than hearing a report of it from ten people. Compare Oju oloju . . .
Ilẹ̀ náà di ìbàjẹ́ tóbẹ́ẹ̀ tí mo fi ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn jẹ ẹ́, ilẹ̀ náà sì ń ti àwọn eniyan inú rẹ̀ jáde. o pa àwọn eniyan rẹ ninu aṣálẹ̀ nítorí pé o kò lè kó wọn dé ilẹ̀ tí o ti ṣèlérí fún wọn. Wọn óo bojú wo ilẹ̀, kìkì ìdààmú ati òkùnkùn ati ìṣúdudu ati ìnira ni wọn óo rí. A óo sì sọ wọ́n sinu òkùnkùn biribiri.OLUWA fi ara hàn wọ́n ninu ọ̀wọ̀n ìkùukùu ninu àgọ́ náà. Ọ̀wọ̀n ìkùukùu náà wà ní ẹ̀bá ẹnu ọ̀nà àgọ́.Òjò pamí, òjò pa ère-è mi; òjò ò pa ẹwà ara-à mi dànù.
Ile naa di ibaje tobee ti mo fi n fi iya ese won je e, ile naa si n ti awon eniyan inu re jade. o pa awon eniyan re ninu asale nitori pe o ko le ko won de ile ti o ti seleri fun won. Won oo boju wo ile, kiki idaamu ati okunkun ati isududu ati inira ni won oo ri. A oo si so won sinu okunkun biribiri.OLUWA fi ara han won ninu owon ikuukuu ninu ago naa. Owon ikuukuu naa wa ni eba enu ona ago.Ojo pami, ojo pa ere-e mi; ojo o pa ewa ara-a mi danu.
Ìmàlé gbààwẹ̀ ó lóun ò gbétọ́ mì; ta ní ńṣe ẹlẹ́rìí fún un?
Imale gbaawe o loun o gbeto mi; ta ni nse elerii fun un?
OLUWA ni olùpamọ́ rẹ.OLUWA yóo ṣíji bò ọ́ ní apá ọ̀tún rẹ.Tí OLUWA àwọn ọmọ ogun ti súre fún pé, “Ibukun ni fún Ijipti, àwọn eniyan mi, ati fún Asiria tí mo fi ọwọ́ mi dá, ati fún Israẹli ìní mi.” Farada ìpín tìrẹ ninu ìṣòro gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ogun Kristi Jesu. Mose gbà láti máa gbé ọ̀dọ̀ ọkunrin náà, ó bá fún un ní Sipora, ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin rẹ̀ láti fi ṣe aya. Wò ó! N óo gbé darandaran kan dìde tí kò ní bìkítà fún àwọn ẹran tí wọ́n ń ṣègbé, kò ní tọpa àwọn tí wọn ń ṣáko lọ, tabi kí ó wo àwọn tí ń ṣàìsàn sàn, tabi kí ó fún àwọn tí ara wọn le ní oúnjẹ. Dípò kí ó tọ́jú wọn, pípa ni yóo máa pa àwọn tí ó sanra jẹ, tí yóo sì máa fa pátákò wọn ya. Ojú ọ̀run ń kéde òdodo rẹ̀ péỌlọrun ni onídàájọ́.Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù OLUWA, ẹ gbẹ́kẹ̀lé e,òun ni olùrànlọ́wọ́ ati aláàbò yín.Èyí ni iṣẹ́ tí Ọlọrun rán Sefanaya, ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedalaya, ọmọ Amaraya, ọmọ Hesekaya ní àkókò ìjọba Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda. Nígbà tí o bá ń bọ̀, bá mi mú agbádá tí mo fi sọ́dọ̀ Kapu ní Tiroasi bọ̀. Bá mi mú àwọn ìwé mi náà bọ̀, pataki jùlọ àwọn ìwé aláwọ mi.Busily wagging tail, busily wagging tail, a goat enters a bachelor's house busily wagging its tail; what does a bachelor have to eat whose left-over the goat can have?
OLUWA ni olupamo re.OLUWA yoo siji bo o ni apa otun re.Ti OLUWA awon omo ogun ti sure fun pe, “Ibukun ni fun Ijipti, awon eniyan mi, ati fun Asiria ti mo fi owo mi da, ati fun Israeli ini mi.” Farada ipin tire ninu isoro gege bi omo-ogun Kristi Jesu. Mose gba lati maa gbe odo okunrin naa, o ba fun un ni Sipora, okan ninu awon omobinrin re lati fi se aya. Wo o! N oo gbe darandaran kan dide ti ko ni bikita fun awon eran ti won n segbe, ko ni topa awon ti won n sako lo, tabi ki o wo awon ti n saisan san, tabi ki o fun awon ti ara won le ni ounje. Dipo ki o toju won, pipa ni yoo maa pa awon ti o sanra je, ti yoo si maa fa patako won ya. Oju orun n kede ododo re peOlorun ni onidaajo.Eyin ti e beru OLUWA, e gbekele e,oun ni oluranlowo ati alaabo yin.Eyi ni ise ti Olorun ran Sefanaya, omo Kusi, omo Gedalaya, omo Amaraya, omo Hesekaya ni akoko ijoba Josaya, omo Amoni, oba Juda. Nigba ti o ba n bo, ba mi mu agbada ti mo fi sodo Kapu ni Tiroasi bo. Ba mi mu awon iwe mi naa bo, pataki julo awon iwe alawo mi.Busily wagging tail, busily wagging tail, a goat enters a bachelor's house busily wagging its tail; what does a bachelor have to eat whose left-over the goat can have?
Ọkùnrin kì í ké, akọ igi kì í ṣoje.
Okunrin ki i ke, ako igi ki i soje.
Nítorí pé àwọn Juu kọ ìyìn rere, wọ́n sọ ara wọn di ọ̀tá Ọlọrun, èyí sì ṣe yín láǹfààní. Ṣugbọn níwọ̀n ìgbà tí Ọlọrun ti yàn wọ́n nítorí àwọn baba-ńlá orílẹ̀-èdè wọn, wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ rẹ̀ sibẹ. OLUWA ní,“Ẹ rọ Moabu lọ́tí yó,nítorí pé ó gbéraga sí OLUWA;kí ó lè máa yíràá ninu èébì rẹ̀,a óo sì fi òun náà ṣẹ̀sín.Ó to àwọn ọ̀pá wọnyi siwaju àwọn ẹran níbi tí wọ́n ti ń mu omi, nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá wá mu omi ni wọ́n máa ń gùn. Ìṣeǹṣe ewúrẹ́, kágùntàn fiyè síi.
Nitori pe awon Juu ko iyin rere, won so ara won di ota Olorun, eyi si se yin lanfaani. Sugbon niwon igba ti Olorun ti yan won nitori awon baba-nla orile-ede won, won je ayanfe re sibe. OLUWA ni,“E ro Moabu loti yo,nitori pe o gberaga si OLUWA;ki o le maa yiraa ninu eebi re,a oo si fi oun naa sesin.O to awon opa wonyi siwaju awon eran nibi ti won ti n mu omi, nitori pe, nigba ti won ba wa mu omi ni won maa n gun. Isense ewure, kaguntan fiye sii.
“Ọ̀rọ̀ yín dára lójú mi, mo sì yan ọkunrin mejila láàrin yín, ọkunrin kọ̀ọ̀kan láàrin ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan. Paradà, OLUWA, jí gìrì sí ọ̀ràn mi,gbèjà mi, Ọlọrun mi, ati OLUWA mi!Kiriataimu, Sibima, ati Sereti Ṣahari, tí ó wà ní orí òkè àfonífojì náà; OLUWA pe Samuẹli nígbà kẹta, ó bá tún dìde, ó tọ Eli lọ, ó ní “Ìwọ ni o pè mí; mo dé.”Eli wá mọ̀ nígbà náà pé, OLUWA ni ó ń pe ọmọ náà. Mose dáhùn pé, “Mo bẹ̀ ọ́, fi ògo rẹ hàn mí.”Ògo ni fún ẹni tí ó lè ṣe ju gbogbo nǹkan tí à ń bèèrè, ati ohun gbogbo tí a ní lọ́kàn lọ, gẹ́gẹ́ bí agbára rẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́ ninu wa. Ọmọdé dáwọ́tilẹ̀, ó ní òún tó ọ̀bọ; bó tó ọ̀bọ, ó tó gẹ̀gẹ̀ àyàa ẹ̀?
“Oro yin dara loju mi, mo si yan okunrin mejila laarin yin, okunrin kookan laarin eya kookan. Parada, OLUWA, ji giri si oran mi,gbeja mi, Olorun mi, ati OLUWA mi!Kiriataimu, Sibima, ati Sereti Sahari, ti o wa ni ori oke afonifoji naa; OLUWA pe Samueli nigba keta, o ba tun dide, o to Eli lo, o ni “Iwo ni o pe mi; mo de.”Eli wa mo nigba naa pe, OLUWA ni o n pe omo naa. Mose dahun pe, “Mo be o, fi ogo re han mi.”Ogo ni fun eni ti o le se ju gbogbo nnkan ti a n beere, ati ohun gbogbo ti a ni lokan lo, gege bi agbara re ti n sise ninu wa. Omode dawotile, o ni oun to obo; bo to obo, o to gege ayaa e?
Mo mọ Efuraimu, bẹ́ẹ̀ ni Israẹli kò ṣàjèjì sí mi; nisinsinyii, ìwọ Efuraimu ti ṣe àgbèrè ẹ̀sìn, Israẹli sì ti di aláìmọ́.”The fire of the stinging tragia plant does not burn a person twice.
Mo mo Efuraimu, bee ni Israeli ko sajeji si mi; nisinsinyii, iwo Efuraimu ti se agbere esin, Israeli si ti di alaimo.”The fire of the stinging tragia plant does not burn a person twice.
Nígbà náà ni wọ́n ké pe OLUWA ninu ìpọ́njú wọn,ó sì yọ wọ́n kúrò ninu ìṣẹ́ wọn.Ìwọ ọgbà àjàrà Sibima,ọ̀rọ̀ rẹ pa mí lẹ́kún, ju ti Jaseri lọ!Àwọn ẹ̀ka rẹ tàn dé òkun, wọ́n tàn títí dé Jaseri,apanirun sì ti kọlu àwọn èso ẹ̀ẹ̀rùn rẹ, ati èso àjàrà rẹ.OLUWA bínú sí èmi pàápàá nítorí tiyín, ó ní èmi náà kò ní dé ibẹ̀. A man does not cry; hardwood does not ooze sap.
Nigba naa ni won ke pe OLUWA ninu iponju won,o si yo won kuro ninu ise won.Iwo ogba ajara Sibima,oro re pa mi lekun, ju ti Jaseri lo!Awon eka re tan de okun, won tan titi de Jaseri,apanirun si ti kolu awon eso eerun re, ati eso ajara re.OLUWA binu si emi paapaa nitori tiyin, o ni emi naa ko ni de ibe. A man does not cry; hardwood does not ooze sap.
“Nígbà tí o bá ń kórè oko rẹ, o kò gbọdọ̀ kórè títí kan ààlà. Lẹ́yìn tí o bá ti kórè tán, o kò gbọdọ̀ pada lọ tún kórè àwọn ohun tí o bá gbàgbé. Ìdámẹ́wàá òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun tí ó kúnná dáradára, tí a pò pọ̀ mọ́ idamẹrin òṣùnwọ̀n hini ojúlówó epo olifi, ni kí o fi rúbọ pẹlu àgbò kinni, pẹlu idamẹrin òṣùnwọ̀n hini ọtí waini fún ìtasílẹ̀. Kaini dá OLUWA lóhùn, ó ní, “Ìjìyà yìí ti pọ̀jù fún mi. Obinrin kan wà níbẹ̀ tí ó ń jẹ́ Lidia, ará Tiatira, tí ó ń ta aṣọ àlàárì. Ó jẹ́ ẹnìkan tí ó ń sin Ọlọrun. Ó fetí sílẹ̀, Ọlọrun ṣí i lọ́kàn láti gba ohun tí Paulu ń sọ. gbogbo oniruuru ẹyẹ ìwò, Nígbà tí ẹ bá wá jọ́sìn níwájú mi,ta ló bẹ̀ yín ní gbogbo gìrìgìrì lásán, tí ẹ̀ ń dà ninu àgbàlá mi.Kò ṣeku kò ṣẹyẹ ò jẹ́ kí àjàò sanwó òde.
“Nigba ti o ba n kore oko re, o ko gbodo kore titi kan aala. Leyin ti o ba ti kore tan, o ko gbodo pada lo tun kore awon ohun ti o ba gbagbe. Idamewaa osunwon iyefun ti o kunna daradara, ti a po po mo idamerin osunwon hini ojulowo epo olifi, ni ki o fi rubo pelu agbo kinni, pelu idamerin osunwon hini oti waini fun itasile. Kaini da OLUWA lohun, o ni, “Ijiya yii ti poju fun mi. Obinrin kan wa nibe ti o n je Lidia, ara Tiatira, ti o n ta aso alaari. O je enikan ti o n sin Olorun. O feti sile, Olorun si i lokan lati gba ohun ti Paulu n so. gbogbo oniruuru eye iwo, Nigba ti e ba wa josin niwaju mi,ta lo be yin ni gbogbo girigiri lasan, ti e n da ninu agbala mi.Ko seku ko seye o je ki ajao sanwo ode.
Òkúta wúwo, yanrìn sì tẹ̀wọ̀n,ṣugbọn ìmúnibínú aṣiwèrè wúwo lọ́kàn ẹni ju mejeeji lọ.Wọ́n bá gbà pé kí Rebeka arabinrin wọn máa lọ, pẹlu olùtọ́jú rẹ̀ láti ìgbà èwe rẹ̀, ati iranṣẹ Abrahamu, pẹlu àwọn ọkunrin tí wọ́n bá a wá. A gba ìkógun lọ́wọ́ àwọn akikanju,wọ́n sun oorun àsùn-ùn-jí;àwọn alágbára kò sì le gbé ọwọ́ láti jà.Jesu wá kìlọ̀ fún wọn gan-an pé kí wọn má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀. Ó ní kí wọn wá oúnjẹ fún ọmọde náà kí ó jẹ.Iyawo ọ̀kan ninu àwọn ọmọ àwọn wolii tọ Eliṣa lọ, ó sì sọ fún un pé, “Olúwa mi, iranṣẹ rẹ, ọkọ mi, ti kú, gẹ́gẹ́ bí o ti mọ̀, ó jẹ́ ẹni tí ó bẹ̀rù OLUWA nígbà ayé rẹ̀. Ẹnìkan tí ó jẹ lówó kí ó tó kú fẹ́ kó àwọn ọmọkunrin mi mejeeji lẹ́rú, nítorí gbèsè baba wọn.”Ó bá mú burẹdi, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun, ó bù ú, ó bá fún wọn. Ó ní, “Èyí ni ara mi tí a fun yín. [Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.” Nítorí a gbọ́ nígbà tí ó sọ pé Jesu ti Nasarẹti yóo wó ilé yìí, yóo yí àwọn àṣà tí Mose fún wa pada.” Ǹjẹ́ fáàrí àáké lè pọ̀ ju ti ẹni tí ó ń fi gégi lọ?Tabi ayùn lè fọ́nnu sí ẹni tí ó ń fi rẹ́ igi?Ǹjẹ́ kùmọ̀ lè mú ẹni tí ó ń lò ó lọ́wọ́,tabi kí ọ̀pá mú ẹni tí ó ni í lọ́wọ́?Gègé ni wọ́n ṣẹ́, tí wọ́n fi pín in fún ẹ̀yà mẹsan-an ati ààbọ̀ ninu ẹ̀yà àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose. Gbọ́ igbe mi;nítorí wọ́n ti rẹ̀ mí sílẹ̀ patapata.Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi,nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.Ṣugbọn mò ń làkàkà pé nígbà tí mo bá lọ tán, kí ẹ ní ohun tí ẹ óo fi máa ṣe ìrántí nǹkan wọnyi nígbà gbogbo.Ó dá wọn lóhùn pé, “Ẹ ṣọ́ra kí á má ṣe tàn yín jẹ. Nítorí ọ̀pọ̀ yóo wá ní orúkọ mi, tí wọn yóo wí pé, ‘Èmi ni Mesaya’ ati pé, ‘Àkókò náà súnmọ́ tòsí.’ Ẹ má tẹ̀lé wọn. Ojú abanijẹ́ pọ́n, kò lè tan fìtílà.
Okuta wuwo, yanrin si tewon,sugbon imunibinu asiwere wuwo lokan eni ju mejeeji lo.Won ba gba pe ki Rebeka arabinrin won maa lo, pelu olutoju re lati igba ewe re, ati iranse Abrahamu, pelu awon okunrin ti won ba a wa. A gba ikogun lowo awon akikanju,won sun oorun asun-un-ji;awon alagbara ko si le gbe owo lati ja.Jesu wa kilo fun won gan-an pe ki won ma je ki enikeni mo. O ni ki won wa ounje fun omode naa ki o je.Iyawo okan ninu awon omo awon wolii to Elisa lo, o si so fun un pe, “Oluwa mi, iranse re, oko mi, ti ku, gege bi o ti mo, o je eni ti o beru OLUWA nigba aye re. Enikan ti o je lowo ki o to ku fe ko awon omokunrin mi mejeeji leru, nitori gbese baba won.”O ba mu buredi, o dupe lowo Olorun, o bu u, o ba fun won. O ni, “Eyi ni ara mi ti a fun yin. [E maa se eyi ni iranti mi.” Nitori a gbo nigba ti o so pe Jesu ti Nasareti yoo wo ile yii, yoo yi awon asa ti Mose fun wa pada.” Nje faari aake le po ju ti eni ti o n fi gegi lo?Tabi ayun le fonnu si eni ti o n fi re igi?Nje kumo le mu eni ti o n lo o lowo,tabi ki opa mu eni ti o ni i lowo?Gege ni won se, ti won fi pin in fun eya mesan-an ati aabo ninu eya awon omo Israeli, gege bi OLUWA ti pase fun Mose. Gbo igbe mi;nitori won ti re mi sile patapata.Gba mi lowo awon ti n se inunibini mi,nitori pe won lagbara ju mi lo.Sugbon mo n lakaka pe nigba ti mo ba lo tan, ki e ni ohun ti e oo fi maa se iranti nnkan wonyi nigba gbogbo.O da won lohun pe, “E sora ki a ma se tan yin je. Nitori opo yoo wa ni oruko mi, ti won yoo wi pe, ‘Emi ni Mesaya’ ati pe, ‘Akoko naa sunmo tosi.’ E ma tele won. Oju abanije pon, ko le tan fitila.
Nígbà tí wọ́n jáde kúrò ninu odò. Ẹ̀mí Oluwa gbé Filipi lọ, ìwẹ̀fà náà kò sì rí i mọ́. Ó bá ń bá ọ̀nà rẹ̀ lọ pẹlu ayọ̀. When the dog sees the eyes of the leopard, it keeps very still.
Nigba ti won jade kuro ninu odo. Emi Oluwa gbe Filipi lo, iwefa naa ko si ri i mo. O ba n ba ona re lo pelu ayo. When the dog sees the eyes of the leopard, it keeps very still.
OLUWA fẹ́ràn òdodo ati ẹ̀tọ́;ayé kún fún ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.Bí wọ́n ti jókòó tí wọ́n fẹ́ máa jẹun, ojú tí wọ́n gbé sókè, wọ́n rí ọ̀wọ́ àwọn ará Iṣimaeli kan, wọ́n ń bọ̀ láti Gileadi, wọ́n ń lọ sí Ijipti, àwọn ràkúnmí wọn ru turari, ìkunra olóòórùn dídùn ati òjíá. “Máa pa àwọn òfin tí mo fún ọ lónìí yìí mọ́. N óo lé àwọn ará Hamori ati àwọn ará Kenaani, àwọn ará Hiti ati àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi ati àwọn ará Jebusi, jáde kúrò níwájú rẹ. Ní Ọjọ́ Ìsinmi kan, Jesu lọ jẹun ní ilé ọ̀kan ninu àwọn olóyè láàrin àwọn Farisi. Wọ́n bá ń ṣọ́ ọ. OLUWA ti dá ẹ̀mí mi sí, gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, láti nǹkan bí ọdún marunlelogoji tí OLUWA ti sọ ọ̀rọ̀ yìí fún Mose nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli ń rìn ninu aṣálẹ̀. Nisinsinyii, mo ti di ẹni ọdún marundinlaadọrun, Àríṣe làríkà.
OLUWA feran ododo ati eto;aye kun fun ife re ti ki i ye.Bi won ti jokoo ti won fe maa jeun, oju ti won gbe soke, won ri owo awon ara Isimaeli kan, won n bo lati Gileadi, won n lo si Ijipti, awon rakunmi won ru turari, ikunra olooorun didun ati ojia. “Maa pa awon ofin ti mo fun o lonii yii mo. N oo le awon ara Hamori ati awon ara Kenaani, awon ara Hiti ati awon ara Perisi, awon ara Hifi ati awon ara Jebusi, jade kuro niwaju re. Ni Ojo Isinmi kan, Jesu lo jeun ni ile okan ninu awon oloye laarin awon Farisi. Won ba n so o. OLUWA ti da emi mi si, gege bi o ti wi, lati nnkan bi odun marunlelogoji ti OLUWA ti so oro yii fun Mose nigba ti awon omo Israeli n rin ninu asale. Nisinsinyii, mo ti di eni odun marundinlaadorun, Arise larika.
nígbà tí agbo mààlúù yín ati agbo aguntan yín bá pọ̀ sí i, tí wúrà ati fadaka yín náà sì pọ̀ sí i, tí ohun gbogbo tí ẹ ní bá pọ̀ sí i, Bí ó di ọdún mẹ́ta tí ẹkùn-ún ti ńṣe òjòjò, olugbe la ó ha rán lọ bẹ̀ ẹ́ wò?
nigba ti agbo maaluu yin ati agbo aguntan yin ba po si i, ti wura ati fadaka yin naa si po si i, ti ohun gbogbo ti e ni ba po si i, Bi o di odun meta ti ekun-un ti nse ojojo, olugbe la o ha ran lo be e wo?
Daniẹli, Ginetoni, ati Baruku, Lẹ́yìn náà Johanani ọmọ Karea, ati gbogbo àwọn olórí ogun tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀, kó gbogbo àwọn tí Iṣimaeli ọmọ Netanaya kó lẹ́rú ní Misipa, lẹ́yìn tí ó pa Gedalaya ọmọ Ahikamu tán, ó bá kó ati àwọn ọmọ ogun, ati àwọn obinrin, ati àwọn ọmọde, ati àwọn ìwẹ̀fà, pada wá láti Gibeoni. Ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ kankan kò gbọdọ̀ ti ẹnu yín jáde. Kàkà bẹ́ẹ̀, ọ̀rọ̀ rere, tí ó lè jẹ́ ìrànlọ́wọ́ nígbàkúùgbà ni kí ẹ máa sọ jáde lẹ́nu. Èyí yóo ṣe àwọn tí ó bá gbọ́ ní anfaani. A little sacrifice, a little medicine, is what keeps the one who does not die alive.
Danieli, Ginetoni, ati Baruku, Leyin naa Johanani omo Karea, ati gbogbo awon olori ogun ti won wa pelu re, ko gbogbo awon ti Isimaeli omo Netanaya ko leru ni Misipa, leyin ti o pa Gedalaya omo Ahikamu tan, o ba ko ati awon omo ogun, ati awon obinrin, ati awon omode, ati awon iwefa, pada wa lati Gibeoni. Oro ibaje kankan ko gbodo ti enu yin jade. Kaka bee, oro rere, ti o le je iranlowo nigbakuugba ni ki e maa so jade lenu. Eyi yoo se awon ti o ba gbo ni anfaani. A little sacrifice, a little medicine, is what keeps the one who does not die alive.
Dídán rẹ̀ dàbí ọ̀sán gangan,ìtànṣán ń ti ọwọ́ rẹ̀ jáde;níbẹ̀ ni ó fi agbára rẹ̀ pamọ́ sí.Ó sọ fún wọn pé, “Ẹ lọ sí ìletò tí ó wà ní ọ̀kánkán yín yìí. Bí ẹ bá ti wọ inú rẹ̀, ẹ óo rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí wọ́n so mọ́lẹ̀, pẹlu ọmọ rẹ̀. Ẹ tú wọn, kí ẹ mú wọn wá fún mi. Elékuru kì í kiri lóko.
Didan re dabi osan gangan,itansan n ti owo re jade;nibe ni o fi agbara re pamo si.O so fun won pe, “E lo si ileto ti o wa ni okankan yin yii. Bi e ba ti wo inu re, e oo ri ketekete kan ti won so mole, pelu omo re. E tu won, ki e mu won wa fun mi. Elekuru ki i kiri loko.
“Gbọ́, oluwa wa, olóyè pataki ni o jẹ́ láàrin wa. Sin òkú aya rẹ síbikíbi tí ó bá wù ọ́ jùlọ ninu àwọn itẹ́ òkú wa, kò sí ẹnikẹ́ni ninu wa tí kò ní fún ọ ní itẹ́ òkú rẹ̀, tabi tí yóo dí ọ lọ́wọ́, pé kí o má ṣe ohun tí o fẹ́ ṣe.”Kí ló dé tí ò ń fọ́nnu nípa agbára rẹ,ipá rẹ ti pin, ìwọ olóríkunkun ọmọbinrinìwọ tí o gbójú lé ọrọ̀ rẹ,tí ò ń wí pé, ‘Ta ló lè dojú kọ mí?’A fún un ní aṣọ funfun tí ń dán, tí ó sì mọ́. Aṣọ funfun náà ni iṣẹ́ òdodo àwọn eniyan Ọlọrun.”“Its likes have been seen before,” is what the host says; “No one has ever seen its likes before,” is what the guest says; if the host says that we should empty the plate, the guest should argue for leaving a little.
“Gbo, oluwa wa, oloye pataki ni o je laarin wa. Sin oku aya re sibikibi ti o ba wu o julo ninu awon ite oku wa, ko si enikeni ninu wa ti ko ni fun o ni ite oku re, tabi ti yoo di o lowo, pe ki o ma se ohun ti o fe se.”Ki lo de ti o n fonnu nipa agbara re,ipa re ti pin, iwo olorikunkun omobinriniwo ti o gboju le oro re,ti o n wi pe, ‘Ta lo le doju ko mi?’A fun un ni aso funfun ti n dan, ti o si mo. Aso funfun naa ni ise ododo awon eniyan Olorun.”“Its likes have been seen before,” is what the host says; “No one has ever seen its likes before,” is what the guest says; if the host says that we should empty the plate, the guest should argue for leaving a little.
A host might minimize his hospitality, but the guest should praise it; if the host is lavish, the guest should not be greedy. Cordia Millenii (Boraginaceae), used for making bẹ̀m̀bẹ́ drums.
A host might minimize his hospitality, but the guest should praise it; if the host is lavish, the guest should not be greedy. Cordia Millenii (Boraginaceae), used for making bembe drums.
Ọlọrun, ìwọ ni a bẹ̀rù ninu ìgbìmọ̀ àwọn eniyan mímọ́,o tóbi, o sì lẹ́rù ju gbogbo àwọn tí ó yí ọ ká lọ?Nígbà tí Saulu gbọ́ pé Dafidi ti sá àsálà lọ sí Gati, ó dẹ́kun láti máa wá a kiri.Bí kò bá sì ní ọmọbinrin, ilẹ̀ ìní rẹ̀ yóo jẹ́ ti àwọn arakunrin rẹ̀. Fún ọpọlọpọ ọjọ́ ni oòrùn kò ràn tí ìràwọ̀ kò sì yọ. Ìjì ńlá ń jà. A bá sọ ìrètí nù pé a tún lè là mọ́.Bí ọkunrin kan bá bá aya ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lòpọ̀, tabi aya àbúrò rẹ̀, ohun àìmọ́ ni, ohun ìtìjú ni ó sì ṣe sí ẹ̀gbọ́n tabi àbúrò rẹ̀, àwọn mejeeji yóo kú láì bímọ. Mo mọ̀ pé lẹ́yìn tí mo bá lọ, àwọn ẹhànnà ìkookò yóo wọ ààrin yín; wọn kò sì ní dá agbo sí. “Ṣugbọn ohunkohun tí eniyan bá ti fi fún OLUWA, kì báà jẹ́ eniyan ni, tabi ẹranko, tabi ilẹ̀ àjogúnbá rẹ̀, yóo jẹ́ títà tabi kí ó rà á pada. Ohunkohun tí a bá ti fi fún OLUWA, ó di mímọ́ jùlọ fún OLUWA. “Ó ní bí Hesekaya bá sì sọ fún òun pé, OLUWA Ọlọrun àwọn ni àwọn gbójú lé, òun óo bi í pé, ṣé kì í ṣe ojúbọ OLUWA náà ati àwọn pẹpẹ ìrúbọ rẹ̀ ni Hesekaya wó lulẹ̀ nígbà tí ó sọ fún àwọn ará Juda ati àwọn ará Jerusalẹmu pé, ẹyọ pẹpẹ kan ni kí wọ́n ti máa sin OLUWA?”26. Nítorí náà, A gbẹsan lara
Olorun, iwo ni a beru ninu igbimo awon eniyan mimo,o tobi, o si leru ju gbogbo awon ti o yi o ka lo?Nigba ti Saulu gbo pe Dafidi ti sa asala lo si Gati, o dekun lati maa wa a kiri.Bi ko ba si ni omobinrin, ile ini re yoo je ti awon arakunrin re. Fun opolopo ojo ni oorun ko ran ti irawo ko si yo. Iji nla n ja. A ba so ireti nu pe a tun le la mo.Bi okunrin kan ba ba aya egbon re lopo, tabi aya aburo re, ohun aimo ni, ohun itiju ni o si se si egbon tabi aburo re, awon mejeeji yoo ku lai bimo. Mo mo pe leyin ti mo ba lo, awon ehanna ikooko yoo wo aarin yin; won ko si ni da agbo si. “Sugbon ohunkohun ti eniyan ba ti fi fun OLUWA, ki baa je eniyan ni, tabi eranko, tabi ile ajogunba re, yoo je tita tabi ki o ra a pada. Ohunkohun ti a ba ti fi fun OLUWA, o di mimo julo fun OLUWA. “O ni bi Hesekaya ba si so fun oun pe, OLUWA Olorun awon ni awon gboju le, oun oo bi i pe, se ki i se ojubo OLUWA naa ati awon pepe irubo re ni Hesekaya wo lule nigba ti o so fun awon ara Juda ati awon ara Jerusalemu pe, eyo pepe kan ni ki won ti maa sin OLUWA?”26. Nitori naa, A gbesan lara
wọn. Wò ô bí ìgbẹ̀hìn àwọn tò kọ
won. Wo o bi igbehin awon to ko
(àwọn òjJÍṢẹ) ṣe rí.
(awon ojJISe) se ri.
ÌDÁ 3
IDA 3
27. Rántí ìgbà tí Ibrahim sọ fún
27. Ranti igba ti Ibrahim so fun
bàba àti àwọn ẹ̀nìyàn rẹ̀ pé, 'Emi
baba ati awon eniyan re pe, 'Emi
kò lọwọ rárá nínú ohun tí ẹ̀yin n
ko lowo rara ninu ohun ti eyin n
sìn,
sin,
28. Àyàfi Ẹni tò dá mi, Oun náà
28. Ayafi Eni to da mi, Oun naa
ni yÒò ṣe amọnà mi.
ni yOo se amona mi.
29. O sì ṣe é ní àpẹẹrẹ rere tí yúò
29. O si se e ni apeere rere ti yuo
pẹ láàrin àwọn àrọmọdọmọ rẹ̀ ki
pe laarin awon aromodomo re ki
wọn. lẹ̀ máa ṣẹrí padà (sọdọ
won. le maa seri pada (sodo
30. Bẹ̀ẹ̀ kọ, ṣùgbọn mo fún àwọn
30. Bee ko, sugbon mo fun awon
àti àwọn bàba wọn ní ààyẹ̀ láti jẹ
ati awon baba won ni aaye lati je
ìgbádùn (ránpẹ) títí tí òdodo àti
igbadun (ranpe) titi ti ododo ati
Òjiṣẹ kan tò wá jẹ̀ (iṣẹ rẹ̀) yanjú
Ojise kan to wa je (ise re) yanju
fi dé wá bá wọn.
fi de wa ba won.
31. Ṣùgbọn nígbà tí òtítọ náà dé
31. Sugbon nigba ti otito naa de
wá bá wọn, wọn wí pé, 'Idán ni
wa ba won, won wi pe, 'Idan ni
ẹ̀yí, àwa sì kọ ọ".
eyi, awa si ko o".
32. Wọn sì tún wí pé, 'Eéṣe tí a
32. Won si tun wi pe, 'Eese ti a
kò fi Al-Kur'an yìí ránṣẹ sí àwọn
ko fi Al-Kur'an yii ranse si awon
ẹ̀nìyàn bí alágbára láti inú ìlú
eniyan bi alagbara lati inu ilu
méjéẹ̀jì??
mejeeji??
33. Ṣé àwọn ni wọn n pín ìkẹ
33. Se awon ni won n pin ike
Olúwa rẹ̀ ni? Àwa ni à nì pín jíjẹ-
Oluwa re ni? Awa ni a ni pin jije-
mímu láàrin wọn ní ilé ayé yìí. A
mimu laarin won ni ile aye yii. A
sì gbé wọn ga ju ara wọn lọ ní ipò,
si gbe won ga ju ara won lo ni ipo,
ṣùgbọn wọn n mú ara wọn sìn. Ìké
sugbon won n mu ara won sin. Ike
Olúwa rẹ̀ sì dára ju ohun tí wọn n
Oluwa re si dara ju ohun ti won n
kòjọ lọ.
kojo lo.
Nítorí kò sí ọ̀kan ninu àwọn eniyan wọ̀n-ọn-nì tí a ti kọ́kọ́ pè tí yóo tọ́ wò ninu àsè mi!’ ”Dá wọn lẹ́bi, Ọlọrun, kí o sì fìyà jẹ wọ́n;jẹ́ kí ìgbìmọ̀pọ̀ wọn ó gbé wọn ṣubú.Ta wọ́n nù nítorí ọ̀pọ̀ ìrékọjá wọn,nítorí pé wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ. jẹ́ ẹgbaa mejidinlaadọsan-an ó lé ẹẹdẹgbẹjọ (337,500) aguntan. OLUWA bá dáhùn, ó ní, “Nítorí pé wọ́n kọ òfin tí mo gbékalẹ̀ fún wọn sílẹ̀, wọn kò gbọ́ràn sí mi lẹ́nu, wọn kò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ mi, Fún ọjọ́ meje tí ẹ óo fi ṣe àjọ̀dún yìí, yóo mú ọ̀dọ́ akọ mààlúù meje ati àgbò meje tí kò ní àbààwọ́n wá fún ẹbọ sísun, ati òbúkọ kọ̀ọ̀kan fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀. Ọlọrun, àwọn agbéraga dìde sí mi;ẹgbẹ́ àwọn ìkà, aláìláàánú kan ń lépa ẹ̀mí mi;wọn kò sì bìkítà fún ọ.Eniyan mímọ́ ni a óo máa pe àwọn tí wọ́n bá kù ní Sioni, àní, àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù ní Jerusalẹmu; gbogbo àwọn tí a bá kọ orúkọ wọn sílẹ̀ pé wọ́n wà láàyè ní Jerusalẹmu. Ní òru ọjọ́ kan, agbọ́tí ọba ati olórí alásè náà lá àlá kan, àlá tí olukuluku lá sì ní ìtumọ̀ tirẹ̀. Àwọn tí wọ́n jẹ́ baálé baálé pọ̀ ninu àwọn ọmọ Eleasari ju ti Itamari lọ, nítorí náà, wọ́n pín àwọn ọmọ Eleasari sí abẹ́ àwọn baálé baálé mẹrindinlogun, wọ́n sì pín àwọn ọmọ Itamari sí abẹ́ àwọn baálé baálé mẹjọ. Bí wọ́n ṣe pín wọn kò sì fì sí ibìkan nítorí pé Nítorí ìmí ẹ̀dùn di oúnjẹ fún mi,ìráhùn mi sì ń tú jáde bí omi.Kò sí ohun tí ó kù àfi kí ẹ kú lójú ogun,tabi kí ẹ ká góńgó láàrin àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú.Sibẹsibẹ inú OLUWA kò ní rọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò ní dá ọwọ́ ìjà rẹ̀ dúró.Ẹni tí ó tó pe ọba ní eniyan lásán,tí ó tó pe ìjòyè ní ẹni ibi;Farao, pẹlu ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ati ọpọlọpọ eniyan rẹ̀, kò ní lè ràn án lọ́wọ́ nígbà ogun; nígbà tí ogun bá dótì í, tí wọ́n sì mọ òkítì sí ara odi rẹ̀ láti pa ọpọlọpọ eniyan. Mo ké pe OLUWA,ó sì dá mi lóhùn láti òkè mímọ́ rẹ̀ wá.Wọn yóo máa wí pé, ‘Ọkunrin yìí bẹ̀rẹ̀ ilé, kò lè parí rẹ̀!’Fi òtítọ́ yà wọ́n sí mímọ́ fún ara rẹ; òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ. Àwọn olórí alufaa ati àwọn aṣiwaju àwọn Juu bá gbé ọ̀rọ̀ Paulu siwaju rẹ̀. Wọ́n ń bẹ̀ ẹ́ pé Ẹjọ́ ẹ̀tọ́ níí dá fún talaka ati aláìní,ohun gbogbo sì ń lọ dáradára.Ṣebí èyí ni à ń pè ní kí eniyan mọ OLUWA?OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.Peteru wá ranti ọ̀rọ̀ àná. Ó wí fún Jesu pé, “Olùkọ́ni, wo igi ọ̀pọ̀tọ́ tí o fi gégùn-ún, ó ti gbẹ!”Wọn a máa sọ gbogbo nǹkan dáradára tí ó ń ṣe lójú mi, bẹ́ẹ̀ sì ni wọn a máa sọ ọ̀rọ̀ témi náà bá sọ fún un. Tobaya kò sì dẹ́kun ati máa kọ lẹta sí mi láti dẹ́rù bà mí.Sikiri, akikanju jagunjagun kan, ará Efuraimu pa Maaseaya, ọmọ ọba, ati Asirikamu, olórí ogun tí ń ṣọ́ ààfin ọba, ati Elikana, igbákejì ọba. “Iranṣẹ rẹ ni wọ́n, eniyan rẹ sì ni wọ́n, àwọn tí o ti fi ipá ati agbára ọwọ́ rẹ rà pada. Ilẹ̀ yín ní ìhà gúsù yóo bẹ̀rẹ̀ láti aṣálẹ̀ Sini lẹ́bàá ààlà Edomu. Ààlà yín ní ìhà gúsù yóo jẹ́ láti òpin Òkun-Iyọ̀ ní ìlà oòrùn. Your junior brother (or sister) buys clothing for you, and you say you will not wear anything with bean-grits patterns; who has the right to opt for clothing with a bean-fritter patterns?
Nitori ko si okan ninu awon eniyan won-on-ni ti a ti koko pe ti yoo to wo ninu ase mi!’ ”Da won lebi, Olorun, ki o si fiya je won;je ki igbimopo won o gbe won subu.Ta won nu nitori opo irekoja won,nitori pe won sote si o. je egbaa mejidinlaadosan-an o le eedegbejo (337,500) aguntan. OLUWA ba dahun, o ni, “Nitori pe won ko ofin ti mo gbekale fun won sile, won ko gboran si mi lenu, won ko si se gege bi oro mi, Fun ojo meje ti e oo fi se ajodun yii, yoo mu odo ako maaluu meje ati agbo meje ti ko ni abaawon wa fun ebo sisun, ati obuko kookan fun ojo kookan fun ebo imukuro ese. Olorun, awon agberaga dide si mi;egbe awon ika, alailaaanu kan n lepa emi mi;won ko si bikita fun o.Eniyan mimo ni a oo maa pe awon ti won ba ku ni Sioni, ani, awon ti won seku ni Jerusalemu; gbogbo awon ti a ba ko oruko won sile pe won wa laaye ni Jerusalemu. Ni oru ojo kan, agboti oba ati olori alase naa la ala kan, ala ti olukuluku la si ni itumo tire. Awon ti won je baale baale po ninu awon omo Eleasari ju ti Itamari lo, nitori naa, won pin awon omo Eleasari si abe awon baale baale merindinlogun, won si pin awon omo Itamari si abe awon baale baale mejo. Bi won se pin won ko si fi si ibikan nitori pe Nitori imi edun di ounje fun mi,irahun mi si n tu jade bi omi.Ko si ohun ti o ku afi ki e ku loju ogun,tabi ki e ka gongo laarin awon ti won ko leru.Sibesibe inu OLUWA ko ni ro,bee ni ko ni da owo ija re duro.Eni ti o to pe oba ni eniyan lasan,ti o to pe ijoye ni eni ibi;Farao, pelu ogunlogo awon omo ogun re, ati opolopo eniyan re, ko ni le ran an lowo nigba ogun; nigba ti ogun ba doti i, ti won si mo okiti si ara odi re lati pa opolopo eniyan. Mo ke pe OLUWA,o si da mi lohun lati oke mimo re wa.Won yoo maa wi pe, ‘Okunrin yii bere ile, ko le pari re!’Fi otito ya won si mimo fun ara re; otito ni oro re. Awon olori alufaa ati awon asiwaju awon Juu ba gbe oro Paulu siwaju re. Won n be e pe Ejo eto nii da fun talaka ati alaini,ohun gbogbo si n lo daradara.Sebi eyi ni a n pe ni ki eniyan mo OLUWA?OLUWA lo so bee.Peteru wa ranti oro ana. O wi fun Jesu pe, “Olukoni, wo igi opoto ti o fi gegun-un, o ti gbe!”Won a maa so gbogbo nnkan daradara ti o n se loju mi, bee si ni won a maa so oro temi naa ba so fun un. Tobaya ko si dekun ati maa ko leta si mi lati deru ba mi.Sikiri, akikanju jagunjagun kan, ara Efuraimu pa Maaseaya, omo oba, ati Asirikamu, olori ogun ti n so aafin oba, ati Elikana, igbakeji oba. “Iranse re ni won, eniyan re si ni won, awon ti o ti fi ipa ati agbara owo re ra pada. Ile yin ni iha gusu yoo bere lati asale Sini lebaa aala Edomu. Aala yin ni iha gusu yoo je lati opin Okun-Iyo ni ila oorun. Your junior brother (or sister) buys clothing for you, and you say you will not wear anything with bean-grits patterns; who has the right to opt for clothing with a bean-fritter patterns?
One should act in accordance to one's station in life. Compare Ẹni tí a bá ńdáṣọ fún kì í ka èèwọ̀. Presumably ékuru is less desirable a meal than àkàrà; but the beggar cannot (or should not) presume to exercise a choice.
One should act in accordance to one's station in life. Compare Eni ti a ba ndaso fun ki i ka eewo. Presumably ekuru is less desirable a meal than akara; but the beggar cannot (or should not) presume to exercise a choice.
Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, àwọn àjèjì tí èdè wọn yàtọ̀ ni OLUWA yóo lòláti bá àwọn eniyan wọnyi sọ̀rọ̀.Wò ó! Mo fi í ṣe olórí fún àwọn eniyan,olórí ati aláṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè.kí ó ye yín pé àwọn ẹni tí ó bá gbàgbọ́ ni ọmọ Abrahamu. Nítorí náà, mo bẹ̀ yín, ẹ jẹun; èyí ṣe pataki bí ẹ ò bá fẹ́ kú. Irun orí ẹnikẹ́ni kò tilẹ̀ ní ṣòfò.” The seller of steamed ground beans does not hawk her wares on a farm.
Bi o ba ri bee, awon ajeji ti ede won yato ni OLUWA yoo lolati ba awon eniyan wonyi soro.Wo o! Mo fi i se olori fun awon eniyan,olori ati alase awon orile-ede.ki o ye yin pe awon eni ti o ba gbagbo ni omo Abrahamu. Nitori naa, mo be yin, e jeun; eyi se pataki bi e o ba fe ku. Irun ori enikeni ko tile ni sofo.” The seller of steamed ground beans does not hawk her wares on a farm.
ó kan ààbà mọ́ ọ lẹ́sẹ̀,ó sì ń ṣọ́ ìrìn rẹ. Nígbà tí ọba rọ̀gbọ̀kú lórí ìjókòó rẹ̀,turari mi ń tú òórùn dídùn jáde.Ẹbọ díẹ̀, oògùn díẹ̀, ní ńgba aláìkú là.
o kan aaba mo o lese,o si n so irin re. Nigba ti oba rogboku lori ijokoo re,turari mi n tu oorun didun jade.Ebo die, oogun die, ni ngba alaiku la.
Ẹ̀yin ni Ọlọrun fi Orebu ati Seebu, àwọn ọmọ ọba Midiani mejeeji lé lọ́wọ́. Kí ni ohun tí mo ṣe lẹ́gbẹ̀ẹ́ èyí tí ẹ̀yin ṣe?” Nígbà tí wọ́n gbọ́ bí ó ṣe dá wọn lóhùn, inú wọ́n yọ́.Obinrin kan wà tí ó ní irú ẹ̀mí èṣù kan tí ó sọ ọ́ di aláìlera fún ọdún mejidinlogun. Ẹ̀yìn rẹ̀ tẹ̀, kò lè nàró dáradára. kí ló dé tí ẹ fi sọ pé mò ń sọ ọ̀rọ̀ àfojúdi sí Ọlọrun nítorí mo wí pé, ‘Ọmọ Ọlọrun ni mí,’ èmi tí Baba yà sọ́tọ̀, tí ó rán wá sí ayé? Jẹfuta ṣe aṣiwaju ní ilẹ̀ Israẹli fún ọdún mẹfa. Nígbà tí ó ṣaláìsí, wọ́n sin ín sí Gileadi, ìlú rẹ̀.Pápá oko tútù tí ìbẹ̀rù kò sí níbẹ̀ tẹ́lẹ̀ ti di ahoronítorí ibinu gbígbóná OLUWA.àti àwọn tí wọn ti wá ṣíwájú yín,
Eyin ni Olorun fi Orebu ati Seebu, awon omo oba Midiani mejeeji le lowo. Ki ni ohun ti mo se legbee eyi ti eyin se?” Nigba ti won gbo bi o se da won lohun, inu won yo.Obinrin kan wa ti o ni iru emi esu kan ti o so o di alailera fun odun mejidinlogun. Eyin re te, ko le naro daradara. ki lo de ti e fi so pe mo n so oro afojudi si Olorun nitori mo wi pe, ‘Omo Olorun ni mi,’ emi ti Baba ya soto, ti o ran wa si aye? Jefuta se asiwaju ni ile Israeli fun odun mefa. Nigba ti o salaisi, won sin in si Gileadi, ilu re.Papa oko tutu ti iberu ko si nibe tele ti di ahoronitori ibinu gbigbona OLUWA.ati awon ti won ti wa siwaju yin,
kí ẹ baà lẹ̀ di olùpayà Ọlọrun.
ki e baa le di olupaya Olorun.
23. Ẹni tí O ṣe ilẹ̀ ní ìtẹ fún yín,
23. Eni ti O se ile ni ite fun yin,